Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 5

Yoruba Names of Animals

======================

Alligator - Ahọnrihọn
Ants (black) - Tanpẹpẹ
Ants (white) - Ikan, Ikamudu
Ants (red) - Abonilejọpọn
Antelope - Egbin/Ẹtu/Olube/Esuró
Ape - Ẹdun
Baboon, Gorilla - Ìnàkí , Inoki, Iro
Bat - Adan
Bed-bug - Idun
Bee - Oyin
Beetles (a species) - Yanrinbo
Bird (a species) - Afẹrẹgbojo/Afe-imojo
Bird (a species) – Olofere
Bird (songbird) - Ẹyẹ-Orin
Bird (Seabird) - Yanja-yanj
Bird (white-feathered) - Lekeleke
Boa Constrictor - Ere
Boar (wild) – Ìmàdò, Ẹlẹdẹ - Igbo
Buffalo - Ẹfọ̀n
Butterfly - Labalaba
Camel - Ràkunmí
Camel - Ibakasiẹ
Cat - Ológbò/Ológìnní
Centipede - Tanisanko
Chamelon - Ọga, Alagẹmọ
Cheetah - Ọ̀wàwà
Chicken - Oromọ-Adiẹ
Chimpanzee – Elegbede
Civet-cat - Ẹta
Cobra - Ọka
Cockroach - Ayan
Colt (young horse) - Agodongbo
Cow – Abo-malu
Cow (bull) - Malu
Crab - Akan
Crane (bird) - Akọ
Cricket - Irẹ
Crickets - Okinrin
Crocodile - Ọoni
Deer (male) – Ìgalà
Deer (a species) - Ekulu
Dog – Aja
Donkey - Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́
Dove - Adaba
Duck - Pẹpẹyẹ
Eagle - Idi
Earthworm – Ekolo
Electric Fish - Ojiji
Elephant - Erin/Ajanaku
Flea/Tick - Eegbọn
Fox (Reynard) – Kọlọkọlọ
Frog - Ọpọlọ
Gadfly - Iru, Eṣinṣin- N la
Giraffe - Agbanrere
Gnats - Kokoro-Ojuọti
Goanna – Awonrinwon
Goat (he) - Òbúkọ
Goat (she) - Ewúrẹ́
Gorilla, Baboon - Inaki, Inoki, Iro
Guinea Fowl - Awo
Guinea Fowl - Ẹtu
Guinea Pig - Emọ́n-Ile
Hare/Rabbit - Ehoro
Hedgehog - Ọ̀yà
Hind (female deer) - Abo-Agbọnrin
Hippopotamus - Erinmi
Horse - Ẹṣin
Horse (colt) - Agodongbo
Hound - Aja-Ọdẹ
Housefly - Eṣinṣin/Eṣin
Hawk - Asa
Hyena/Wolf - Ikoko
Insect - Ipin
Jackal -Akata/Ajako
Jelly-Fish - Ẹja-Odo
Leopard - Àmọ̀tẹ́kùn
Kine (female bovine) – Abo-Malu
Lice - Ina-Ori
̀ iu
Lion - Kin ̀ ́n
Lizard - Alangba
Lobster - Alakasa
Millipede - Ọkun
Monkey - Ọ̀bọ/Ẹdun
Monkey (brown) - Ìjímèrè
Monkey (yellow-haired) - Sọmidọlọti, Oloyo
Mosquito - Ẹfọn/Yanmu-yanmu
Mouse - Eliri
Nocturnal Animal - Ajao
Ostrich - Ogongo
Owl - Owiwi
Ox, Bull - Malu
Palm-Bird - Ẹga
Palm-Bird - Ologiri
Pangolin - Akika
Parrot - Odidẹrẹ
Partridge - Aparo
Peacock - Ọkin
Pelican - Ẹyẹ-Ofu
Pig/Swine - Ẹlẹdẹ
Pigeon - Ẹyẹle
Pigeon (wild) - Oriri
Porcupine - Oorẹ, Eerẹ, Ojigbọn
Pouch Rat - Okete
Python-Constrictor - Ojola
Rabbit/Hare - Ehoro
Ram - Agbo
Rat/Mouse - Eku/Ekute
Raven - Ẹyẹ-Iwo
Red-Ants - Abonilejọpọn
Reynard (fox) - Kọlọkọlọ
Rhinoceros - Àgbánréré
Scorpion - Ojogan/Akeekee
Seagulls - Pẹju-pẹju
Shark - Akurakuda
Sheep – Àgùntàn
Shrew - Aşin
Song Bird - Ẹyẹ-Orin
Snail - Igbin/Aginniṣọ
Snail (fresh water) - Iṣawuru
Sparrow - Ologoṣẹ
Spider - Alantakun
Spit-Snake - Sebe
Squirrel - Ọkẹrẹ
Stallion - Akọ-Ẹṣin
Steer - Ẹgbọọrọ-Akọ Malu
Swallow - Alapandẹdẹ
Swine/Pig – Elede
Tick/Flea - Eegbọn
Tiger - Ẹkùn/Ògìdán
Toad -Kọnkọ
Tortoise - Àjàpá/Ìjàpá
Trout - Ẹja
Turkey - Tolotolo
Viper - Paramọlẹ
Vulture - Igun, Gunnugun, Gurugu, Akala
Wall-Gecko (house lizard) - Ọmọnle
Water-bird - Osin
Wild Goat - Edu
Wild Pigeon – Oriri
Wolf/Hyena - Ikoko
Wood-Carrier - Arigiṣẹgi
Woodcock – Agbe
Woodcock (a species of) – Aluko
Woodpecker - Akoko
Zebra - Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́-Abila/Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ abilà

You might also like