Itan Okanran Ofun

You might also like

Download as txt, pdf, or txt
Download as txt, pdf, or txt
You are on page 1of 1

lgboro ki awo wón lode igboro ki

A d'ífá fún wón lode igboroki


lgboro fa awo wón lode igboro fa
A d'ífá fún wón lode igboro fa
Agogo nlá lo bale lo ro gbangan bi okó gbangan bi okó
A d'ífá fún alapa ose
Eyi ti n se omo aro
Alapa ósé omo aro
Lodifafun n o ní onigbega leyin
Eyi ti n se omo odofin
Ó ní onigbega leyin omo odofin
A d'ífá fún opatere salakó
Opa tee re salakó ti a bi legun mogo
Opa nal o iwo wón ni
lwón ní o kógun wa jalu o
lwo wón ní
Opa n láo iwo wón ní opere gbe
A d'ífá fún eyele
lgba ti n sawo lo si ilu opere gu é
Okán winsin winsin
Babalawo eera
A d'ífá fún eera yíó kan gangan kán kán gangan
A d'ífá fún gangan
lgba ti n sunkun pe oun oni onigbeja leyin
Ajeun iku kán ija láfisi
A d'ífá fún ajana oye
Eyi ti yíó fi okele mu eran iku
Dede aya ifa
Abeje aya Qrúnmilá
O gbeyan kale
O pa oose isere re isere re
O gbeyan kale
O pa oose iserere iserere
lfa ti sangbandan
lfa ti ní oun o jeun ose mó
Mani ifa pele o omo enire
Órúnmilá pele o omo enire
Okó aje abile gbindin gbindin bi eni n layin
Okánkán ní ile ogun
Kóro odo ní ile obalufon
Aarin gbingbin ní ori ti a jokó
A d'ífá fún ewa luade
Omo akókó lokun
lgba ti n je lokó igba iraye
Ebo ní wón ní kó se
O gbebo nibé o rúbo
Nje e sode hin
lfa a hin-in haa e sode

You might also like