Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 2

OSOLE

Omo aguntan kekere tioti ja lenu omun kan. Ao soro si leti

mejeji pelu nkan ti a ba fe. Ao wa dunbu re sinu agbada

tuntun. Ao to gbogbo Owo ti a na papo, koda a le lo dolar kosi

laburu. Ao fi we awo ti Oga bosile (iboho Oga) bi siga, ao ki si

enu aguntan yen leyin ti ati ge ori re nio. Ao wa gbe sori eje

Re. Ao ge ese re mererin na si. Ao wa ma sun ara-eran to ku.

Ao ma ha sori ori-atese yen titi ti ao fi sun tan. Ao la laya, ao

ko gbogbo nkan inu re sori awon nkan yen ninu agbada. Ao

wa ko awon nkan wonyi le lori : Kowe kan, Kannakanna kan,

Eiye otata dudu kan, Opolopo ewe ajesefunsefun, opolopo

tannagbowo, ewe orijin, sawerepepe pelu odd atare meta....

Odi jijo. To ba ku die ko jo tan, ao da iye agbe meta, iye aluko


meta pelu ikode meta si. Ao jo papo. Ao lo kuna dada. Ao ro

sinu igo nla ff kan toba gba tabi inu ado-ato.

Akiyesi : Ao fi die lara eje yen ra ara igo na.

Lilo re : Emeta larin osu ni ao ma lo pelu okan ninu awon nkan yi : 1-

Ekuru ff, 2-eko-tutu, 3-Oyin gidi. Ni ago marun idaji kato soro

siyan ninu awo ff. Ao si pa kaja aso ff.

Etutu re: Ao jo ewe ebe, eiye ofefe pelu atare aja papo. Ao ge gbogbo

eran toku si kekeke, ao bo pelu alubosa ff, ao din pelu ori, ao

ko gbogbo e sinu igba ipese nla kan, ao bu ebu die ninu oogun

towa ninu igo yen, ao dapomon gbogbo ebu eyi ti a jo fun

ipese yen, ao fan gbogbo e patapata si ori eran towa ninu igba

You might also like