Agbo Yoruba 1 PDF Nature

You might also like

Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 2

Search

Agbo Yoruba
Download now 1 !

Uploaded by Nass Minallahi Adekunle on Jun 12, 2019

" 93% (41) · 17K views · 37 pages


Document Information #
By awon Eni olohun
Date uploaded
Jun 12, 2019
Download now
Copyright !
© © All Rights Reserved

Available Formats
PDF, TXT or read online from Scribd

Share this document

Facebook Twitter

$
Email

Did you find this document useful?

EGBO
Is this content inappropriate? Report this Document

IGI

IWOSAN
TI ILE

YORUBA

Improve Your Experience '


Rating will help us to suggest even better
related documents to all of our readers!

% Useful

& Not useful

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OOGUN INU RIRUN


Alubosa Onisu funfun, Baaka, Iyere die, ao gun pomo ose dudu, ao
wa su ose yen rondo rondo, ao ma fi mu eko gbigbona diedie tabi kia
ju senu ka mu oti oyinbo die si tabi omi gbigbona. Inu rirun naa yo
lo patapata lase edumare. O daju.

IDAKOLE(AMOKOLE)
Ododo Asunwon Oyinbo, ao sa ko gbe daada, ao lo kahun die pelu e,
ao ma fi ogi gbigbona mu ni sibi kan laraaro.

OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE


Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni
gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro
eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo
n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...
Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna
daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.
Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti
o ba ni arun jerejere(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo
omi lasan.

OORU INU(INTERNAL HEAT)


Ewe Ibepe, Ewe igi Cashew ti o ti gbe, ao se, ao ma mu ni ife kan
leemeji lojumo.
OGUN GIRI.
Eku Asin gbigbe 1,Iseta Ewe Taba tutu, Kataba gbigbe, Taba
juku, Ewe Taba Oyinbo, Alubosa elewe, Ao gun po, ao da sinu oti
oyinbo
ao ma mu. A si le da si meji kafi idakeji po ose dudu ao ma fi we omo
na.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OOGUN IKO TO DAJU


Ao loo wa aidan ti kogbe tan ao ha ibi isu re ao ki sinu ike kan,
alubosa elewe,ao da omiikan(omi ogi) le lori, ao je ko toro di bii
irole ojo ti aki tabi aaro ojo keji. Ao maa mu laaro ati ale. Walahi
talahi, ajebiidan ni. Ao nii saisan o!

ATOSI
odindi epa ikun, odindi bara kan, ako kanhun, baka die, a o fi emu
da lagbo, a o gbe pamo fun ojo meta, a o ma yo mu lehin ojo keta.
Odaju
AKOKORO
Oti oyinbo, egbo agbasa, a o ge egbo agbasa na, a o da sinu oti pelu
egbo ata, didi si ereke fun iseju marun, lehin na a o tu danu. Odaju
o.
EGBOGI GBOGBONISE
isu alubosa meta. Kahun bilala. Iyere. Oga meta. Ise eta kan. Egbo
gbogbonise. Imi ojo. Atare meta. Eruru. Alubosa elewe. Aidan.
Egbo ojola igbo. Eku asin meta. Iyo die. Orogbo. Efirin. Ata pupa
die. Baka. Isirigun die. Eepo oganwo die. Ao gun gbogbo re gege bi
agunmu. Ao maa fi muko gbigbona. Danwo ajebida ni fun gbogbo
arun.

EGBOGI JEDIJEDI (OGUN JEDIJEDI)


egbo idi egbo ayin kafura pelebe. Ao re sinu omi Ao maa mu.
OGUN STROKE
Omin igbin topo Dada ewe taba tutu ao gbo iwon OMI taba ri ninu
ewe yi ni iwon OMI igbin yi gbodo je pelu iwon oyun igan ao da
papo sinu igo tabi ike kan leyin ojo KEJI idi mimun haaaa ise ni sa
odaju bi iku iba eyin agba o

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

OGUN LAPALAPA
Ila Tutu Kan, Osun Die, Kanhun Bilala Die, Agun Pomo Ose Dd ,
Lilore: Leyin Igbati Abafi Apadi Haa Ibe Tan Afi Ose Naa Kan Omi
Fira Ibe
OGUN KOKORO ARA
ewe taba tutu, aidan, enu opiri, eru alamo, ao gun po, ao da die sinu
ipara wa, ao po iyoku mo ose dudu tabi eyikeyi, ao ma fi we.. Odara
lopolopo

FUN KOKORO ARA EYIKEYI


Ifo,eela, tabi lapa
Elo wa imi-ojo, e lo kuna bi elubo. E da kerosene die mo ki o mu
Dada, e lo atare meta mo. Ki e ma fi pa ibe.
Olorunlogbontan
OGU LAPALAPA
imiojo pelu eyin aro amri eyin aro yi Ni odo awon olose dudu amalo
imiojo yi si inu eyin aro ama bo oju lapalapa yi aoma fi ra oju re ti
aba ti we ton

OGUN IKO/COUGH
Oyin Gidi, osan wewe, ati adin eyan. Gbogbo idaji igo kid. Aodapo.
Fun omode sibi kan laro ati lale. Omona yio mabi tabi ya igbe.
AGBO MIMU FUN EHIN-DIDUN(BACK PAIN),ALE(MAN
POWER),ATI JEDIJEDI
Egbo-Egbesi Tutu,Egbo-Sapo Tutu,Muru Awon Hausa,Eso-
Abere(A O Gun Pepe).A O Wa Fi Soft Drink(COCA-COLA)
RE(Soak) Won Po Fun 3Days.A O Ma Mu Ni Araro Ki A To Jeun
Aro.OLOHUN NIKAN NI OLUWOSAN TODAJU.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGUNMU FUN GBOGBONISE ARUN INU ARA.


Enu-Opire,Isu-Baka,Iyere,Odidi-Atare Merin(4),Ose-Dudu Gidi
Ti Yoruba Die,Ako-Kanwun,Oro-Alago.A O Jo Won Po,A O Lo
Won Ebu Won Kuna-Dada.A O Wa Ma Fi OMI-LASAN Tabi OGI-
GBIGBONA(Hot Pap) Lo Ebu Na Ni Araro.OLOHUN NIKAN NI
OLUWOSAN TODAJU.
BACK PAIN
Ewe tagiri pelu kafura pelebe odidi kan, gigun ao fi ori ko ...ao ma fi
wo
AGBO JEDIJEDI TODAJU PA
Egbo egbesi a o ge kekeke ao yin odidi atare kan si a o fi sinap ki
fun ojo marun leyin ojo Karun odi mimu

AGBO FUN ORUN SLEEPING


1. ewe epin, ao gbo pelu omi ao da oti stout si, or ale gun kada stout
si. Ao se ao ma mu ni aro, osan ati ale.

2. Oyin igan Gidi, ao ma mu spoon meji lale leyin oje,

3. Egbo aso feyeje , ao re sinu omi tabi oti schnapps, ao ma mu sipi


merin tabi jubelo lalale

OGUN_DIABETES_TODAJU
Abere lopolopo,Aolo kunna dada, omi osan wewe, aoro omi osan yi
sinu igo abi white plastic, aoda abere yi sinu omi osan yi, aomamu ni
gaa si kan ni aaro, gas kan ni ale.
ADODUN_TIKOGBODO_GBA_NKAN_TI_LOWO_AHUN_O
KUNRIN_OR_OBINRIN.
Ora agilinti,Ewe kooko (cocoyam leaf) Ewe aluki,Aolo ewe koko
yen ati ewe aluki papo, aofi oyin gidi Po papo ma ora agilinti,
aomafi pa oko /obo loba eniti afejeki oti oribo takute
naaa,Hmmmm, ina koma oju eniti oda ooo....

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

RHEUMATISM
Agumun Aromonleegun ti amo
si Romathsim Akuko ti o ba je okunrin Abo adie to je Obinrin awa
yo gbogbo egun ti owa Lara adie na awa gun Mo egbo jebo aosa ti
yio gbe a ma Fi mu eko gbigbona
APORO
eso agbalumo die, enukopiye, kafura, Kanfo, aolo aoda sinu adin
eyan aoma mu

APORO
Ewe taba tutu, aogun aofun omi re sinu oronro malu, agbalagba yio
ma lo ni sibi meji, omode sibi kan
KI OMODE LE TETE RIN
aowa ese aparo mejeji aojo pelu odidi atare kan aofi singbere si
orun ese omo na, ese mejeji nio.
OYUN IJU
Epa iyan, eso bara, ewe akoko, ewe ekaja, iyo die, aofi omi nkan se
po ni agbo aoma mu ni cup kekere ni aro
ALEKO
Ikanrahun igbin, aosun ninu ina toba ti jona, aowa lo sugar pelu
kaunbilala, aoda papo mora won aoma fi mu eko tutu ni
WARAPA
omo aja kekere kan, opolo kan aojo papo, aoda obu otoyo odidi
mejo si Aowa po papo pelu adin, odi jije ? ? ?
LOW SPERM
E lo wa Ireke, Egbo Ogbolo, Sugar onikoro merin ki e ki ni agbo
pelu omi Ti o ba mo. Ki won ma mu ni e meta ni ojumo. Ki wo lo be
yen gba ko osu kan lai sunmo obinrin leyin na ki wo lo se ayewo a ti
wa ok.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO FUN JEDIJEDI ATI ALEKO


Epo Igi-Orira,Epo-Emi,Eso-Ebere,Kannafuru,
Emi-Gbegiri,Egbo-Akogun,Epo-Idin,Epo-Ogbogbo,
Eso-Boni,Epo-Oganwo,Egbo Aidan-Toro,Egbo-Gbonyingbonyin,
Epo-Okuku(A .o Ge Won Si Wewe),A o Wa Fi OMI- LASAN TABI
OTI-SINAPU RE(SOAK)
Won Po Fun 3Days.A o Ma MU Diedie.olorun lelesan,
OOGUN IKO TUBERCULOSIS
1.Atare
2. Ata ijosi
3. Aayu
4. Egbo Igi Guava gbigbe
5. Egbo Igi Cashew gbigbe
6. Alubosa Elewe
7. Ojere epo
8. Iyo
Ao lo 1 to 6 po ni ori olo gege bi a se ma nlo ata lori olo. Ao ge eran
maalu bi oni #500 tabi iye ti owo wa ka si mesan fun okurin, meje
fun obirin, ao gbe ojere epo ka ina lori adiro sugbon a ko ni je Ki o
gba o. Ti o ba ti gbona di e, ao da elo ti a lo lori olo si pelu eran ti a ti
ge. Ao je Ki o so papo fun igba di e Ki a to fi iyo si Ki o le ni adun. Ao
je ki o jina daada. Eni to ba ni arun yi nikan ni o leto lati je obe yi. Ko
si ohunje ti ko le fi je. Arun na yio poora pelu Ase Edumare.
DIABETES CURE INSULIN PLANT
(Costus igneus)
Costaceae plants are known as insulin plants because they can
lower the high blood sugar naturally. These plants grow in Asia and
South America and can also fight free radicals, destroy bacteria,
and act as a diuretic.
How to use
The leave must be chewed.
Pregnant or Nursing Mum stay away .

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

Also Drinking the insulin leaves boiling water will optimally work
to inject the natural insulin essence to reduce the level of blood
sugar.
It is called....
Yoruba = #Tete_Egun
Igbo = #Okpete
Hausa = #Kakizuwa
Efik = #Mbritem
FUN ENITI OBA NI OMO TUNTUN LOWO TABI ITOJU AWON
OMO WA.
1. OGUN TI AFIN WO OKA ORI FUN OMO TUNTUN.
Aowa ongo Ori isu
Ekuro oju ona die
Aojo papo Aoda sinu adin eyan aowa ma kan Omo naa Lori die die.
2. OGUN TI OMODE KOBA TETE RIN
Aowa
Panti tohu Lori kukute igi
Igo funfun tofo
Ose dudu
Aowa gun papo ao ko lose aowa kosi Inu Eku igo yoku yen.
Aoma Fi we Omo naa .
Pelu ogo Olohun Kia ni Omo naa yio ma Rin.
3. OGUN ASE ORI OYAN
Aowa Ewe Ailu
Okan owo eyo 9 fun okunrin 7 fun obinrin
Ose dudu
Aogun papo aowa mafi we OYAN naa die die. Pelu ogo Olohun
Omo naa yio gba omu naa. Beeni owulo fun obinrin ti OYAN re
koba yo Omi omu daadaa.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

4. OGUN BI OMODE BAFE HU EYIN OKE.


Aowa
Omunu ewe okika die
Ao ko soju owo eyo.
Aoma Fi kinri enu Omo naa. Ehin naa yio wole ni kiakia.
NB..
Ewe ekika awon nkan pe ni EWE IYEYE.
DIDE ABIKU MOLE.
Aowa
Eso ejinrin pupo
Kerengbe tofo si oju ona odo
Ewe kehinsorun
Ewe dagunro
Odidi atare nla kan
Aojo papo aofi die sin gbere kan si ese mejeji ATI owo mejeji Omo
naa.
Aowa ran die ni igbadi awo dudu si ni idi. Yio ma fisi idi titi di Odun
meji pere.
Pelu ogo Olohun Omo naa yio kuro ni ABIKU yio di alaaye...
OGUN TI OMO BAKO OYAN
Aowa
Agogo Enu eye Agbe
Egbo igi obi (kola nut)
Aowa lowan papo aomafi pa Ori OYAN.
Kia ni yio gba Oyan naa.
Lati owo oludasile egbe
OKO_TI_KOKIN_LETAN_TOBAFE_SE_HUNNN
Poporo oka baba,
Bara 1,
Epa ikun
Aoge gbogbore si wewe, aokosi inu Igo, aobu HOT Lee Lori, aoma
mu die die,
Hmmmm, oko na yiole ti gbogbo isan arare yio jade tan daradara,
kosi tunni tete da enu kole.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

APAGUN
EGBO GBOGBONISE,,EGBO AKO IBEPE,,ERUN
ALAMO,,ALUBOSA OLOWO,,YANKO,,AO GE GBOGBO
EGBOGI YISI WEWE,AO GI SINU IGO,AO DA YANKO SI
LORI,,MIMU LATIJO KETA LO,,SIBI KAN PERE...

OGUN ITO SUGAR TODAGU


tested and trusted: egbo ipeta ao sa wewe ao ko sinu igo kan ao wa
da omi osan wewe original si ao file fun bi ojo meta Kofi toro Dada
ao ma wa yomu, to mu pe ose kan eni kolose test odamiloju.
NARUN OLOJU SUSU
Afomo okuta, ao lo ti yio da bi tiro, ewe eyin olobe to po, alubosa
elewe to po, ata dudu topo, kahun bilala to po, epo igi pandoro to po,
epo igi isin to po, ao gun papo ao mafi mu eko gbi gbona
OGUN IPAKE TABI KUNNU KUNODE
Igi oro agogo, igi oro adete ati ewe re, topo, alubosa onisu topo,
kanhun bilala topo, obuotoyo topo, iyo obe topo, ao jo oro mejeji
papo, ao lo kanhun, obuotoyo, ati iyo obe, ao lo po daada mo eyi
toku, ao mo bu die die da sinu omi orombo tabi ogogoro, mimu 3x
daily
Ewe rekureku weere topo, odidi atare kan, jijo po, ao popo mo ori,
lila 3x daily
Eso bonni, lilo kunna daada, pipo die mo ori, ao mo fi pa oju ipake
na, ao ebu toku sinu schnapp, mimu ni gas kookan 3x daily
Oro agogo topo, oro adete, ibaka topo, teyo die, isu alubosa topo,
odidi atare mewa, enu opiye, ao jo papo, ao fi soto, kanhun bilala
topo, obuotoyo topo, etu ibon topo, ao lo gbogbo re papo, ao da papo
mo ogun ti ajo yi, ao ro pamo
LILORE :- Ao ma to sibi ogun yi kan sinu cup, ao tu oti schnapp le

Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million


titles without ads or interruptions!

Start Free Trial


Cancel Anytime.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

lori ao ro papo, yio ma mu bee 3x daily, gbogbo re ni yio yo die die ti


yio fi yo tan pata pata
OGUN ARAN KINISA
Alubosa Elewe Ogiri Ijebu Egbo Ijaganyin Aolopo Moalubosa
Elewe Yen Aopomo Ogiri Yen Ao Fi Adin Eyan Din Kojina Dada Ao
Maropo Laro Yio Ma Yo Sibi Kan Mu
OGUN ARAN
Ewe Taba Gidi Eepo Atorin Dudu Aoge Wewe Sinu Kolobo Aobu
Omisi Aogbe Kana Aose Lati Aro Titi Di Ago 12 Osan Tiaba
Wasokale Aoju Kanwun Die Toba Tutu Aoro Sinu Igo Olomori Yio
Ma Mu Ni Igasi Kan Ojo Marun Marun, *hmmm Ise Ni*
OGUN ATOGBE TABI KI A MA TOJU LALE (TO PREVENT
URINATING MORE THAN TWO TIMES OVERNIGHT).*
Ewe yanrin toopo aogun kuna dada .laini omi.aowa
fun omi ibe Dede omi no ni omi osan wewe yio
je gas kokan laro lale
EDA
je Aarun to ma nse Obinrin to ba ti balaga daada ati pe kii se
Okunrin rara o=Sugbon gbogbo iwadii ti awon Onimo ijinle si nse
titi doni fi han gbangba pe ko si Oogun Oyinbo to kajue yato si
Oogun ibile wa”Aarun yii kii jeki Obinrin loyun ati pe ko si irufe
obinrin ti kole kolu`yaala Omidan tabi Adelebo to si ma ndena
Oyun nini lai se familii planii{feto somo bibi o}Oruko ti gbogbo
yoruba mo`Arun yi si ni Èd à
Sugbon laatari Orisirisi Ona to ngba ba awon Obinrin finra ni won
se ba yaa Oruko re sotooto ”Bi Eda _Naaro”___Eda Duubule
abbl....
iwadi koiti fi idi mule pato ohun to nfa Arun yi Sugbon bi Aarun naa
ba se pe si lara Obinrin ni o ma nlagbara si ”Nitorina ni o se ma nso
awon Onisegun ibile di Eeke tabi Opuro.....
Ti Okunrin ati Obinrin ba ni ibalopo"Loju ese nibe ni ukan
omokunrin ti a mosii Aato{sperm}ma daa pada tabi Nigbati

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

Obinrin na ba dide duro'ta npe ni Eda inaaro”Sugbon ti Elomiran


le je pe lehin Ojo keta lo to ma daa pada o=Awon iwadi keekeke
fihan wa pe ki awon Obinrin Sora fun unkan Alaadun jije tabi
mimu Eleridodo bii kokakola{coke}ati bbl;opolopo obinrin lo ma
nsope ti oun ko baiti mu awon unkan Aladidun yi!Oun o mo`bo se
unse oun=paapa nigbati a ba ti wa ni Olomoge ni ki a ti ma kilo fun
awon omo wa Obinrin o=
*Ona Abayo* :-Ti a ba ni awon omo ti o ti balaga daada tabi ti ojo
ori re ti nto omo odun meedogun soke tabi ti o ti nse unkan osu re=
*E lo ja Ewe Ewuro{Bitter Leaf}A o gboo Pelu Krest tabi Schwepps
igo bi meji tabi meta”A o gboo daada ninu Abo tabi ike ti o
mo`daada”mimu ni Gaasi kokan ni Owuro kutukutu ki won to
jeun lo dara ju o*
{O tan lenu”O ku sikun Agba}
OOGUN EDAA TO CONFIRMED
{1}Ojele ewe idagbaa, a o lo kuna dada, a o fi ogede iboyin se Asaroo
, a o faa ewe ti a lo yi si , a o se jina Pelu epo ati ata sugbon a o ni fi
maggi si o, a o ma je die die.
{2}A o lo jaa ewe jeleruberun Nigbati o ba panudee lale laisoro kato
ko delee, a o lo laseje , a o fi eja aro pelu Ring kan sii, a o se jina lepo
niiyo, a o je , a o ma fii ring na sowo wa. Sugbon ihoho la o lo egbogi
yi lai fohun nidi e rara o.
*Tested_confirm*
EGBO ADAJINA
Epo orogbo, ekute ti aba ri ni oju ma ti a ko mo nkan topa, ao sagbe,
ao waa gun po mo epo orogbo naa, ao ma yosi oju egbo naa.
NB:- Egbo naa yio jina laarin ojo mefa.
OGUN KI OROGUN MEJI NIFE ARAWON
Ori Ewure ti won fi se etutu, ao fi ada pin ori na si meji ti ko ni ge
dele, ao ko ewe Odan Abalaiye sarin meji ori na, ao ju odindin atare

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

kan si, ao jo ao ma fun awon iyawo mejeji na la. Won yio nife ara
won, won koni ja rara. Odajau
AGBO IGBE EJE TABI OGBE INU
Ewe Idoro, ao gbo ao fi ori die si, ao gbe le lan yio gbona foro, enina
yio ma mu. Odaju.
Oluwakoremide
OGUN TI AFI NLA ODI LOHUN
Ori Odidere 2, Ori Awoko meji, Odindi atare kan, ao jo po ao gba
Epo pupa lori ina ao da sinure yio mala. Odaju
2. Ewe Ela, Ahon Ofafa, odindi atare kan ao jo papo ao da sinu oyin
igan yio mala. Odaju
3. Ewe Ela odindin atare kan, ao jo po ao ma da sinu Agogo ao bu
omi Isu si, yio mu, ao malu Agogo na si leti. Odaju
Oluwakoremide.
OSE AJEGUN
Ifun Ako Alangba, ao gun ao fi ose po ao ko opolopo oruka irin sinu
kokoradu agbon ao ko ose na le lori, ao ma fi oss na fo owo(hand),
eniti aba fun ni oruka yen ogun yio ma je fun o hun na. Odaju
Oluwakoremide
AGBO AKO JEDIJEDI TODAJU
Bara kan, ao ge kekeke, Akogun, Muru, Epakun, ao ko gbogbo re
sinu ike tabi Igo totobi ao bu omi ti o ba mo dada le lori, leyin ojo
keta ao ma mu ni ekan lararo.
Oluwakoremide
AGUNMU INU GBIGBONA
Iresile ewe asunwon, Iyere, Eru Awoka, Imi Orun, ao gun yio kuna
dada ao ma fi mu eko gbigbona lale laro. Odaju
Oluwakoremide

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO FUN ENITI OBA SANRAJU TABI KO MA LA O GUN


NIGBA GBOGBO
Egbon Ifon tutu, ao ge wewe sinu ikoko nla, ao bu omi si, tio ba di
ojo keta ao mamu, ao ma we. Odaju
Oluwakoremidex
OGUN HYPERTENSIN (EJE RIRU)
(aowa Ododo Ori Ako Igi Ibepe Aodasinun Omin Tiwan Bafise Iru
Aofi Sibe Fun 4days After 4days Aomamun Nin Aro Ati Ale Nigbati
Aobafimun Fun Ojo Meje Pelu Ase Olorun Yioti Kuro Nibe
OOGUN OGBE INU (ULCER)
Ao wa efo gbure ..ao gbo daada ti yio MUN bi igbati won ja
ewedu..ao gbe sori ina..ao ni fi omi sio..
Ao da gari si ti obati gbona daada..ao fi teba...ao wafi eba naa je obe
toba wuwa...walahi walahi walahi DANWO...kosi bi ulcer naa se pe
Lara to..
OGUN NANRUN INUN ARA
(aowa Ewe Apasa Tiwanhunpe Nin Ewe Imin Esu Aoja Ewe Nan
Aodasinun Omin Aose Bi Enin Se Efo Aowa Lo Ata Si Aofiro Efo
Nan Pelu Iru Aofi Efo Nan Je Eko Aowa Ja Eso Ori Imin Esu Nan
Aowa Sa Ti Yiogbe Aowa Gun Papo Aowa Dasinun Epo Ogere
Aomafi Ra Oju Kokoro Tioba Sujade Lara Wa Pelu Agbara
Olorun Gbogbo Nanru Tiobawa Ninun Eje Gbogbo Re Nin Yioku
ALASE FUN OBINRIN
Eepo Osan Wewe,orogbo Gbigbe Merin,odidi Atare Kan,alo
Kanhun,egbo Inabiri,ao Jo Papo Dada, Obinrin Naa Yio Ma Fi Eko
Gbigbona Lo.
ABIWERE
Ewe Odundun,ao Lo Yio Kunna Dada,ao Fi Ori Po Papo
Dada,obinrin Naa,yio Ma Fi Wo Ikun Re Wa Si Isale Odaju.
Stroke(roparose)

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

Alubosa Ayu,ao Ge Sinu Igo,ao Wa Fi Omi Igbin Si,ao Ma Mu Ni


Sibi Meji Fun Agbalagba,sibi Kan Fun Omode Lojojumo,olohun
Koni Fi Stroke Ba Wa Ja Oo.
FUN INU RIRUN
Akogun,ao Re Sinu Igo Kan,ao Fi Omi Tutu Ki Lagbo,ao Ma Mu Ni
Sibi Kookan Lojojumo
JEDIJEDI
Ewe Efinrin,ewe Owu Akese,ewe Ewuro,ao Wa Omi Tutu Gbo Pelu
Iyo Die,mimu Larolale.
IDI YIYO
Ao Fa Paki Ege(cassava) Olomo Kan Tu,ako Ni Je Ki O Kan
Mole,ao Wa Jo Paki Naa Pelu Iyepe Arare Ati Odidi Atare Kan,ao
Ma Fi Foko Tutu Mu.
OGUN IKO
Egbo Ipete,egbo Ifon,ao Ge Kekeke Sinu Ike Ragolisi,ao Bu Iyo Die
Si,ao Wa Tu Omi Ororo Maalusi,ao Wa Gbe Pamo Fun Ojo
Meta,ao Ma Mu Ni Sibi Kankan.
OGUN IKO IFE/AWUGBE (ASHTMA OR TB)
Ewu Ogan, Obu Otoyo Adin Dudu.
Ao Da Ewu Ogan Yi Sinu Ikoko Oru Ti A O Sun Ti Yoo Di Eru, Ti O
Ba Ti Fe Dudu Tan Ao Fi Obu Oto Yo Si Ni Iwon Ba, Ao Je Ki Ewu
Ogan Ti Ati Jo Yen Ki O Tutu, A O Wa Bu Adin Si, Eni Na Yoo Ma
Mu Ni Sibi Kankan Ni Araaro.
QUICK EJACULATION.
Orogbo, obi gbanja,etu ibon,ako okuta,esuru funfun,ege tia fi ngun
iyan,ogede agbagba dudu,agbado ,iyere,ao fi sugar die si, ao gun
po,ao ma fi fo eko tutu mu.

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

AGBO INU IGO FUN ALE OKUNRIN* (MAN POWER)


Itaku gbonyingbonyin,Itaku eruju,ao ge mejeji sinu igo kan, ao wa
ro 7up si tabi oti oyinbo, gaasi kokan ni ojojumu.
2.Itaku gbonyingbonyin, Itaku Igongon,Itaku Aka,Itaku
idiapata,Itaku osun,Itaku ogbolo,Egbo Asunrun oyinbo,Egbo
Asunrun yoruba, Ako okuta were funfun mesan,Eso Abere
mewa,Iyere die,Konnofuru die. Ao ko okuta wewe pelu awon nkan
toku yen papo sinu igo, ao da oti oyinbo si, ao ma mu diedie. Odaju.
Omode lo nse mi ooo.
OGUN IGBEBI FUN OBINRIN TO DE ORI IKUNLE.
Ojo ti agbami ojo ba ro, ao lo si ona oko tabi odo, ao mu igo ofifo tabi
ado ato lowo, ao ri awon ekolo dudu kan, awon miran npe ni kola
tabi olooji, o ni pon to ika, o we lorun bi okoto, ao fi owo lale siwaju
ekolo na, ao fi igo tabi ato yen niwaju re, ao je ko bo sile fun rare, ao
ko opolopo atare le lori, to ba di ehin ojo keje ti obinrin na ba de ori
ikunle ao fun ni mesan tabi mewa ninu atare na, wipe kio je pelu
omi gbona idaji tombila.
OGUN ALASE TI OBINRIN KO BARI NKAN OSU RE.
Iye aluko, ikoide, poporo ehin oka baba,iyo die, osun buke,ewe
owu,epo amuje,egbo oruwo ati egbo lali,ao gun po,obinrin na yo ma
fi mu eko gbona.
OGUN ILE TUTU
Esan,epo ose,eru,aidan,egbo elu,egbo about,alubosa elewe,ao se ni
agbo daadaa,ao fun omo naa mu.ao si ma fi we lati orun de le.
AGUNMU IBA TODAJU
Epo pandoro awon miran npe ni iyan tabi amuyan,ata dudu,egbo
oruwo,alubosa elewe,kanhun,eru,ewe ewuro ati iyo.ao gun po
daadaa,ao ma fi mu eko gbona...Odaju.....
OGUN ITO SUGAR DIABETICE
ao wa ako kahun bulala ,epo oronbo ,ewe koropo,obu otoyo ,ose
dudu ajo gbogbo kini yi papo pelu ose dudu ao lo ao mon fi orombo

EGBO IGI IWOSAN TI ILE YORUBA

lo laro ati lale......dan wo kio fun mi laboo abara mun pelu ase
olorun oo

OGUN ATOSI
ao sun bara ni ina tio fi ro dada ao wa be epo re danu ao wa ge bara
yi wewe ao fun omire sibi kan ao wa da sugar si omire ao tun da
orombo dede omi bara yi sii ao mon mun ni sibi kan larin ijomete
meta ..........odaju gan nioo abara mun pelu ase olodu mare

AGBO ARAN
eyikeyi tabi alepe agbo gbogbo aran, Egbo sapo Egbo ifon Egbo
tude ao fi omi re ao mamu diedie laro ati lale
2.Egbo arunpale ao fi omi osanwewe re ao mamu ni gasi kokan
*Ogbe nu (hulcer)* ogede agbagba dudu ao ge bi Eni pe afefi din
dodo ao wa sa si Abe ile tabi inu yara tobagbe dada aolo kunna dada
ao mafi wara tabi milk lo siwaju ki ato jeun aro
OGUN HYPERTENSION,
eso pandoro ao sa ti yio gbe dada ao wa lo kunna dada ao mafi mu
eko gbigbona sun lalale

OGUN EJE RURU/H.B.P


Ao Ja Eso Isin Toba Pon Daadaa,ao Jo Pelu Odindi Atare Kan,ao
Maa Fi Coca Cola Loo Daaadaa.
OGUN ITO SUGAR
E o wa efo gbagba ti yo pon die,omidun lafise pelu kanu bilala die
tobati jina dada ,ero si inu kegi kan efi suger oni koro mefa si
,tobadi ojo keji eni ye yo bere sinu mu odaju gan motise fun opo
eniyan ri,,,aisan koni fi ago ara wa se bugbe o ,,
OOGUN IKO TUBERCULOSIS
1.Atare
2. Ata ijosi
3. Aayu

Improve Your Experience '


Rating will help us to suggest even better
related documents to all of our readers!

% Useful

& Not useful


Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million


titles without ads or interruptions!

Start Free Trial


Cancel Anytime.

Share this document


( ) * $ +

You might also like

The Ifa for Protection


Martin Gonzalez More

Ewe
Oluwo

AKOSE AWORO ARIMON1


Richard Pedraja

Magazines Podcasts

Sheet Music

Akose Ifa to Kill Iyami Aje


Richard Pedraja

AFOLABI
ramr1962

AKOSE IFA TO ATTRACT


FINANCIAL SUCCESS.doc
Richard Pedraja

Nature

OFO ESE
Richard Pedraja

25
ika ose

Ifa Oogun Preparations


andre

Incantation
Iregbemi

Documento 16.pdf
Osvaldo Araujo da Silva

love-collection.docx
Anonymous BZMrf3Jkv

Show more

About Support

About Scribd Help / FAQ

Press Accessibility

Our blog Purchase help

Join our team! AdChoices

Contact us Publishers

Invite friends
Social
Gi`s

Scribd for enterprise Instagram

Twitter
Legal
Facebook

Terms Pinterest

Privacy

Copyright

Cookie Preferences

Get our free apps

Books • Audiobooks • Magazines • Podcasts •

Sheet Music • Documents • Snapshots • Directory

Language: English

Copyright © 2022 Scribd Inc.

What is Scribd? ,

Millions of titles at your fingertips


Home Only $8.99/month.
Books Cancel anytime.
Audiobooks Documents

You might also like