Professional Documents
Culture Documents
Hymn 168
Hymn 168
Hymn 168
1. Ohun t’Oluwa yio se 1. fOluwa awa de 1. Olorun eleda t’o da’jo seraf’
Oba mi ko fi y’ enikan ) 4ce lati yin O logo, Ati Kerubu s’orile ede aye,
fun ayo nla ta n yo loni , Lat’owo Jesu Olugbala owon,
Egbe: Awon enia pataki lo ti ku larin Ijo Seraf’ Awa n yin oruko Re loho.
Opo enia pataki lo ti lo o
Egbe: A! e ku ayo, e ku ayo)
Eda to ba wa laye
Ko wa fi iyin f’Onise egbe: Oluugbala, a de, Ijo Serafu )
Nla ) 2ce lati f’iyin fun O, A! e ku ayo, e ku ayo )
ogo , iyin, f’Oruko Re, Ijo Kerubu ) 2ce
2. Owo l’Oluwa fun o Alagbara julo.
Ara mi jowo fi han )4ce 2. Nibo l’awon ayanfe Olorun wa?
2. fKabiyesi! Oba, E wa gbo ohun Oluso agutan yi,
Egbe: Awon enia pataki lo ti ku
ogo f’Oruko Re! E ronupiwada, e wa w’oko
3. Ore t’Oluwa ba se fun iyanu Re larin wa, Igbala na ku si atelewo.
Ore mi jowo fi han o ) 4ce eyi t’a ko gbo ri. Egbe: A! e ku ayo, e ku ayo)
egbe: Oluugbala, a de…
Egbe: Awon enia pataki lo ti ku 3. Ijo kerubu dupe lowo Olorun
3. fOrin Halleluyah! Tesiwaju ninu ogun emi jija,
4. Omo l’Olorun fun o
L’awa yoo ma ko, E fere gbo’hun Oluwa Jesu,
Ore mi jowo fi han o ) 4ce
Awa y’o f’iye fo b’idi, Wi pe, o seun, omo rere.
Egbe: Awon enia pataki lo ti ku Leyin irin ajo wa. Egbe: A! e ku ayo, e ku ayo)
egbe: Oluugbala, a de,
5. Ile l’Olorun fun o 4. Eyin ti n koja lo ya sodo Jesu,
Ore mi jowo fi han o ) 4ce 4. fAye sun m’Olorun, Lati gb’ore-ofe ninu Ijo yi,
akoko sunmo le, Mase kegan oko igbala ‘kehin,
Egbe: Awon enia pataki lo ti ku
iiekun anu fere ti, T’Olorun Metalokan fun wa.
6. Ohun t’Oluwa fun o ) e wa wo oko na . Egbe: A! e ku ayo, e ku ayo)
Jowo fi yin Messiah o ) 4ce egbe: Oluugbala, a de,
5. Jesu Oluwa mbo wa joba aye,
Egbe: Awon enia pataki lo ti ku 5. fJesu, Olori wa, Larin ijo kerubu ati serafu,
a gb’oju wa si O, Egberun odun ni ‘jOba Re,
‘wo l’a o ma yin titi aye, Ijo Mimo at’oke wa yi.
Aye ainipekun. Egbe: A! e ku ayo, e ku ayo)
egbe: Oluugbala, a de,
6. Jesu Kristi Oluwa Oba Ogo,
6. pA f’ogo fun Baba, L’opa iye ainipekun wa lowo
A f’Ogo fun Omo Re, Re,
Ogo ni fun Emi Mimo, Yoo ko gbogbo awon t’o gbagbo
Metalokan lailai. lo,
egbe: Oluugbala, a de, Siwaju ite Baba l’oke.
Egbe: A! e ku ayo, e ku ayo)
Amin
Amin
HYMN 1