Ina Loju Ekun

You might also like

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 29

INA LOJU EKUN INTERNATIONAL

HERBAL ASSOCIATION

ASIRI TOPE

19
INA LOJU EKUN GROUP

S
1. IMULE ASINA OWO
Alangba adaripon 1
Owo tuntun ilu ti aba wa 1
Eso werenjeje 51
Ewe ola die
SISE RE:
Ao ka owo naa, ao ti bo alangba naa lenu
Ao ro eso ewerenjeje naa si pelu ewe ola die
Ao fi odindi atare kan si
Ao wa jo ao sodi ebu
Ao ma lo ni ago kan oru pelu epo tabi peak milk tabi hot drink
N.B
A kii pin lo ,eni kan soso ni o ma lo. O daju
By Alfa soliu al aronu
2. OGUN MUIBA/IFERAN

Suratu samsi
Ibepe ti ko kanle

SISE RE:
Ao han suratu samsi lati oke dele sinu paper kan
Ao bu (enlarge) gbogbo hao ti o wa ninu sura yen loju ,
Ao fi oruko okunrin soke oruko obinrin si isale
Ao we ni tira
Okun ti afi we tira yen ao oni g e
Ao ju tira naa sinu ibepe yen
Ao wa we ibepe yen naa
Ao lo rimo ibi abata ti omo kiiti gbe rara
N.B
Ise yi eni ti aba ma lo fun koje eni ti o je wipe iku nikan lole yawa o.odaju
By Alfa Soliu Al Aronu

3. ORUKA AGBELEPOTA

Ibepe tiwantiwa odidi kan


Oruka
Eyin ibile kan
Etu ibon
SISE RE:
Ao pa ibepe yen lori
Ao ki oruka yen bo inu re
Ao fi etu ibon si
Ao fi eyin ibile le lori
Ao de ibepe yen pada,odi jijo
Ti aba jo tan ao yo oruka yen kuro
Ao singbere merin si ikun lona mererin tabi kasin yika

2
INA LOJU EKUN GROUP

NB
Enikeni ti oba lo ise yi, ti o ba gbo wipe won robi si oun eni yen si ku ,ao gbodo kawo lori o .
By Oluwo matagbamole

4. OGUN IYONU AWON AGBA

Ewe oju olongbo


Atare

SISE RE:
Ao ko atare le lori
Ao ko senu ao je pelu
By oluwo matagbamole

5. OSHOLE AYARA JE BI IDAN

Olongbo to ya ehana dada 1


Ogede omini 3
Eran elede ti ko lawo
ikoko
SISE RE:
Ao ge ogede omini si meje meje sinu ikoku
Ao gee ran elede si meta sinu ikoko
Ao lo gbe pamo fun ojo meje
Enikeni ko gbodo de idi ikoko yi titi yio fi pe ojo keje
To ba di ojo keje yio ti yo aje ti wonpe ni idin sugbon ako gbodo pe ni idin o
Ao so wipe aje kaabo !!!
Ao gun ose mo
Ao pa olongbo yen sinu ikoko yi
Ao re ori olongbo yen ja
Ao fi si ori olongbo yen gun ori ose yen ti oju olongbo yen ma koju si sanmo(oke)
Esinsin kogbodo bale eje olongbo yi ti abandu lowo
Ao tun gbe pamo fun ojo meje miran
Leyin ojo meje yi, ao gbe jade
Ao ma we laraaro
N.B
Amin ti a mari ni wipe esinsin ode ba wole ibi ti agbe ose yen pamo si, owa ki niyen ase
olohun si ti bale.odaju
By Alfa Asimolowo

7. AKO OHUNMO AGBAYE

ERONJA:
Oju inaki ile 16
Oju oka 16
Oju olongbo 16
Oju Aja 16
Oju Agutan 16
Oju esin 16

3
INA LOJU EKUN GROUP

Oju karo 16
Kokoro idandan kopo die
Atare aja 16
SISE RE: Ao jo gbogbo eronja yi papo
Ao di ni ikobere
Ao pa lawo ekun
LILO RE:
Ao ma gbe ko orun
N.B
Ao fi okun si o
By Alfa suffisim

8. ABO OHUNMO AGBAYE

ERONJA:
Oju olongbo 2
Oju inaki ile 2
Oju Aja 2
Oju karo 2
Oju amotegun 2
Ewe ohunmo
Ewe
Atare kan
SISE RE: Ao jo gbogbo eronja yi papo
Ao di ni ikobere
Ao pa lawo dudu ati funfun
Ao re sinu eje aguntan fun ojo mesan
Leyin ojo kesan ao yo kuro
Ao sa sinu ile
To bati gbe ao ma fi ko orun
By Alfa suffisim

9. OHUNMO AYERAYE NLA

ERONJA:
Okan igala ti koti gbe tope(complete)
Okan aja
Okan olongbo ati ori re
Okan ajeyo
Ori igun
Ori akala
Odindi ataare
Odindi eye karo
Ewe karo
Imo ope ti ama fatu lekan naa
Ewe ogbon
Kokoro alake oju ona

4
INA LOJU EKUN GROUP

Ewe ohunmo
Odidi akuku adie kan to tobi(to ti kojaye ja orun)
Eja ojiji
Igbin apinu kan
ijapa
SISE RE:
Ao ko gbogbo eronja yi sinu ape ijogun
Ao mu owo ijogun kuro ninu re o
Ao pa eje adie yen le eronja yi lori
Ao ge ori adie yi , ao mu sonsori imo ope
Ao tibo adie yen lenu
Ao ge imo ope toku keekeke ao ko sinu ape ijogun yen
Ao ge apa otun ati osi adie yen naa si
Ao so di ebu
Ao ro sinu sere
Ao fi aso tabi odidi di lenu
Ao lo rimo oju ona ti awon eyan ngba dada tabi orita meta fun ojo mesan
Ao lo wu kuro ni ojo kesan
Ao pa akuko miran si lara ,ao fi eje re ra lara dada
Ao gbe sinu apo asunwon fun ojo meta
Lehin ojo keta oti bere ise, ao bu die ninu re ao fi sin igbere meta meta si okan aya wa.
Egbe otun ati osi,awuje wa
Ao mafi oti lo eyi toku
N.B
Ale fi adie to bakun se saara sugbon eni ti oni ise ko gbode je nibe.
Ohunmo yi ma nsise fun odun mewa si ogun odun. Odaju gan
BY: Dr Owo Agbara(Balogun Ina loju ekun)

10. OHUNMO NLA

ERONJA:
Ipabo egun (original)
Oga aye
Odidi ataare
Akara gbendu 9
Alake oju ona
Isasun tuntun
SISE RE:Ao gbe isasun si ori aaro
Ao gbe oga sinu isasun tuntun yi, yo ma jo lo
Ao fi ake ojo ona gun akara gbendu yen , ao wa fi sile fun igba die
Ao ri wipe awon eera ti pebo awon akara yi
Ao wa ma ju sinu isasun ori ina lokokan
Ao so won di ebu
Ao ma fi oti lo. O daju
N.B
By: Dr Owo Agbara(Balogun Ina loju ekun)

11. SIGIDI IRANSE

5
INA LOJU EKUN GROUP

ERONJA:
Omi odo tonsan
Sparo powder
Ewe ogbo
Ewe abamoda
Ewe apada
SISE RE:Ao fi omi odo yi mo sigidi to lapa ,oju ,imu, enu ati ese
Ao gbo gbogbo awon ewe wonyi mo sparo powder
Ao fi kun ara sigidi yen dada
Ao sa si iboji
Ti oba ti gbe , ao gbe sinu apoti to ni kokoro kan
Ao gbe sinu re ao depa
Ao fi sile fun ojo meta
Lehun ojo keta ao difa lati beere lowo re boya oti to asiko lati ma lo
To bati funwa ni yonda
Ao je atare lenu, ao fi owo gba lemeta
Ao pe gbolohun re si bayi wipe
Ogbo loni ki oma gbo ohun enu emi lagbaja omo lagbaja, apada loni koi o mase pa ohun
enu mi da, aba ti alagemo bada oun ni osa oke ngba.
Aba ti emi lagbaja omo lagbaja da fun e loni di ase
Ki o sare tete ki owa lo jise bayi bayi fun mi
Ao gba nidi. O daju
N.B
By: Awolere Akanni omo odo agba

12. ARINNA TO DAJU(IMULE AGBA)

ERONJA:
Igba totobi to lomori
Eyele funfun to daju to gbo dada
Afomo ewe iyalode funfun
Iyere
Ewe ajeobale die
Egbo ajeobale die
Epo ajeobale die
SISE RE:Ao gun afomo ewe iyalode ati iyere si ibi kan
Ao gun ewe ajeobale,egbo re ati epo re mo iyere si egbe kan
Ao pa eyele yi ao fi eje re pa eyin igba ye(ao ni fira omori re o)
Ao sa lorun ti yoo gbe
Ao tu eyele yen,ao ge si 16 (including it head and leg)
Ao ni fi omo kan ara re o
Oti oyinbo abi omi agbon ni ao fi fo
Ao da epo sinu igba yen pelu ina werewere
Ao din ti yo gbe dada
Ao da awon ebu yen si pelu iyo
Ao ro po dada
Ao so kale sori osuka
Ao gbe wole

6
INA LOJU EKUN GROUP

To ba tutu ao bora si ihoho .ao se adura si gbogbo oun ti abafe ao je ni ihoho


omoluabi. odaju bi iku
N.B
1. awon ewe yen ko gbodo kanle
2. ao gbodo fi omi lasan fo tabi fitu eyele yen o
3. ojo Monday tabi tuesday ni o dara lati se ise yi
4. ti abaje aseje tan ,ita ni igba yen yoo wa, ako ni ri mole o taki da oju re bole o
yoo mawo sanmo (oju fo)ni ao fi igba yen si kosi gbodo da oju bole fun ojo meje
5. lehin ojo keje ao lo fo igba yen mole lorita meta.
By Oluwo asape ola ina loju ekun

13. OSHOLE TO DAJU

ERONJA:
Ori inaki ile ti amo oruko re
Owo tuntun to tobi ni ilu ti an gbe
Ori topo die
Oju olongbo(eso werenjeje) topo die
Odidi atara
Oti oyinbo
Okan malu ti ko wo omi
Ape ibi
SISE RE:Ao ro idi aro ti ati fe jo iseyi
Ao fi oti gin fo ori inaki ile yi
Ao fi owo tuntun ha lenu
Ao fi ori bo gbogbo re pata
Ao le oju olongbo mo gbogbo ara re ti ibi Kankan koni han sile
Ao jo, ao sodi ebu
Ao dasi meji, ida kan fifi se okan malu yen mi aseje ninu ikoko ape ibi
Ao da ida keji sinu oti oyinbo
Ise yi yoo koko gbe 11million wa,lehin naa yoo ma gbe eyi to ju bee lo wa lehin ojo bi
meta.
N.B
Ti aba njo lowo agbodo mo se saara fun gbogbo awon ti won ba bawa nibe.saara bi oti
ati owo.
Ti abajo ise yi tan idi koko yen ko gbodo kan ile o,ori osuka lama soo le.
Gbogbo igbati oba ti gbe owo yi wa, agbodo ma pa agbo funfun fi se saara re.
By Oluwo asape ola inaloju ekun

14. ATINUDENU

ERONJA:
Eku ago kan
Irawe to jabo to doju bole
Epo iroko
Iyere
Ewe sawerepepe
Osun

7
INA LOJU EKUN GROUP

SISE RE:Ao yan eku ako yen, ao ko ifun re kuro


Ao lo awon eronja yoku papo
Ao gbe epo kana, ao se eku yen lepo niyo pelu awon eronja ti ati lo kunna
Ti obati fee jina tan , ao fi osun ti ati lo kuna dada te odu odi meji si owo wa
Ao da sinu aseje yi, ao ro po dada
Ti oba di lale
Ao gba ile enu ona wa
Ao dobale ,ori wa ma yo sita die ao da asje yen si enu ona naa
Ao ma koje pelu ofo re wipe
Ise tie mi lagbaja omo lagbaja nje lowo lowo bayi,
ko sare tete ki olo ran iwi lagbaja omo lagbaja
nitori wipe ojo ti eku ago ba kola ,ojo naa ni onkola jade sinu omo re
nitori irawe kan kii dajo ile ko sun oke, gbogbo ohun timo ba se loni kolo ba iwo lagbaja
omo lagbaja.
N.B
By Oluwo asape ola inaloju ekun

15. GBEWA 30 MILLION

ERONJA:
Ewe ojuotanagbin
Ewe ogbon
Ewe esisi
Ewe tana gbowo
Oga aye kan
Apadure kan
Atare kan
Okan maalu ti ko womi
SISE RE:Ao so gbogbo eronja yi di ebu
Ao ge okan maalu si 16
Ao se lepo niyo pelu ebu yen
Ao je , ao mu omi alijannu le lori.
N.B
Ao gba 30m ni ojo yen gangan naa,eni tofe wa kiise eniyan o, amoko ni wa pelu tipa
tipa, yoo gbe wa nirorun ni.
Ao ko gbodo je aseje ye ku o
Ao gbodo jade ni ojo yen rara o
By Oluwo asape ola inaloju ekun

16. OGUN TI AFI NLE EMI BURUKU KURO NINU ILE ABI ARA.

ERONJA:
Ewe afeloru oojo topo die
Ewe origin oojo
Ewe ayo oojo
Epo obo
SISE REao gun gbogbo re papo
Ao gun po mo ose dudu

8
INA LOJU EKUN GROUP

Ao fi sile fun ojo meta


Lehin ojo keta odi wiwe
N.B
Ti aba ngun lowo to ba jabo le, ao gbodo mu o
Ti abari wipe emi buruku kan wa ninu ile, eje kamu die ninu ose yi ki apo po mo omi ,ki
a fi fan ile ile naa fun ojo meta
Ti o baje alaisan ni yoo fi we fun ojo meta, ti o ban we lowo ti kainkain ba jabo le ko
gbodo mu mo o.
To baje asasi abi alakala ni ao we ose yi fun igba meta ni nkan bi ago kan oru. Ki a ju
kainkain yen nu ti aba ti we tan.
By:Awolere akanni omo odo agba.

17. OSHOLE OWO NLA

ERONJA:
Ewe olujongbodu(ewe jemi ni o)
Iyere
Igbin
osun
SISE RE: ao gun ewe olujongbodu pelu iyere,ao fi se igbin kan
Ao lo osun kuna dada, ao fi te ejiogbe ogunda, ao da sori aseje yen
Ao ro po dada, ao daniyan si, ao je aseje naa.o daju.
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

18. IRAPADA

ERONJA:
Iti ogede to ga to eyan
As funfun opa meta
Imole meje
SISE RE:

Ao losi inu akinju


Eni yen ma dubule ,ao tan imole yi ka ni titan
Ao gbadura ao korin isegun,
Ao fi candle yi ni gbogbo ara
Ao fi aso funfun gbon lara
Ao gbe iti ogede yen bi posi,ao ko candle yen sinu re
Ao fi aso funfun we, ao sin bi oku.
N.B
Iku owo eniyan kole pa eni yen mo
To baje ti olohun ni,pelu adura ole ma ku
By prophet jonah

19. GBOGBO NSE

ERONJA:
Omi osan wewe toba po die
Awon nkan oloorun ti afi nse agbo bi
Ayu

9
INA LOJU EKUN GROUP

Iyere
Ata le
Kanafuru
Ata ijosi
Eru etc

SISE RE:
Ao lo gbogbo eroja yi papo
Ao fi omo osan wewe si,ao fi ose dudu die si , ao se ti yoo jinna
Ao ro pamo odi lilo

N.B
On sise fun apagun,giri omode,afunje etc
Abiyamo gbodo ni nile
By:woli kayode lati togo

20. OSE EYONU

ERONJA:
Alubosa onisu funfun
Obi gbanja funfun
Egbo ipeta
SISE RE:
Ao gun gbogbo re papo mo ose, ao mafiwe lore kore
N.B
By Woli omo emi

21. E YONU AGBA.

ERONJA:
Ewedu die

Ose joy

Iyo die
SISE RE: ao gun gbogbo re papo , ao ma fe ni ojo jimoh
N.B
By woli omo emi

22. OGUN DIDA IGBE EJE

ERONJA:
Ogede agbagba dudu kan
SISE RE:
Ao ju ogede yi sinu ina , ao sun ti yoo dudu ao lo
Eni yoo ma fi foko mu lale ati laaro
N.B
Eni yen ko gbodo mu oti titi yoo fi lo ise yi tan
By woli omo emi

23. GBOGBO NSE

10
INA LOJU EKUN GROUP

ERONJA:
Ewe ejinrin tutu
Omisinmisin pelebe tutu
shynapp
SISE RE:
Ao ki awon ewe yi sinu igo bi agbo , ao da oti yen le lori
Ao ma mu die die leyin ojo keta.
N.B
Eni ti ko bale mu shynap ko ma se ise yi o
Ise yi nsise fun kokoro inu eje,ara riro, ara yiyun,aleko fun okunrin etc
By woli omo emi

24. OSE ASIRI BIBO

ERONJA:
Ewe iyalode oojo
Ewe aladun oojo
Ewe orijin oojo
Ewe anu oojo
Ose dudu
N1000
SISE RE:
Ao gun awon owo yi papo loto
Ao lo owo yi kuna loto
Ao popa mo ose
Ao ko sinu ike funfun, ao gbe pamo fun ojo meta, lehin ojo keta
Ao ma we laararo
N.B
By woli omo emi

25. ASINA

ERONJA:
Etu ibon original
Imi ojo
Epo obo togbo
Ose dudu
SISE RE:
Ao gun epo obo ati etu ibon papo pelu imi ojo
Ao po papo mo ose dudu
LILO RE
To baje wipe inu ile ni ati fe we, ao we fun ojo meta
Ojo akoko ao fi epo para ao we pelu kainkain kana o ri kain kain yen mole
Ojo keji aofi ori para ao we pelu kainkain kana o ri kain kain yen mole
Ojo keta ao fi oyin para ao we pelu kainkain kana o ri kain kain yen mole.
N.B
By woli kayode from togo

26. ASINA

11
INA LOJU EKUN GROUP

ERONJA:
Kainkain 7
Ewuro
Ori
Ose
SISE RE:
ao gbo ewuro yen dada yoo kuna
ao fi po ose ao te otura meji si, ao gbe ori le lori
ti ori yen ba ti yo, ao po mo ose, ao bu ose sori kainkain meje
yio fi epo para lemeta yoo we
yio fi ori para lemeta yoo we
yio fi oyin para lekan ,o ma duro die ki oyin gbe mo lara yoo tun we
to ba we tan yoo da perfume sara yoo ma bo wale.
To ba je wipe ona tidi mo eniyen tan pata yoo se sara fun olodo ki oto waleyoo bu iyo
sinu basia yoo wa ma da iyo ye sinu odo , yow a ma bere gbogbo nkan to bafe.
N.B
By woli kayoed from togo

27. ASINA

ERONJA:
Ewe taba tutu oojo
Ewe ewuro oojo
Epo obo
SISE RE:
Ao gun gbogbo re papo
Ao fi oronro maalu pomo ose dudu
Leyin ojo keta odi wiwe

By woli omo emi

28. OSE ITUWO

ERONJA:
Kanu bilala
Epo obo
Ose dudu
SISE RE:
Ao gun kanu ati epo obo kuna dada
Ao ko lose dudu
Ao ma fi we
N.B
Ikilo ose yi kii wo inu ile o, eje kagbe si ita ni o
By woli omo emi

29. OSE AWORO

ERONJA:
Oronro malu oojo

12
INA LOJU EKUN GROUP

Eran elede ekiri kan


Isasun
Ewe ekuya tutu
SISE RE:
Ao fie ran elede sinu isasun, ao ko ewe ekuya le lori pelu ataare kan
Ao de pa,ao gbe pamo fun ojo meje
Lehin ojo keje , ao jo, ao po papo mo lose
Ao fi oronro maalu po papo
Ao ma fi we. O daju
N.B
By woli omo emi

30. AWENU ATUDE

ERONJA:
Epo obo
Apata ori apata
Ose dudu tabi eyikeyi
Eyin ororo kan
Awo tasa kekere
SISE RE:
Ao lo apata ori apata yi mo epo obo ti yoo kuna dada
Ao po lose, ao fi owo wada iho si arin ose yi
Ao fi eyin ororo si
Ao fi ose bo mole, ao gbe ose na sinu awo tasa
Ao gbe pamo fun 16 days
Leyin 16 days ao ma we laaro tabi lale. O daju

By pastor taiwo

31. ATUDE ATUWO

ERONJA:
Ako pepeye kan
Egbo tude topo niwon ba
Ose
Aso funfun
Ike funfun
SISE RE:
Ogbe ako pepeye eyo ka , ao gun mo ego tude
Ao fi eje pepeye po ose yen dada
Ao gbe sinu aso funfun
Ao wa gbe sinu ike funfun
Ao ma we lalale fun odidi ojo meta
Lehin eyi ale ma we lekan lose.
N.B
Ako gbodo je ki idi ose yen kanle moo, ale su osuka fun ka gbe sibe

13
INA LOJU EKUN GROUP

Ao gbodo jade mo ti aba ti we ose yi tan, afefe aburu koni fe lu wa o. o daju


By prophet Taiwo

32 ASINA

ERONJA:
Kaun bilala
Ose
SISE RE:
Ao gun kaun bilala pomo ose
Ago mejila la ma we ise yi.odaju
N.B
Akii lo iseyi ka tun jade mo o
By Khadihat from cotonu

33. ASINA

ERONJA:
Ewe ewuro
Ewe iyalode funfun
Ewe ajeobale
Ewe akoko
SISE RE:
Ti aba ti ja awon ewe yi ako nije ko kanle
Ao gbo gbogbo re sinu omi
Ao fi we lago mejila oru
Ale fi any ose we iwe yi
N.B
By Khadihat from cotonu

34. OSHOLE TI AFI NPAWO NI KIA KIA

ERONJA:
Oju maalu mejeji
Ewe tanagbowo
Eyan aja
Cast biscuit
Oti oyinbo tabi oyin
SISE RE:
Ao ko ewe tanagbowo le oju maalu lori
Ao fi eyan aja die si pelu cast biscuit
Ao jo papo, ao fi oti oyinbo tabi oyin lo
N.B
O dara kalo oti oyinbo ju oyin lo o
By Oluwo asape ola ina loju ekun

35. ISE OMO YAHOO

ERONJA:
Ewe irawe 7
Ewe ina funfun

14
INA LOJU EKUN GROUP

Ewe ina pupa


Ewe iyalode pupa
Blue
Ewe abamoda 7
Koko ajere
Ewe sisi
Ori alangba adaripo kan
Etu ibon
SISE RE:
Ao ko ewe irawe merin te isale inu koko ajere ti yoo ko oju sita, ao fi oruko oyinbo ati
oruko ti omo yen nje lodo oyinbo ti ati ko sinu paper kan si
Ao ko ewe sisi si
Ao ko ewe ina tele,ao da ewe iyalode pupa bo
Ao gbe ewe ina funfun le lori
Ao ko ewe abamoda le lori
Ao bu blue le lori
ao gbe ori alangba le lori, ao da blue le lori
ao wada etu ibon si isale, nibi iwaju idi koko yen
ao pe gbolohun re si bayi
irawe kan kii dajo ile ko soke,iwo lagbaja nje wa sanwo fun lagbaja lati onilo
nitori wipe were were lomode lo oko, warawara bayi lomode ti oko esisi bo
abamoda kan koni da tie ko ma se, akii riyalode funfun nibi kan kama ri pupa re
nje to bari be ki iwo lagbaja sanwo fun lagbaja loni kiakia
ao wa fi ina si etu
ibon yen
ao wa gbe si igun ile wa, ojo ko gbodo pa o
ao ma tan candle funfun ati pupa fun, si ile le idi re ni o. o daju
N.B

aki sunmo obinrin ka lo sidi ise yi o

By Oluwo asape ola ina loju ekun

36. IMULE AWON AGBA

ERONJA:
Eyin eyele dudu 2
Ewe alelendoru 1
Ewe ajeobale 1
Afomo igi kigi
Jakunjakun ori ope
SISE RE:
Ao ko gbogbo re papo, ka sodi etu
Ao ro sinu ado kekere kan
To badi ale ao dasi enu ona wa ao fi epo la
N.B
Ti abati sun ao ba ara wa larin awon agba, won o ma ko wa loogun abi ki won fi ejo
sunwa. O daju gan ni o

15
INA LOJU EKUN GROUP

By Oluwo asape ola ina loju ekun

37. ATUDE AYERAYE

ERONJA:
Ewe akoko
Egbo igi akoko
Epo ara akoko (ti igi kan naa ni o)
Orogbo kan
Ewe iyalode funfun
Egbo iyalode funfun
Epo ara iyalode funfun
ose
SISE RE:
Ao gun ewe akoko, epo ati egbo re papo
Ao ko lose si ibi kan
Ao gun orogbo, ao ko lose si oto
Ao gun ewe iyalode, epo ati egbo re papo
Ao ko lose si ibi kan pelu oyin
Ao ko gbogbo re odi odo pelu kainkain meta
Ao we ose ewe akoko ni akoko
Ao we ose oni orogbo leekeji
Ao fi epo para ki ato we ti ewe iyalode
Ao gbo ewe akoko si ibi kan ,ao fi sanra ti aba we tan. O daju

N.B
By Oluwo asape ola ina loju ekun

38. APASE ATI ISOYE OMODE

Ile eye alapandede


Eyere
ayu
SISE RE:
Ao gun gbogbo re papo,ao se ko kunna dada, ao da sinu oyin
Ao ma la
N.B
Gbogbo oro ti abaso di ase
Ti aba tun fun omo ile iwe lo yoo mowe gan. Odaju o
By Oluwo asape ola ina loju ekun

39. ITUSILE AWON AGBA ATI ASINA

ERONJA:
Awo agiliti kan tope
Ewe ajeobale
Odindi atare kan
SISE RE:
Ao so gbogbo eronja yi di etu(ao jo papo)

16
INA LOJU EKUN GROUP

Ao ma fi foke mu abi oyin abi oti oyinbo lo lojo madi


N.B
Ti abati nlo odi dandan ki a ka owo
By Oluwo asape ola ina loju ekun

40. OSHOLE

ERONJA:
Odindi atare kan
Ewe alupaida eyi ti alu to parada 16
Ewe aje
Ewe awerepepe
Iyere
Eyin ibile 2
SISE RE:
Ao lo gbogbo re papo kafi din eyin ibile meji je
Lepo niyo, ka daniyan ka je
N.B
Ao ri wipe laarin ojo melo kan , ao ri iyanu olohun
By Oluwo asape ola ina loju ekun

41. OSHO TI AFI NGBA ISE NLA NLA

ERONJA:
Eyele funfun to daju aye kan
Epo obo
Epo igi nla
Owo eyo ti ko lu 9
SISE RE:
Ao jo gbogbo re papo

Ao fi fokomu leekan laaro kutukutu


N.B
Ao ko gbodo jade ti aba ti lo o
Ti aba ni imule lara dada, yo bere ise lojo yen gangan. O daju o
By prophet taiwo

42. OHUNMO

ERONJA:
Eye oga kan
Ikode kan
Ado meta
Odidi atare kan
SISE RE:
Ao ki ikode si oju eye oga yi , ko jade loju keji
Ao jo pelu atare kan,ao ro sinu ado kan
Ao tun jo, ao lo , ao da sinu ado keji
Ao jo, ao lo ao ro sinu ade keta
Inu iyen la ti ma loo laraaro

17
INA LOJU EKUN GROUP

Ao ma fi foko mu. O daju

N.B
By Oluwo asape ola ina loju ekun

43. TESO UNISEX

ERONJA:
Ewe kukunduku
Ewe omisinmisin
oyin
SISE RE:
Ao lo awon ewe yen po , ao ko sinu oyin
Ao ma fi pa abe
N.B
By Alfa Serifudeen

44. TESO TI OBINRIN

ERONJA:
Eso werepe 1
Akeeke 1
Eyo atare 7
SISE RE:
Ao lopo kuna dada, ao fi singbere kan si awe otun ati osi oju ara wa.
N.B
Ti okunrin ba ba eni yen lajosepo tan, yoo bere ohun to ba fe. O daju
By Alfa Serifudeen

45. TESO

ERONJA:
Iwo etu 2
Eyo atare kan
Ori
SISE RE:
Ao mu eyo atare kan sinu iwo etu kan, ao jo
Ao fi ori po sinu iwi keji
Ti a ba felo, ao pe gbolohu re si wipe
Osanyin mole o dowo re x3
Ika kan nigba iwo etu, iwo etu kii gba ika meji
Ao fi owo kan, ao fi pa nkan omo kunrin wa
Ao fib a obinrin na lajo sepo. O daju

N.B
By Alfa Serifudeen

46. TESO

ERONJA:

18
INA LOJU EKUN GROUP

Irun ori akile


Akigbonnaku kan
Toko tepon akuko adie kan
Odidi atare kan.
SISE RE:
Ao jo gbogbo re papo
Toko taya yoo fi foko mu leekan na
N.B
Ti won bati lo, okunrin miran kole gori obinrin yen mo lailai,to bad an wo, kole ri nkan
kan se. o daju By Alfa Serifudeen

47. ASEJE OWO

ERONJA:
Afomo ewe iyalode
Iyere 16
Eran elede
SISE RE:
Ao lo afomo ati iyere papo
Ao gee ran elede yen si 16
Ao se lepo niyo ni dede 12.30pm
Ao je ni ihoho ni dede 1.00 pelu adura
N.B
Ewo re ni wipe eni ti oba nwa omo ko gbodo je aseje naa.
By Alfa Serifudeen

48. AWURE ITAJA AGBEKO

ERONJA:
Ori eye agbe

Ori eye aluko


Ori eye aparo
Iyo akogbe
SISE RE:
Ao jo gbogbo re papo
Ao ro sinu ado
Ao so ko enu ona ile itaja naa
N.B
By Alfa Serifudeen

49. AWURE SIGIDI ARIMOLE

ERONJA:
Esu igbo
Ori obuko ti won fibo esu
Iko odide kan
Ewe sawerepepe
Tannatanna eyo kan
SISE RE:Ao fi esu igbo mo sigidi olowo 16

19
INA LOJU EKUN GROUP

Ao jo awon ewe yen pelu iko odide


Ao ro seun obuko
Ao gbe ori yen si owo sigidi yi
Ao fi aso funfun yi papo
Ao ri ti yoo koju si ita ni inaro
Ao ko atori si legbe
N.B
Ao ma fi ekuru ti afi epo, oyin ati iyo si oju ibe
Ao gbodo gbe nkankan si oju re o
By

50.ASINA ATUDE

ERONJA:
Eyele funfun kan
Ewe ejinrin oojo
Ewe sawerepepe oojo
Odindi atare 3
SISE RE:
Ao pa eyele yi tie je ko gbodo jade lara re
Ao jo gbogbo re papo
Ao pin si ona meta
Ao mafi shynap lo fun ojo meta
N.B
Pelu ogo ologun ki ojo meta tope , ao ri iyanu olohun
By mukhadam ibraheem

51. OSHOLE

ERONJA:
Biscuit die toba fe die, toje ti taarin
Eyele funfun balau
Odindi atare
SISE RE:
Ao fi biscuit tele ape, ao du eje eyele si
Ao ge ori eyele si lori, ao la eyele toku . ao daya de lori
Ao fi odindi atare kan si, ao jo, ao lo, ao ro sinu ibi kan
Ti aba ti fe lo. Ao te nifa ogun dabede
Ao wape gbolohun re si bayi wipe
Asare owo wolu loruko ti anpe ifa
Arinrin ola wolu loruko ti anpe esu odara
Olu kowon je loruko tanpe eyin iyani oshoronga
Eyin meteta ni kinlode ti mo fi npe yin
Moni tori kinle lowo lowo ni
Moni tori kinle mo eniyan atat lawujo ni
Eyin leni eyele kii leran ise lara
Ifa o ifa o ifao wa bami yan ise ara mi danu loni

20
INA LOJU EKUN GROUP

Ogun dabede iwo ni olori ole, owo nla nla ni ole mangbe
Owo nlanla ni ki won ma wag be fun emi lagbaja omo lagbaja lati oni lo.
Ori gbigbe o x3 ki olo wa ounje wa fun ori tutu emi lagbaja omo lagbaja lati oni lo.
Ao tun se adura si
Ao da senu.
Ao ma fi oti to gbona dada lo
N.B
By mukhadam ibraheem

52. EYONU

ERONJA:
Opolo aye to tobi dada
Epo obo
Odidi atare
SISE RE:
Ao lo epo obo ti yo kuna
Ao ro senu opolo yi ti yiyo bamu
Ao gbe sinu ape ijogun pelu odidi atare kan, ao jo
Ao lo ti yoo kuna , ao ko si ibi kan
Ao fi foko mu fun ojo meta
N.B
By woli omo emi

53. ATUWO

ERONJA:
Ewe iyalode pupa ati funfun
ose

SISE RE:
Ao lo mejeji papo , ao fi ose ko
Ao pin ose yen si meta
Ao fi we fun ojo meta ni deede ago kan oru tabi ago mejila ninu ajadi apere
N.B
To baje okunrin ni ewe iyalode pupa ati funfun 7
To baje obinrin ni ewe iyalode pupa ati funfun 9
Ti aba nwe iwe yen lowo, ti aba gbo ohun kan tabi apeere kan
Ao gbodo jade kuro ninu ajadi apere naa o, olewu dieo

By woli mercy

54. OSHOLE

ERONJA:
Ede funfun die
Awo inaki
Iye odidere
Irun afin
Ekanna owo mewewa

21
INA LOJU EKUN GROUP

Akisa ori akitan


Iyepe saare ti won sin oku si
Ose
Ikoko ajere
SISE RE:
Ao jo gbogbo re papo
Ao dasi meji, ida kana o fi ko ose, ao ko sinu ikoko ajere
Ida keji ao dasi inu oti lord, ao ma mu oti yi laaro
Oru lao ma we ose yi. O daju gan
N.B
By woli mercy

55. OSHOLE

ERONJA:
Olongbo ileto tip e ninu ile, to ti gbo dada
Yerupe saare okunrin
Yerupe saare obinrin
Yerupe oja
Iru ori were
Olori owo meta (N1000)
SISE RE:
Ao pa olongbo yen
Ao ko gbogbo ifun re jade
Ao ko gbogbo eronja yoku si inu re
Ao we lowu dudu, ao wa jo
Ao po papo mo ose dudu
Ao ko sinu apo kan

Odi wiwe lago kan oru. O confirm


N.B
By woli mercy

56. OSHO OWO NLA

ERONJA:
Eku asin meta
Oga gbigbe meta
Ori olongbo to niru meta
Alangba ako aye meta
Opolo aye nla meta
Odidi atare meta
Eso werenjeje agolo kam
Isasun titun kan
SISE RE:
Ao jo gbogbo re papo ninu isasun titun yi
Ao lo ninu isasun naa
Ao so detu,ao ma lo ni ago kan oru pelu peak milk
N.B

22
INA LOJU EKUN GROUP

By woli mercy

57. EYONU ASINA

ERONJA:
Ewe rere abo
Eyin 3 (ibile tabi agric)
Olokun die
SISE RE:
ao lo ewe rere abo
ao da po mo eyin ti ati fo pelu olokun die
ao da sinu lylion, ao se lori ina
to ba jina , ao daniyan nkan ti anwa si
ao je
N.B
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

58. OSHOLE ITAJA/ASINA

ERONJA:
Eje malu topo die
Ewe tanagbowo
Ewe orijin
Ewe ewon
Ewe aje
Eru Alamo ti ati la
SISE RE:
Ao gun gbogbo eronja mo ose
Ao fi eje maalu po dada ti yio fele

Ao ko sinu ike funfun


Ao ma fi we lemeta losu. O daju
N.B
A kii we lojo jimoh o
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

59. ASE TI AWON TO BAWA SADEHUN FI MA WA MU SE

ERONJA:
Ewe aluro(ewe padimo padimo)
Olokun
Oyin gidi
SISE RE:
Ao gun ewe aluro papo mo iyo
Ao ko sinu ike funfun olomori kan
Ao da oyin gidi le lori
Ao gbe pamo fun ojo meta
Lehin ojo keta ao ki owo bo inu ike yen ao wa ma wi bayi pe
Gbogbo awon ti won ti bami ladehun lojo toti pe ati awon ti won sese bami
Sadehun ki won wa ma pe adehun won bayi bayi

23
INA LOJU EKUN GROUP

Ao la , odi ase niyen. O daju


N.B
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

60. GBEWA 9 MILLION

ERONJA:
Agolo tomato/ kolibu tomato
Igi oba
Ewe alupaida 31(eyi ti alu to parada)
Owo paper ilu ti awa
SISE RE: ao jo gbogbo re papo, ao lo ninu ape ti afi jo
Eda Holland milk kan si, e gbe mu.
N.B
Ekan soso ni yoo gbe owo yen wa.
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

61. EYONU ASINA AWON AGBA

ERONJA:
Ewe orijin oojo
Ewe yanrin oojo
Yerupe idi esu (eyi ton jeun daada)
Yerupe oko (farm)
Ewe ominsinminsin gogoro
SISE RE: ao gun gbogbo re papo, ao po mo ose , ao fa sinu igba kan, ao ma we pelu
kainkain ibile pelu gbolohun re bayi wipe
Aje ogedengbe loruko ti anpe ifa,abidi tenu boorun loruko ti anpe esu odara,
Aje kolonje to je loruko tanpe eyin iyami aje, eni kinlode timo finpe yin, moni nitori ire
owo tonbe lowo omo araye ti won nna ti emi ko rina ni mo se npe yin,
Eni edu ni mi mi kii se ai mo foloko, ibi gogoro la nba ominsinminsin, ibi gogoro ni ki
omo araye ti ma bami.
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

62. AJEEGUN

Ajeegun yi wa fun ki gbogbo ewe ti aba ti ja ki o ma sise fun wa


ERONJA:
Eso isin 2 (eyi ti oti yanu to sip e daada)
SISE RE:ao po ose dudu ko fele dada, ao fi di enu eso isin to la sile yen mejeeji
Ao fi odindi atare aja jo alakoko si ibi kan loto
Ao fi odindi atare jo ekeji naa loto
Ao fi akoko sin igbere si isale orun owo wa
Ao fi ekeji sin igbere si oke orun owo wa
N.B
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

63. OSHOLE OWO NLA

ERONJA:

24
INA LOJU EKUN GROUP

Omunu ewe onitikuti


Glass cup (glass cup talonpemi) to ma nsaba wa lori oti shynap
SISE RE:ao fi owo gbo ewe yi lai fi omi si o sinu cup yi, ao fi oti gin white si
Ao w ape gbolohun re bayi wipe
Ewe oniti kuti, lo ti olowo, olola wa fun mi loni, kinri taje se
Aaro kutukutu la o mu.
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

64. ASEJE ASIRI BIBO

ERONJA:
Adie funfun eyokan
Suratul isawaka 2
Agbon 3
SISE RE: ao han suratl isawaka si ona meji, ao fi omi agbon fo si ona meji otooto
Ao fi idakan se adie yen, ao ma mu idakeji ti aba nje adie yen lowo. odaju
N.B By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

65. OSHOLE TO NMU CUSTOMER WA FUN NI

ERONJA:
Opolo gbigbe mefa
Odindi atare mefa
Eso yerepe mefa
SISE RE:ao jo metata papo dada, ao lo ,ao ro sinu ike funfun kan
Laaro kutukutu ti ao ti soro si enikeni ,ao bu die sowo ao te nifa ejiogbe
Ao wipe gbolohun re wipe, ao juba awon to laye
Omode kiilu yerepe koma royin nile,agbalagba kiilu yerepe koma royin nile
Okunrin kiilu yerepe koma royin nile,obinrin kiilu yerepe koma royin nile
Gbogbo eyin ti e ti mo emi lagbaja omo lagbaja, oya e malo pokiki mi fun omo ara aye
lona todara, fun okunrin fun obinrin , fun omode, fun agbalagba, nitori wipe iwa irefa kii
fara won ti, lodindi lodindi latare ndi tie, atare kan kii di tie labo,lomode yin lagba yin ,
lokunrin yin lobinrin yin,ema gbe ore odindi wa ba emi lagbaja omo lagbaja nibi ti mo ba
joko si,Ejiogbe o gbera nile ki owa lo gbe olowo nlanla lokunrin lobinrin lomode lagba ki
won mafi owo owo won se emi lagbaja omo lagbaja laanu.
N.B
By alfa ola oluwa phone no:08082392705

66. MAYEHUN FUN CUSTOMER

Ise ti ogun yin se ni wipe ti aba so fun awon customer to wa ise lodo wa, won ko ni naa
ise na wo ki won to san owo fun wa
ERONJA:
Itanna ako ibepe to po lopolopo
Eye Kowe kan
Odindi atare kan
Oga aye kan
SISE RE:ao itanna ibepe die si isale inu ape,ao gbe kowe le lori pelu odindi atare kan,
ao wad a itanna to ku le lori , ao jo dada, ao lo kunna, ao wa igo bi igo bama kan

25
INA LOJU EKUN GROUP

Ao ju oga aye yen sinu re, ao da etu yen le lori, ao wada mohu li ayati le lori, ao mi po
dada, ao gbe pamo fun ojo meta.
Lehin ojo keta laaro kutukutu ao ma bu die niwon ba mu, ase ni. Odaju,
By By alfa ola oluwa phone no:08082392705

67. ATUDE TO GBONA

ERONJA:
Ori etu
Egbo tude topo lopolopo
Atare kan
SISE RE:ao gbe ori etu sinu ape Ijogun, ao ko egbo tude le lori , ti yoo po dada pelu
atare kan,ao jo, ao lo , ao da sinu nkankan.
Ti aba fe lo lale tabi laaro, ao te ifa iwori otura si, ao pe gbolohun re bayi wipe
Ao juba awon to laye, alade riko mope x3,etu lontumo fun olu igbo, efun edi asasi
aransi, wa lo tu danu lara emi lagbaja omo lagbaja. Tude o x3 walo tu gbogbo ide
buruku tonbe lara emi lagbaja omo lagbaja wa lo tu danu lati oni lo.
Iwori otura o x3 imo otun, imojo awon ota lori emi lagbaja omo lagbaja wa bami lo tu
danu lati oni lo, ki ona mi kosi, ki ona mi kola ,komo araye la ona ire kan mi, ao se adua
si dada, ao da senu.
N.B
By alfa ola oluwa phone no:08082392705

68. IMULE AWON AGBA

ERONJA:
Eye kanakana kan
Oga gbigbe meta
Eku asin gbigbe meta
Opolo gbigbe meta
Atare meta
SISE RE:ao jo gbogbo re papo, ao lo kunna dada, ao ma fi mu eko gbigbona pelu ori
N.B
Ao ju ori sinu eko ki o yo, ki ato da ebu yen si. O daju
By woli omo emi phone no:+22892588990

69. AWURE

ERONJA:
Iru wooro,iru pete,ogiri ati ewe tangiri
SISE RE:
Ao lo won papo , ao pomo ose Ghana(lagos di), omi agbon la o fi po papo
Ao fi iku ijebu si arin ose yi, ao gbe pamo sibi oju miran ko ti leri
Ao ma we laararo. odaju
N.B By woli omo emi phone no:+22892588990

70. AWORO NLA

ERONJA:agbado funfun topo ti ko si idoti Kankan lara re


Ewa funfun topo die tosi mo dada
Odindi atare kan, ao yin omo inu re lookokan

26
INA LOJU EKUN GROUP

\
Igba ademu nla kan to nideri
Eyele funfun original kan
Igo epo
Iyo die
Oti die
Apo ao funfun
SISE RE:ao ko agbado,ewa ati atare sinu igba nla yen, ao gbe eyele yensi laaye, ao tu
epo si legbe , ao de pa, ao gbe sinu apo as funfun yen, ao gbe ile si shop abi office ti
afe gbe si , ao s saara ki ato ri mole, ao bu iye die ati oti die si isale, ao gbe igba ye
sinu re ao gbe pako kan le lori, ao bo mole. O daju
N.B: ti eyele yen ba lo ogun odun ko ni ku.
By woli omo emi phone no:+22892588990

70 B. AWORO NLA

SISE RE:ao ko agbado, ewa,oka baba, gbogbo re funfun sinu igba , ao gbe eyele sinu
igba, ao da oyin ati epo si, ale da igo kokan si tabi die die, ao de igba yen , ao gbe sinu apo aso
funfun , ao ri mole.

N.B: ti o ba pe osu mefa eyele yen ma jade, yoo fo kaakiri inu shop abi office wa,ao
gbodo pa o, yoo wole pada. Ti o ba di osu meta si yoo tun jade , yoo lo fun osu mefa , ti oba ti
npada bow a, oun ati awon eyele to po ni won yoo jo wa, ao se sara fun won, oun yoo wole
pada , awon yoo ku ma pada lo. Oti bere ise niyen oo. O daju
By oluwo asape ola ina loju ekun phone no:+22961928327

70 C. AWORO NLA

Aworo yi dara debi wipe aworo awon emere ni emi manpe


ERONJA: eleyi ni adun,imumu, ireke,omi ti won fi we omo tuntun ati wipe igba kolo/
igba aje ni won fin se eyi, koni epo sugbon oni oyin ninu.
SISE RE: ao se bi ati se awon yoku sugbon ti aba ri mole ao ri flag funfun mo ibi ti aba ri
ise yi mo, ti igi/ irin re yoo wa legbe igba yen. Lehin ojo keje eyele yi yoo jade , yoo wa
si ori flag yen , yoo fo kaakiri, yoo lo ko awon eyele miran wa, ao se sara fun won, yoo
si wole pada. Ise bere niyen. o daju.
N.B By Dr. owo agbarabalogun ina loju ekun phone no:08063207857

71. ASIRI BIBO

ERONJA: eyin pepeye kan


Atare kan
Ewe bomubomu 28
SISE RE: ao fi ewe 16 tele ape ,ao fi eyin le lori pelu atare, ao ko ewe toku le lori,ao jo
Ao lo, ao pin si ona meta, ao ma fi Holland peak milk lo ikokan lojo mejomejo.
By woli omo emi phone no:+22892588990

72. ISORA AGBARA

Ise yin ma nse fun ti eyan ban leri ogun siwa tabi awon kan nsasi wa tabi ala alakala
kan, ti aba sa ise yi lese kese ni nkan yoo ma sele si eni ti o se nkan si wa
ERONJA:alakan aye kan

27
INA LOJU EKUN GROUP

Odindi atare 3
Alangba aponri aye 1
Opolo aye 1
Ikoko tuntun meta
SISE RE:ao jo alakan pelu odindi atare kan ninu ikoko kan, ao lo, ao ko si egbe kan
ao jo alangba aponri pelu odindi atare kan ninu ikoko keji, ao lo, ao ko si egbe kan
ao jo opolo pelu odindi atare kan ninu ikoko keta, ao lo, ao ko si egbe kan,
ao ro meteta sinu ado ato kekere kan, ao fi super glue le enu re pada, ao pa lawo
dudu(black) , ti abati fe lo ao mi ado yen si eti otun ao so gbolohun yi wipe
talo nba mi fori wonri x3,alagbaka ton bami foriwonri iye ko lori, opolo ton bami fori wori
ko niru,alangba ton bami fori wonri oro ido bale loba, gbogbo eni ti o ban ba emi lagbaja
omo lagbaja fori wonri, osho ile ni,aje ile ni etc ki won ma ri emi lagbaja omo lagba se,
ao mi bee si eti osi na pelu gbolohun yi. o daju
By suffism abu fatihat li hairi abu tohaphone no:08037384289

73. AWORO NLA

Ise yi je aworo nla to tun sise oshole ton mu nkan nlanla wa fun ni
ERONJA:Olongbo dudu kan
Odindi atare mewa
Eku asinrin mewa
Opolo mewa
Orogbo mewa
Oju musu(eso werenjeje) agolo kan
Adie abo dudu kan
SISE RE:ao jo olongbo, atare, asinrin, opolo,oju musu ati orogbo papo, ao lo ti yoo
kunna , ao ko si ibi kan
Ao pa adie dudu yi ao gun kunna dada, ao fi ko ose, ao da etu ti a gbe si egbe kan si ao
gun kunna dada , ao ko sinu ike nla kan. Odi wiwe.o daju
By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289

74. OLUGBOHUN

ERONJA:
Oromodie ti o sonu leyin iya re
Iwo agbo kan
Ewe ewuro
Aso pupa
Ose dudu
SISE RE: ti aba ti ji ni aaro kukukutu lai ti soro si eni Kankan, ao lo ja ewe ewuro, ao
gun mo ose dudu,ao mu oromodie tele inu iwo agbo yen, ao fi ose dudu ti a gun yen bo
lori , ao fi aso pupa we, ao gbe si igun ile ti idi re ko ni kanle fun ojo mesan,lehin ojo
kesan ka danwo. O daju
By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289

75. OSHO OWO TUTU

ERONJA: odidi eye okin kan


Ori akala 3

28
INA LOJU EKUN GROUP

Ori oka 3/ 7
Ori ere 3/7
Iye agbe 7, iye aluko 7,ikode 7,
Ewe etiponola 101
Ori eye okin kan
Ori igun ti ko ju rara
SISE RE: ao gun odidi eye okin,ori akala,ori aka,ori ere, iye agbe, iye aluko,ewe
etiponola gbogbo re papo mo ose oni ye kiye,
Ao wa awo funfun ti ama ko ose yi si, ao fi ori eye okin tele awo yi, ao ko ose ti ati gun
le lori, ao wa fi ori igun kan gun lori. Emeji pere lao ma we ose yi laarin osu kan
By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289

76. OSHOLE ASINA

ERONJA:
Ewe ajeobale (ti aja laaro kutukutu ti a ti soro si eyan kan)
Ako alangba 16
Abo alangba 16
Odindi alare 15
Oti shynap igo kan
Eyin ororo
Oyin igan kidi
SISE RE:ao jo ako ati abo alangba pelu atare, ao gbe si egbe kan,
Ao gbo ajeobale ti a lo ja laaro kutukutu lai soro si eni Kankan pelu oti shynap kan,
Ao fo eyin ororo kan si ati oyin gidi, ao po papo dada, ao ma fi lo ebu yi larolaro. O daju
faa
N.B
Ale fun eyan lo ninu re sugbon ao ni ti fieyin si omi yen ki ato fun eniyen, eniyen naa ma
foe yin odidi kan si tie naa ni o
By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289

77. OSHOLE TON SISE AWORO

ERONJA: omo aja 1, omo olongbo 2,ileke itun, ileke ifa,oga aye 4,abeere topo die
Iye agbe 4, iye aluko 4,ikode 4,obi ifin oloju merin 4, obi ipa oloju merin 4,yanrin okun
.yanrin osa.
SISE RE: ao gun gbogbo eronja yi papo ti yoo kunna dada,ao gun mo ose ti yoo kunna
dada, ao ko sinu igba olomori kan,ao fi kale fun ojo mesan, lehin ojo kesan ao bere
wiwe re, o daju
By suffism abu fatihat li hairi abu toha,phone no:08037384289

78. OSHO OWO NLA

ERONJA:

SISE RE:

29

You might also like