Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 2

Iba agba o

Uses of Oju olongbo (cat eyes)

Die Lara iwulo ESO oju olongbo,

1: Ifunra (body__Teller)

Ao mun ESO oju olongbo kan, ESO olonsepetu kan na, (opa_esu), omo Atare kan, Ao lo papo Ao fi
singbere kan soso sii Aya....

2.. Eyonu {Favor}

ESO oju olongbo mesan 9

Omo Atare mesan 9, Ao lo papo Ao fii singbere EJIOGBE SII APA OSI NIKAN, ODAJU

3, Afoibon (to break gun)

ESO oju olongbo 16,

Omo Atare 16, Ao lo papo, Ao fi singbere yipo APA mejeji ,, ODAJU PA

4, Ayeta ibon TODAJU

ESO oju olongbo mesan

ESO omo irula mesan

Oju eyele mejeji,

Karahun igbin die, Ao lo papo Mon Ara won,,

Ao fii singbere Ejiogbe Mesan sii Aya ati Eyin wa ..

5, OGUN IBON AGBEKORUN


ESO oju olongbo mesan

Omo Atare mesan

Arigisegi to wa ninu ile,

Ao ko awon ESO yi sinu Iwo arigisegi na, Ao di ni ikobere ...

Ao GBE korun,

Ao ma WO singlet tele aso wa, ao sese wa GBE korun,

6, gbere ajeegun omo yahoo,

Ao bo eepo inu ESO oju olongbo meta kuro ao wa lo yellow inu re Mon omo Atare meta, pelu eepo obo
die, ao.lo kuna

Ao fi singbere sii orikerike ara ... ATUDE NII..

Dupe kio bale je fun e

08065545310 & 08089905098

Ado ijogbon ☠️☠☠


️ ️☠☠
️ ️

You might also like