Reviewed Yoruba Scheme - All Classes - July 2009

You might also like

Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 20

CHILD OF PROMISE SCHOOL

YORUBA LANGUAGE SCHEME OF WORK ( GRADE 1 6)


GRADE 1
SAA KIN-IN-NI (FIRST TERM)
1.

Mo mi n mo o.

2.

Ikini--Laarin ojo.

3.

Alifabeeti A --- GB.

4.

Orin: Kin ni mo ko soke yii o?

5.

Alifabeeti: GB - O

6.

Alifabeeti: O -Y

7.

Alifabeeti A - Y

8.

Orin - Awa soja kekere.

9.

Orin - Awa soja kekere

10.

Aworan kika

11.

Atunyewo ise saa

12.

Idanwo

13.

Atunse idanwo

14.

Ipari saa

GRADE 1

SAA KEJI (2ND TERM)


1.

Faweli akosori (a, e, e i, o, o, u)

2.

Konsonanti.

3.

Konsonanti ati faweli.

4.

Apapo konsonanti ati faweli.

5.

Fifi alifabeeti pile oro.

6.

Fifi alifabeeti pile oro.

7.

Orin: Iya ni wura ..

8.

Orin: Iya ni wura

9.

Atunyewo ise saa.

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa.

GRADE 1

SAA KETA (3RD TERM)


1.

Onka: 1-5

2.

Onka: 5-10

3.

Ewi ---Ja itanna------------

4.

Orin ---Ja itanna-----------

5.

Lilo oro ni gbolohun

6.

Orin: Labe igi orombo

7.

Ewi - Yi ese re si apa kan.

8.

Ewi - Yi ese re si apa kan (contd).

9.

Atunyewo ise saa

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa.

GRADE 2
SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)

1.

Lilo oro ni gbolohun

2.

Awon ohun ti o wa ninu kilaasi

3.

Yiya aworan awon ohun ti o wa ninu kilaasi

4.

Awon ohun ti o wa ni ayika ile iwe

5.

Awon ohun ti o wa ni ayika ile iwe

6.

Orin - Ijo mojo lanaa.------

7.

Ohun ti o wa ninu iyara idana.

8.

Ohun ti o wa ninu iyara idana (contd.)

9.

Iwe kika.

10.

Sipeli.

11.

Atunyewo ise saa

12.

Idanwo

13.

Atunse idanwo

14.

Ipari saa

GRADE 2

SAA KEJI (2ND TERM)


1.

Ojo ninu ose

2.

Orin: Aiku, Aje, Isegun, abbl.

3.

Orin idaraya - Eye meloo tolongo waye..

4.

Onka 1 -10

5.

Onka - 11 - 20

6.

Aworan kika Alawiiye iwe kin-in-ni eko 19.

7.

Ewi Bo oju re bi o ba ji

8.

Ewi -- Bo oju re bi o ba ji

9.

Atunyewo ise saa.

10.

Idanwo

11,

Atunse idanwo.

12.

Ipari saa

GRADE 2

SAA KETA (3RD TERM)


1.

Eya ara - Ti ori

2.

Eya ara Gbogbo ara.

3.

Eya ara -- Gbogbo ara

4.

Orin ori mi, Ejika mi.......

5.

Iwe kika Alawiiye 1; Eko 21

6.

Orisi awo dudu, funfun.

7.

Ise sise lori awo.

8.

Orin ----Bata mi a ro ko ko ka

9.

Atunyewo ise saa.

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa.

GRADE 3
SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)
1.

Akoko laarin ojo-Aaro, osan, irole ati ale

2.

Oruko awon ojo ninu ose

3.

Onka : 1 - 10

4.

Onka : 11 - 20

5.

Onka : 21 -30

6.

Osu inu odun.

7.

Osu inu odun (contd)

8.

Orin Osu inu odun

9.

Ounje ile wa

10.

Ounje ile wa

11.

Atunyewo ise saa.

12.

Idanwo.

13.

Atunse idanwo.

14.

Ayeye ipari saa


j

GRADE 3

SAA KETA (3RD TERM)


1.

Oro ati idakeji

2.

Oro ati idakeji

3.

Orin:- E ma weyin o

4.

Ere idaraya: E ma weyin o..

5.

Ewi: ise loogun ise 1 7 lines

6.

Ewi Ise loogun ise (contd)

7.

Ihun gbolohun - Oro oruko

8.

Ise sise lori oro oruko

9.

Agbeyewo ise saa keji

10.

Oruko olorun

11.

Oruko olorun

12.

Ayeye ipari saa.

GRADE 4
SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)
1.

Silebu Oloro meji ati meta

2.

Isomoloruko: Awon ohun elo isomoloruko

3.

Orin Omo lao fi gbe / Kulumbu yeye

4.

Asa isomoloruko

5.

Oruko abiso

6.

Oruko amutorunwa

7.

Mimo aago--aago kan, aago meji---------

8.

Ise sise lori aago.

9.

Orin - Agogo baba mi------------

10.

Orin - Agogo baba mi------------

11.

Atunyewo ise saa.

12.

Idanwo.

13.

Atunse idanwo

14.

Ayeye++++++++++++++++++++++++++++++++++ ipari saa.

GRADE 4
SAA KEJI (2ND TERM)
1.

Oge sise Itoju ara.

2.

Oge sise Ohun elo itoju ara.

3.

Orin Imototo -------

4.

Awon eso nile Yoruba.

5.

Ihun gbolohun: Oro ise

6.

Iwe kika: Alawiiye iwe kin-in-ni, Eko 5

7.

Orin--Kawa sile eko wa.--------

8.

Ewi: Ise loogun ise-------

9.

Atunyewo ise saa.

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa

GRADE 4
SAA KETA (3RD TERM)
1.

Orin orile ede Naijiria

2.

Onka 1 - 20

3.

Onka 21 30

4.

Onka 31-40

5.

Ise sise lori onka.

6.

Ipinle Yoruba ati Olu-ilu won

7.

Iwe kika Akotun Yoruba Eko 5

8.

Orin: Ka wa sile iwe wa lakoko.

9.

Atunyew o ise saa.

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo

12.

Ayeye ipari saa.

GRADE 5
SAA KIN-IN-NI (1ST TERM)
1.

Faweli geere ati aranmupe

2.

Ami ohun: Ifaara (orisi ami ti o wa)

3.

Fifi ami si ori awon oro

4.

Aroso: Emi

5.

Aroko: Emi

6.

Oro ati idakeji

7.

Oro ati idakeji

8.

Eje orile ede Naijiria

9.

Eje orile ede Naijiria

10.

Orin: Ile iwe Korona

11.

Atunyewo ise saa

12.

Idanwo.

13.

Atunse idanwo .

14.

Ayeye ipari saa

GRADE 5

SAA KEJI (2ND TERM)


1.

Awon ohun elo igbeyawo (idana)

2.

Awon oba alaye ile Yoruba

3.

Awon oba alaye ile Yoruba

4.

Ewi: Ise ni oogun ise

5.

Ihun gbolohun-Oro apejuwe

6.

Ounje ile Yoruba.

7.

Ipapanu nile Yoruba.

8.

Orin omode Omo to mo iya re loju.

9.

Atunyewo ise saa.

10.

Idanwo

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa

GRADE 5

SAA KETA (3RD TERM)


1.

Onka:1- 40

2.

Onka 41-50

3.

Oge sise: irun didi

4.

Ohun irinse atijo

5.

Ohun irinse ode-oni

6.

Orin: Kayode, Kayode, sare wa abbl

7.

Ewi - Ewure jeran ile -----

8.

Ewi - Ewure jeran ile (contd)

9.

Atunyewo ise saa.

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa.

GRADE 6
SAA KETA (3RD TERM)
1.

Orin orile- ede Naijiria

2.

Eje orile-ede Naijiria

3.

Ami ohun (fifi ami si ori oro)

4.

Akoto Yoruba ode oni.

5.

Awon igi owo ni ile Yoruba (igi koko, obi abbl)

6.

Iwe kika Alawiiye iwe keji Eko keji

7.

Orin ---- Olurombi.

8.

Orin ---- Olurombi

9.

Agbeyewo ise saa.

10.

Idanwo.

11.

Atunse idanwo.

12.

Ayeye ipari saa.

Name :___________________________________
ONKA YORUBA
1. Ookan

______________________________

2. Eeeji

______________________________

3. Eeta

______________________________

4. Eerin

______________________________

5. Aarun

______________________________

6. Eefa

______________________________

7. Eeje

______________________________

8. Eejo

______________________________

9. Eesan

______________________________

10.Eewa

______________________________3

YORUBA
ORUKO AKEKO : ______________________________________________
ORO ATI IDAKEJI (WORDS AND OPPOSITE)
ORO

IDAKEJI

Otun

Osi

Tobi

Kere

Funfun

Dudu

Okunrin

Obirin

Baba

Iya

Egbon

Aburo

Ga

Kuru

Sanra

Tinrin

Ibere

Opin

10

Le

Ro

11

Oke

Isale

12

Agba

Omode

13

Oko

Iyawo

14

Ore

Ota

15

Oluko

Akeko

ORUKO ABISO

(NAME GIVEN AS THE PARENT WISHES)

Oluwatosin ____________________________________________________
Funmilayo ___________________________________________________
Akinjide

______________________________________________________

Modupe

____________________________________________________

Eniola

_____________________________________________________

Oluwafemi

__________________________________________________

Omolola

____________________________________________________

Temitayo

____________________________________________________

ORUKO AMUTORUNWA (NAME GIVEN BY SITUATION OF BIRTH)


Taiwo ____________________________________________________
Kehinde ___________________________________________________
Idowu

______________________________________________________

Alaba

____________________________________________________

Babatunde
Yetunde
Iyabo

________________________________________________

__________________________________________________

____________________________________________________

Abosede ____________________________________________________
Abiona

__________________________________________________

Abioja

____________________________________________________

You might also like