Professional Documents
Culture Documents
271 Yoruba Senior
271 Yoruba Senior
ALAY
Ilana lrun ati Iha ti Eniyan K Si I
Igbeyawo j asop ti o w titi di j ik. Bibeli k wa pe ik k tabi ti aya nikan ni o le fi opin si majmu
igbeyawo. O s pato pe: “Nitorina ohun ti lrun ba so kan, ki enia ki o me y wn” (Marku 10:9; Malaki
2:14). (Ka 1 Krinti 7:39 plu). Ilana lrun ni eyi lati ipil nigba ti lrun fun kunrin iaaju ni oluranlw
ti o dabi r, a si le ri i ninu awn k Kristi pe ilana lrun ni eyi fun awa ti ode-oni. Lai si aniani, ilana lrun
ti k ni yipada lae ni eyi.
O ti di iwa m eniyan lati maa fi oju tinrin ofin ati ilana lrun lna kan tabi lna miiran. Iwa abuku yii mu
ki iwa buburu gba aye kan ni akoko kan to b ti lrun fi pa plp eniyan run kuro lori il. Lyin ti omi ti gb
kuro lori il, lrun ba awn ti o d si d majmu pe Oun ki yoo fi omi pa aye r m. O si eleri ibukun ati anfaani
pup fun awn ni ti o ba pa majmu R m ti wn si r m ileri R. ugbn k p ti eniyan tun br si e afojudi
si Majmu ti lrun ba wn d, awn eniyan si brsi fa syin kuro ninu iwa rere, iwa jagidijagan si br si gbil
lati igba naa wa.
lrun ti mu ipinnu ti R -- ipa ti R ninu Majmu naa, -- bi o til j pe awn eniyan ti da Majmu yii niye
igba ati awn majmu miiran ti O ba oniruuru eniyan inu aye d. lrun fi aanu ati ododo ba Oril-ede Ayanf ni
lo, ugbn nigbakuugba ni wn n t, nikyin wn e ohun ti o buru jai ju l nigba ti wn k ireti igbala wn ti
wn si fi m lrun k sori igi.
Awn Keferi plu ti ni anfaani ti wn, lati gba ba If tabi lati k ; ugbn lna pup ni awn paapaa ti k
ba If yii, ni ti O sanwo irapada wn. Jesu s astl fun awn m-yin R pe yoo gbil kan, paapaa ju l
nigba ti bib R lkeji sinu aye ba k si dd. O s bayii pe, “Bi o si ti ri li j Noa, bni yio ri li j m-enia.
Nwn nj, nwn nmu, nwn nbeyawo, nwn si nf iyawo fun ni, titi o fi di j ti Noa w inu k l, kikun omi si
de, o si run gbogbo wn. Gg bi o si ti ri li j Lti; nwn nj, nwn nmu, nwn nr, nwn nt, nwn nbn, nwn
Page 1 of 3
nkle; ugbn li j na ti Lti jade kuro ni Sodomu, ojo ina ati sulfuru r lati run w, o si run gbogbo wn. Gg
bni yio ri li j na ti m-enia yio farahn” (Luku 17:26-30).
A le ri imu awn r astl wnyi lj oni. Iwa ibaj awn eniyan inu aye ti n p si i, paapaa ju l lati dun
melo kan syin, a si woye pe ni toot, eyi j apr pe ipadab m lrun k si dd.
Igba le yipada, m-eniyan plu le yipada gg bi j ti n yi lu j. m-eniyan le e aibikita ki wn si
na lrun t -- na ti o t ti o si dara ju – ki wn si yan na ti yoo t ifkuf kn wn lrun. ugbn r lrun,
Ilana lrun, ati Ofin R yoo w bakan naa titi lae. lrun s ni ateteke pe kunrin yoo fi baba ati iya r sil,
yoo si fa m aya r (k i e awn aya r), awn mejeeji yoo si di ara kan. r lrun yii k yipada sib. O w
bakan naa loni.
Ainaani Ilana lrun ati Idaj lrun
Johannu Baptisti tako panaga nigba ti ijoye kan gba iyawo lomiiran lati fi e aya (Matteu 14:3, 4).
panaga j eyi ti a k ni lati yra fun, a si fi if lrun han gbanba ninu awn apr ti lrun l lati fi aioot
Israli w kunrin alaioot ti o l f obinrin ajeji tabi ti o ubu sinu panaga (Malaki 2:11-15). Nigba ti Dafidi
ubu sinu yii, o fi aye sil fun oruk lrun lati di isr odi si laaarin awn keferi, o si fa idaj lrun sori ara
r nitori yii (2 Samuli 12:13, 14).
Jesu b obinrin ara Samaria sr titi o fi jw fun Jesu pe alabagbe krn-n ti oun ni ki i e k oun (Johannu
4:16-18). mi Mim plu, lati nu Paulu Apsteli k wa pe awn ti o ba d buburu ti i e panaga ki yoo ni
ipa ninu Ijba run afi bi wn ba ronupiwada ti wn si k na wn sil (1 Krinti 6:9; Galatia 5:19-21; 2
Peteru 2:14-17).
Ibi pup ninu r lrun ni o tako iwa abuku ti awn eniyan n hu si igbekal ti lrun e fun gbogbo araye.
plp ni o n l awn k Bibeli lrun, awn miiran si n a a t ki wn ba le bo wn ml. ugbn r
lrun duro, idaj lrun yoo si w sori gbogbo ni ti o ba d yii bi o til j pe ofin ilu tabi aa ibil fi y sil
fun panaga.
Igbeyawo Toot
r lrun yanju lori igbeyawo. lrun s fun wa pe ki i e if Oun pe ki awn eniyan Oun ki o fi aidgba
dap m awn alaigbagb (2 Krinti 6:14). (Ka 1 Krinti 7:10-16 plu). lrun s wi pe igbeyawo ni la (Heberu
13:4) ugbn O ti e ikil gidigidi nipa ojue aya si k r ati ojue k si aya r (Efesu 5:22-33; Romu 7:1-3; 1
Krinti 7:2-6, 10-16, 27-33).
Gg bi a ti s tl, lrun k gba iksil tk-taya ly ninu ilana R, nitori awn idi pataki di si ni lrun
e fi aye sil fun ipinya. Ik nikan ni o le t awn meji ti lrun ba so p kan k. Ifarabal lati e akiyesi ilana
lrun yii ni finnifinni ati ni kunrr yoo bojuto gbogbo ioro, yoo si yanju gbogbo adiitu. lrun bu la fun
gbogbo igbeyawo. K di igba ti alufa lrun so wn p, tabi ti a e ni ile lrun, niwn igba ti igbeyawo naa ba
ti ba r lrun mu ti k si lodi si ofin ilu tabi ofin ibil ibi ti a gbe e igbeyawo naa.
A le ri bayii pe igbeyawo ti lrun k fi w si ni awn wnni ti a e laaarin awn eniyan meji lyin ti ni kan
ninu wn tabi awn mejeeji ti e igbeyawo plu lomiiran tl ri, ti ni keji wn iaaju si w laaye sib. Nitori
naa, niwn igba ti k tabi aya ti o tna fun ni ti o ba f e igbeyawo ba w laaye, j igbeyawo iaaju wa sibsib,
igbeyawo keji k tna, o si lodi si a lrun. Iru igbeyawo b ni a n pe ni panaga. Ide igbeyawo iaaju w sib,
ik nikan ni o le tu u; igbeyawo miiran lyin eyi si j aifi igbeyawo iaaju p.
Ioro pup ni o dojuk oji lrun ti a fi i ati maa gba awn ni ti eu, ta wa mi ti fi ti o wp yii d
ni igbekun, niyanju. Eniyan lrun toot yoo gbadura pup yoo si y ran igbeyawo naa wo finnifinni lati wo bi
o ba eto lrun mu. A lrun ati ilana ti O fi lel lati ateteke nipa igbeyawo saba maa n t lati s boya
igbeyawo kan tna tabi k tna. Ifihan if lrun yii ni atna ati odiwn ti awa, gg bi ni kkan, ni lati lo lati
fi diwn iriri wa ati na wa, ki igbesi-aye wa ba le j itwgba niwaju lrun, ki iwa wa si le j alailgan niwaju
gbogbo eniyan. Nitori naa, “Si ofin ati si ri: bi nwn k ba s gg bi r yi, nitoriti k si iml ninu wn ni”
(Isaiah 8:20).
Page 2 of 3
AWN IBEERE
1. S ilana ti lrun e ni ateteke nipa igbeyawo ati bawo ni awn ohun ti o beere ti lagbara t?
2. Daruk di ninu awn ajagun fun lrun ninu Bibeli ti wn tako panaga; ki o si s ni ede ti r, ohun ti
olukuluku wn s nipa r.
3. Nigba wo, ati ni igba kan oo wo ni ide igbeyawo n t?
4. Nj o di igba ti a ba e igbeyawo ni ile lrun tabi niwaju alufaa nikan ki lrun to fi w si i pe iru igbeyawo
b tna? S idi ti o fi dahun b.
5. Ojue wo ni lrun n beere lw aya si k r?
6. Ojue wo ni lrun n beere lw k si aya r?
7. Ir igbeyawo wo ni k tna niwaju lrun?
8. Bi a ba f e igbeyawo ki ni lrun s ti a gbd e akiyesi? S s r lrun ti o fi idi idahun si ibeere yii
mul ninu Krinti keji.
9. Nj lrun fi y sil ni ateteke fun iksil?
10. Ki ni idahun ti obinrin ara Samaria fun Jesu nigba ti O s fun un lati l pe k r w? Ki ni e ti Jesu fi s pe
o fesi rere?
Page 3 of 3