Professional Documents
Culture Documents
Promise and Fail: 1. Okoti Ituwo Atude
Promise and Fail: 1. Okoti Ituwo Atude
AO GUN ESO YEN LORI OLO TIYIO KUNA DAA DA , AO TUN GUN EPO IGI OBO YEN NA
TIYIO DI POWDER DAA DA, AO WA GUN EWE EWURO YEN PAPO PELU ATA IJOSI MO OSE
AGANYIN FUNFUN, TIE BA GUN TAN, AO WA MIX POWDER ESO IWERENJEJE ATI TI EBO
IGI OBO YEN PAPO MO OSE TIE GUN YEN, AO WA FI OYIN IGAN GIDI PO OSE YI. AO WA FI
OWO OYEKOYE BI 200 NEW NOTE OR 1K TELE INU IKE FF, AO KO OSE YEN SI.. AO WA MU
OORI BI ONI 100 SORI OSE YI, EO WA LOGBE OSE YI SINU ORUN ( SUN ) KI OORI TIE MU
SORI OSE YI BALE YO, LEHIN TI OORI YEN BATI YO DAA DA, AO GBE ETO YI AO WA
SHADUA SI BAI PE, NI KETE TIE BASE ADUA SI TAN AO LO GBE ETO YI PAMO FUN OJO
META
ADUA_RE_NIYI - OLORUN AYERAYE OOO 3X OBA TIO NI ASIRI IMO GBAANGBA ATI IMO
IKOKO LODO, OBA TIO NJE EMI NI, EMI NI, EMI NI NINU OHUN GBOGBO TIO DA - WA JERI
AGBARA EMI NI RE LORI ETO YI NI KETE TI EMI WOLY TUNMISE ( EO DARUKO ARA YIN )
BATI NLO ETO YI KI GBOGBO AWON ENIYAN TIWON SE ADEHUN LATI SE OORE ATI
IRANLOWO FUN MIH RONU LATI BERE SINNI MU ADEHUN WON SE NI KIA KIA, IWA MI
DARA TABI IWA MI KO DARA KIWON PINNU LATI RANMI LOWO TORI PE GBOGBO
ENIYAN LOMO DAJU PE IWA OMO ATA KO DARA SUGBON OJUMO KONI MO KI ARAYE
MAJE ATA, OJU MEJI NI ESO IWERENJEJE NI O NFI IKAN WO AIYE, O NFI IKEJI WO ORUN ,
LATI ONI LO OJU RERE NI KI GBOGBO ENIYAN BERE SINNI FI MAWO MIH, ( EO TUN
SHADUA SI BIE BATI NFE )
LILO_RE - EO MA JIWE LARARO PELU SISE ADUA FUN ARA YIN WIPE KI OLORUN DARI
OKAN GBOGBO AWON TIO SE ADEHUN FUN YIN LATI WAMU ADEHUN NA SE NI KIA KIA,
PELU ASE OLORUN KOSI ENIKENI TIYIO LO ETO YI TIRU ENI BE KONI RI OORE ATI
IRANLOWO OLORUN ( FUN EYIN TI EO BANI EKUN RERE IMO IJINLE NIPA SISE IRU AWON
ETO BAYI BIE BALE SAN OWO E , AO FI ETO YI RANSE SIYIN NIBIKIBI TIE BAWA KODA
KOJE UK YIO KANYIN LARA , TORI NIGBA MI OHUN TI ENIYAN KOBA MO NIPA E DAA DA
BI ENYAN BASE O SESE KIO MA GET NUKAN NA DAA DA )
_ASETA.
Biwon nbinu siwa lotun losi,bi ota bawa niwaju ati leyin Ema beru
Elobami wa........... padi atare meta, ejekia tu sinu ragolis kan, eso werenjeje lopo ejekia
da lelori,ao wa ju arigisesigi Kan tikoiti ku sinu re,ejekia da h*t lelori. Leyin ojometa odi
mimu ni shot kokan pelu gbolohun wipe
..funra arigisesigi lo segi lera re lori, ..funra otami ni kio fi owo ara re se rare
Yio bara mu oo.
10. TURARI_AGBARA_NLA_TI_AFI_NLE_EMI_BURUKU_JADE_NINU_ILE
TODAJU*
Enikeni yowu ti awon emi buruku ba(evil spirit) banda lamu ninu ile tiwon kosije ki
awon iyawo ati awon omo onisinmi re o ni isinmi, ti won sin se eru ba won ninu ile naa
Nipa yiyo siwon loju ala tabi loju aye gan an paapa akoko ti okunkun ba nbe tabi ki awon
ara ile na magbo orisirisi ohun, tabi ipa ese tiwon kositi eni nrinlo tabi eni nsoro.
awon tobawa niru inu igbekun be bayi.........
ojulowo ako alangba adaripon ti orire pon dara Dara (16)
abo re (16)
opolopo eso owenrenjeje,
iko odidere (16)
ewe ajeofole (1200)
Epo erun
epo igi asorin
opolopo ewe karufimila (omisinmisin gogoro)
Turari Al miski gberefu
turari tufauljinu
Ikun ojia
Turari lubanzakara
ao gun gbogbo re papo ao kosinu apo asunwon eyiti ati aso pupa ati dudu ranaosimafin ni
deede agogo mejila ale...
Ewo nifun eyikeyi ninu awon emi airi buruku latifi oju ri efin turari yi, tabi lati gbo orun
turari naa, odi dandan ki iru enibe ti aye nasile ni tipatipa bibeko yio padanu agbara re yio
sidi okan yepere larin awon emi airi buruku egbere n won yosile kuro lawujo won
nitoripe atigba ase ati oun imuse agbara kuro lowo re odaju pupo dandan ni osiribe lase
olohun alaaye.
20.