Text 3

You might also like

Download as txt, pdf, or txt
Download as txt, pdf, or txt
You are on page 1of 1

AWON ISE IWOSAN TI ALE LO OYIN GIDI FUN__OYIN WULO NINU IRIN AJO AYE OMO EDA.

1,BELU BELU:-AO LO ESO ABERE EKUNWO KAN KUN NA DAADAA AO POMO OYIN GIDI ,AO MALO
SIBI KAN NI WAKATI KO KAN TITI TI YIO FI RA.
2,ARAN INU :-AO LO ESO IBEPE PIPON, ARA FUN OMI ARA IBEPE YI, PELU OYIN GIDI AO DA
GBOGBO RE PAPO, AO MALO SIBI MEJI NI EMARUN LOJUMO .
3,APORO MAJELE:-AO LO OROGBO GBIGBE KUNNA DAADAA ATI ESO ABERE DIE,AO DA OYIN SIBI
MERIN ATI EPO PUPA DIE MO,AO WA PONO AGOLO MILK KAN, ENINA YIO MU LESEKESE.
4,ALESE DEEDEE OKUNRIN LODO OBINRIN:-AO SE ALUBOSA ONISU FUNFUN META TI YIO RO
DAADAA, AO FUN OMI RE, AO SE, AO DA DEEDEE OYIN RE PAPO MO OMI ALUBOSA YI, AO GBE
KANA AO SE FUN ISEJU MARUN, AO MALO EMEJI LOJUMO.
5,ORA INU ARA:- AO PO OYIN GIDI MO OMI OSAN WEWE DEDE IYE IWON KAN NA, AO FII OMI
DIE SI, AO MA MU IDAJI CUP LEMETA LOJUMO FUN OSE KAN AO SI MA SE EXERCISE,
6,ATO SISAN:-AO LO OPOLOPO ESO OGBOLO KUNNA DAADAA , AO RE SINU OMI FUN OJO KAN, AO
MA BU IDAJI GLASS CUP PELU SIBI OYIN GIDI MEJI SI AO MA MU LEKAN LOJUMO.
7,AISAN ENU RIRUN:-AO PO OYIN GIDI ATI OMI OSAN WEWE DEDE IYE IWON KAN PAPO,AO MA
FIFO ENU WA LEMETA LOJUMO.
8,ULCER:-OYIN IGO KAN ,ADIN EYAN IGO KAN, AO DA MEJEJI PAPO MO ARA WON ,AO GBE PAMO
DI OJO META , LEYIN OJO KETA AO MALO SIBI MEJI LARARO ATI LALALE LEYIN OUNJE.
9,AISAN ARA TI ENIYAN BA NI IDA DURO OMO:-TAGIRI META AO RO EPO ARA RE BI RE NI RO
OSAN AO WA FI BLADE GE SI WEWE ,ADI EYAN IGO KAN, ALUBOSA ELEWE IDI MERIN AO AO FI
BLADE GE SI WEWE, AO WA GBE ADI NA KANA, AO WA DA TAGIRI TI A GE SI PELU ALUBOSA
ELEWE TI YIO GBE (DRY) DADA ,AO WA SO KA LE KO TUTU TO BA TI TUTU AO WA SI ASERE
GBA SI NU IKE (PLATE) KAN , AO LO KAUN BILIALIA MO ,AO WA DA MO OYIN ILAJI IGO ODI
MUMU NIBI META NI ARO ATI ALE....
10,EDA OBINRIN:-OROGBO GBIGBE 9,EWE PATAN MO ABO,EWE IYEYE,EGBO AKA,EWE IROKO PELU
EGBO RE,EWE TUDU PELU EGBO RE,EGBO AKO IBEPE ODO ASUWON DIE BI AGOLO KAN, ISAWURU
KAN,OBI ABATA OLOJU MERIN KAN,PELU ATARE AJA KAN, AO JO GBOGBO RE PAPO AO DA SINU
OMI OSAN WEWE

You might also like