Yoruba Reproduction Biology

You might also like

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 2

ARA ENIA -HUMAN BODY- Ẹ̀ YA BIBI ARA - REPRODUCTIVE S... http://yoruba-scipedia.wikidot.com/wiki:ara-enia-human-body-e-ya-bibi-...

site-name .wikidot.com Share on Join this site Edit History Tags Source Explore »
Expert tip #4: Meet the experts at http://community.wikidot.com! Create account or Sign in
spiders discuss edit this page view source history other tools

ARA ENIA -HUMAN BODY- Ẹ̀ YA BIBI ARA - REPRODUCTIVE SYSTEM

THE REPRODUCTIVE SYSTEM

ÈTÒ BÍBÍ-ARA
navigation
ORGAN SYSTEMS OF THE BODY
Main page
Contents ÀWỌN ÈTÒ Ẹ̀ YÀ-ARA
Featured content
Glossary Level of readership Primary, Secondary, advanced
Random article
by Fakinlede K
search

Search

About this site


Recent changes
Contact
Donate
Legal
Help

toolbox
Printable version
Site manager
Edit this menu
Edit top menu
Manage snippets

pages

new page

- applied curriculum
delete-this-page research

s yoruba
watchers
Mz Shetzy
Dr Abayomi
Ferreira
Diipo Fagunwa
Kayode Afolabi
bayo_rep
nellista
ifayemi
Jesus Rodriguez
Alabi Taofeek
Owolabi Reproduction: The sexual or asexual process by which organisms generate new individuals of the same kind.
Prince_Analyst Bíbí: Bíbí ti lákọlábo tàbí ti ògbo jẹ́ ìlànà bí àwọn ẹ̀dá oníyè ti nṣe ìpilẹṣẹ àwọn ẹ̀dá bíi ti ara wọn.
Oyekunle
All living things reproduce. If this did not happen, all living things would slowly die out and disappear from the earth.
Ridwan
juliusfakinlede Gbogbo ẹ̀dá oníyè ní ó nṣẹ̀dá ara wọn. Bi bẹ́ẹ̀kọ́, gbogbo àwọn ẹ̀dá oníyè ni yóò rọra kú tán, tí wọn yóò sì parẹ́ kúrò ní ilẹ ayé
balogun
The reproductive system or genital system: a system of organs within an organism which work together for the purpose of reproduction.
oafak
Olamide Olobi Ètò bíbí ara: Ètò àwọn ẹ̀yà kan nínú àwọn ẹ̀dá-oníyè tí wọn nbá ara ṣiṣẹ́ fún bíbí.
herziz
VOCABULARY / ÌTÚMỌ̀– Ọ̀RỌ̀
Vincent
ogoubiyi
Kunnuji Afterbirth Olóbi Male Akọ
Ridwane Ade Afterpains Àgàrọ, Àgùnrọ Male (man) Okunrin
Seggylee
Amniotic fluid Omi-ọmọ Male sex Akọ ìnrin
Watch: site | category |
page
Amniotic sac (amnion) Àpò ilé-ọmọ Mammary gland Ẹṣẹ́ wàrà; Orísun wàrà

Anus Ihò ìdí Menstrual cycle Oṣù abo

Asexual reproduction Bíbí àìgbakọ Menstrual period Ìgbà àṣẹ

Birth canal ọnà ibí Menstruation Nnkan osu; Àṣẹ

Bladder Àpo itọ̀ Mons pubis Imu

1 of 2 11/06/2020, 20:10
ARA ENIA -HUMAN BODY- Ẹ̀ YA BIBI ARA - REPRODUCTIVE S... http://yoruba-scipedia.wikidot.com/wiki:ara-enia-human-body-e-ya-bibi-...

.wikidot.com Share on Join this site Edit History Tags Source Explore »

Cervix Ọrùn ilé-ọmọ’nú Offspring Ìran, ọmọ

Childbirth Ọmọ-bíbí Organs Ẹ̀ yà-ara

Clitoris Idọ Ovary Ibú-ẹyin

Cowper’s gland Ẹṣe Káópa Ovulation Ìrọyin

Egg (ovum) Ẹyin Penis Okó

Ejaculatory duct Òpo atọ̀ Placenta (afterbirth) Olóbi

Embryo Ọlẹ Pregnancy Oyún

Endocrine system Prostate gland Ẹṣe omi-àtọ̀

Endometrium (lining of the uterus) Ìwọ ilé-ọmọ Puberty Ìbàlágà

Epididymus Ìfun atọ̀ Pubic hair Irun abẹ; Irunmu

Fallopian Tube Ìfun eyin Pubic hair Irun imu (Irunmu)

Female (woman) Abo, Obìrin Reproduction Bíbí

Female sex Abo ìnrin Reproductive System Ètò bíbí-ẹ̀dá

Fertilization Ìgbàrin Scrotum Ẹpọ̀n

Fertilized egg (zygote) Ọlẹ Seminalvessicle Àpò àtọ̀

Gamete Séẹ̀li ìnrin (sex cell) Sex Ìnrin

Gene Ẹyọ-ìran Sex cell (gamete) Séẹ̀li ìnrin

Genetic disease Àrùn ìdílé, àrùn ìrandíran Sex chromosome Okùn-ìran ìnrin

Genetic material Sexology Ẹ̀ kọ́ nípa ìnrin-ẹ̀dá

Genital System Ètò ẹ̀yà-ìnrin Sexual intercourse Ìbásùn, Àsùnpọ̀

Glans Penis Orí okó Sexual reproduction Bíbí ìgbakọ/ Bíbí ti lákọlábo

Gonads Ikóró - ẹ̀pọ̀n Sperm Àtọ̀

Gonads Ibú Séẹ̀li ìnrin Testis Ikóró epọ̀n

Hormones Oje-ara, Ojera Umbilical cord Olóbi, Iwọ

Implantation Ìgbégbìn Urethra Ọ̀nà ìtọ̀

Labia Ètè Uterus Ilé Ọmọ’nu

Lactation Ọmún-ṣiṣẹ́ Vagina Òbò

Male Akọ Vas deferens Ìfun àtọ̀

Male (man) Okunrin Vulva Ojú-òbò

Male sex Akọ ìnrin Zygote Ọlẹ̀

_b
page revision: 8, last edited: 16 Nov 2018, 16:57 (573 days ago)
Edit Tags History Files Print Site tools + Options

Powered by Wikidot.com Help | Terms of Service | Privacy | Report a bug | Flag as objectionable

Unless otherwise stated, the content of this page is licensed under Creative Commons Attribution-ShareAlike 3.0 License

2 of 2 11/06/2020, 20:10

You might also like