Yoruba Bible - New Testament

You might also like

Download as pdf
Download as pdf
You are on page 1of 221
THINRERE MATTEU 1IWE iran Jesu Kristi, om9 Dafidi emo Abrahamu. 2Abrahamu bf Isaaki; Isaaki si bi Jakobu; Jakobu si bf Juda ati awon arakunrin re; 3Juda si bi Faresi ati Sara ti Tamari; Faresi si bf Esromu; Esromu si bi Aramu; 4Aramu si bi Aminadabu; Aminadabu si bi Naasoni; Naasoni si bi Salmoni; 5Salmoni si bi Boasi ti Rakabu; Boasi si bi Obedi ti Rutu; Obedi si bi Jesse; SJesse si bf Dafidi gba. Dafidi oba si bf So— lomoni lati odo eniti o ti nse aya Uria; 7Solomoni si b{ Rehoboamu; Rehoboamu si bi Abia; Abia si bi Asa; 8 Asa si bi Josafati; Josafati si bi Joramu; Jo— ramu si bi Osia; 8Osia si bf Joatamu; Joatamu si bi Akasi; Akasi si bf Hesekiah; 10Hesekiah si bi Manasse; Manasse si bf Amoni; Amoni si bi Josiah; 11 Josiah si bf Jekoniah ati awon arakunrin 1@, nigba ikolg si Babiloni. 12Lehin ikolo si Babiloni ni Jekoniah bi Sa latieli; Salatieli si bi Sorobabeli; 13Sorobabeli si bi Abiudu; Abiudu si bi Eliakimu; Eliakimu si bi Asoru; 1 Asoru si bi Sadoku; Sadoku si bi Akimu; Akimu si bf Eliudu; 1Eliudu si bf Eleasa; Eleasa si bi Matani; Matani si bf Jakobu; 16Jakobu si bi Josefu oko Maria, lati odo eniti a bf Jesu, ti a npé ni Kristi. an gbogbo iran lati Abrahamu wa de Dafidi je iran merinla; ati lati Dafidi wa de ikolo si Babllon j je iran merinla; ati lati igba ik6lo si Babiloni de igba Kristi o je iran merinia. 18 (Bi ibi Jesu Kristi ti ri niyi: li akoko tia fe Maria iya re fun Josefu, ki nwon to pade, a ri i, o loyun lati ow6 Emi Mimé wa. 18 Josefu oko ré, ti ise oléto enia, ko si fe do~ juti i ni gbangba, 0 fe ikd 9 sile ni ikoko. 20Sugbon nigbati o nro nkan wonyi, wo 0, angeli Oluwa yo si ili ojualé, o wipe, Josefu, iwo ‘omg Dafidi, ma foiya lati mu Maria aya re si odo; nitorieyi tio yin ninu re, lati ow¢ Emi Mims ni. 21Yio si bf omokunrin kan, Jesu ni iwo o pe oruko ré: nitori on ni yio gba awon enia ré 1a 22. Ghogbo eyi si se, ki eyi tia ti so lati odo Oluwa wa li enu woli kio le se, pe, 23 Kiyesi i, wundia kan yio lyun, yio si bi omokunrin kan, nwon o ma pé oruko ré ni Emmanueli, itumo eyi ti ise, Olorun wa pelu wa. 24 Nighati Josefu dide ninu orun rg, 0 se bi angeli Oluwa ti wi fun u, o si mu aya ré si odo: 25On ko si md 9 titi o fi bf akobi ré omo~ kunrin: o si pe oruko ré ni JESU. 1 NIGBATI a si bi Jesu ni Betlehemu ti Ju— dea, nigba aiye Herodu gba, kiyesi, awon amoye kan ti tha ila—6rimn wa si Jerusalemu, 2Nwon mbére wipe, Nibo li eniti a bi ‘gba awon Ju wa? nitori awa ti ri irawo ré ni ila—Sriin, awa si wa lati foribale fun u. 3 Nigbati Herodu gba si gb6, ara ré kd lele, ati gbogbo awon ard Jerusalemu pelu re. ‘4 Nigbati o si p gbogbo awon olori alufa ati awgn akowe awon enia jo, o bi won lére ibiti ao gbé bi Kristi. 5 Nwon si wi fun u pe, Ni Betlehemu ti Judea ni: nitori béli a kowe ré lati ow6 woli ni wa, §]wo Betlehemu ni ile Judea, iwo kd kere julo ninu awon ome alade Juda, nitori lati inu re ni Bale kan yio ti jade, ti yio se itoju Israeli awon enia mi. TNigbana ni Herodu p8 awon amoye na si 1koko, 0 si bi won lesoleso akoko ti irawo na £0 si ran won lo si Betlehemu, o wipe, Elo iwadi ti om9-ow9 na lesoleso; nigbati enyin ba si ri i, e pada wa iso fun mi, ki emi kio le wa iforibale fun u pelu. Nigbati nwon si gb¢ oro oba, nwon lo; si ‘wo 0, irawo ti nwon ti ri lati iha ila~rin wa, 0 ju won, titi 0 fi wa iduro loke ibiti omo-gwo na ghé wa. 10 Nigbati nwon si ri irawo na, nwon yd ayo nlanla. 11 {Nigbati nwon si wd ile, nwon ri omo— we na pelu Maria iya ré, nwon wole, nwon i foribale fun u: nigbati nwon si td isura won, nwon ta a lore wura, ati turari, ati ojia. 12Bi Olorun ti kilo fun won Ii ofu ala pe, ki nwon ki o mége pada td Herodu lo mé, nwon gba dna miran lg si ilu won. MATTEU 2—4 13Nigbati_nwon si ti lo, kiyesi i, angeli Oluwa yo si Josefu li oju ald, 0 wipe, Dide gbé ‘omo-owe na pelu iya ré, ki o si sélo si Egipti, Ki iwo kio si ghé ibe titi emi o fi so fun 9; ni- tori Herodu yio w4 omo-owo9 na lati pa a. ‘Nigbati o si dide, o mu gmg-gwo na ati iya ré li oru, o si lo si Egipti; 150 si wa nibé titi o fi di igba ik Herodu; Ki eyi ti Oluwa wi lati enu woli ni ki o le se, pe, Ni Egipti ni mo ti pé omg mi jade wa. 16 GNigbati Herodu ri pe, on di eni itanje Igdg awon amoye, o binu gidigidi, o si ranse, © si pa gbogbo awon omg ti o wa ni Betlehe— mu ati ni ekiin ré, lati awon omo odin meji jale gege bi akokd ti o ti bere lesgleso lowo awon amoye na. 17 Nigbana li eyi ti a ti so lati enu woli Jere— miah wa se, pe, 18Ni Rama ni a gbé ohn, ohinréré, ati ektin, ati Of nla, Rakeli nsokun awon omo re ko gbipe, nitoriti nwon ko si. 19GNigbati Herodu si ki, kiyesi i, angeli Oluwa kan yo si Josefu li oju alé ni Egipti, 20 Wipe, Dide, mu om9-ow9 na, ati iya ré, kio si lg si ile Israeli: nitori awon ti nw4 emi ‘omo-owg na lati pa ti ku. 210 si dide, o mu omg-gwo na ati iya r, 0 si wa si ile Israeli. 22 Sugbon nigbati o gbé pe Arkelau joba ni Judea ni ipd Herodu baba ré, o béru lati lo sibé; bi Olorun si ti Kilg fun u li oju ald, 0 yi— pada si apa Galli. 23Nigbati o si w4, 0 joko ni ilu kan tia npe ni Nasareti; ki eyi ti a ti so li enu woli kio le se, pe, A o pé e ni ard Nasareti. 3 1NI ijo wonni ni Johannu Baptisti wa, 0 nwasu ni iji: Judea, 20 si nwipe, E ronupiwada; nitori ijoba run ki si dade. 3Nitori eyi li eniti woli Isaiah so oro re, wipe, Ohin enikan ti nkigbe ni ija, E tan ona Oluwa se, ¢ se oju—dna re t6. 4 Aso Johannu na si je ti irun ibakasie, o si di amure awo si égbe re; onje ré li ésti ati oyin igan. 5 Nigbanali awon ara Jerusalemu, ati gbogbo Judea, ati gbogbo ekiin apa Jordani yikA jade t o wa, § A si mbaptis! won lodo ré ni odd Jordani, nwon njewo ese won. 7 |Sugbon nigbati o ri 9p9 awon Farisi ati Sadusi wa si baptismu r@, o wi fun won pe, Enyin omg paramole, tali o kilo fun nyin lati s4 kuro ninu ibinu ti mbd? 8 Nitorina, ¢ so eso ti o ye fun ironupiwada: 9Ki e md si se rd ninu ara nyin, wipe, Awa nf Abrahamu ni baba; ki emi wi fun nyin, Qlogrun le yo omg jade lati inu okuta wonyi wé fun Abrahamu. 10 Ati nisisiyi pelu, a ti fi ake le gbdngbo igi na; nitorina ghogbo igi ti ko ba so eso rere, a0 ke e lille, a 0 si w6 9 ja sinu ind. 1114t9 li emi nfi omi baptisi nyin fun iro- nupiwada: sugbon enikan ti o pdju mi lo mbd Iehin mi, bata eniti emi ko to gbé; on ni yio fi Emi Mimé ati ina baptisi nyin. 12Eniti ate re mbe li ows r, ylo si gba ile ipaka re mé toto, yio si k6 alikama ré sinu aba, sugbon iyangbo ni yio fi ind ajoku sun. 13Nigbana ni Jesu ti Galili wa si Jordani sgdo Johannu lati baptisi lodg re. 14Sugbon Johannu kd fun u, wipe, Emi lia ba baptisi lodo re, iwo si to mi wa? 1SJesu si dahiin, o wi fun u pe, jowo re bé na: ritori béli o ye fun wa lati mu gbogbo ‘ododo se. Bali o jowo r8. 16 Nighati a si baptisi Jesu tan, o jade lese~ kanna lati inu omi wa; si wo 0, orun sf sile fun u, 0 si ri Emi Qlorun sokale bi adaba, o si ba le e: 175i kiyesi i, ohn kan lati orun wa, nwipe, Ey{ ni ayanfe omo mi, eniti inu mi dim si gidi— aidi. 'NIGBANA li a dari Jesu si ija lati ow6 Emi lati dén a wo lowo Egu. 2 Nighati o si ti ghawe li ogoji osén ati ogoji ory, lehinna ni ebi npaa. 3 Nigbati oludanwo de odg r@, oni, Bi iwo ba ise Qmo Olorun, pase ki okuta wonyi di akara. *Sugbon o dahin wipe, A ti kowe re pe, Enia Id yio wa layé nipa akara nikan, bikose nipa gbogho oro tio ti enu Olorun jade wa. 5 Nigbana ni gu gbé e lo soke si ilu mimé ni, 0 gbé e le sonso tempili, 60 si wi fun u pe, Bi iwo ba ise Omo Olo~ run, bé sile fun ara re: A sd ti kowe re pe, Yio pase fun awon angeli ré nitori re, li ow6 won ni nwon 0 si gbé 9 soke, ki wo kio mé ba fi ese re gbiin okuta. 7Jesu si wi fun u pe, A tin ko 9 pe, Iwo ko dan Oluwa Qlorun re wo. gbé e lo si ori Oke giga-giga ewe, o sifi gbogbo ile oba aiye ati gbogbo ogo won han a; $0 si wi fun u pe, Gbogbo nkan wonyi li 685 emi 6 fifun 9, bi iwo ba wole, ti o si foribale fun mi. 1Nigbana ni Jesu wi fun u pe, Pada kuro lehin mi, Satani: nitori a kowe ré pe, Oluwa Olorun re ni ki iwo Ki o foribale fun, on ni- kansoso ni ki iwo ma sin. 11 Nigbana li su fi i sile lo; si kiyesi i, awon angeli t 9 wa, nwon si nse iranse fun u. 12 {Nighati Jesu gbé pe, a fi Johannu le won lowo, 0 dide lo si Galili; 13Nighati o si jade kuro ni Nasareti, 0 wé ijoko ni Kapernaumu, eyi ti o mbe leti okun li ekiin Sebuloni ati Neftalimu: 14Ki eyi tia wi lati enu woli Isaiah wa le 5, Pe, 18 Ile Sebuloni ati ile Neftalimu li gna okun, li oke Jordani, Galili awon keferi; 16 Awon enia ti o joko li dkunkun ri imole nia; ati awon ti o joko ni ibi iku ati labe oj ni imole la fun. 17 qLati igbana ni Jesu bére si iwasu wipe, E ronupiwada; nitori ijgba orun ki si déde. 1YJesu nrin leti okun Galili, o ri awon arakunrin meji, Simoni, eniti a npe ni Peteru, ati Anderu arakunrin ré, nwon nso awen sinu okun: nitori nwon je apeja. 190 si wi fun won pe, E ma td mi lehin, emi 6 si so nyin di apeja enia. 20Nwon si fi awon sile lojukanna, nwon si td 9 lehin. 21 Bi o si ti ti ibe lo siwaju, o ri awon ara~ kunrin meji, Jakobu omo Sebede, ati Johannu arakunrin re, ninu 9kQ pelu Sebede baba won, nwon ndi awon won; o si pe won. 22Lojukanna nwon si fi ok) ati baba won sile, nwon si td 9 lehin. 23 Jesu si rin ni ghogbo ekiin Galill, o nkoni ni sinagogu won, o si nwasu thinrere ijoba, 0 si nse iwosan gbogbo arun ati gbogbo aisan li ara awon enia. 24Okikf re si kan yi gbogbo Siria ka; nwon si gbé awon alaisan ti o ni onirdru arun ati irora w sodg re, ati awon tio li emi ésu, ati awon tio nsinwin, ati awon ti o li gba; o si wo won san. 25 Qpolopo enia si td 9 lehin lati Galili, ati Dekapoli, ati Jerusalemu, ati lati Judea wa, ati lati oke odd Jordani. 5 1 NIGBATI o si ri po enia, o giin ori dke : nigbati o si joko, awon omo-ehin re 19.9 wa. 20 si ya enu re, o si k6 won, wipe, MATTEU 4,5 3 Alabuktin—fun li awon dtosi Il emé: nitori tiwon ni ijoba orun. 4 Alabuktin—fun li awon eniti nkanu: nito- riti a 6 ti won ninu. 5 Alabuktin-fun li awon olokan—tuti: nito- ri nwon o jogiin aiye. 6 Alabuktin-fun li awon eniti ebi npa ati ti ongbe ngbe sipa ododo: nitori nwon 6 yo. TAlabukdin-fun li awon alénu: nitori nwon 6 ri anu gba. 8 Alabukiin—fun Ii awon oninu-funfun: ni- tori nwon 6 ri Qlorun. 8 Alabuktin—fun li awon onilaja: nitori mo QOlorun ni a 6 ma pé won. 10 Alabukdnfun li awon eniti a se inunibini si nitori ododo: nitori tiwon ni ijoba orun. 11 Alabuktin-fun li enyin, nigbati nwon ba nkegan nyin, ti nwon ba nse inunibini si nyin, ti nwon ba nfi eke sdro buburu gbogbo si nyin nitori emi. 12E ma yd, ki enyin ki o si f9 fun ayd: nitori ére nyin pd li orun: béni nwon sé se inunibini si awon woll ti o ti mbe saju nyin. 134 Enyin ni iyd aiye: sugbon bi iyd ba di obu, kini a o fi mu u din? kd nilari m6, bikosepe a daa ni, ki o si di itemole li atelese enia. 14Enyin ni imole aiye. Ilu tia tedo lori dke ko le farasin, 18Beni a ki itan fitila tan, ki a si fi i sabe dsuwon; bikose lori gpd fitila, a si fi imole fun gbogbo eniti mbe ninu ile. W8E je ki imole nyin ki o mole tobé niwaju enia, ki nwon ki o le ma ri ise rere nyin, ki nwon kio le ma yin Baba nyin ti mbe li orun logo. 17E mse rd pe, emi wé lati pa ofin tabi awon wolf run: emi kd w4 lati parun, bikose lati muse. 18Léto ni mo s4 wi fun nyin, Titi orun on aiye yio fi koja lo, ohun kikini kan ninu ofin ki yio koja, bi o ti wit ki o ri, titi gogho ré-yio fi se. Enikeni ti o ba ri okan kikini ninu ofin wonyi, ti o ba si nké awon enia bé, on na lia 0 pé ni kikini ni ijoba orun: sugbon enikeni ti © ba nse won ti o ba si nk won, on na li ao pe ni eni-nia ni ijgba orun. 20Nitori mo wi fun nyin, bikosepe ododo nyin ba koja ododo awon akowe ati ti awon Farisi, enyin ki yio le de ile-gba orun bi 0 ti wit kio ti. 24 {Enyin ti gbé bi a ti wi fun awon aré igha— ni pe, Iwo ko gbodo pania; enikeni ti o ba pania yio wa li ewu idajo

You might also like