Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 1

OOGUN ASEGBE

Orogbo nla 9 2. Awo Inaki 3. Odindi Ataare 9 4. Owu

Alantakun ati Alantakun ibe lona 9 5. Ewe Apada. Ao jo

gbogbo re pa po. Ao di ni ikobere pelu owu dudu ati funfun

lona 9. Ao waa di mon Suku Agbado, (Owu pupa ni ao fi di

mo Ara Suku na). Ao wa lo gbe ile si Orita meta.. Ki ato ri

Ogun yen mole ao pe

Ofo si bayi.... hunjo Hunjo Enu enu ni Inaki nfi kolu kojo lo soja 3x

Ojo ti Inaki ba kolu kojo lo soja ojo na ni ki Lagbaja Ranti oun

tio wa lokan re Enikan ki roju fi owu Alantakun Ran Aso 3x

Ki Lagbaja maa roju ri Oro ti o wa nile yii 3x Ewe Apada loni

ki Lagbaja pa Oro mi ti o wa ninu re da ko gbagbe 3x ao wa ri

mo ile yen ao waa fi ese Osi bo mole ..

You might also like