Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 1

Nooti Ikeeko fún Kíláàsì Olodun Kini Sekondiri Kékeré fún Ose Keji

Kíláàsì: Olodun Kini Sekondiri Kékeré


Ìṣe: Yoruba
Orí Ọ̀rọ̀: Ìtàn Isedale Yorùbá
Kókó Ọ̀rọ̀: Orírun Yorùbá
Déètì: 11th - 15th September, 2023.
Ìwé Itokasi:

Ìjíròrò:
Itan Isedale Yoruba
1. Itan so pe ilu meka ni Yoruba ti wa
2. Itan fi ye wa pe Lamurudu ni baba nla Yoruba
3. Lamurudu je Ogbontegi abogipa
4. Itan so pe awon elesin musulumi gbe ogun ti Lamurudu lati fi esin iborisa sile
5. Itan fi ye wa pe inu ogun yii ni Lamurudu ku si
6. Ba kan naa, itan so pe Lamurudu ni baba Oduduwa
7. Leyin iku Lamurudu, Oduduwa ati awon eniyan re sa wa si ilu ile ife
8. Ilu ile-ife ni o je orisun fun gbogbo ile Yoruba
9. Oruko omo Oduduwa ni Okanbi
10. Okanbi ti o je omo Oduduwa bi omo meje. Awon ni:
S/N ORUKO ILU TI WON TE DO SI OGUN TI WON PIN
A Olowu Owu Aso
B Alaketu Ketu Ade
D Oba Ibini Bini Owo eyo
E Orangun Ila Iyewo
E Oni Sabe Sabe Eran Osu
F Onipopo Popo ILeke
G Oranmiyan Oyo Ile

Igbelewon:
- Ni sisentele so itan isedale Yoruba
- Daruko awon omo Okanbi pelu ogun ti won pin leyin iku baba won
Ise asetilewa: ya maapu omo eya ile yoruba

You might also like