Professional Documents
Culture Documents
Orunmla Nipa E M Lijadu - 003
Orunmla Nipa E M Lijadu - 003
OR! 5.
48. Eesi un-tu-kan,Iku pa Erikiija; Eesi lin-tiikan,- iku pa Imoioogbe: *ko ku e.mi omp kekere inu won,
ebp mi ko ko ru ko kpwe na, ko di ki ng maa Ip ku i?
Irete-Egutan.
t *Nigba atijo, Eu, Orunmla ati Aje jum p nspre, nwpn si nrin pp.
Bi nwpn ti nip spna oko nijp kan, nwpn gbp igbe buruku kan bi ti awon
ti nru oku bp, nwpn si yara sa sinu igbo nitoripe eewp ni fun won lati fojukan oku. Adi awon pmp-iya meta kan-Erikija, Imoioogbe ati aburo wpn
ti o Ip spdp li o pa odidi agbpnrin kan, ti nwpn te e sori patako kan, nwpn
fi asp funfun bo o, pnikan ninu wpn gbe e ru nkc bp bi-enipc fun oku.
Bi nwpn ti kpja ibiti Esu, Orunmla ati Aje sapamp si, Aje dahun o ni
eran ni nwpn m a nru lo ti nwpn pe li oku y i! Sugbpn awpn ore rp
meji iyokun njiyan pe ki ise eran. Ajp ni bi nwpn ba ba on jiyan, ki nwpn
jum p pada tele wpn Ip sile ibiti nwpn ngbpran naa !p. Nwpn se bpe,
nwpn si ran Esu wple Ip iwo o wa. Nje, E?u parada di arugbo kegekpge,
o de o mpwp le ilekun pe on yio wple fpnna, awpn pmp meta naa dahun
pe aye ko si nitori awpn nse nkan Ipwp o. Arugbo pada. Esu tun parada
di omidan pekepeke, o kan lekun pe on yio wple fpnna, nwpn tun kp
nwpn ni awpn koi ti raye se o. Omidan pada. Esu tun parada di pmp
kekere ti o ses? nra, o si f ori silpkun wple; nwpn jpwp re o ri gbogbo eran ti
nwpn kun siie, o si pada Ip isp fun Aje on Orunmla pe eran ni nitootp.
O si wa je pe b?e ni awpn pmp-iya meta nwpnyi ti ima se nigbagbogbo si
awpn ara-iie wpn nibe.
Nigbanaa ni Aje dahun o ni je mo ti wi bee? Nje pipin Iao pin awpn
metepta naa paje: iwp Qrunmla, mu pkan tire, iwp Esu mu tire, eniti ko ba
pa tire yio ma kan nkan ke! Iwp Orunmla saa ni oninu dindinrin ti
ngba gbogbo aiye sile.
Q
'
K i ale to ile Ipjp na otutu aburadi kplu Erikija, Imploogbe sare wa ida
a wo Ipdp Orunmla: Orunmla ?an ppele waa o ni Haa! Eesiun-tu-kan.
e.n. pe ko si nkan; sugbpn ki Imologbe to ipada dele, Erikija ti ku!
Nijp keji ti nwpn kita-kije oku yi tan ni otutu aburadi kplu Imoioogbe,
aburo phin re si sare tp Orunmla, on si dahun bi ti isaaju. Lphin pjp
meje ti oku Imoioogbe, nigbati otutu kplu aburo wpn yi ni on tikararp sare
Ip beere Ipdp Qrunmla; Orunmla dahun pe ko si nkan? N igbanaa ni
aburo yi nspkun bpwa ile nwipe; Esi un-tu-kan, - iku pa Erikija,
Esi un-tu-kan, - iku pa Imoioogbe: ko ku emi pmp kekere inu wpn, pbp
mi ko kpru ko kpwe na, ko di ki ng maa Ip ku i?
ORI 5.
55
56
OR!
5.
*Nigba atijp ni lie If^, nigbati pdun ba jo, ti gbogbo ilu ba se ase ti
nwpn ba si nse ajpyp odun titun, kiki pmp-ibilp ni imaa se e, eru ko gbpdp
jade ba wpn se e; eru ki iba wpn je, eru ki iba won m u; awpn pmp a se eru
wpn mole kije nwpn ki si ifun wpn li onje, opplppp pru a si maa ku sinu
isemp naa Ipdppdun: awpn pmp ro pe nwpn nfi pna bayi jaiye. Sugbpn
lehin pdun pupp awpn eru nwpnyi peropp, nwpn gun oro silp igbo-malp de
awpn pmp tobee ti ppclppp pmp ti o farakan oro naa ku lodun naa.
Awpn eru si nse bpp Ipdppdun, iku si nja larin awpn pmp-ibile Ife gidigidi.
Nigbati iiu fere run tan ni awpn iyokun ronu, nwpn se ajo ip beere Ipwp
Orunmla ohun ti awpn iba se ti pdun naa ti nwpn nfe ise le san wpn.
A ri Ogbewpnri. Orunmla bi wpn leere pe pna wo li e ti ngba se pdun
ti ko san nyin? N wpn dahun pe awpn a maa se pru mpie kije laij? laimu,
sugbpn gbogbo pmp-ibilp a m aa jp nwpn a maa mu, nwpn a maa jaiye pmp
kiri ilu. Nigbanaa ni Orunmla yan obukp kan ati pgbaata aridin li pbp
fun wpn, a ni k in w p n k e d e y ig b o g b o ilu a tiig b e rik o k a p e T pru-tpmp ni Male pe ki o bo on Toduunni o Ife gbp, lie r u : enu si ya awpn
eru pe a kede bayi: nwpn si yara mu pro ip buwpn igbo-malp naa, tobp?
nigbati tpru-tpmp papp se pdun naa, nwpn jum p je, nwpn jum p mu,
iku aburadi ko si ja lodun naa bi ti atphinwa. Ayaani o ko ri i, -A se
pspsp epa, a ko wun plpru je, a ko wun plpru mu, plpru ngpsp spna
de-ni!
ORI 5.
57
**Nigba atijp, Qba A do ko niyi loju ara ile r? rara tobe? ti awpn ijoye
$ ki iwol? fun u, nwpn ki iko eruku fun u, awpn enia re ki imu isin odpodun wa ifun u, \ s 6 a si ma s6 oba loju won. Nigbati iwa yi tubo nwp
58
ORI
5.
Ado lara, Lisa ati Jomu nio ba oba joko lori ite re, nwon a si maa fowQko
oba lorun laiberu. Sugbon nigbati oba rubp Irosu-sa tan ti a si se ifa si
ida re fun u, o sun loru o ri baba re nko o bayi pe Nijo miran bi ajp
ba kun tan, fa ida re yp lojiji ki o be Lisa lori ki o si so p lu Jpmu li
aiya. Oba se bee tootp gbogbo ilu funka si igbo, o di iberu fun wpn
lati wa fojukan pba, nitori nwon ko mo eyiti o ku ti yio se. N inu ibanuje
yi gbogbo wpn gbarajp, nwon ni awpn yio kuku to Olodumare Ip ki
O kuku tikalare run wpn leekan. Beeni gbogbo w'pn forile pna orun.
O pe die ni nwon ko pkpnrin kan nti prun b p : o bi wpn pe kini gbogbo
wpn nwp !p se lorun bayi? Nwpn ro fun u pe awpn mbinu tp Olodumare
Ip ki O le tikare pa wpn Ieekan. Okpnrin na beere pe eni melo ni
gbogbo nyin? nwpn dahun pe awpn to pke mefa en ia: Okpnrin naa ni
O mase o! o si ku pke meta enia ki e le to eyiti onibode prun nfi rubp
owurp Olodumare. Bi nwpn ti gbp eyi, aiya wpn ja, nwpn pehinda,
nwpn tun funka sinu igbo, nwpn si mpa erin, pfpn ati oniruuru eran kaakiri
nwpn ndi i li eru titi olukuluku fi ni eru tire: nwpn si ru gbogbo re Ip
spdp Oba Ado.
Nigbati pba wa wo wpn, o bi wpn pe kini e tun nfe nihin? ?ru ba
wpn, nwpn nwariri, nwpn si dahun pe nigbati a ronu wa wo a ri pe a koi
ti sin p lati pjp ti o ti jp b a ; nitorinaa ni a se mu eru-eran wpnyi wa ifun p.
O ba Ado wipe ki nwpn joko ki on ri wpn, nw'pn dahun pe awpn ko ro pe
o to ki nwpn maa ba pba joko, nitorina iduro ti awpn vya yi dara to.
Ii Atijpnaa ni awpn ara Ado ko ti nffS i'balf nile pba wpn titi di oni oloni.
**01ppbede Ipetu sise tan o mbpwa ile li al? o ya sidi ikan yi lati ji die
' ka ninu re. Bi o ti nawp lati ka ikan naa, beeni o gbp ori gbigbe ti a fi paalele e n k e w ip e m afpw pkana, m afpw pkana, tabi o ko ri mi nihin ni?
Eru ba Olppbede Ipetu o sare wa ile, o Ip rohin li aafin pba pe on ri
ori gbigbe ti nfphun Ioko loni, ki pba yan nia kalp wo o. Oba jiyan sugbpn Olppbede tenump p pe bi ko ba ri bee ki pba pa on: pba sileri afi-fi
idaji ijpba r^ jin Olppbede bi ohun naa ba ri bee nitootp. Bayi ni nwpn
leri titi gbogbo ilu yan ijoye meji tele Olppbpde pe bi ori gbigbp ko ba
fphun ki nwpn pa Olppbpde sibe. Nigbati nwon de idi ikan naa Olppbede
se titi ori gbigbe kp ko fphun a si pa Olppbede sibe. Bi nwpn ti nmura
ati-kuro nibe, ori gbigbe dahun o ni E seun o, o rp mi sii-sii-sii. Eru ba
wpn nwpn si sare wa iwi nile, nwpn si fi ileri ti i gege bi Olppbede ti se
nigba tire: a tun yan enia bi mejp le awpn naa ki o Ip igbp wa ki o si pa
wpn sibe bi ohun naa ko ba ri bee. Nwpn de phun nwpn se titi ori gbigbe
kp ko fphun, a si pa awpn meji naa sibe; sugbon bi nwpn ti yipada nip.
ORI
59
Oliiwa mi atoobajaiye.
A pe Orunmla ni atoobajaiye, nitoripe awon_bab%:nla-Wa
gbagbp pe bi Orunmla ba wa^lodp wpnjJabrbTawon b a wa
\ lodo re nigbagbogto, ko si ohun buburu kan ti oTe ba won.
Ero yi li_p inu w p i i d r E m o r a lo si ona ajo, lo si oju ogun,
I tabi si ibi ew_u rnirap. NimTerb won ylTprirn ati ibugbe prun
j jiiina fere sf pkan v/pn, nitoripe:
1
I
60
ORl
5.
ORI
5.
61
Awon apeere nwonyi filianni pe ni pipe Orunmla ni Atoobajaiye, orun ati ibugbe orun jinna rere si ero awon baba-nla
wa; aiye yi nikan si ni opin aniyan okan won. Nje, awon
baba wa ngba Orunmla sile won, tabi nwon ngbe e io si ajo
won nitori aabo ti nwon nreti lowo re li aiye yi. Ka awpn
ese wpnyi
58. Odp ji kiitu o ni on nwa okp pmpran lo ini, o de
le odide o ba ikd mbe sekeseke, o ni on yio saya re; odide ni
ki o bp sile. O dijp keji, o ri odide nfese mu eyin nile si
enu, oju ti Odp o binu o kd jade. Odp rin siwaju o de le
akukp, o ni Akuko o siansian o yeniyeni, o mp idaja, o mii
irere pyin, ngo saya re. O kogba sile. Ni kutu pjp keji,
akuko daja. Odp ji o pa ile pa pna 6 gbe isa, o re eri; bibp
ti o ti odo bp li o ba ti Akukp su petepete si gbogbo ile.
Oju ti Odp, Odp binu ko jade.
Odp mu ogoji mp asp ro, 6 mu ago aasara mp asp ro,
o ni on sa nwa pkp pmpran Ip ini. O rin siwaju o ya
Ipna o suba le ori oka, ago aasara pelu ogoji pwp re bp sibe
pelu, ewe ti o 16 siiba bp sori eran edii: Odp ko fura titi
o fi de ile Orunmla ti o ni ki o jare ye on wo. Orunmla gbe
iporun re lele, o da a, a ri Ogbe-sete o ni. Haa! Odp,
o ni o nwa pmpran Ip ini li pkp, o dele Odide 6 nfese meyin
senu; o dele Akukp 6 nsu sile; asehinwa-asehinbp o fori le
agbo ti ko ri iru oran bee ri, o beresi ise iypnu, o nkandi o si ngbe Qrunml a
WQ inu igbo kiri. Awon irunmald nke si Orunmla pe M aa kalp o-o-o-o I
On si nda won lohun pe:
O-o-o-o-o!
E m a wi fun won o-o-o-o!
Agbo Edu ma re korin o-o-o-o!
Ninu sise bayi gbogbo irunmale fi sile de prun, onibode si ti tile kun ki
Orunmla to ide. Nigbati Qrunmia nkankun ibode prun ni onibode dahun
pe M aa pada sphun o; eewp ni, aki.isilekun prun nigba meji. Kini
Orunmla gbp eyi e? O yipada biri, o spkalp lori agbo o nfa a sare
bpw a le aiye nkprin bayi pe:
Olprun tikun mee wa,
igidimpgba, sigidimpgba-si!
62
ORI
5.
59.
Ojiimo mo, Qrunmla nmura ati-lo segbe, o ko
iporiin re lele o da a, a rl Ogiidabede, a ni ki o ru ada owo
re, apere irawe pelu akuko adie kan, ki ibiti o nlo le san a.
Qrunmla gbo, o ni. Petebi ti mba a Ip binu pe kini yio ha fi
se pkpnrin Ipna nigbati o Ip ifi ada re rubp bayi? Qrunmla
dahun pe irpfa on to ifise pkpnrin.
Nwpn de pna nwpn ba pka, Petebi Ipgun; sugbpn Qrunmla
fi irpfa pwp re si pka o si gbe e sinu pke Petebi.
Nwpn rin siwaju, nwpn de oju ida awpn onisiimpmi nibiti
Igara ile Ara, Iforifo awo Ijero ati Akdnije-munita awo
QlQgptun nko gbogbo ero nigbesin, nwpn jade lojiji si Petebi
Qrunmla, nwpn mu u nwpn si nwp p Ip si ibudo wpn. Petebi
nke wipe Qrunmla gba mi o, ogun mu mi Ip o: Sugbpn
Qrunmla ndahun bp lehin pe maa ba wpn nso o! Nibo ni
nwpn yio mu p de? Nwpn mu Petebi de iwaju tan ni
nwpn ntu pke re nwpn njijadu tpwpbp p lati mii ohun inu re,
pka si nyan wpn Ipkppkan titi gbogbo won fi kii.
Qrunmla ti nrose wpn bp lehin wa ide ibudo wpn 6 ba
Petebi re nikanso?o laarin gbogbo oku ogun. Qrunmla si wp
inu ibudo Ip o ko gbogbo eru aimoye ti nwpn ti nko sibe o si
kiiku ngbe ibe. Ayaani oo ri i a nwipe Qrunmla do sinu aje
tontasp sasii, Ogudabede.
5 ?
*N ihin ni Qdp fgwp lu ara wo bi yio ri ago aasara ati ogoji, ugbpn ko
ri won, Qrunmla si wa iyan awpn Amoosu ati Am ppre tele e ki nwpn b a a
Ip si ibiti o ti ya subaa: nwpn ba gbogbo nkan wpnyi nibp gpgp bi C runm la
ti wi. E nu si ya Qdp o wa imp pe on de pdp pniti o to iba jaiye w'ayi o,
o si joko ti Qrunmla lati pjp naa o n?e aya rp.
ORI 5.
60. Aisi Ogbe mi ehin, ogun ja ile
Ogbe - Wori.
63
Eleriwo.*
Oro a-biku-jigbo.
Awon baba wa mpe Orunmla ni a-biku-jigbo, nitori
nwon gbagbo pe
i . Orunmla nikansoso li o to Ikii iba-sire laifarapa, ati pe
i i . Orunmla nikansoso li o to Ikii iba-ja laigbe si i.
Ka ese - ifa wonyi
61. Orunmla Ji o m ori sile Ikii, o mese sile Arun, o
meegbe mejeeji si Ojiji Barisa iko Ikii. Awon babalawo
dahun nwon ni Orunmla nigbati o mii ori sile Ikii, Ikii ko
ni pa o
C.'
*Iyanhun ni ise Qmo ^l??wi, o pe ti ?w i ti ngbogun Ip si iiu Eleriwo ti
Ogbe nkifa fun Eleriwo spetp Ewi. lyanhun jpeje fun baba re pe on nwa
Ogbe Ip, o mu egbinrin obi kan bpni, o de phin odi ilu naa o ko Ogbe,
o beere pniti nje bep Ipwp re, eleyiini wipe on ni njp bpe, o si tele e Ip sile.
Nwpn de ile tan o ki i o mu obi fun u, o ni on ti ngburo re pe on si wa ise
aya rp nisisiyi. Ogbe fi ibugbe fun u. O to itadogun lyanhun ni on nyara
Ip iwo baba on ki on bp: o padawa iyp fun Ewi pe on ti ri Ogbe na o.
O pp dip o tun pada wa igbe bi itadogun Ipdp Ogbe. Li ppkpta ti lyanhun
ti rnpaara bayi ni o ji ada Ogbe pplu pppip re ati pwpifa kan ninu Ifa
rp sinu okp laijeki Ogbe mp, o mura o ni on nip bp baba on wo wa o.
Ogbe m ura o nsin i spna, nwpn nsprp Ip o ndun-mp Ogbe ko mp igbati
on rin jinna. Nigbati o fura o ni H aa! bi mo mp pe ngo Jinna to eyi,
se ng ba mu ada mi bpni! lyanhun yara tu pkp o mu ada Ogbe fun u:
nwpn si tun jum p nsprp rin Ip. O tun pp ni Ogbe tun duro pe on iba mp
on a mu pppip on bpni: nibp lyanhun mu ppple r^ fun u. Titi bpp Ogbfe
ko mp igbati on ba lyanhun wple Ewi; lyanhun mu Ogbe Ip iwp si yaara
iya rp o si wa Ip sp fun baba re li odi pkppsan Iphun pe on ti mu Ogbe de o I
Ewi ni ki a mu u wa iki on, o si ta a Iprp gidigidi. Loru pjp naa gan
ni Ewi ran ogun Ip ko ilu Eleriwo, nwpn si segun, nwpn si ko gbogbo enia
ibp wa fun Ewi. Ni kutu pjp keji Ewi tp Ifa re o ransp pe Ogbe ki o wa
iwo o fun on. A ri Ogbe - Wori. Ogbe dahun o ni H aa! Aisi Ogbe mi
phin, ogun ja ile Eleriwo o! Enu ya Ewi o si beere pe Kini pbp? A
ni agbebp adip meji ni; Ogbe pa pkan si pppip rp o tu iwu rp kiri ile nkprin
wipe
Otete pmp oliwu
Qran iwu To dun aladip, pran iwu.
E?u ko iwu adip wpnyi Ip ilp-mp iwaju awpn ara ile Ogbe ki a le mp
wpn sptp bi a ti nko wpn wple Ewi wa. Ewi si ko wpn pada patapata fun
Ogbe, o ni ki o maa pada Ip ijoko si Eleriwo ile re o.
v1
64
ORI 5
V.
63.
Oke se geere wpdo, adifa fun Orunmla Tkii ntp p
bpwa ipa a. A ni ki Orunmla ni olugbdro mefa, ewusa mefa*
-Ogbesete.
ati egbefa. Orunmla gbp, o ni; o sete.
ORI
5.
65
mu olugboro de loru, o fi lu okan ninu aya re mefa pa. Enu ya Iku lowurp
lati ri pe ki ise Qrunmla ni on pa; o roju dake o si tun fi Orunmla w6
sibomiran lal? naa: ugbpn loru, pkan ninu aya rp m arun iyoku li o Jp
lu - pa dipo
** nkan naa rin titi Iku fi pa gbogbo aya
re tan ni ireti ati -pa Qrunmla. Nigbati ile pjp kejp mp Orunmla ki
Iku, o ni on nip sile wayi o. Iku ni on yio sin Orunmla Ip. Orunmla ni
ki o mase sin on, ki o maa spfp awpn obirin re, on nip. Orunmla wa iji
gbogbo olugboro ti Iku nfi pania o ko o le ejika o Ip. Lati ojo naa ni a
ti nki Qrunmla ni A-ba-Iku-jigbo.
N inu awpn itan wpnyi a ri bi iwa Qrunmla ti yatp si ti Olugbala ti a
fihan-ni ninu Iwe Mimp Qlprun to. Lati ibpre Bibeli Mimp li a ti sptele
pe pniti yio se Olugbala araiye ko le jai-gbpgbp. Gen iii. 15 wipe Oii yio
fp Iku li ori, Iku yio si pa a ni gigiis^. Heb. ii. 14 wipe Nje niwpnbi
awpn prnp ti e alabapin ara on ejp , on tikarare pelu si mu ipa ninu re naa;
pe nipa iku ki o le pa pniti o ni agbara iku run, eyini ni Eu. Iwe Mimp
Qlprun sp daju pe ebp piyp ati pran ko le tan gbese iku ti pmp araiye ti je
sprun afi bi Olugbala naa ba le fi pmi ara r6 ati ori tir^ tati gbese naa.
Ninu Psalmu xi 6-8 aspt^l6 naa daju, a si turrip r$ ninu Heb. x. 4-10 bayi
pe Nitori o soro ti ejp akp maalu ati ti ewure, yio fi m u psp kuro. N itoi inaa nigbati o wa si aiye, o wipe, pbp ati pbp pip iwp ko f |, ?ugbpn ara ni
iwp ti pese slip fun mi: ninu pbp prp sisun ati pbp nitori pp iwp ko ni
inudidun si. Nigbanaa ni mo wipe, Kiyesi i, mo de lati se ifp tirp Qlprun(ninu apo iwe ni li a gbe kp p nipa ti emi). Nitisaaju nigbati 6 wipe,
Ebp ati pbp prp, ati pbp prp sisun, ati pbp nitori psp ni iwp ko fp, bppni
iwp ko ni inudidun si i ti a nru nipa ti ofin; nigbanaa li o wipe, Kiyesi i,
mo de lati se ifp tirp, Qlprun. O mu ti isaaju kuro, ki o le fi idi ekeji
mulp. N ipa ifp yi naa li o nsp wa di mimp nipa ifi ara Jesu Kristi tprp
lppkanoso. Jesu Kristi tikalarp si tum p ifi ara-rp tprp yi ninu Markii
X. 45 bayi pe Gpgp bi pmp-enia ko ti wa ki a se iransp fun u, bikose lati
m aa e iranp funni, ati lati fi pmi re se irapada fun ppplppp enia
Olugbala bi iru eyi ti o fi pmi rp lele fun awpn pmp araiye ko si loju
Qppn Ifa, ki isi ise Qrunmla ti awpn babalawo ilp wa nki.
ORI 6.
66
ORI VI
r
O
Oluwa mi Ajiki,
Qgege a-gb aiye-gun,
Odudu ti idu ori emere
O tun ori eni ko sian set
ORI 6.
67
^8
ORr 6.
Enit o mose jije ni ije Onise, aimojije ni ije Onie;a da a fun Sango Onikoso Ilaju nijo ti Olodumare nran a re
Ife Ooye Ilu Agbo Ip gba igba ori wa. Sango de Ife o duro
Ipja o k6 wipe E ku o enyin ara Ife, Olodumare ni ki ng da
igba ori wa o!
Gbogbo Ife gbp nwpn ho Ip kiihii,
nwpn ni Haa, kinla! ori ye re tabi ti ba re i? O di kitikitikiti nwpn le Sango gbpnre.
Enit 6 mpse jije ni ije Onise, aimpjije ni ije Onie,a da a fun Qrunmla Qsingbo nijp ti Olodumare nran a re Ife
Ooye Ilu Agbo Ip gba igba ori wa. Qrunmla de Ife 6 duro
Ipja 6 ke wipe E kii o enyin ara Ife, Olodumare ni ki ng
gba igba eku tontigba eja wa o ! Gbogbo Ife gbp nwpn ho
Ip kuhu, nwpn n i Qrunmla, o wii re 0 -0 -0 ! O di wiriwiri
gbogbo Ife yara da priin eku tontpnin eja wa fun Qrunmla
ki 6 jpwp ip ba wpn fi be Olodumare wipe awpn nwa iyokun
bplaipe o. Qrunmla gba eku on eja naa ogbeede pdp Olodumare o ni Eyiti awpn ara Ife i ri mii wa niyi o, nwpn nwa
ORI
6.
69
70
ORI 6.
ORI 6.
71
69.
Asese-pa ajuba ni ifese le ori eran geregeregere, a
da a fun Qrunmia nip gba ppa ptptpptp waiye. O mbp o ba
arp Iona 6 ni kilo se iwp ti o ri wpngu-wpngu bayi?
O ifi ppa ptptpptp kan a, lesekannaa arp na.
Asese-pa ajuba ni ifese le ori eran geregeregere, a da a
fun Qrunmla nip gba ppa ptptpptp waiye. O mbp o ba abuke Ipna 6 ni kil 6 e iwp ti etiin re e gannaku bayi? O fi ppa
ptptpptp kan a, lesekannaa abuke na.
Asese-pa ajuba ni ifese le ori eran geregeregere, a da a
fun Qrunmla nip gba ppa ptptpptp waiye. O mbp 6 ba afin
Ipna 6 ni kil 6 se iwp ti ara re funfun gboo bayi? O fi ppd
ptptpptp kan a, lesekannaa afin di dudii.
Aese-pa ajuba ni ifese le ori eran geregeregere, a da a
fun Qrunmla nip gba ppa ptptpptp waiye. O mbp 6 ba
aboyiin Ife ndaawp ati-bi spna, o ni kil 6 se iwp aboyun Ife
ti 6 nrapala bayi? O fi ppa ptptpptp kan a, lesekannaa
aboyun Ife bi tibi-tire. Ejiogbe.
Latihin ni awpn baba-nla wa ti nka ppplppp ie iyanu
iwosan ati omiran ti Qrunmla se laarin araiye.
Akiyesi; A se akiyesi ninu Bibeli Mimp awpn pna ti
imp yi gba de pkan awpn baba-nla wa. Nibi pipp li a ri ti
Bibeli Mimp nfi ppa se apeere pla, ase ati agbara.
72
ORI 6.
,(4)
Opa yi Ipwb Olprun je ppa agbara, ppa irin.
Psalni'a' i 10, 1-2;Oluwa wi fun Oluwa mi pe, Iwp joko li
pwp ptun mi, titi emi o fi sp awpn pta re di apoti-itise re. Oluwa
yio na ppa agbara re lati Sioni wa; iwp jpba laarin awpn
pta re. Psalmu 2, 7-9. Emi o si robin ipinnu Oluwa:
O ti wi fun mi pe, Iwp li pmp mi, loni ni mo bi p. Beere Ipwp
mi, emi o si fi awpn orile-ede fun p ni ini re, ati iha opin ile
li prp-ile re. Opa irin ni iwp o fi fp wpn; iwp o si run wpn
wdmu-womu bi ohun-yo amp.
(b) Opa yi Ipwp Jesu Kristi je ppa Olusp-agutan fun
aabo ati itunu awpn agutan re.Psa. 23, 1-4.
Oluwa li Olusp-agutan mi; emi ki yio se alaini. O mu
mi dubule ninu papa-oko tutii; o mu mi Ip si iha omi didake
rprp, O tu pkan mi lara; o mu mi Ip nipa pna ododo nitori
orukp re. Nitootp, bi mo tile nrin laarin afonifoji ojiji iku,
eriii'ki yio beru ibi kan; nitori ti Iwp wa pelu mi; pgp re ati
ppa re nwpn ntii mi ninu.
(d) Opa naa lowo Jakobu Je opa ase enu agba - idile
Heb. 11; 21.
Nipa igbagbp ni Jakpbu, nigbati o wa ni ibule ikii, o sure
fun awpn pmp Josefu mejeeji; o fonbale, o fi ara ti ori ppa tite
re.
(e) Opa naa Ipwp eya Judah je ppa-alade fun ipo pla
ninu Ijpba Gen. 49: 10.
Opa-alade ki yio ti pwp Judah kuro, beeni olofin ki yio
kuro laarin ese re, titi Siloh yio fi de; on li awpn enia yio gbp
tire.
(e) Opa naa Ipwp Mose ati Aaroni, Ipwp Elisa ati Ipwp
angeli ti o farahan Gideoni, je ppa ise iyanu. Eksod. 8.
16-17. Oluwa si wi fun Mose pe, Sp fun Aaroni pe, Na ppa
re, ki o si lu eekuru ile, ki o le di ina ja gbogbo ile Egipti.
Nwpn si se bee; Aaroni si na pwp re pelu ppa re, o si lu
erupe ile, ina si wa lara enia, ati lara eran; gbogbo eekuru
ile li o di ina ja gbogbo ile Egipti.
Num. 20 7-8. Oluwa si sp fun Mose pe. Mu ppa ni, ki
o si pe ijp awpn enia jp, iwp, ati Aaroni arakpnrin re, ki e sprp
si apata ni li oju wpn, yio si tu omi re jade; iwp o si mu omi
ORI 6.
73
lati inu apata naa jade fun won wa: iwo o si fi fun ijo ati fun
erah won mu. 9 Mose si mu opa naa lati iwaju Oluwa lo,
b i o ti fun Li li ase'
ii. Oba 4. 29 Elisa si wi fun Gehasi pe, Di amure re,
ki o si mu opa mi li owp re, ki o si Ip, bi iwp ba ri enikeni li
ona, mae ki i; bi enikeni ba si ki p, mase dd a lohiin: ki o si fi
ppa mi le iwaju pmp naa.
Onid. 6, 21. Angeli Olprun si wi fun Gideoni pe. Mu
eran nad, ati akara alaiwu naa, ki o si fi wpn le ori okuta yi,
ki o si da omi eran naa sile. On si se bee. Nigbanaa ni
angeli Oluwa na ppa ti o wa li pwp re , p si fi ori re kan eran
naa ati akara alaiwu naa; ina si la iati inu okuta naa jade,
6 si jo eran naa ati akara alaiwu; angeli Oluwa naa si Ip kuro
niwaju re.
Oniruuru pna wpnyi ni awpn baba-nla wa nfe ki a mp-mp
Opa Otptpptp Ipwp Orunmla fun ise atunse-aiye ti nwpn
gbagbp pe Olodumare ti fi le e Ipwp.
(d)
Awpn ohun miran ti Olodumare fun Orunmla lati
maa mu bpni fun ise titun-aiye-se ni Irpfa ati
Irukere.
70. Orunmla ni Asape, mo ni Asape, 6 ni bi a ba
sa-pe pde a gbapo re.
Orunmla ni Asape, mo ni Asape, 6 ni bi a ba sa-pe
ajagun a gbasa re.
Orunmla ni Asape mo ni Asape, 6 ni bi a ba sa-pe
osowo a gbe owo anakii re.
Orunmla ni Asape, mo ni Asape, 6 ni bi a ba sa-pe
emi Orunmla, emi a mu Irpfa ide, emi a mu Irukere, okun,
ko si eniti o le gba adie temi sin.Osa-meji.
Latihin ni gbogbo Oluwo (eyini ni Olu awo tabi Olori
ninu egbe awpn babalawo nibikibi) a maa je Asape li ooki
oye re.
(e) Ohun pataki miran ti awpn baba-nla wa gbagbp pe
Olodumare tun fifun Orunmla ni Osumare Egp
ti imaa bi ohun rere gbogbo jade fun ilo Orunmla
ni oniruuru ati ni iwpnkiwpn ti Orunmla ba ti fe
fun atunse aiye.
ORI 6.
71. Irofa mi ki ise ei, Irukere mi ki ise ida, Iboju mi
ki ise apata; a da a fun Qrunmla nlo fe Osumare Ego se aya
Osumare Ego ti iomo Qlpoja Ororo.-Osumare Egg ni iu
owd, Osumare Ego ni iu okim, Osumare Ego ni isu ide:
Osumare Ego! iwo ko je pada ki o wa su temi fun mi,
Osumare Ego!
Latihinvi nelu ni awon ogbo awo ati olosanvin ati adahunse ni iie^wa iti imiaa's'alen ohun awamaari kan ti nwoma maape_
ni Imi O su m are/ nwnn nehagho pe 6 ni agbara lati maa bi
ohun alumoni gbogbo fun enikeni ti 6 ba m i sil^ nito'ri'
nigbati Qrunmla ni Usumare, 6 di ploro nmu ohun gbogbo
nipa agbara ibisi ti Osumare ni, ti 6 si imaa 16 fun, ati nipa
ase Qrunmla.
Akiyesi:Iro yi ko de okan av/on baba-nla wa lasan;
Olorun ti ise Eleda won li 6 gbin i sibe. Lati ni ohun gbogbo
je apakan ola Olorun, nje enia ti a da li aworan Olorun ko
le saife lati ni ohun gbogbo pelu. Bi enia tile je alaimona naa
ti a igba ini ohun gbogbo, sibe eyiini ko wipe ki aare ki 6
mu u, tabi ki suuru tan a ninu sise aferi ipa naa. Sugbon,
iwo ti nka iwe yi, mo fe ite e mo o lokan nihinyi pe bi iwo ba
life ni ohun gbogbo, kotete saferi Olorun ati Kristi Re.Matt.
6: 31-33. Nitorinaa e ma gbero wipe, Kili a o je? tabi,
kili a o mu? tabi, nibo H a o ti fi aso wo wa? Nitori gbogbo
nkan wonyi li awon keferi nwa kiri. Baba nyin ti mbe li
orun mo pe, enyin ko le se alaini gbogbo nkan wonyi. Sugbon
e tete maa wa ijoba Olorun ati ododo re: gbogbo nkan wonyi li
a o si fi kun u fun nyin.
Osumare Ego Qlooja Ororo.
Itumo oruko vi Osumare jasi Osu ti o tobi julo. A
kiyesi i pe ati Osumare ati ojuyosii, ko si eyiti o le le soju orun
ninu ewa ati ogo re laisi agbara ooriin. Latinu ogo oorun ni
osumare ti ijade soju sanma:Latinu agbara oorun kannaa ni
ohun oro gbogbo lori ile ati ninu omi nisale ile ti njade wa pelu.
Lati wadi oran yi siwaju kiyesi ifiwe ti ala Josefu ni legbe awon
ibukiin re. Gen. 37. 9-11 O si tun la Ma miran, o si ro o fun
awon arakonrin re, o wipe, Sa wo o, mo tun la Ma kan si i ; si
wo o, oorun ati osupa, ati irawo mokanla nforibale fun mi. O
si ro o fun baba re, ati fun awon arakonrin re: baba re si ba a
wi, o si wi fun u pe, Ala kili eyi ti iwo la yi? Emi ati iya re, ati
awon arakonrin re yio ha wa nitooto, lati foribale fun o bi?
Awon arakonrin re si se ilara re; sugbon baba re pa oro naa
mo.
74
ORI 6
75
76
ORI 6.
ti nko ese aiye lo, Iwo Qdo-ajgutan ti a pa, ti o si tiia mbe laaye
lai ati iailai, ani IwQ JESU KRISTi li o da ohiiii gbogbo, ati
nitori wiwii re ni nwon fi
ti a si e da won.
Nje lehin gbigbo ati mimo orp-orin yi daju, iwo onigbagbp
ati olufe Kristi yio pa ara-re mp kuro Ipdp awpn ti nsaferi
Agamrara ati Imi Osumare (aii Ipdp awpn ti ndeda) fun ati-ni
prp pipp: iwp yio kiikii maa tele impran iyebiye ti Paulu fifun
gbogbo enia Olprun bi a ti kp p sinu i Tim. 6, 16.Sugbpn
iwabi-Olprim pelu itelprun ere nla ni. Nitori awa ko mu ohun
kan wa si aiye yi, o si daniloju pe awa ki yio si le mii ohun lean
jade Ip. Bi a ba si li onje ti on ti asp, ki eyiini ki o te wa Iprun
sugbpn awpn ti nfe di plprp a maa bp sinu idanwo ati idekiin,
ati sinu were ifekufe pipp ti ipanilara, ti si nri enia sinu iparun
ati egbe. Nitoripe ife owo ni gbomgbo iwa buburu gbogbo:
eyiti nigbati elomiran nfi ojukokoro wa kiri, a ti tan wpn je
kuro ninu igbagbp, nwpn si fi ibinuje pipp gun ara-wpn li
pkp. Sugbpn iwp, enia Olprun, sa fun nkan wpnyi; ki o si
maa tp ododo, iwabi-Olprun, igbagbp, ife, suuru, iwa tutu
lehin. Maa ja ija rere ti igbagbp, fi pwp le iye ainipekun,
nibiti a gbe pe p si pelu ti iwp si se ijewp rere niwaju eleri
pupp. Mo fi ase fun p niwaju Olprun, ti nsp ohun gbogbo di
aaye, ati niwaju Jesu Kristi, eni, niwaju Ppntiu Pilatu, ti o
o jeri ijewp rere; Ki iwp ki o pa ase yi mp li ailabawpn, li
ainibawi, titi ifarahan Jesu Kristi wa: Ni igba tire, eniti yio
fihan, Olubukun, ati Alagbara naa kansojo, Oba awpn pba,
ati Oluwa awpn oluwa; Eniti on nikansoso ni aiku, o tedo
sinu imple ti enikan ko le sunmp; eniti enikan ko ri, beli a ko
le ri i: ti pla ati agbara mbe fun Iailai. Amin.
Odudu ti idii ori emere,
O tun ori eniti ko sian e.
Awpn baba-nla wa gbagbp pe pwp awpn emi buburu kan
wa ti imaa le pmp tootp kuro ninu aboyiin lati gba ipo nibe.
Nigbati a ba bi iru pmp bee, nwpn ki ipe iku mp iya wpn Ipwp:
tabi, nwpn a dagba de akoko ti iwp gbogbo enia lara tan,
nigbanaa nwpn a se-kii mp gbogbo enia loju. Iru awpn
eni bee li awpn enia ile wa mpe ni emere. Nitorinaa, lati
du ori rere fun awpn emere tabi eleere be, awpn pkp a maa
fa aya wpn fun babalawo tpju bi nwpn ba ti loyun: nwpn ni
igbekele pe nipa riru ebp igbagbogbo fun aboyiin bee, awpn
emi emere ki yio le pa orirere ti pmp-titun naa mba bpwa
aiye di buburu mp p ninu. Eyi ni ije didii-ori emere.
'V
O RI 6 .
\9 ^ /
77
Ewe, ninu igbagbo ile wa, awpn enia ti ifiiwa buburu titi
kan iku gbigbona je olori aisiin; bee gege ni gbogbo eni rere ti
i?ubu spwp eni buburu je olori aisian: bee gege ni gbogbo enia
ti wahala, ippnju tabi idaamu mba ni abale-abale ni olori
aisian. Awpn baba-nla wa gbagbp pe Orunmla a maa tun
ori aisian bawpnni e nipa yiyan ebp igbagbogbo lati tii
wpn.Ka ese - ifa wpnyi;
72.
Orunmla ni A-ro-de mo ni A-ro-de, O ni Enyin
pmp weere ti nip sinu aiye, nigbawo li e o pada bp? Nwpn
dahun wipe nigbati pja ba ti to gaan li awpn mpada bp.
Orunmla ni Mo wp! emi ki iba awpn eleyi se ajprin.
Qrunmla ni A-ro-de mo ni A-ro-de, O ni Enyin
igiripa ti nip sinu aiye, nigbawo li e o pada bp? Nwpn
dahun wipe nigbati pjp ba ti kan tari gaan li awpn mpada bp.
Orunmla ni Mo wp! emi ki iba awpn eleyi se ajprin.
Orunmla ni A-ro-de mo ni A-ro-de, O ni Enyin
agbaagba ti nip sinu aiye, nigbawo li e o pada bp? Nwpn
dahun pe O di pjp ti a ti ile di agube, ti prp godogbo to wa
nikiile Olodumare fu imii lese sarasara. Orunmla ni
Een-een! mo ri awpn ti ngo ba se ajprin wayi o. O wa mekiin
sekiin igbe, 6 mohim sohim iyere, 6 ne
Akp eranla f ori tarapo,
Iware prun m aa ba-rin
Mee bemere rinl
73. Qrunmla ni Arode mo ni Arode,a da a fun
awpn pmp weere-weere nip sinu aiye ti Onibode nda wpn
dehin Ipna nwpn nkii li pmp k6k^k6. A ni Eetiri? A
ni nwpn ko duro de Qrunmla ni.
Meji tpkpnrintobirin ninu wpn ti Qrunmla beere Ipwp wpn pe Tani e ha
duro de? Nwpn ni Iwp Qrunmla ni, O ni Nje, o dara, e
e maa kalp. Nwpn ba Qrunmla de ibode, Onibode nfe da
wpn dehin; Qrunmla bebe fun wpn, o si san ojoojuliigba
lori wpn. Ayaani o ri ojoojuliigba naa li a nsan fi gbp ori
pmp- titun titi di oni.Ogoofu.
74. Qrunmla ni Qkanrandi mo ni Qkanrandi O ni
Ori pmp eku ti Qkanrandi ha gbo bi? Mo ni Ori pmp eku
ko ma gbo o!
Qrunmla ni Qkanrandi mo ni Qkanrandi O ni Ori
pmp eja ti Qkanrandi ha gbo bi? Mo ni Ori pmp eja
k6 ma gbo 6!
2
78
y
ORI 6.
V)
/75. Ori rere ni isegun ota, ori aisian ni ota idi li adipa.
Nje tani bi mi 6? Ogiida t a tura pa! E je ki nwon o maa
^subu le ra won, ki nwon k 6 maa para won. Gbogbo pta ti
mo ba ni ko ni iye, pipa ni ki nwon o maa para won lo
beerebe. Sugbpn emi kd ma mpta emi ko ma modi 6!
\ I
\,
awegbd ma n i;
awegbd ma n i;
awetp ma ni;
awetp ma n i!
awemp ma ni,
awemp ma n i!Otura-Ka.
ORI 6
79
80
ORI
IPARI
IWE
NAA.
ASOJO
AWON
ORI IWE
NA A
C o n c e n t r a t e d s a n c t u a r y s o Ap ;-
6 ; 10s
s a n c t u a r y po w d e r
:-
S a n c t u a r y o i n t m e n t :-
10s
Sa n c t u a r y
o il
:-
17/-6
Branch Office:
5, Campbell Street,
Lagos.
. L ij A d u ,
Ajihinrerelofe Flouse,
64, Lokun Street,
P.O. Box 76,
Tel. 85, Ondo.