Download as pdf
Download as pdf
You are on page 1of 2
EKO KERINLELOGBON SANGO ‘Sang6 je dris kan ti iran ré kun fun ibéru. Iris drisa yi tile ba’ni Péri: pala. Ise ati isdrd ré paapaa kun fun ibéru nigba ti o wa I’dayé nitori pé eniyan I'a gbo pé Sangé je Kio to di Orisa dara In so niparé pé ome Oranyan ni Sangé fae ati pe Qya, Osun ati Oba je iyawo ré. Ni dk6kd kan, gegebi itan ti so, Sings je Oba l'odeQyo- VE ti nje “Eyed,” tabi KAningé ni Ak6k6 naa. Gegebi Oba, “4 “Agbara o si niigboya. Bio ti ni agbéra to I’o si ldogiin to. 2 féran lati maa fi agbara re han awon eniyan. Ni igbamiran, bi $angé ba mba awon eniyanré soro, seni ind maa nyo l'enu Sangé bulabula. jaye tio ba si so pe ti Sangé kéré 'akoko naa y6d fi iyan ré je isu ni. Bayi ni wa bi Vi titi 0 fi te Fowg awon ijoye ati mé Sang6 I'a gbo pe o da ija sile laarin awon ijdyé meji_kan ni id ré. ja naa po debi pe okan pa ekeji ré ku patapata, ‘Kaka ki $ang6 pari ij fun won, se I’o mbu epo si i fun won. ibogbo eniyan il Qyo si mo’ pe Sangé I’o da rigidi sile Taarin awon ijdyé naa. Gbogbo eniyan bere sii fi ind ro gbogbo biburi ti Sangé ti se arin won. “Omo pa igin ké gb’édiin, omo pa akalamagbd kd gb’ési.” Riiduriidu ti mbe ni ili Qyo da, da, dé, 0 dé lori $ngé, Oba Oyo. Tomodé Vagba dide ot8 st Sings, Qba wa di “Ote-yimiké.” Ija ti o be sile l'aarin awon ijoye meji yi ni Sango fi j'eran de egungun gun igi koja ewé, o takit! lai wo'le. O di eni ti omodé t'agba nyo suti été si. Oté naa po debi pé Sings ko rou enikeni nile mg. Nigba ti ilé si gbéna mo 9 lara, 6 k’éri, 0 sa kuro I'ode Qyo. 0 ai igh o dl awo r& 0 ba ese 18 ord. Sugbon Sings KO ni Agbdjilé ibi ti y6d lo. O ga bere silo. “Kf burt ké ma ku enikan mg ni, sugbon eni ti o maa ki !’a kd md.” Awon iyaw6 Sangé l’o ki ti ntele¢ I’ehin, awon naa ni Oya, Qsun. ati Oba. Awon irdnsé ré bi Osimaré ati Oru ti pada Phin ré 284 ni kété ti 9té nla nda de sii, SAngé kd i tii rin jinna si Qyo nigba tio wo ehin ti kd ti_awon eniyan 18 m6 bikose Oya, okan ninu awon iyawé ré. Trond di meji fun Sangé, ko 11 ile duro k6 si ri eniyan lati thu ninu, Sangé ro’nu ara r@ titi ko ri ohun tio le se, o wa ya si idi igi AYAN kan I’eba na nibi ti Sango so ara ré si, tia npe ni Kaso. Kaso kdjina si Qyo. Nihin ni Sango pari Ord ré si nigba ti ibandjé d’ori r$ kodd. , iyawd Sings salo si apd ariwd, o si di odd Qya. Gogbo eniyan ti nkoja bere sii" Sangé seleyi, nwgn nye sti si i nwon si nwi pe “Oba 0," Oba so, Oba so Fo gl gbogbo agbégbé. Ind bi awon eniyan dig ti o kil fun Sangé. Ind won kd dun si bi nwon ti nfi Sangé s‘eléya, sugbon nwon ko le s'Ord. Nwon yo kélékélé lo si il Ibariba nibiti nwon ti gba odgin biburii ti nwon fi mba awon ota Sangé ja. Nwon tun ko ‘ggb6n ti nwon fi njo ilé awon Ota won naa. Bi nwon ba si ti s'ana bg ilé oru, nwon a ni Sango ti nwén fi nseléya I’o s'ana bg ilé, "Nigba miran éwé, bi ile ti njo ni atégun a maa fe, ti y6o si maa ran ind I'6w6. Ile jijo naa po to béé gee ti awon 285 i | i innu lati le, be Sangé. Nwon pa enu da, nwon si ba kd so.” lyipadi oro enu ayen ara Qyo yi I'o di i SAngé so si titi di oni yi, “KOSO,” eyi ni Oba kd To mu ki awon ara Oyo Io be Sangd. Bi eré, bi eré, alaboriin d'ewu, SAngé se bee 0 di Orisa ti gbogbo eniyan in ni Oyo. Awon Oyo kannaa I'o tun mu Orisa Sango lo si eniyan fi ns ry’ i1é miran ni Ibikibi tia ba ti bo Sangé I'a Ui inioris Aword ré ni Onisango tabi Adési-Sng6. Awon asaaju ninu awon aword Sango Fa npe ni Magba tabi lya Magba. Adési- ‘Singé maa ndi irun ori ré ni bi o tile je okiinrin. Aso ala ni Eni Sangé ba de s‘ori ré ghédé lo lak6kd odun Sang6. Ki i ge gbogbo eniyan ni drisa Sangé nde le l'ori. © maa nyan omo ré ninu awon oldrisa nipa yiyi oju onitghin pada. O maa dede mbo si i pe I'akoko odun $Ang6, yp abe 1p. Bi oy! ge i bes 2 ko le so, sugbon awon Oni- gingé gba pe Sango ni nmu dj6 wa l'akokd odun ré. Bi dj ti rg ni nwon o maa jo kiri ninu jd, nwon a maa sire, nwon a si maa gba ébiin. Ohun miran tia tun le se akiyést ni pé ard maa nsdn l'ak6ko ti 0jd ba nrg. Awon olifé Sangé si ro pé Sango ni i fi Okiita ré ja. Idi niyi ti a se tun npe Sangé ni ‘JAKUTA", eyi ni eni ti nfi okita ja. Idi ni yi ti o fi je pé won Onisinge ni nsin Oki eni dard ba pa. oléyé. Awon ‘Awon Qyo l'o ni gdun Sangé ni ikaw6 titi di i, Awon agbégbé miran ti gdun Sango ti an fi ese oe deacan, iséyin, Iwo ati Opdlopd ilu ni agbegbé tal sun. Amo a maa nri awn ti nsin Sangé ni Abgokuta, {j Ondo ati Ekiti, bi o tile je pé nwon kd ju ékin'w6 Io ni agbe, gbé kookan. K’d ma tan ara wa je, kd si eni ti nwon le bi ni ile Onisangé ki odin orig naa maa wu u, B’o ku k'a jd bata K’a poyt raninranin k’a tapé, iran odin Sangé dun i wo gan, _ Ordgbé ni obi Sangé, bi o ti ngba ordgbé be ¢ ni ngb: i agitan boldjd. Ko si ibitiaotiseodun Sango kigka nitori ounje ré ni oka. “Sangé ko j'obi, ordgbé ni i Qpolepe eniyan, paapaa awon tio ni igbagbé si i nimaa 1} omo l'owo ré. Awon gma tia ba ti ipa ond bee bi tabi ti a bi ni idilé onisingé I'a npe mo Sango. Apere oriiko bee ni: fingodeys, Sangéwanwa, Sangéfayd, Sangogbami ati bee- Ig. Awon ti Sango ba se fun bayi ki i fe fi ord ré fale, L’oje odin ré, bi nwon ti nr ni nwon yo maa ti, nwon a si maa kii bayi ° Qkunrin alégbara inu aféfé Titi ibi gegele Ba Oke ja.” -) ATUNYEWO EKO 1, So bi orukg ilu kan tia npé ni Kdso ge waye. 2. Daruko awon ilu ti a ti mbo Sangé ni ile Yoruba. 3. Onibon run ni Sangé i se. Beg ni tabi bee ko? E se ariyajiyan lori re. SS 287

You might also like