Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 3

ASIRI TI AMA NSA FUN ENITI OBA WA NI ILU OYINBO(AMERICA) 

TI OFI MARI ANU ATI IWE IGBELU


GBA

Ao wa ,abela pupa kan, abela funfun kan, abela dudu kan, ao wa iyanrin okun ,ao te ni ejiogbe ,ao wa
tan abela yen rand re, ao wa se ADUHA ti abafe si daada, ao wa jeki abela yen Jo tan patapata, ao sa be
fun ojo meje , ao ko awon ajoku awon abela yen fun ojo mejeje, ao wa gun papo Mon iyanrin okun yen,
ati ose eyikeyi toba wuwa, ao fi lofinda onala po ose yen papo, ENITOBA se ADUHA yen yio mafi fi ose
yen we tabi ki agbe ranse si eniti aba se ADUHA yen.

IMULE AWON AGBA TODAJU

Eiyele funfun kan, ikode kan, odidi atare kan, ado ijama 2, ilaji opa aso funfun. Ao le eiyele yen mole ti
yio ku yanyan, ao ti ikode bo loju otun ti yio jade loju osi re, ao wa we pelu aso funfun yen ao lo ri mole,
dede ago ti a ri mole yen ni ao lo wu ni ojo keji, iyen ni wipe ti a ba ri mole ni 10am loni, 10am ola ni ao
lo wu. Ti a ba ti wu ao wa gbe sinu ape, ao fi atare kan si ao wa jo, ti o ba jo tan ao ro si inu ado ijama kan
ao wa tun gbe ado yen sinu ape ao jo, ti o ba jo tan, ao lo kuna dada ao wa ro sinu ado keji idi re ko
gbodo kanle .ao malo pelu omi laale.Ofore: Eiye wo nu eiye. Ado wo nu ado. Eniyan wo nu eniyan. Bi
eiye ba wo nu eiye, eiye a rinu eiye. Bi ado ba wo nu ado, ado a rinu ado. Bi eniyan ba wo nu eniyan,
eniyan a rinu eniyan. Emi lagbaja omo lagbaja ti wo nu yin loni o e je ki ona si funmi, ki ona la funmi, kin
ri towo se. Ao se adua si. Ao ma lo pelu omi lalale.Akiyesi Pataki: Ti a nba lo ise yi lowo o sese ki awon
agba ma fi ara han wa o, edakun ki se gbogbo nkan ti oju ba ri ni ki enu o ma so o. Ki a sora.

OSHOLE TODARA

Isu esuru pupa, ako alangba kan. ao gun papo aofi ose dudu po dada ao ko sinu ike funfun ti abati fee we
ama wa ada,CUTLASS ao duro sori ada naa ao maawe pelu OFORE gbami gbami ni alangban ke leba ogiri
ki omo araye mawafi owo owo won wa ke gbami gbami wabami...

OWO TODAJU Orogbo kan, eso eyinolobe, Eyin opę eyo kan, ao ge orogbo yen lori ao pani pansa, ao lo
eso eyinolobe ati dudu idi eyin opę yen papo ao ro sinu orogbo ti apani pansa ao fi ideri ti a ge de pada,
ao di ni owu dudu, ao ma fisi apo jade.

ASIRI OSOLE OSIN OLUWERI

Ao han ISAJA mokanla (11).TABATIADA mokanla (11),.ao po omi agbon..oyin igan gidi..lofinda bintu
meta ao po papo ao fi fo hontu yii sinu awo funfun kan Eegun ori inaki to fe die..ori ijimere kan..ori obo
kan..ori alakedun kan..owo eyo tiko luju (201)..owo otun elegbede..ewe orijin..ileke
itun..ifa ..abere..oga.ao Jo eegun ori inaki..ori obo..ori alakedun..owo elegbede..pelu odidi atare kan..ao
lo daada ao kosi apakan. Ewe orijin..oga gbigbe meje.. Ifa ..itun..abeere..owo eyo tiko luju 201..ao lo
papo ti yio kuna bi atike..ao wa po papo mon eyiti ajo..ao po mo ose dudu ..ao wa fi omi hontu tia ti fi
oyin igan..lofinda..omi agbon..fo sinu awo funfun olomori po ose naa papo sinu awo funfun yii... ao ma
we ni emeji ninu ose..ojo aje (Monday) ati ojobo (Thursday ) ..AKIYESI ki a jeki aso funfun po ninu aso ti
ao mawo ni gbogbo igba ti a bà n lo ise YII.. Odaju
ASEGBE ATI AFORAN Iyepe ile tio ti di ahoro(ile ti o titu ti ko si eni ti o n gbebe mo ni o),aroti agbara
ojo,ao mu yepe die ati ewe die nibe,ao wa di sinu owu otutu pelu owu dudu ati funfun,ase be lona meta.
ao mu akoko lo sinu iho alakan ti owa nile,ao sope akii fi oro tutu bi ile,akii fi oro aroti bi agbara,oro to
ba wole alakan,oti di omi,oro l omo l to wa nile ejo etc ki o domi.

a mu ikeji lo si ori akitan,ao ya igbe le lori tabi ki ri mole pelu sisope akii fi oro tutu bi ile,akii fi oro aroti bi
agbara,akii fi oro jakujaku bi akitan.oro ti won ba emi l omo l fa ti di jakujaku etc. ao mu eleketa,a o lo ri
si ori saare,a wa sope,akii fi oro tutu bi ile,akii fi oro aroti bi agbara,akii bere gbese ana lowo oku,ki oro ti
l nba emi l fa nibi baibai ki odi oro ana komase gberi mo. odaju

ASEGBE TODAJU Ao ge ori ako alangba looye ...ao wa imon ope ao ge die nibe ao wa lofi ko owu
alantakun ao wa ti igi ti afi ko owu alantaku si enu ori alangba yii ao wa jo laini atare ninu....tiaba jotan
ao ko etu resinu owu akese ao di lowududu ati funfun Mon eyin agadagodo OFORE: ori alesinu ni
alangba nle, Akunsinu ni oro nkun, Owu alatakun kija ki omode roju so, Oro bayi bàyi to sele kodi asegbe
ao wa ti agadagodo yii pa ao wa kan iso kan Mon ara ogiri ao wa fi ko.

ABO OSOLE GBEWA TODAJU

Ipatako ese esin, oloungbo dudu,abo adie funfun,ori eye igun , ori eye akala,orogbo 11,obi ajopa
11,atare odidi 11,iye gbe 11,iye aluko 11,ikode 11, aojo gbogbo awan kini yipo , aowa po man ose
dudu,aowa ko si inu igba olomori,aogbe igba ye si inu apo aso funfun ,agbodo pa eran agbo kan sile lojo
ti abase ise yi, eje eran yi lao fi po ose yen.(eniti o ni ise o gbodo je nibe) aora kein kein titun ,aoju sinu
apo aso yen, ago mejila oru laomawe ise yio,ti abawe tan aowako keinkein ati lajogba ti afiwe wa si
ile ,aowa tun pada wa si baluwe , aoba iya arugbo kan nin ibe,aobere owo lowo re aman owo tama bere
kogbodo koja 1million,ti koba mun lowo ,iya yi yiolo, aowa pada lojo ko de iyayi ninu ile ningba ti yioba
fito iseju mewa si medogun walai l asimi iya yi ma mun owo nan wa. odaju sugbon taba fese iseyi kari pe
ase imunle awan agba todaju pelu ajegun tori ise awon agba ni. emeji losu ni wiwe re.

Ao wa eye Koowe Dudu eyokan (1) Ao wa Ori ofafa Toba ni irun Lori na eyokan Odidi Iko odidere Toba
pon dada meta,(3) iru wooro (locus beans) ti koni iyo (without salt) abo kan, ede pupa abo kan bakan na
ao wa jo gbogbo re papo pelu Odidi atare meta(3) ao ma fi oti (501) lo iseyiSISERE_NIYI Ao Koko fi Ori
ofafa yi tele ao fi eye Koowe si ni egbe ao da iru bo monle ao da ede le Lori bakan na ao ko atare le Lori
ao wa fi awon ikode na gun Lori bakan na odi jijo papo ao ma fi eje alujannu (501) ti adaruko yi lo laro
kutu kutu ki ato soro si eni keni odaju.

TURARI OSHOLE GBEWA TO DAJU BIIKU

Odidi agbari inaki Igboro kan, lofinda bintu (16) ori oka kan,ori ere kan, ori Monamona kan, iye agbe (16)
iye aluko (16) ikode (16) iye Lekeleke (16) Ewe alupaida tiko luju (16) Ewe abamoda (16) aso funfun opa
kan, Ao te aso na sile ao ma gun awon elo yi lototo ao mako sori aso na bi aba ngun tan,Ao ropo ao tu
lofinda bintu yisi ao po mo ao sa yio gbe ao maa fi sun alale akoni sun ti enikeni rara o ni ojo ti aba fi
turari yi. Aso funfun ao wo sun ni ojo na aso funfun na ni osi gbodo wa ni ori bedi wa, ao wa pakaja aso
ibora funfun yi ti ile bamo ao ni tete jade nile yio de laipe laijina ani lati gba alejo kan ti yio wo ile wa ba
wa yio si bi wa ni ibere wipe iru Kini anfe ao sofun pe kolo gbe owo wa fun wa yio si lo gbe owo na wa
fun wa ako gbodo dupe fun rara yio lo bi abatun lo yio tun gbe owo miran wa bi aba se tan, Ao da sii abo
tabi awo funfun olomori ti aba lo turari inu abo na tan ako gbodo fi abo yi jehun mo rara o.

Add up from Kinsman

1. AFUNJE CUSTOMER/OBINRIN: Aoya igbe sinu fila ni aro kutu kutu laiti fohun rara ati rara aoki ori
aparo kan sinu igbe na ao wa gbe papo fun ojo meje leyin ojo keje aogbe sinu ape ijogun tuntun pelu fila
na..aojo toba jotan... ti onibara bade aofun ni die kofi oti lo.

ERO RE: Niitori (ti aba lofun obinrin) ao fun ni ebu na loo leekeji... yio da Loju re...

IKILO... onibara ogbudo lo leemeji ooooo ojo kan pere ni lilo re ..... ti o ba lo leemeji obaje niyen o

2. AFUNJE IFERAN: Ao wa, eran obo gbigbe kan,, ao wa fi abere gun owo wa ikamugodogbo osi,, ti eje
yio jade nbe,,eje tio ba jade nbe lao yi eran obo yen laara daada,, ao wa saa ti eje yen yio gbemolara.,,ao
wa ewe rekureku gbigbe,ewe amunimuye gbigbe,, ao lo won ni ototo,,tiwon yio kunna,,kia towa dawon
papo, LILO RE... Ao fun eni naa je.

3. AFUNJE IFERAN TODAJU: Eyo igbado meta ti abafesun lale aokosi atelewo osi aose aduasi daada bi
asefeki eninaa nifewa, aowadasi enu aosun tabaji nijokeji aosa igbado na tiyogbe ao wa ge irun ori die,
irun abiya, irun abe, Ekanna owo ati tese ao lopapo ao fun eninaaje.3

You might also like