Professional Documents
Culture Documents
Yoruba Midterm 1ST Term
Yoruba Midterm 1ST Term
Apa keji
INSTRUCTION: Dahun ibere meta pere
1 daruko marun nini omo oduduwa
2 ko bi a se n ki awon eniyan wonyii
Agbe , akope , apeja , babalawo , ode
3 daruko eya Yoruba marun
4 ko bi won n se n ko oro yii ni akoto ode oni
Ebute metta
Offa
Oshogbo
Ogbomosho
Otta
EAGLES’ LANDING SCHOLARS SCHOOL
7, Oduwole Street, Abule-Odu Bus Stop, Egbeda-Idimu Road, Lagos.
Tel: 08108920734, 081711483333, 08183929361
FIRST MID-TERM TEST 2023/2024 ACADEMIC SESSION
SUBJECT: YORUBA CLASS: JSS 2
SECTION A
INSTRUCTION: ANSWER ALL QUESTIONS
1. Asa igeyawo pin si______(a) meta (b) merin (d) meji
2. _______ ni ohun akoko ti okunrin maa n se ti won ba ti balaga (a)ifojusode (b) alarina (d)
omo osu
3. _______ nio maa n wa laarin oko ati iyawo ni akokoti won bansese n fe ara won (a) omo
ile (b) agab ile (b) alarina
4. _______nigbati won lomaa n toro omo lowo awon obi re (a) osan (b)owuro kutukutu (d)
irole
5. Gbolohun _______ni a fi maaakan gbolohun miran po mo ara won (a) gbolohun ase (b)
gbolohun ibere (d) gbolohun alakanpo
6. Gbolohun _____ ni a fi maa bere oro (a) gbolohun ibere (b) gbolohun ase (d) gbolohun
iba
7. _______ lo maa n difa iyawo (a) iya iyawo (b) baba iyawo (d) oko iyawo
8. Awon ______lo maa n tele iyawo lo ile oko (a) omo ile (b) ore iyawo (d) iya ile
9. _______niye ojoti akowe kootu yoo fi koiwe sita (a) ojo mejo (b) ojo mankanlelogun (d)
ojo mokanla
10. Aaye wa fun okunrin lati fe iyawo miran ni igbeyawo ______(a) soosi (b) kootu
(d)musulumi
11. Ibale se Pataki ni aye ______(a) atijo (b) aye ode oni (d) kosi
12. Ni igbeyawo kootu asile fe elomiran afi ti won ba ________(a) yara won (b) ku (d) kosi
13. _______ni aya gbolohun yii ‘dakee” (a) gbolohun ibere (b) gbolohun ayisodi
(d)gbolohun ase
14. ______nigbati ebioko maa n toro omo won (a) osan (b) oru (d) owuro kutukutuk
15. _____ni won maa n bu si ese iyawo (a) omi (b) eje (d) iyepe
16. ______ni iye ojo ti alufa yoo fi kede ninu ile ijosin (a) ose meta (b) ose merin (d) ose
kan
17. ______niigba (a) 100(b) 200 (d) 210
18. Ookanlerugba tumo si ______(a) 210 (b) 201 (d) 200
19. Oga lo ile amok o ni moto je eya gbolohun _____(a) ase (b) iba (d) alakanpo
20. Bi mob a lowo maa jaye je eya gbolohun _____(a) gbolohun ase (b) gbolohun ibere (d)
gbolohuniba
Apa keji
INSTRUCTION: Dahun ibere meta pere
1. daruko ilana marun ninu igbeyawo atijo
2. daruko ewi alohun ti oje mo ayeye marun
3. ko awon ounka wonyi ni ede Yoruba
200 210
220 205 204
4. daruko eya gbolohun marun
EAGLES’ LANDING SCHOLARS SCHOOL
7, Oduwole Street, Abule-Odu Bus Stop, Egbeda-Idimu Road, Lagos.
Tel: 08108920734, 081711483333, 08183929361
FIRST MID-TERM TEST 2023/2024 ACADEMIC SESSION
SUBJECT: YORUBA CLASS: JSS 3
SECTION A
INSTRUCTION: ANSWER ALL QUESTIONS
Apakeji
INSTRUCTION: Dahun ibere meta pere
1. ko bi a se n sin awon eniyan wonyii
Abuke
Alaboyun
Afin
Eni ti ara pa
Eni ti o pokun so
2. ko igbese marun ti oku ba ku
3. salaye ni soki bi a se n se gari
4. daruko ona marun ti a ngba ran ara wa lowo
5a kin litireso
5b daruko ori litireso ti a ni
EAGLES’ LANDING SCHOLARS SCHOOL
7, Oduwole Street, Abule-Odu Bus Stop, Egbeda-Idimu Road, Lagos.
Tel: 08108920734, 081711483333, 08183929361
FIRST MID-TERM TEST 2023/2024 ACADEMIC SESSION
SUBJECT: YORUBA CLASS: SS 1
INSTRUCTION: ANSWER ALL QUESTIONS
1. Silebu ni _____(a)ori oro (b) ege oro (d)ese oro
2. Awon agbe lo maa n se ______(a) pese ohun ti a n je (b) mo ikoko(d) gbegilere
3. Faweli ni a pe nigbati ti ______(a)idiwowafun eemi(b) kosi idiwo fun eemi (d) kosi
4. Faweli aranmupe je _______(a) merin (b) meje (d) marun
5. Faweli airanmupe je ______(a) mefa (b) meje (d) mejo
6. Kansonanti wa je _____(a) merinla (b) mejidinlogun (d) mejilelogun
7. _____niwon fi maa ngun iyan (a) gbaguda (b) ako isu (d) isu ewura
8. _______nibiase n pe M (a)afetepe (b) afeigipe (d) afeyinfete pe
9. ______ni bia se n pe F (a)afeyinfetepe (b) afitannape (d) afajape
10. Silebu _____lowa ninu aake (a) meji (b) meta (d) merin
11. Silebu melo lo wa ninu panapana (a) mejo (b) mefa (d) merin
12. Abinbola je silebu melo (a) marun (b)mefa (d) meje
13. Oro oni selebu mejini_____(a_)bata (b) repete (d) gongosu
14. J pe _______(a)afajape (b) aferigipe (d) afafase pe
15. Isu ___la maan fise ikokore (a) ako isu (b)isu ewura (d) koko
16. Awon _____ lo maa n je EGBO (a) ijebu (b) Ibadan (d) Ilorin
17. _______ lafimaan se asoro (a)ako isu (b) isu koko (d) isu ewura
18. Lafun je ounje ti o wopo julo ni a rin awon _____(a)egba (b) eko (d) ijebu
19. Owe ni _______(a) ege oro (b) esin oro (d) ori oro
20. Bami naa omo mi _______(a)inu olomo ndun (b) kedu olo mi (d) olomo n sare
Apa keji
INSTRUCTION: Dahun ibere meta pere
1. ko bi won n se ko awon oro wonyii
M
F
S
G
B
2. pa owe marun
3. daruko orisi ounje ile Yoruba marun
4. dariko orisi ise abinibi marun
5. pin awon oro wonyii si silebu
Panla
Alagbara
Konko
Panapana
Oluko
EAGLES’ LANDING SCHOLARS SCHOOL
7, Oduwole Street, Abule-Odu Bus Stop, Egbeda-Idimu Road, Lagos.
Tel: 08029557089, 081711483333, 08183929361
FIRST TERM MID-TERM TEST 2023/2024 ACADEMIC SESSION
Apa keji
INSTRUCTION: Dahun ibere meta pere
1. daruko orisi oro asopo marun
2. ko bia se nki eniyan ni awon akoko yii
Owuro
Ale
Irole
Igba ojo
Igba ogbele
10
5
9
4
3
3. ko faweli aranmupe
4. ko faweli airanmupe
EAGLES’ LANDING SCHOLARS SCHOOL
7, Oduwole Street, Abule-Odu Bus Stop, Egbeda-Idimu Road, Lagos.
Tel: 08029557089, 081711483333, 08183929361
FIRST TERM MID-TERM TEST 2023/2024 ACADEMIC SESSION
Pupa
Awo ewe
Omi osan
Bulu
2. ko nomba wonyii lede Yoruba
20
30
22
10
7
3. daruko orisi ila marun
4. ko awon nomba wonyii lede geesi
Ogbon
Ogun
Eewa
Mokanla
Eejidinlogun
5. ko iwa omoluabi marun
EAGLES’ LANDING SCHOLARS SCHOOL
7, Oduwole Street, Abule-Odu Bus Stop, Egbeda-Idimu Road, Lagos.
Tel: 08029557089, 081711483333, 08183929361
FIRST TERM MID-TERM TEST 2023/2024 ACADEMIC SESSION
Apa keji
INSTRUCTION: Dahun ibere meta pere
Odun eyo
Odun ijesu
Odun ibeji
Odun igunu
Odun egungun
4. daruko onjeti won je ni awon ilu wonyii
Ondo
Osogbo
Ibadan
Ilorin
Abeojuta
Osu sere
Osu ogun
Osu agemo
Osu owewe
Osu gbelu
3. fala sioro oruko ninu gbolohun yii
Ajoke lo oko
Ibadan fe pupo
Ewure po ni le wa
Eko ile okun
Abeokuta ni ayo w
5. ya opon ayo