Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 1

awure

Agbe ni i gbe're k'Olokun


Aluko ni i gbe're k'Olosa
Odidere-Moba-Odo Omo Agbegbaaje-ka ni
naa ni i gbe're k'Oluwoo;
Ela-lwori, .gbere pade lona dandan
Olojo-Esinminrin-kuntelu-telu
Je k' Aje wa ku sile bayii
Ibiokabasi,
Igba eranko ni ba nibe ti i je;
Ifa ere kii-je k' ebi ko
Oju kan tesa ba'jokoo si
Laa gbe' re tiree wa ba
He ni ataso n joko t'okerekere i wo to
lleTatapo ijokode'di:
Ajigbore ni t'aatan;
Ojumo kii mo k'aatan mo gbore
Olojo-oni tatemi lore
Gbogbo omi ni i fori fOlokun;
Gbogbo abata ni i fori fOlodo, ''
Ise gbogbo agbara ba se
Olodo ni i fi sin;
Osin lo ni ki won wa sin
Aso alapo loga i gba;
Ti gbo ti'ju ni j gbonwu eegun
Omode ilu, agba ilu, e waa fire gbogbo sin mi o
Ire gbogbo lagbara fi sin olodo.
Ire gbogbo

You might also like