Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 1

ORK S DR

Ka sure tete ka pErin ti ise elehin i refe, Erin elehin-i-refe ni ki enikeni ma pe oun
mo. O ni oun ki ise onimodumodu ninu eranko. O ni oun ki ise onimodumodu ninu
eranko. O ni oun ki ise onimodumodu ninu eranko. Ka sure tete ka pEf on omo
Ajaka Igede. Ka sure tete ka pEf on omo Ajaka Igede. Ka sure tete ka pEf on omo
Ajaka Igede. PAgbonrin galaja ti ise omo Olu-igbo. PAgbonrin galaja ti ise omo
Olikolo Adaka. PAgbonrin galaja ti ise omo Olikolo Adaka. PAgbonrin galaja ti
ise omo Olikolo Adaka. PEtu beleje ti ise ono Olu-igbo. PEtu beleje ti ise omo
Olu-igbo. PEtu beleje ti ise omo Olu-igbo. PEkiri dudu aladuja ti ile Oluwonran
Aja sori gbongbo gbe. Atikara-nikoko, oruko ti aipe Ibon, Iji-mawo oruko ti aipe
Ori, Korimawo ni oruko ti aipe Olodumare, Ela-garara ni ise Oluwo isalu Orun.
Eyin lonile Akunrun ti won ntanna ola wo. Elgarararar! O to gege kiowa tanna Ola
temi fun ni. Ijo tiaba fi ewe ina tanna nile aye won kasaigbOrun mo. Elagararara!
Wa tanna Ola temi fun mi. Elagararara Eyele mi fo won a rOkun, Eyele mi fo won
a rOsa Apa Otun, apa Osin oun ni Eyele fi i ko; re aje wole Elagararara! Orunmila!
Wa tanna Ola temi fun mi Elagarara! Osetura! Iwo lo ngbe ebo de doe Orun, O ki i
sun osan, o ki i sun oru, Osetura! Ki o wi fun Eledumare ki o ni mo kunle Ola temi
dandan, Elagararara Ijo ti won ba fowu akese tanna nile aye won kasai gbOrun
mo. Elagarara! Wa tanna Ola temi fun mi! Elagarara! Ase.

You might also like