Ori Cantigas Pricipais

You might also like

Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 1

Kolobo se re n’agbó se re kolobo Awure o Komo nre Odara

Orí ení kini sàka ení


Orí ení kini sàka yan
Orí olóore ori jè o
A saka yìn ki ya n’to lo ko
A saka yìn ki ègbón mi gbè
Ìta nù mo bo orí o

Mo júbà àgbóonìirègún
Mo júbà àbóonnìirègún
Àwa ipàdé l’ònòon ipòorun, ipòorùn
Àwa méesòn òrun koorin ki òrúnmìlá
Àwa tún wo tún wa koorin kí òrúnmìlá
àwa orí oofee! Oofee eeleeda wa!
Àwa orí oofee! Oofee eedùnmarè!

Ajala Ori
Ori lewa, lewa, lewa
Ope eyin edunmare
Wa ori e ku o
E ku orun
e ku osupa
e ku ojo
Ojo gbo ile
ire ori o ji
o ji ire ori
ire ori o ji
o ji ire ori

Ori eni kini saka eni


Ori eni kini saka yan
Ori oloore ori je o
a saka yin ki ya n’to lo ko
a saka yin ki egbon mi gbè
Ìta ní mo gbo orí o

Yemonja ni se keni iya ori ni se keni o


Ori òse Iyemonja ni se Keni

Oloro ko da Gborò
Oloro ko da gboro
Ori òse
oloro ko da gborò
Dide Dide
Dide Onon
Dide Dide
Dide Onon
Baba Bo r’okon
Ojo dide Onon
Dide Onon

You might also like