Professional Documents
Culture Documents
Alaye Nipa Awon Irawọ Mejila To Wa
Alaye Nipa Awon Irawọ Mejila To Wa
Alaye Nipa Awon Irawọ Mejila To Wa
IRAWỌ MEJILA TO WA
SAARA TI ELESE
Lara ohun ti Aseda feran ju ni saara wa tisi mon ran EDA lowo Lati tete ri esi adura ko si nti ao lefi saara
gbalodo olorun Eyin te nlo Irawo yi Epo pupa ,OWO pupa ,abi kama pa nkan ti baka ni dede ago 12:00 pm
OJO isegun Tuesday ni odara fun o lati ma lose saara AWON nkan toba kadara Remu
Bi apere inu omi ni oda eja si, gege bi nto ba lara mu ko mo ngbe ojoto ba siti ni ori ile ni ohun yi o gbe
waa laba niyen beni oda eranko sinu Igbo leyi ti kole losi nu omi magbe tiko bafe mu miku be nani o da awa
eniyan na si ototo aye enitiko GBE ibiti ise dare wa igbe aiye inira ni yi o ma gbe yi o wa sebi aje kan ni
koda o fide ibi
IYAWO FIFE
Iwo ti onlo irawo yepe ,omi lo dara ju kofe niyawo Iwo ti onlo omi towalofe INA koda looto Iran omi ka
nwa to lefe INA bi omi ile kejo nitori INA nipase ni bi omi yen ni ofi lefe ni omi gbi gbona sewa , Olefe
iyawo to nlo irawo Ina 5) OSI tu nle fe INA 9) ati INA 1) iyen number 1bi tie.
iwo to nlo INA ile kinni (1)Gbogbo OJO aba meta Saturday ti owa ninu OSU keji odun February ati osu keji
yen fun rare mo da wole nkankan tonise pelu aiye re ninu OJO ati OSU yi
3
AWON OSU ATI OJO TO DARA FUN IRAWO INA 1 ile AKOKO
Osu kerin Odun April ati gbogbo OJO isegun Tuesday ti owa ninu osu kerin April naa
ATI OSU kinni odun January ati gbogbo OJO abameta ti owa ninu OSU kinni January naa oni anfani lati se
nto ba wu e ni awon asikoyi tiyi si ja si ire fun o koni si aba mon nibe
1) you were born under the Sign of the TWINS 6) you are confused by fact's
2) you never sit still 7) you are great as multi- tasking
3) you are really funny 8) No body understand you
4) you love new stuff 9) your Motto-: I believe everything
5) you make a great friend
SAARA AFEFE 3
Saara yato pata pata si Ogun tabi ajo sise kosi nti eyan lefi tako saara sise ayafi Alani ikan se,tori gbogbo
Esin Religion, lofiidi saara mule gboin gboin
Saara AFEFE Ile Keta
Nkan pupa bi epo pupa,oka baba ,owo pupa abi obi pupa
AWON OJO ATI OSU TI KOBA IRAWO AFEFE YI MU RARA
Mo nse daba pewa bere nkan gidi nipa igbesi aiye re ni Awon ojoyi ati OSU yi
OSU keta March ati Thursday to wa ninu OSU naa
Bakanna OSU karun may ati gbogbo OJO eti Friday towa laarin OSU naa
Awon OJO ATI OSU TO DARA JU FUN IRAWO AFEFE YI
Ojo ati OSU yi ni adara Lati mon foju sun kan toda wole Ohun kohun
OSU kefa June ati gbogbo OJO RU Wednesday ati OSU kesan September pelu gbogbo Ojo Wednesday to
wa nbe
6
IKILO FUN AWON TO NLO IRAWO YI
Ma se ilara enikeji mase ro ra e pin nipo yi o wu ko wa sora lati dasi Oro oloro ko ma ndi tire mo nsekọ imọ
nran bere fun ito sona ọlọrun ko to da wole nkan (da kun ye ra fun oru, tabi ibi to ba gbona Abi onje gbi
gbona) Suuru ni Oro re gba ninu ohun gbogbo Sora fun ibinu.
IYAWO FIFE
Okan yin tete mọ nru soke nipa iyawo fife ti esimọ nni ife iyawo yin tori bi awa da bi awa da ni emọ nse
sugbọn eni la ti ni suru keto yan eni ti e fefe, elefe eni to nlo omi ile kejo oct22 - Nov21 Omi ile kejila
feb19- March 20 Ati yepe April 21- may20 pelu Omi ile kerin yi gangan june21- july20
To ba se pe EDA mo ibi ti olorun ko kadara pamọ nsi ni ao ti lọ yi pada oju kaba mọ nja si koto ma ko ku
ogiri ni nbe lagbari wa eda die ni oni oju inu
Dakun ibiti omi baposi ni ko mo ngbe tobafe Surfer tofe ki ile aiye lemon o
Ti yen koba sese omi gbọdọ mọ nwa ni sitting room, Palor ni aro wo tore ILU bi Iago's abi ile Igbo abi ki
kahunga wa nibi to ngbe
Dakun mose losi ile awusaooo
SAARA.
Awon onje eyo bi ewa,oka baba,Rice, abi ko gbe onje lo mosque or church ati funfun nkan osinlomi pelu
OWO sugar, iyo oyin omipure water
Ni asiko iyaleta 8:45- 11:45
9
e, oje eni ti nman farada isoro yi o wu ki oje osini ebun pe ti isoro bade wa tu nmọ ọna ti waa gbegba ti
efimo nje mo nmu tikoni han pe inu soro kan lewa ororun fun e lati koya njo abi bawon kegbe ti waa si
tunda Awon kan yan loto ninu won nipa taki toje ayan fe re ti oko lefi oro wọ sere rara beni watun maa mu
awon kan mora won kii repo ba lewa larin won oje eniti irisi ojure ma nfani mora ti OSI tutu ni iwa osi feran
Lati mọ ngbe inu ile tiase loso Iwo gan tun mọ nse ọsọ Si arare tori onifesi oje eyan Toni ifura to si ma nfi
oju inu wo nkan igbamiran osese komọ nkan towa lokan eniyan Awon ni ma wo e pe oni itara esin nigbati
wọ nkomọ Abudare ,lgbagbo ti e nipe kosi esinkan tope ni ile aiye yi toju irepolo ati isokan larin edakan ati
eledare lo,looto ku kuni nitori esin ko wulo rara ni biti eni togbe esinlori ti nwuwa to mu okanre jinna si
olorun ti o si nwuwa ta ni yi o mumi Ami IRAWO YI ni si keli ti o mo nfeki nkanwa ni dọgba dọgba la ipọ
si bi kan ju bi ka nlọ Akiesi pe bi isoro kan bade si o iru eyi ti yi o GBE elo miran mi patapata NSE ni
olorun yi o fun o ni ogbon ati iru agbara kan ti yi o mun e jade kuro ninu re laisi ipalara to buru Irepo je
nkan ninu Awon ohun yi oma nmu Anfani wa fun o julo, ona anfani keji ni ibasepo abi ibakegbe ona mejeji
yi ti obagba ona yi sise owo haa wadi olowo lata ra ibe bi ape juwe ki oma ta OTI mimun wadi eyanla la
tibe abi kioko Awon omo sejo wa jere nibe ,eyan to ni suru ti ko feran IJA ni e beni oko le diyan sinu fun
igba pipe koda bi onba eyan ja ida mun ni yi o je fun e titi ijana yio fi pari igbami a jo gunba iwa abi
awokose iwa onmon tako eyi ti IRAWO so ni pawa ni gba miran eyiti ajogun lodo babawa abi iya bi wọ
baje eyan to NSE ika abi aburu ,olemo nje ki olegba irepo laiye abi kiko yanjo OSI lemon wu iwa idale ni
eko kan ati a re kereke aifi okan ara eni bale iwa ole abi imele kooda beni oferan Lati ma ba gbogbo eyan
sore laisi ota ṣungbo iberu ifoya pe lagbaja yi o gba ogomi abi yi o Mon ta jumi lọ abi yi ma ndimi lowo
nikan loleso eyan di ota lọdọre oti ledi onikara abi ojowu Lati ibe irawo yi tete ma nfi oju aanu WO Awon
tonlo irawo yi won tete ma ndi Olowo, onipo olola ni owuro OJO aiye won elomi lekoko jiya but koni pe ti
igbadun yi o fide irawo yi na lo njoba ewa ati oso sise iwogan yio ni ewa towoni loju orire sini fun e ti onba
sise oso sise abi sise nibi tiwon se loso
IWA ALEEBU RE
Igbesi aiye re yi je eyi ti okun fun opolopo isoro ati wahala, sugbọn pupo ninu AWON isoro yi ni yi o je a fo
wo fa fun rare, ti ile aiye re yi o si so kun kun a si tu nku nfu n egun ati okuta ni gba miran iku baba abi iya
ni gba kekere abi aini owolowo Awon obi ti yio fi ni ekọ iwe abi itoju to peye abi ori sirisi Miran gbogbo be
lo mo nfa iriri yi
Sugbọn iwo ga nni o ma nso kun fa opo ninu isoro re ni bi Awon iwa a fọ wọ fa re ti onsi nko ba e ti o si nso
e di ota a won eniyan, iwa agidi okan, ibinu abi ju, abi iwa esan gbigba Lara eni to ba se wa ti ntu mọ nsi ki i
wọ to nlo irawo yi oogbudo GBA esan ogbudọ ma nfa wọ nle olorun lowo ni ti olorun na yio si ma ngbija re
lesekese to ba ti fii le olorun lowo tan igbami gan otu nni aseju eyi ti yi o si je ki won maa ko rira re, ki rare
ni janu pelu Ahon re ni bi ọ rọ siso tori oponi enu re tiko ba e ti o mọ n dakun ma se da si IJA koda sora ti
on ba nla IJA pelu pupo igbani ola IJA ti won o si ko nka nbowo ti on laja is your lucky paapa julo ki IJA
oni ja yi o di tire sora ooo ki ọrọ ti o ba sọ si ma pa enikeni laraooo
ISE ASELA IRAWO ILE KEJO 8 SCORPION
O see se ki a pin Ogun (Legacy) kan fun o ni gbakan ni gbesi aiye re sugbọn so ra re ma se ba ya nja ni tori
oro ogun o na re si asiki ati oro Nile aiye ko rorun rara sugbọn OTUN wa lowo bi iwo gangan base lo igbesi
aiye re,boya odi igbati oba su nmo eni ogoji odun 40yrs ki owo re to bere si to ire, asiki ati oro gege bi o ti
fe abi 40-45 mo si fe leso pelu ida ni loju wipe on bo wa de ori oke patapata ni igbesi aiye re Akoko kan
11
mbowa ti oo ri ara re ni IPO ola ati ike Ige ni irorun oo si seese ki ogunlogo aimonye eniyan maa teriba fun
o ki won si maa bowo fun o
ISE ASELA OMI ILE KEJO 8
Ise Amofin
Ise lsegun ati ti PSYCHIATRY
Ise Atunlu se
PSYCHOLOGY
Ise mekaliki
Ise Apata eran
Ise olopa inu Detective
Ire wafun e ti on ba sise to je mon ek ọ ijinle Mysticism or Occultism
A ju mo nse po yio Mon mu opolopo anfani wa fun e sugbọn kiko ise owo yi o pe fun e ju owo sise lo
IYAWO FIFE IRAWO ILE KEJO 8
Fi fura si oko abi aya lai ni di Awon wo nyi ati omiran be ko nije ki ile toro,ki alafia ati ibale okan si ma wa
ni oda, kosi mon jowu mo nseje ororo si aya re abi Awon omore ni gbami ran oro IFE ti ase ni bo ke le ti afi
pa mon lasiri ti kosi gbodo tu sita yio wa fun e osi sese kari oro IFE abi igbeyawo ti o yo risi idaru patapata
Orisi meji Pataki ni Awon to nlo irawo yi pi nsi okan ni Awon o ninu lile eni ti ngbe san Ororo eniyan
orisikeji 2) ni oni suuru ti on tete nronu piwada ti osi Mon fi sọ kan ni gba gbogbo pe iwa rere nikan lole
GBE EDA de ibi giga ni le aye yi ati lorun paapa dakun elekeji yi ni kiwo je ooo
AWON OHUN TI O BA ORIRE RE MU
Ojo Isegun( Tuesday) ni OJO orire re Lucky day
Number 9 ni onka Orire re Lucky Number
AWO re ni pupa Lucky Color RED
Isora ati Awure ti won o base fun e ko je eyi ti won se pelu RUBY lodara fun e ju
Imo nran mi fu e ni pe su mọ Awon Toni imon ijinle Lati le doju ijako isoro to ndo ju ko ni igbesi aiye re
AISAN IRAWO YI
Odami loju pe Jedi Jedi maa ma yio le nu ,owo bi eko okan Laku egbe Arun eya ara Toni se pelu ibi mon ile
jogun omi abi ki won ko ran e
AISAN RE
Isan ara ati eje abi E do kiki le Mon yo e lenu lilo opolo ni aloju abi idaru okan Psychological tension le
maaje Arun re bi o BA.nwa oko tabi gun alu pupu, ma sora gidi gidi ijamba kekeke nipa iru nkan be le yoju
si o be careful
13
IRAWO ILE KEWA IYEPE
Oni suuru ologbon ni o ma ni Abuda re
Saturn ni o njoba re o je eni to ni IFE si ise sise, ti ki fi ohun kohun se re, gbogbo nto BA da wole ni on Mon
fi t ọkan tara re see, sibe o je eda kan to ni suuru tosi so rare gidi, ti e ni emi igbin yan ju la i ko aare igba
gbogbo si ni on ma nna ga Lati De ori oke sa Nile aiye re o sije o lo titọ o se gbokan le gidi ni GBA pupo,
Ao fun o ni a ti ma nko rare ni janu nibi oro enu re tori oro ahon re lagbara pupo to hun ti be o ki fe ki o ro
buruku jade le nu re tori a fu n ọ ni ogbon ati oye lọọpọlọpọ eniyan to se Pataki ti o si lagbara pupo ni o je to
si lemi l si n ọ kan re yio le gidi gidi si nkan to ba fe tabi eyiti o ko fe, nitori e ni to ba tọs ibinu re yi o ka ba
mo nni ọ jọ na Lai si IYE meji gbogbo eni to BA mo o ni yi o ma a bowo fun o ti won o si maa fun o ni
igbega, IPO olori ni o saba mon wa larin egbe ati ogba re, koda bi politics ni onse wa nsa ba fi o je chairman
abi ni ilukan ka nfi eje olori ilu na kadara ti e ni o korira ayipada Nkan afi bi kadara BA mun e Lati se be
loku, boya o je Omo riran abi ti ko tete da gba soke lati kekere re osi leje pe a are ni ofa Sugbọn bi o ba ti
nda gba si ni ayipada rere yio mo de ba o Sugbọn giga re yio ya wa Lati odo awon obi re boya wo nga loku
ni Iwo na fi le gun gbongbonran giga irawo yi sa nwọn,
IWA ALEEBU RE
Oni ori kunkun ,oferan Lati te ra mon ona tabi iwa abi ohun kan pu po ju bi o ti yelo, igbami wa o ni ogbon
ti o mu yan yan to, ni biti o gbeti nfi suuru ati isora se nkankan, ibeni e lomiran ti koni isora to yio ti ki ire
na ma nle ti yi o si di titire, sora Lati mo ngba irewesi ọkan laye ninu re jubi O ti ye lo maa ra nti ni gba
gbogbo pe bi oju EDA ti wu ko le po n ola si nmbọ wa dara SAA ni
ISE ASELA RE
Kadara ko fun e ni an fani ati aye to Lati ya nbo nigbati obadi oro ise,eyi si leje koje isoro fun o nigba pupo
Lati so wipe Dan Dan iru ise kan to wu mi se bi ko sepe koya tete wa ise ti kadara re ba ya nfun e
Nkan meji Pataki lo lodun momi ninu julo nipa igbesi aiye re 1st EMIGIGUN ti o je ebun irawo re yi 2nd
sini ADUN ITURA ati ORO PUPO ti o saaba ngbeyin aiye Awon to nlo irawo yi leyin irin a Jo toti kun fun
isoro ati wahala, lgbakan nbo nigbesi aiye re ti Iowa ni so nso ori oke, si iyanu Awon eniyan ti wo nkoro pe
o le de iru IPO na Sungbon sora fun isubu ya kata lehin ti o ti de Ori o ke tan nipa AYO ayo pora ati ai bi ki
ta ai ka kan kun
Ise ijoba lorisirisi
Oselu politics
Ise isegun
Ise photo Ayaworan
Ise ile kiko bricklayer architecture
Building contractor
Agbe farmer abi nkan osin si sin
Iwe kiko abi titejade Authorship or publishing
ALEEBU RE
Ai se dede ,Ai ni te lo run, ai le farada nkan fun igba pipe, Fifi ori kun kun maa. Se atako eniti ida agbara
nbe lowo re, so ra re ki oleni ilosiwaju mo nje ki won ba e ni di iwa ai to abi iyapa si o ti to,yi o ba le mura
lati bori awon ai le bu reyi isoro re yi o di nku Nile aiye pupo
AISAN ARA RE
Si sun eje ka kiri ara re, Fifi ara pa ni oju gun abi ko ko se ti apa ogbe bawa Lara re yi o le ti yi o han palaba
abi ko yo ko lo bo arare kiigbe nkan pa mon afi ko han pelu ipọ nju idamu ti o maa ko ko ri ni kekere abi ni
odo ti o ba kun fun adua saara igba ti oku jepe irawo yi ni ka nso lonjoba igbesi aiye re ni pa be boya agbara
re ko le po pupo Lori re ti Iwo na yio si Mon gbadun isemi re
17
IRAWO ILE KEJILA
Eni olorun, omo lu abi EDA
Irawo yi lo gbeyin gbogbo irawo ooje eni kan ti Okanre ntete nmon RU soke, osi ni ebun isi paya gbigba yi
o sije ki o rorun fun e lati mon ri ohun to nbo abi ohun to fe sele si ọ abi si elo miran o je e da kan to Mon ro
nu ji nle pupo Lati fi apere rere lele fun e lo miran be ni eti inure na gboran gidi eyi yio je ki o mọ hun ti
ILU nbaso ni yio ma gbo koda otunje eni to mon ijojo sugbọn ebun yi o kii se gbogbo won afi awon die
Abuda re ni Lati ni ife si esin abi ohun ti o je Mon emi, ooje eni ti ko ni Ma soro fun Lati ba igba yi si ibi
toba yi si abi Lati fara mon ohun ko hun to bade ba, o seese koje eni ti kose fi tara tara gbọ kanle , iriri to jeti
ASIRI yi o pọ ni ile aiye re ni tori irawo re ni o njoba re ti anpe ni Neptune ohun na si tun lo njoba ni isale
okun eyi yi o si mun ki opolopo isele ati iriri ti o so kunkun wa fun ọ, pupo ko si eni to leso bi okun se jin to
ati kini Awon nkan to wa ninu isale re o da mi loju pe ojure yio tutu ti yio si da bi eni pe o da ke roro ni sale
ninu, ao ri agidi ati ibinu yio le pupo pelu okan riru ni ekokan bi okun se mo nda oju re ru lehin ohun to ti jo
idake roro, ooje eniyan to maa fi rare si IPO ỌWỌ to si ma nko rare ni janu koda OTUN ma nfi rare si ro
elo miran IRAWO ti anpe ni JUPITER eleyi ni agbara ati ase Lori igbesi aiye re ti nja sipe agbara ati ase
irawo 2 meji loni, eyiti Jupiter yio se e ni orire ti yio si je gbajumọ eniyan yio si ran e lọwọ Lati de IPO
giga, Lati mun e ni arisiki ati ore lona to gboro ati latise e ni enia ti o ga Lola, ti gbogbo eniyan yio Mon bu
Ola iyi fun e bi ki won ma yan e ni Alaga obirin abi kansa Mon yan e si IPO giga
Ni dakeji iyen irawo NEPTUNE eyi to ni ise pelu isale omi okun ati ohun asiri pelu ijinle yio dara tie na ni
igbesi aiye re nipa eyi yi o je elege to si ni ewu pupo oseese koni opolopo ota ikoko ti o fori mule ti won si
le maa wa isubu ati ipalara fun o, gbogbo ebi ore ojulu mon re ni lati maa fi sọkan ni gbogbo igba pe ira
nlọwọ ati ojurere re ni won nfe julo tori ohun gbogbo toba ti sele ni igbesi aiye re ni won o maa fi apere rere
abi buburu , ni tootọ eniyan to beru isoro , wahala ati ijangbon ni e, ohun lose mo nka imoran elomi kun
Pataki mofi eleyi GBA e ni Mọran Lati kobi wati mon lo isipaya re ko ma ba silo ti yi o si fidi onje fun e,
iseda omi je nkan ti oni ise pipo pelu igbesi aiye re bi isale okun abi odo se kun fun orisirisi ohun ti aole fi
ojuri afi ti a ba le losi isale omi yen loku bena ni iriri ojure fa ni mora ti isale ikunre ku nfun iberu, ifoya,eni
ti ara ntete nmon rin ni e sugbon ooje oninu re ati alawada ooje eniyan to maa nko egbe Jo, abi kan si fie je
olori egbe ni eyiti okanre si fufun ati OWO re si gbogbo eniyan koda ka nma se aburu si e watun mo se
daada si won ni o si feran Lati gbon inira enikeji kuro, beni okorira iya njija, A si fun o ni imon ogbon ati
oye ohun to ba ta koko wasilo imon ati oye si yio si tu,won ki saaba ba eyan ja afi ti won ba su nwa nkan
ogiri, won si feran ijosin fun oluwa ti okan re ntete nmon fa si olorun ti won si maa f i apere rere si le fu n
Awon to nbọ leyin, eti inu won yio gbo ILU eyi yi o je ki elomi mo ijojo,ti won si je olo rire ninu aiye won,
iyen ti won ko ba si ỌKỌ fe ti won fe eyiti irawo won ba ra wo nmu, koda won yio tu nje gbajumon ti won
o Mon won kakiri aiye ti won si Mon to e yan si ona rere ati igbani ni imọ nran to da,won si ko rira egbin idi
eyi ibi imọ ntoto ni eo ti ba won won ni imọ ntoto
AISAN ARA RE
Ni lokan pe elege ni ese re.mejeji won ko lagbara rara tin nkan bagun o lese eje le maa rush koda ole fa egbo
adaijina ,to ba mura si
Anpendicitis si le MA se o
Sora re pelu OTI mimu, Sora pelu Ma njele oti yi o tete ma ba gbara ita ni gbongbon Lori re Awon ota si
lelo iru ayeyi Lati pa ọ, Ao pa se fun ọ pe ki o maa se mu OTI rara o Sugbọn yio se o ni ire julo bi o ba kuku
nmu ninu ile ara re ,ti o si nmu ni wọ ntu won si
ÈYÍ NI AWON AÁJÒ TÀBÍ OOGUN TO LÈ ṢÍṢE LARA ENI TOBA NLO IRÚ ISEDA IRAWO YI
(1)
Bio ba nlo aájò tí a fi iná jó koni sise lára rẹ rárá
(2)
Bio ban we ìwé odò pelu ose funfun tàbí pelu iyọ̀ lásán tàbí kio maa we nínú omi òkun oje atude gidi fune ona re yio si maa la
Bio ba ńṣe adua daada pelu aawe létí odò òkun pelu aṣọ funfun wàá tete maari ìyanu
(3)
Bio ba nlo aájò to jemo Agbo odara yio tete maa sise lára rẹ
(4)
Bio ba nlo aájò to jemo oyin tàbí aadun pelu oyin odara fún ẹ yọnu gidi
(5)
Bio ban fi ẹja aro ṣe saara pelu oyin gidi sínú odò tí ẹja pò nínú rẹ onare yio tete maa là
(6)
Bi Oban ṣe saara daada fún àwọn ọmọ wewe dáadáa waama rí ona àbáyọ lórí ìṣòro ayere
(7)
19
Bio ban fi ekuru funfun àti eko tútù ṣe saara onare yio tete maala
(8)
Bio ban bù omi tútù laaro kutukutu tiosi ṣe adua sínú rẹ láti sọ̀ rọ̀ sì ẹnikẹni kio mú nínú rẹ kiosi fi ìyókù wọn ilé itaja rẹ bakan naa kio fi
ìyókù we laaro laaro
(9)
Bio ban se saara daada ni ayajo ojo birthday 🎂 rẹ daada kọọ tọju àwọn ọmọdé daada àti àgbàlagbà boo banse eleyi ona are yio la
(10)
Bii Banfi egbo tàbí rice sise láìní iyọ̀ ninu ṣe saara daada sínú odò lanla wat ète maari aanu gba
Èyí nu die tí ao koko menu bá ní jure ao máa te síwájú lorie Lágbára Ọló ̣run aoni tọju ilé mọ́lẹ̀ amin
Idi tí àwọn ènìyàn fi kò orisirisi eso losi etí òkun nìyí moti jeko Yéwá wipe Alijannu inú omiyi Obìnrin ni tiosije Olomo pupo
Alijannu omi tioje ọkùnrin náà wá àwọn Alijannu omiyi feran èso láti máa jẹ pelu orisirisi nkan ti àwọn ọmọ wewe manje bíi
sweet, ireke, Aadun, Ọ̀gẹ̀dẹ̀ epa, guguru, wàrà tútù àti oyin líla, Sugar, iyọ̀, Chweries, àti bẹẹbẹẹ lọ yini àwọn Alijannu omi
yìí man feran daada Sungbon wọn feran èso pupo ju bí ona badi mo ẹniti oje on irawo omi tàbí ìṣòro kan wà níwájú rẹ bio
base irú saara bayi àyípadà yóò dé bàa ní kíákíá bí kò bá sì idiwo ota nínú ọ̀ rọ̀ ayé rẹ bo obase irú saara yi yóò tètè rí ìtura
ao toju orisirisi èso yio dáa sínú odò lanla sungbon asiko tó bá ṣe saara yi aṣọ funfun ni yóò saaba máa wò sun lágbára
Ọlọ́run ọ̀rọ̀ ayé gbogbo wa ni yio loju tú bí ase nfe amin
20