Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 2

u ojo meta, e gba ise kekere yi,Ogun ti afi maa n ba eniyan soro ni, eru maa ba gbogbo awon

to ba n gbo
ohun wa tori bi ara ba san tigbo tiju lo maa mi titi,Eo lo ra ekuru funfun kan eo wa bo sinu abo eo wa fi
edun ara kan so eo wa ro ekuru yenmo edun ara yen ninu abo lai fi epo tabi iyo si, eo wa je ekuru yen.
Opari

Aforan to daju, eleyi ni akoko aforan ti maa fi sita, o wa fun gbogbo awon to ba lejo nile ejo tabi nibikibi,
ojo abameta la ma n sise yi, ojo aba meta la tun maa n we ose yi, eroja re ko le rara o wa lori ate,Eo lo ra
iye eye igun meta, iye eye Aluko meta, iye eye agbe meta, ao wa jo papo lojo abameta, ao te ni ifa eji
ogbe ao wa po mo ose dudu, ojo abameta lao maa we ose na,

Ofo re

Mo da aba meta mo fi ikan fun eye igun, igun loni kenu aye ma se gun lemi lori, mo daba meta mo fikan
fun eye Aluko, eye aluko loni kenu aye ma se ko lemi lori leni, mo daba meta mo fikan feye agbe, agbe
loni gbogbo nkan ti mo ba se leni dasegbe! ao wa we ise yi lo ibi ta ti lejo yen! odaju, maa so bi a se tun
maa n lo ise yi laarin ose to ba ya! eku ise o, e maa yawo, e si fi sokan wipe rere lo pe ika o pe, tori esan
nbe fun mejeji.

Fun eni to beere lilo ewuro fun isegun ota e gba nkan te beereeo lo wa ewe oriji die, ewuro die, ajeobale
die, ako okuta kekere, eo wa lo papo lori olo,eo fi ose dudu po papo eo maa fi we,

Iwulo ewuro fun atajere oja,Eo ji laaro lo ja ewe ewuro die, ti e ba ti wa de enu ona ile yin eo duro ni enu
ona, eo koju si inu ile, eo wa lo ewe yen ni enu ona yen, eo popo mo ose dudu! eo ma fi we lo ibi oja tita
yin

Eleyi wa fun awon to n ta tete baba Ijebu tabi tete oni number, opolopo igba ni mo ti ba ibeere re pade
sugbon e gba bai,ao wa ekolo (earth-worm) aye kan ao lopo mon ose iwe eekansoso ao fi ose na sinu
kain kain ibile tuntun toba wa di ni ale bi ago mokanla 11pm ao fiepo pupa pa gbogbo arawa pata lati
oke deele ao wafi ose na we ao lo sun ao gbodo jademon o, warinumber baba ijebu ni oju orun tiwon
ma gbewafun o.

Eleyi ni nkan lara iwulo omi ojo, ise eleyi ni asiri bibo fun ile (land) rira.ao gba omi ojo sibi kan, ao bu sinu
ike 5litre funfun kan ao wa foagbon meta sinu e ao gbe pamo funojo meta ao gbodo je ki ike na kanle
nibi ti ao gbe si o toba kanle ara le san pa eni na ni o tabi kioro ile aye onitoun daru ,leyin na ao ju
owoeyo meta tabi eyo kan sinu re ao ma da diesinu omi iwe larin osu kan.

Eleyi ni asiri bibo oni ororo goya. ao lora awo ekun pelu oga aaye kan, ewesawerepepe to po die, atare
odindi kan, owo #100tuntun kan (muri marun), ao fi owo yen hanoga yen ti yio mu awo owona, ao wa Jo
gbogbo re po,ao wa lo ra igo ororo goya kan, ao wa da ebu yen sinu ororo yen, aowa #200 meji,ao ju
sinuororo na fun 21 days lehin 21 days ao mafi ororo na para, ao wa yo #200 kan ninu owo ta so sinu
ororo yen ao sa si ategun ti yio gbe ao wa ma ju sinu ibiti a nko owo si tabi apo,asiri wa yio ma bo
lagbaro olorun, aa ni nakan tan kato ri imii lase oodua.Eyi ni asiri bibo oni ororo fun eni to ba nife si

Afose to daju,ewe ogbo ati egbo re, aseokete, ewe alupaida, igbin ilako kan,odidi atare kan, ahan okete
tutu oójo, ao jopo ao fi singbere si isale ete wa,

ofore:- ogbo loni ki lagbaja gbo temi loni, alupaida loni ki lagbajamale pa oro mida leni, oro ti okete
batiba ile so ni ile ngbo, sise kose nitilako se, ikodi ki ko oro si omoolorun lenu, ao fi ahan kan ibi ti gbere
yi wa aoma fi so nkan ti a ba fe so, opari

You might also like