Professional Documents
Culture Documents
Awure Olokiki
Awure Olokiki
Odindi atare 1, kahun bilala, ewe taba, obi abata oloju merin,obi gbanja, ao gun gbogbo re po mo ose,
ao ko sinu igbaolomori, ao ma fi we.
OFORE
Iromi agbowa, iro atare ni wongbo wo wa lo si ilu aimoye, aimoye olowo, oloro, olola ni kiwon ma wa
emi lagbara omo Lagbaja wa towo towo owo won. (Adua)