Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 1

OSE MEJI

1. Opo ile ni ose molonkun adifa fun ara Ibadan ojegbin eyi ti yio jegbin ti yio fikararun re fori fomo mu
nijo tiwon n sunkun pe awon ko bimo ebo ni wonni ki won o se, won gbe ebo won rubo, won gberu won
teru, nje ara Ibadan ojegbin eyin le jegbin le fikararun re fori fomo mu, eropo ero ofa, ewa bani ni wowo
ire gbogbo.

2. Woorowo ni ejo n wogbe adifa fun eji ose eyi ti yio segun ota laye tio si tun segun ota niwarun, ebo ni
wonni kose, o rubo o teru, eropo ero ofa, ewa bani ni wowo ire gbogbo.

3. Ose wuru bi eni seke adifa fun agarawu eyi to se ebo titi ti ebo re kofin, o se etutu titi, etutu re kogba,
o sure titi, ire re ko dorun, ebo ni wonni kose, o gbebo o rubo, o gberu o teru, nje agarawu, aye o e,
agarawu, ebo dorun ebo dorun taarata.

4. Eku kuudu kuudu, eja kuudu kuudu, kuudu kuudu niti Babalawo adifa fun afinju oga, eyi ti omo araye
n roko ete si, wonni ko rubo, o gbebo nibe o rubo, o gberu o teru, leni nibi o di nibi a lo, erigialo, leni nibi
a di nibi a lo.

5. Oose meji o baje adifa fun ide, adifa fun baba, o bowo kan foje, o bowo kan fun irin, ebo ni wonni
kiwon o se, nje baba ro baba se, ide ro ide se, irin ro irin se, oje ro oje ko se o, erigialo ewa bani ni aiku
kangiri.

6. Ose womu o run womu adifa fun ori oun lo re gbobi niyawo, kutukutu lewe ti gbobi niyawo o, tani n
gbaya eni lowo eni, kose ni tin gbaya eni lowo eni.

You might also like