Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 15

***OSO OLA GBOWO WA***

odidi eiye igun kan, ori oka kan, ori olufa kan ,ori akala kan, ori agbe kan, oga aye kan ,gbogbo owo
paper tia na patapata, ao fi ha oga lenu ni eyo kookan ao wa ko gbogbo wa papo ao fi bo oga ni enu,ao
wa diju la mole lekana ao ma sowipe

Ohun: idin diju ni owo lagbaja,

Ao wa ko gbogbo re sinu agbada,ao jopo ao wa lo ti yio kunna dada ao wa rosinu seere,ao wa ra aguntan
ti oti bimo ri dada ao gbe enu si leti ao ma soro bayi si leti pe

Ohun: oso timo mose yi oso owo ni oo,mio fi emi mi seso,mio fi omo mi seso,mio fi ebi mi seso, iwo
aguntan yi ni mofi seso

Ao wa pa aguntan na ao fi eje re ra ara seere yen

*LILORE* ao te aso funfun opa kan kale,ao bu die lara ebu yi ao fi foko tutu mu laro,ti aba fomu tan,ao
mareti alejo ti obade yio beere pe kilafe,ao wa sofun yio silo gbewa bi ao sima lo ogun yi niyen

***ELEYINI APASE FUN OUN KOUN YALA AFE GBA ISE NIBIKAN NI TABI WON PEWA FUN INTERVIW E.T.C
ODAJU. BIIKU NI EMA BAMI KALO

OBI IWAREFA META,EWE OLOMUYENYEN OOJO,EWE ABAMODA OOJO,ITANA SAWEREPEPE OOJO 41,AO
GUN GBOGBO RE KUN NA DADA AO WA SEGBE,AO TUN WA LO KUNA DAADAA AO WA TENI OBA ODU
AO WA PE GBOLOHUN RE SI AO WA DA SINU IGO FUNFUN AO WA GBE PAMO

LILORE:AO BU DIE SOWO AO YA SI LEMETA AO WA PE GBOLOHUN RE SI AO WA DAJE

GBOLOHUN RE:AWON AGBA BO WON NI OBI IWAREFA OLOJU META KOKI N JARA WON NIYAN 3*,OHUN
GBOGBO TI EMI LAGBAJA FEBA LAGBAJA SO LONI KOMA SE JAMI NIYAN,NI TORIPE ABAMODA KAN KII
DA TIE KOMA SE,GBOGBO ABA TI EMI LAGBAJA FEDA NIWAJU LAGBAJA LONI KOMA SAI SE,NITORIPE
EWE OLUMOYEYE KII PA OHUN ORISA DA,KI LAGBAJA MASE PA OHUN ENU MI DA LONI,IFA KAN KII FA
KO BORI EJIOGBE, ORO TIMO BA BA LAGBAJA SO LONI OHUN NI KIO GBO SIMI LENU KIO GBA,KIO SE
NKAN-------------------- TIN BA BERE LOWO RE

**ELEYI NI OSOLE ASIRI BIBO LARIN 7/9DAYS**

ODIDI OKETE AYE TOBATOBI KAN,EWE EWURO AI KANLE OOJO,AO FI DIE TE NINU APE TUNTUN AO
WAGBE OKETE YEN SI AO FI ODIDI ATARE NLA KAN SI LEGBE,AO WA KO EWE DIE LELORI AO WA KO
GBOGBO OWO TIA NA LE LORI BERE LATI ORI #5 DE ORI #1000 AO TUN WA KO GBOGBO EWE EWURO
TOKU LE LORI TI KONI HAN SITA MO RARA, AO WA JOPO AO LOKUNNA AO MA FI MILK OLOPE LO FUN
7/9 DAYS,

AKIYESI: IDI IKOKO NA KO GBODO KANLE O,TIO BA JEPE AKO OKETE NI ALO,OJO MESAN NI AO FI LO
LERALERA,KIA TO WA MALO IYOKU NI OJO KETAKETA,AO SI GBODO SUNMO OBINRIN NIGBA TABI LOJO
TIA ABAN LO ISEYI LOWO,AARO KUTUKUTU LAITI BA ENIKENI SORO NI LILO RE,TIA BATUN LO GBOGBO
EBU YI TAN,ODUN MEJE NI YIO FI SISE LARA WA ODAJU

PASSWORD: IMULE AGBA TODAJU GBODO WA LARA

**AGADAGODO KOSI OHUN TI ALEFI TI OSISE FUN OMO YAHOO NA ODAJU PA**

Okan elede,okan pepeye,adiye opipi,owo ati ori ijapa,panumo abo,panumo abafe,panumo idi,EWE
odundun,ewe alofohun,ewe agunmona,ito alaboyun,ao fi odidi atare kan si,alaboyun ni yio bawa lo
gbogbo re ,ito alaboyun naa lao mafise omire ti aban lo lowo..nigbati o ba lotan,ao ko sinu owu etutu,ao
fi owu dudu ati funfun we mo ara agadagodo..Ao lo si ile alagbede ao so wipe kio bawa ro sekeseke ati
aba,lai kibo inu omi titi yio fi ro mejejji tan,ao fi sekeseke si legbe otun ao fi aba si legbe osi..ao fi awo
egbin si legbe otun,awo ekun si legbe osi ..ao ran pa..ao lo fi sinu omi eku tiwon tin se epo pupa fun ojo
meje..leyin ojo keje ao lomu kuro..ao sasi oorun...o di lilo

..LILO RE-ao je meje eyo atare lenu,ao tu sidi agadagodo naa..OFORE-- abo mun,aba kanmole,sekeseke
de mole,oun ti abani ki abomu ni abomu,oun ti abaniki abakan ni abakan,panumo abo kijeki abo
mi,panumo abafe kijeki abafe fohun,panumo idi ni di idi lenu,agunmona ki roju gun igi re jari,adieopipi ki
roju gun ori orule,towo tese ni ahun fin wo igba,odundun loni kio male dun,alofohun loni kio male
fohun,oyi ni omi inu eku npa,omo tuntun kigbe inu iyare woran,alanu fohun niti pepeye,inu egbin ni
egbin gbinsi,owu dudu owu funfun kija arawon niyan .. Ao timo nkan ti abafe timo..koda toba je eye oju
orun ladanwo larare yio jabo NI..ale danwo Lara alangba egbe ogiri.tested and confirmed ni odaju pupo
lati owo emi

**BIBO ASIRI TOLALE**

AO RA ISASUN TUNTUN KEKERE KAN AO GBE SI LELE,AO WA FA GBOGBO IRUN ABE WA ,AO KO SINU
ISASUN NA,AO WA TOLE LORI NI ARO KUTUKUTU,AO WA KO SIRI ERU ALAMO TI NKANNKAN JA KURO
LARA RE SI,AO RA ERAN MALU EKIRI KAN TIKO NI EGUN RARA,AO JUSI,ATA IJOSI DIE,ESO IDO DIE,AO
DASI AO WA LO RIMO ORI AKITAN FUN OJO META,SUGBON KIA DA YEPE BO MOLE AO TU EPO PUPA LE
LORI, AO KO EWE AJEOBALE LE LORI LEYIN OJO KETA AO LO WU WA SILE,KA TOWA BERE JIJO RE AO
KOKO DA EPO PUPA TELE INU ARO TIA FELO,AO KOKO KO EWE AJEOBALE TELE INU ARO AO DA EPO
PUPA DIE SI KIA TO GBE ISASUN YE SORI INA,AO MA FI EPO PUPA KO INA RE TITI YIO FI JO TAN AO WA
DA EBU NA SI MEJI,AO PO IDAKAN MO OSE,AO DA IDAKAN SINU EPO PUPA AO MA WE NI ALAALE AO
MA LA EPO TINU EPO NA TIA BATI WE OAE TAN

AKIYESI: AO TI KOKO FI OGEDE OMIMI TOPON DADA PO OSE KALE NA KIA TO PO EBU YIMO NINU
ISASUN TI ATI JO ISE YI NI AO TI PO MOSE IBE NANI AO TI MA BUWE NI ALAALE,AO YO IGI IDANA TI
ALOKU BI META SINU ILE BI ARO,ORIRE NI AO GBE OSE NA SI,BIA ABASEN WE TAN ABE ISASUN YI NI AO
MA TOJU KAINKAIN NA SI OJO KAN KAINKAIN KAN NIO

**OSHOLẸ́**

OLONGBO NLA KAN, Ẹ́IYẸ́ KOWE KAN, OKETE OYẸ̀ KAN, AO KO IFUN INU OLONGBO SI TI OKETE, TI OKETE
SINU OLONGBO, AO GBE MEJEJI SINU APẸ́, AO FI KOWE SINI ARIN,AO FI ATARE ODIDI KAN SI PẸ̀LU EGBO
TUDE, AO JO PỌ̀ , AO LỌ̀ KUNA Ao ro sinu sere NLA kan ao pa akuko adie kan fun ao GBE sinu Asuwon ff,
AO MA FI HOT 501 LO.

* *OSHOLE TIA FINRI OWO* *

Ao wa opolo totobi kan, ao wa fi #1000 tuntun kan we eran akile die, ao tii bo inu opolo yen tiyio wole,
ao wa tun kii ewe ola bo inu opolo yii ti yio po daada, ao gbe sinu ape pelu odidi atare kan, ao ko ewe ela
16 lelori, ao jopo, tobadi ago kan oru, ao fi oti loo leekan soso.

Ao gbodo sunmo obinrin fun odidi ojo meta. ODAJU GAN NI, ISE TIMO MA FINRI OWO GIDI NIOOO

** OGUN TI AFI NDI ERU ENIYAN LORI**

osuka imu meta,ao sun sile ,osuka imo ope meta,osuka ewe OGBEDE meta ,ao ko won lori ara won ,ao fi
iyerosun tefa ejiogbe le lori.

*Ofore:-*Ao pe aya ota na si ao so pe,iwo ejiogbe lagbaja ti (ao da oruko ota na) lo so pe o ko ri eru lati
ru ,ki Iwo ejiogbe ba wa eru ,ki awa ma se ba ru eru yi o,ejiogbe odi Iwo re dandan o. Ao gbe okuta ti
enikan ko le ru le mole .

*Erore:-*Ao lo yi okuta wonyi kuro,ao si tu awon osuka wonyen.

Obabi-olorun-kosi.

** OGUN SUKE SUKE TIODAJU TAARA**.

Aowa agudu igbin( polofo igbin) solo kuna daada, aoda sinu Oyin original, ki enina Maala nigbogbo igba.
Odaju gan

** OSE AFARO**

Fofo olokun ao gun papomo ose ti yio Luna Dada ao wa pa eyele kan si ori ose yi ao fi eje re po ose na
dada pelu oti ibile,ao wa ge apa eyele yi mejeji tele inu igba ,ao wa ko ose yi sinu igba na ao depa fun ojo
meje gbako lehin na ,ao ma bu ose yi we laro kutu haihai pelu kainkain ibile.

**EYONU /ASINA**

Ako alangba meta,eyin ororo meta ,epo obo die,odidi atare kan ao jo po ao ma fi ogere epo pupa lo
lalale taba ti fe sun.

Obabi-olorun-kosi

****Oshole Asina to lagbara sise fun omo Yahoo to confirm ti moti seri to damiloju****

ologbo nla kan, eiye owiwi kan, eiye kowe Kan, eiye igun tope to ni ifun ninu odindin Kan, one dollar
pelu #1000, isu esuru funfun, odindin akuko adie kan, igo epo pupa Kan, igo oti schinap kan, ao se
opolopo owo si wewe, ewe ewuro ojo, ewe abamoda to po dada.

Sisere:- Ao la inu ologbo yen ao fi #1000 odindin yen sinu e, ao ran pa pelu owu dudu ati funfun.

Eiye igun ao fi dollar sinu e, ao wafi eiye kowe si apa otun, eiye owiwi si apa osi ao wa we ni owu dudu
ati funfun. Ao fi ologbo yen te agbada ao fi eyin lele ko ayare soke ao gbe eiye igun yesi ao gun esuru yen
papo ao da lelori ao fi owo mo lelori beni re ile, leyin igbati abati se be tan ao wa gbe kana odi jijo papo.
Ao matu epo pupa si nu ina yen ti abajolowo eniti onjo ise ye yio ma mu epo na diedie bo se jo lowo,
atun gbe igo oti schinap yen kan le gbogbo enikeni ti oba bawa ni be ama fun ni oti na mu adetun ma fi
owo ti ase yen fi se sara fun enikeni to ba bawa ni di ise yen. Titi afi jo tan. Ti abajo tan odi lilo papo ao
waro sinu sere kan ao pa akuko adie yen ao fi ejere ra ara sere yen awa tun iye die lara adie yen ao lemo
ara sere yen ao gbe sere sinu apo asunwon funfun kogbodo kanle mo.

Lilore oti tabi ikan ti obagbona. Pelu ogo olohun to ba ba anu olohun Allah pade enina yio la yio si gba ise
gidi abi owo gidi. Lati odun keta ti moti se fun onijalabi mi kan di siyin osi san owo e fun mi. Abawa lara
mu o. Gbogbo agbara ti olohun ni.
**OSHOLẸ́**

OLONGBO NLA KAN, Ẹ́IYẸ́ KOWE KAN, OKETE OYẸ̀ KAN, AO KO IFUN INU OLONGBO SI TI OKETE, TI OKETE
SINU OLONGBO, AO GBE MEJEJI SINU APẸ́, AO FI KOWE SINI ARIN,AO FI ATARE ODIDI KAN SI PẸ̀LU EGBO
TUDE, AO JO PỌ̀ , AO LỌ̀ KUNA Ao ro sinu sere NLA kan ao pa akuko adie kan fun ao GBE sinu Asuwon ff,
AO MA FI HOT 501 LO.

**OSO INU LUKUDI TODAJU**

Akuko adie asa kan, Eyele funfun kan. Eyele pupa kan. Eyele dudu kan. igba olomori nla kan. Owo eyo
tiko lu 201, Eyin pepeye16.

Ao ko gbogbo re sinu igba ni ooye bee, ao de igba naa aofi aso funfun opa meji we igba yen, ao sese
wadi ni owu funfun, ao lo rimo orita fun ojo mesan, ti ojo mesan bape ao lo wu, ao gbe sinu ape, aojo
tigba tigba lodi di bee.

Ao lo kuna, ao fi ro ekuru funfun je leekana pata pata.

iwo ti oba rise, ti oba ri owo walahi ma ki mi i..

** OSHOLE TONSISE GID*I*

Ao wa egbo tude idi mewa, ao dasinu ikoko, ao wafi eyin pepeye meta se aaro sori egbo tude naa, ao
wafi egun ajiyo tofe die lelori, ao wafi #1000 tuntun sori egun ajiyo yii, ao wafi odidi atare meta lelori, ao
jopo, ao lo kunna, ao dasinu tray kan, ao wafi te gbogbo ODU MERINDINLOGUN, tobadi ojo keji, ao bu
die sowo, ao fi oti loo, Bi ao sema loo larolaro niyen. KOSI OJO TIA BALO ISEYII TI AO NI RI OWO ISE
TODAJU NI

***EYONU ASINA TIPA TIPA TODAJU****

Eku asin 3, Oga gbigbe 3, Opolo gbigbe 3, Alakan oke 3, Akeke to pe 3,Iginla, Epo obo, Ewe mafowokan
omomi, Ewe iyalode funfun ati pupa, Ewe orijin, Ewe ajeobale.

Ao Jo gbogbo e papo, ti aba Jo tan ao dasinu sere kan ao wa pa adie akuko si ara sere ohun ao tu ihuru
re si. Ao fi epo yi aro kaa ti abafejo iseyi.

LILORE ao maafi ogeere epo pupa lo lalaale, aosimaa fiii eko tutu lo laraaro. odaju pupo
** Iwe Asina Ore**

Epo Akoko die Egbo Akoko die ,Omudun Akoko die. Ao gun pomo ose,ao fi epu pupa para kato we Laale.
Odaju pupo

**Osole owo**

: Ewe omisinminsin mejeji eyin ibile mesan ..ikoko aseje tuntun .amagun ewe yiivamawa pomo ose.ama
wa fo eyin yen sii leyokankam .ama gun gbogbo re papo morawon .ama wa ko sinu ikoko yen ama
tojuee fun ojo meta leyin naa wiwe night igbakugba

***AWURE OSE OLA TODAJU.***

;EWE AJE,EWE ISAJU,ewe anu,ewe owuakese,oga aaye meta,owo eyo (38)awo funfun olomori,eyele
funfun meji,Ao gun gbogbo re papo,ao ko owo eyo yen soto,ao fi eje eyele yen po ose na,ao fi eyo owo
yen tele koro iyara,ao gbe ose yen le lori,eje eyele ni ao fi po ose na oo, PSALM RE:Tani papa,obara
funfun yeye Aje,ole kolejaba niwon ndasa sangele sangele,awon ni won difa faronke ti ise akobi won ni
ijo eleye,ni igbati faronke so wipe oun yio ba ijo eleye je,woni ese faronke ti iwo yio fi ba ijo eleye je,won
be faronke titi faronke ko kogba,wonba lo fi ejo faronke sun esu odara,nigbati faronke de odo esu
odara,esu odara bere lowo faronke wipe kilode ti iwo fi fe ba ijo eleye je,faronke wipe gbogbo nkan rere
to wa nile aye,won ko jeki oun faronke ni nkankan nibe,esu odara ni toba ribe,oun yio maa dawonru ni
isale,lati oni lo gbogbo nkan rere yio ma je tire,esu odara bo si igboro ilu,ki o da aarin awon
olowo,olola,oloro ru lati oni yii lo,ki gbngbo oun rere maje temi L OMO L,ASE EDUMARE.

***OSO OLA GBOWO WA***

odidi eiye igun kan,ori oka kan,ori olufa kan,ori akala kan ori agbe kan,oga aye kan,gbogbo owo paper tia
na patapata,ao fi ha oga lenu ni eyo kookan ao wa ko gbogbo wa papo ao fi bo oga ni enu,ao wa diju la
mole lekana ao ma sowipe

Ohun:idin diju ni owo lagbaja,

Ao wa ko gbogbo re sinu agbada,ao jopo ao wa lo ti yio kunna dada ao wa rosinu seere,ao wa ra aguntan
ti oti bimo ri dada ao gbe enu si leti ao ma soro bayi si leti pe
Ohun:oso timo mose yi oso owo ni oo,mio fi emi mi seso,mio fi omo mi seso,mio fi ebi mi seso, iwo
aguntan yi ni mofi seso

Ao wa pa aguntan na ao fi eje re ra ara seere yen

*LILORE* ao te aso funfun opa kan kale,ao bu die lara ebu yi ao fi foko tutu mu laro,ti aba fomu tan,ao
mareti alejo ti obade yio beere pe kilafe,ao wa sofun yio silo gbewa bi ao sima lo ogun yi niyen

Odaju tia bale na owo re tested and confirm

**APASE FUN OUN KOUN YALA AFE GBA ISE NIBIKAN NI TABI WON PEWA FUN INTERVIW E.T.C ODAJU.
BIIKU NI EMA BAMI KALO""

OBI IWAREFA META,EWE OLOMUYENYEN OOJO,EWE ABAMODA OOJO,ITANA SAWEREPEPE OOJO 41,AO
GUN GBOGBO RE KUN NA DADA AO WA SEGBE,AO TUN WA LO KUNA DAADAA AO WA TENI OBA ODU
AO WA PE GBOLOHUN RE SI AO WA DA SINU IGO FUNFUN AO WA GBE PAMO

LILORE:AO BU DIE SOWO AO YA SI LEMETA AO WA PE GBOLOHUN RE SI AO WA DAJE

GBOLOHUN RE:AWON AGBA BO WON NI OBI IWAREFA OLOJU META KOKI N JARA WON NIYAN 3*,OHUN
GBOGBO TI EMI LAGBAJA FEBA LAGBAJA SO LONI KOMA SE JAMI NIYAN,NI TORIPE ABAMODA KAN KII
DA TIE KOMA SE,GBOGBO ABA TI EMI LAGBAJA FEDA NIWAJU LAGBAJA LONI KOMA SAI SE,NITORIPE
EWE OLUMOYEYE KII PA OHUN ORISA DA,KI LAGBAJA MASE PA OHUN ENU MI DA LONI,IFA KAN KII FA
KO BORI EJIOGBE, ORO TIMO BA BA LAGBAJA SO LONI OHUN NI KIO GBO SIMI LENU KIO GBA,KIO SE
NKAN-------------------- TIN BA BERE LOWO RE

**OSOLE ASIRI BIBO LARIN 7/9DAYS EMA BAMI KALO**

ODIDI OKETE AYE TOBATOBI KAN,EWE EWURO AI KANLE OOJO,AO FI DIE TE NINU APE TUNTUN AO
WAGBE OKETE YEN SI AO FI ODIDI ATARE NLA KAN SI LEGBE,AO WA KO EWE DIE LELORI AO WA KO
GBOGBO OWO TIA NA LE LORI BERE LATI ORI #5 DE ORI #1000 AO TUN WA KO GBOGBO EWE EWURO
TOKU LE LORI TI KONI HAN SITA MO RARA, AO WA JOPO AO LOKUNNA AO MA FI MILK OLOPE LO FUN
7/9 DAYS,

AKIYESI: IDI IKOKO NA KO GBODO KANLE O,TIO BA JEPE AKO OKETE NI ALO,OJO MESAN NI AO FI LO
LERALERA,KIA TO WA MALO IYOKU NI OJO KETAKETA,AO SI GBODO SUNMO OBINRIN NIGBA TABI LOJO
TIA ABAN LO ISEYI LOWO,AARO KUTUKUTU LAITI BA ENIKENI SORO NI LILO RE,TIA BATUN LO GBOGBO
EBU YI TAN,ODUN MEJE NI YIO FI SISE LARA WA ODAJU

PASSWORD: IMULE AGBA TODAJU GBODO WA LARA

**AGADAGODO KOSI OHUN TI ALEFI TI OSISE FUN OMO YAHOO NA ODAJU PA**

Okan elede,okan pepeye,adiye opipi,owo ati ori ijapa,panumo abo,panumo abafe,panumo idi, EWE
odundun,ewe alofohun,ewe agunmona,ito alaboyun,ao fi odidi atare kan si,alaboyun ni yio bawa lo
gbogbo re ,ito alaboyun naa lao mafise omire ti aban lo lowo..nigbati o ba lotan,ao ko sinu owu etutu,ao
fi owu dudu ati funfun we mo ara agadagodo..Ao lo si ile alagbede ao so wipe kio bawa ro sekeseke ati
aba,lai kibo inu omi titi yio fi ro mejejji tan,ao fi sekeseke si legbe otun ao fi aba si legbe osi..ao fi awo
egbin si legbe otun,awo ekun si legbe osi ..ao ran pa..ao lo fi sinu omi ekutiwon tin se epo pupa fun ojo
meje..leyin ojo keje ao lomu kuro..ao sasi oorun...o di lilo..

LILO RE-ao je meje eyo atare lenu,ao tu sidi agadagodo naa..OFORE-- abo mun,aba kanmole,sekeseke de
mole,oun ti abani ki abomu ni abomu,oun ti abaniki abakan ni abakan,panumo abo kijeki abo mi,
panumo abafe kijeki abafe fohun ,panumo idi ni di idi lenu,agunmona ki roju gun igi re jari,adieopipi ki
roju gun ori orule,towo tese ni ahun fin wo igba,odundun loni kio male dun,alofohun loni

kio male fohun,oyi ni omi inu eku npa,omo tuntun kigbe inu iyare woran,alanu fohun nitipepeye,inu
egbin ni egbin gbinsi,owu dudu owu funfun kija arawon niyan .. Ao timo nkan ti abafe ,timo..koda toba je
eye oju orun ladanwo larare yio jabo NI..ale danwo Lara alangba egbe ogiri.tested and confirmed ni
odaju pupo lati owo emi

**BIBO ASIRI TOLALE***

AO RA ISASUN TUNTUN KEKERE KAN AO GBE SI LELE,AO WA FA GBOGBO IRUN ABE WA ,AO KO SINU
ISASUN NA,AO WA TOLE LORI NI ARO KUTUKUTU,AO WA KO SIRI ERU ALAMO TI NKANNKAN JA KURO
LARA RE SI,AO RA ERAN MALU EKIRI KAN TIKO NI EGUN RARA,AO JUSI,ATA IJOSI DIE,ESO IDO DIE,AO
DASI AO WA LO RIMO ORI AKITAN FUN OJO META,SUGBON KIA DA YEPE BO MOLE AO TU EPO PUPA LE
LORI, AO KO EWE AJEOBALE LE LORI LEYIN OJO KETA AO LO WU WA SILE,KA TOWA BERE JIJO RE AO
KOKO DA EPO PUPA TELE INU ARO TIA FELO,AO KOKO KO EWE AJEOBALE TELE INU ARO AO DA EPO
PUPA DIE SI KIA TO GBE ISASUN YE SORI INA,AO MA FI EPO PUPA KO INA RE TITI YIO FI JO TAN AO WA
DA EBU NA SI MEJI,AO PO IDAKAN MO OSE,AO DA IDAKAN SINU EPO PUPA AO MA WE NI ALAALE AO
MA LA EPO TINU EPO NA TIA BATI WE OAE TAN

AKIYESI: AO TI KOKO FI OGEDE OMIMI TOPON DADA PO OSE KALE NA KIA TO PO EBU YIMO NINU
ISASUN TI ATI JO ISE YI NI AO TI PO MOSE IBE NANI AO TI MA BUWE NI ALAALE,AO YO IGI IDANA TI
ALOKU BI META SINU ILE BI ARO,ORIRE NI AO GBE OSE NA SI,BIA ABASEN WE TAN ABE ISASUN YI NI AO
MA TOJU KAINKAIN NA SI OJO KAN KAINKAIN KAN NIO
**** OGUN TI CONTRACTOR FIUN RI ISE NLA NLA GBA TODAJU BIKU***

ao wa isasun tuntun olomori kan abo alaamu aye kan ako alaamu aye kan oga ibile tiwa ntiwa aye nla
kan iyanrin okun yanrin osa,omonigelegele oojo,ojuda aso egun togbayi dada,pelu gbogbo owo tia na
patapata pelu odidi atare kan

SISERE:eo pa awon alaamu yen ti eje koni yo lara won eo bu yanrin okun ati ti osa si egbe ara won ninu
isasun na eo mu abo alaamu yen sinu isasun ti yio si aya soke eo si fi aya ako alaamu yen de abo alaamu
eo fi oga yen gba awo gbogbo awon owo yen pata tio bati gba awo owo na tan dada eo wa pa oga yen
eo ro eje re sinu isasun yen eo ju oga yen si eo wako gbogbo awon owo yen si eo fi odidi atare yen sori
awon owo yen eo fi aso egun yen le eo wa ko omonigelegele bo won mole dada eo fi omori isasun yen
de pada eo wafi owu dudu ati funfun we isasun yen dada eo wa gbe isasun ise yen ao lorimole soju ona
ti opolopo awon eniyan ma nrin fun odidi ojo meje

Tio bawa dini ojo keje eo lohu ise yen eo gbe wale eo wa gbe ise yen kana eo jo

EEWO RE : ao gbodo siwo titi yio fi jotan patapata ooo olewu gan tori ti eniyan ba siwo laijepe o jotan o
sese kio tope ojo meje ki oju enina fo ooo nitorina agbodo ri daju pe ise yi jotan kia to si omori isasun
yen tio ba jotan

Ao Lo ao pomo ose aganyin dudu tabi eyikeyi ose tia ba nfe

AKIYESI:odidi agutan lao pa ti ao fi eje re po ose yen dada Kia tun tofi omi awamaridi po Kia tun tofi oyin
igan Gigi po ose yen inu awo funfun balau lao ko ose yen si tabi kia kosi inu isasun yen pada akiun ko ose
yi sinu ike oooo eeewo ni oooo

ISE TISE WALAHI

LILORE: igba meji larin ose ni ao mawe ose yi ojo aje ati ojo jimoh

SARA RE: ni ososu lao mafi eje pepeye bo ose yen titi ti ao fi lotan , mobura pelu oruko olohun ise nla ni
oooo

Eni ti obari ise yise iru enibe tidi eniti aje nba gbe koda kosi idiwo kankan tabi idena awon agbalagba kan
tio leda ise yi duro pe kio ma sise oooo odamiloju gidi gan

*** ASIRI AFERI TO DAJU ***

Ao wa orogbo kan ao ki bo enu oku ti won yoo sin loojo, ti won bati sin oku naa tan ao wa lo ibiti won ba
sin oku naa si ni dede ago mesan ale (09pm) ao mu omonri igba nla kan dani, ao wa duro nibi ori saare
oku naa ao sowipe Lagbaja Omon lagbaja oti oku lati onilo ounriwa awa oriomon , ase ti ofi ri wa ti awa
osi rio naa ni agba kio yonda ase naa fun wa ao fi omonri igba naa bo dede ibi ori saare naa ao pada wa
sile ti oba di owuro kutu ojo keji ao ji lobe ao wa si omonri igba naa ao ba orogbo naa nibe ao gbe wa sile
.

LILORE Ao ma ju orogbo naa senu, Eda alaye kankan kole ri wa mon titi ti ao fi yo kuro enu.

AKIYESI Gbogbo awon ti awa naa ao ma ri ao ni ri ori lorun won. Odaju bi iku.

Emi Omon eyin Agbalagba nio Alfa issa ARIDUNU MOBA

** Asiri ti a fi n ti ojo(rain)**

Ewe etiponla kan ti ko dalu rara ati eyo atare kan ao fi eyo atare kan yi si ori ewe na ao wa gbe sinu aso
akisa die ao wa ri igi kan mole ao wa la igi na ni enu ao wa fi kini na ha igi na lenu

Akiyisi:Ti kini ti a fi ha igi na lenu ko ba tun ojo ko ni ro hmmm hmmm hmmm asiri ni

***OSO AJE OGUGULUSO OLA NLA***

EYELE FUNFUN (10)OGA GBIGBE (2)ORI OLUFA (2)ORI OSIN (2)ORI AGBE (2)ORI ALUKO(2)ORI
AIYEKOTO(2)ORI OFAFA (2)ORI IJIMERE(2) ORI AGILINTI(2)ORI ALEGBA (2)EWE ---OOJO

EWE--OOJO , ORI ___ TUTU, AWO IJIMERE , AWO FUNFUN , PELU APOTI , *ETUTU RE*AGBA FUNFUN
BALAU NI OJO AKOKO , OBUKO NI OJO KEJI, AKUKO ADIE EYIKEYI NLA KAN NI OJO KETA , OPARI OOOO
HMMM

*LILORE. *MONDAY,TUESDAY,SUNDAY NI

*SARA RE::: TI ABA TIUN LO* AO MAFI OBUKO SE SARA NI OSU META META TI OWO YEN BATI PO

Oti pari oooo ni aje bade ooo ositun sise okiki

* ** AJALA KERUKERU NLA PATAPATA***

ORI__KAN ODIDI IGUN KAN ODIDI AKALA KAN ODIDI KANAKANA KAN ODIDI OLONGBO DUDU BALAU
KAN ODIDI EIYE LEKELEKE KAN ODIDI ORI EKUN TOPE DADA KAN ORI AGBIGBO TONI ERU LORI KAN ORI
OKA TOLASE KAN ORI ERE TOLASE KAN OKO OJU OMI TOTI KO ERU DADA RI DIE EWE__OOJO

EWE __OOJO , EWE __OOJO , IGO OYIN OGIDI KAN , OTI SODABIA IGO KAN EIYELE FUNFUN BALAU KAN
EIYE ETU KAN , AGBO FUNFUN BALAU KAN , OPON IROKO , PELU IKODE META

*OFORE*___
AHHHHH ISE NLA NI ISE YI ENI TOBA TISE ISE YI LAYE RE KOMA WULE TUNSE OSO OWO KANKAN MO
KOKAN MASE ISE AGBARA LOKU

HMMM ENIYAN MEFA PERE LOLE LO OOOO KIISE ISE OLOWO KEKERE OOO ISE TI AWON OLOSELU
MAUN SE NI

**AWURE OSE OLA TODAJU**.

EWE AJE,EWE ISAJU,ewe anu,ewe owuakese,oga aaye meta,owo eyo (38)awo funfun olomori,eyele
funfun meji,Ao gun gbogbo re papo,ao ko owo eyo yen soto,ao fi eje eyele yen po ose na,ao fi eyo owo
yen tele koro iyara,ao gbe ose yen le lori,eje eyele ni ao fi po ose na oo, PSALM RE:Tani papa,obara
funfun yeye Aje,ole kolejaba niwon ndasa sangele sangele,awon ni won difa faronke ti ise akobi won ni
ijo eleye,ni igbati faronke so wipe oun yio ba ijo eleye je,woni ese faronke ti iwo yio fi ba ijo eleye je,won
be faronke titi faronke ko kogba,wonba lo fi ejo faronke sun esu odara,nigbati faronke de odo esu
odara,esu odara bere lowo faronke wipe kilode ti iwo fi fe ba ijo eleye je,faronke wipe gbogbo nkan rere
to wa nile aye,won ko jeki oun faronke ni nkankan nibe,esu odara ni toba ribe,oun yio maa dawonru ni
isale,lati oni lo gbogbo nkan rere yio ma je tire,esu odara bo si igboro ilu,ki o da aarin awon
olowo,olola,oloro ru lati oni yii lo,ki gbngbo oun rere maje temi L OMO L,ASE EDUMARE.

*AGADAGODO TOGBONA DAADA TIA FIN RAN OTA LO SORUN TABI TIA FIN LE ENIYAN KURO NILU
TODAJU*

Ao wa ori aparo tiwon ki won ese mejeji bo lenu, labalaba 7 tabi 3, alabahunbahun 7 tabi 3, ati ela ileke,
ao ao wa gun gbogbo nkan yii papo kunna daada, ao ko sinu efe owu, ao dii mo ara agadagodo, ao fi
owu dudu ati funfun we, ao wafi awo ekun ran gbogbo ara agadagodo yii, Tia bafe loo, ao je eyo atare
merindinlogun lenu, ao pe ohunre yii,

OHUNRE - Bi aparo bafi ese lele oma nfi ori legbo ni, L omo L lati wakati yii lo kofi ilu yii sile fun emi L
omo L kofi ori legbo tabi koma losi orun apapandodo, ela ileke kii roju raye gbokun si, ogbodo roju raye
bawa gbe aye yii mo, labalaba ati alabahunbahun won kii dagbere kiwon tofi aye sile, ogbodo dagbere
koto fi aye sile, tabi ogbodo dagbere koto fi ilu sile, koorin tefefete kama pade mo.

Ao pe ohun yen si bee, ao wa tu atare enu wasi, ao somo oferefe ti ategun yio ma gbelo gbebo.

Pelu ogo olohun tiyio bafi to ojo keji si ojo keta ti eniyan ko bafi ilu sile yio dagbere fun aye. Ise todaju
ni.

* *TIWON FINPE ENIYAN PADA SIBI ISE KIAKIA**

Ao wa ori okere kan, abo alangba aye kan, awo ewiri alagbede, awo ilu gangan tiwon tilu ri daada, ewe
jingbinni, ao jo gbogbo nkan yii papo, ao poo mose, ao fima we pelu ohunre

Enu ọkere ni okere fin pe olode, fúnra wọn ni ki awon oga mi kope mi pada, enu ewiri ni ewiri fin
fena, enu won naa ni ki awon oga mi fi pe mi padà sibi ise, enu gangan ni gangan fin pe eniyan jo, enu
ara won ni kiwon fi pe mi pada senu ise mi,

Ao mawe ose naa pelu ohunre pelu ogo olohun wọn yio pe pada.

***OSHOLE IMULE TI ENIYAN FIN NI CUSTOMER NLANLA TABI ALEJO TUNTUN TABI OMO YAHOO TIKOTI
NI CLIENT* **

Ao wa ako alangba 6, ikode 6, obi iwarefa(oloju mefa) 6, odidi atare 6, ao ma la inu alangba yii
leyokokan, ao mafi ikode kan obi iwarefa kan sinu re leyokokan titi yio fipe mefa, ao gbe sinu agbada, ao
ko odidi atare mefa yen si, ao jopo lai ni siwo titi yio fijotan, ao lo kunna, ao dasinu keg kan, ao da oti
sinu re pelu milk olope kan, ao ma mu larolaro.

Wallahi ojumo koni mo ki alejo tuntun mawa ba wa. Ise todaju nio.

**Ise oshole todaju Tojepe larin ojo meta si ojo mefa ire ayo yio wole***

Ao wa ori ako alangba mefa toje tutu, ao wa obi alawe mefa eyokan, ati eran ajiyo die ti ao tigesi ona
mefa, Ao mu eran die pelu obi alawe kan, ao fi ha enu ori alangba naa, bi ao se se niyii tiyio fipe mefa
yen, ao fi odidi atare kan sarin ikoko kekere, ao wa to ori alangba yii round atare naa ninu ikoko yen, ao
jopo, ao gbodo siwo tiyio fijo tan, ao lo kunna, Tobadi ni ago kan oru, ao fi oti tabi eko loo leekanna, ao
gbodo sunmo obinrin fun ojo mefa leyin ojo mefa wallahi ao gba nkan tiwon npe ni owo, ona yio si gan
nio, ise todaju ni...

"**OSHOLE OWO PONBELE TOGBONA***

B*LARIN OSU KAN OWO YIO TIWA LOWO ONITOHUN, ISE TODARA NIO*

Ao wa odidi olongbo dudu balawu kan, ao la olongbo naa laya, ao fi odidi yadu ajiyo otun sinu re, ao wafi
eiye kowe kan, ori igun kan, ori akala kan, owo eyo tikoluju 201, ao ko gbogbo nkan yii sinu olongbo naa,
ao ranpa tabi kagbe sinu agbada bee, ao wa da afara oyin topo daada boo monle, ao jopo, ao ro sinu igo
funfun kan, ao wa pa akuko adire funfun kan sara igo naa, Eni toni iseyii kogbodo je ninu adire naa, Ao
mafi oti loo lemeji lose kan lojo Monday & Thursday

NOTE Eniyan koni lo iseyii koma ri towo se laye, enitoba loo larin osu kan tiko bari towo se, ko lo se
ayewo ara re, nkan toba ndi lowo, Iba baba mi IFALOBA tofi iseyii lewa lowo.
*Imule awon agba tosise daada*

Ao wa okete tutu aye kan, ao la laya, ao ko gbogbo ifun inu re kuro, ao lo rimonle, ao wa da epo pupa
igo kan lelori, ao da iyepe boo monle, ao wafi eiye kowe olori dudu kan ati eiye ologeesa kan sinu okete
yii, ao ran pa, ao gbe sinu agbada, ao fi odidi atare kan si, ao pa epo obo pepe, ao ko lelori, ao jopo, ao
mafi epo pupa yika aaro tia banjo lowo, ao lo kunna, ao ro sinu igo kan, ao mafi ogeere epo loo lalale kia
tosun, pelu ogo olohun awon agbalagba yio mafi apeere daada han wa, won yio sima wa bawa lalejo,
imule todara ni ti aye fi ngba eda, ti eda fin rise kiakia...

**ATUDE OWO KOWO TI O N FA IDIWO ATI IDENA BA EDA.**

Esuru pupa, isu ogirisako, ewe Ina pupa ati funfun tutu, ewe esisi tutu, ewe araagba tutu, ewe kini
efefimise, ewe ajeobale tutu, ata ijosi die, epo obo, ao gun ninu odo tabi ori olo kuna daada pelu ose
dudu tabi ose ganah, ao ko sinu isasun tuntun olomori, ao de pa, ao gbe pamo fun 16days, leyin ojo yi, a
o mafi we ni aro ati ale pelu warm water.

Ewe ti a ko ba ri tutu re, a le lo gbigbe, igbati a bafi malo ose yi ni ose kan, gbogbo owo kowo, ide, idiwo,
idena, ogun aye pata pata ni o ma tu danu.

*OSHOLE OWO KIAKIA*

Ao wa eiye kowe olori dudu 3, eiyele funfun 3, oga gbigbe 3, obi ifin 3, obi ipa 3, odidi atare 3, ao wa jo
papo, ao ro sinu ato kan, ao gbe sinu asunwon aso funfun, ao gbe ko, Idire kogbodo kanle mo, ao mafi
oyin loo lalale, aomafi fo

**OSHO 1 MILLION TODAMILOJU LARIN 16 DAYS***

*MOFI ILE TIMA WO SUN BURA, ISE TODAMILOJU NI WALLAHI TALLAHI*

Ao wa alangba topon daada kan, ao ge eran ole ojuda kan si mesan, ao wafi idi biro ti wole ti yio fi pe
mesan, ao wafi biro ko zero meta seyin #1000 tuntun kan, yio je #1million, ao wa ka roborobo bi sigar,
ao tii wole senu alangba yii, ao wa gbe sinu ape, ao fi atare kan segbe re, aojopo, Ao fi peak milk olope
loo laro kutukutu fun ojo meta.

# Irawo omi ko le loo ooo

**ASEJE OSHOLE TODAJU*

*EDAKUN EJEKI A DAN ISEYII WO KIA FUN ILE LABO*

Ao wa eran ajiyo basi 4, eyin ororo 4, igbin nla odidi 4, ao bo igbin yen, ao bo eyin ororo naa, ao kosinu
isasun tuntun kan, ewe abamonda tofe tikoluju eyo 4, #500 tuntun kan, iyere, ao wa lo gbogbo awon
nkan yii papo, ao wa da sori aseje yii, ao wafi epo, iyo, iru se obe naa, Toba tutu, ao so sori osuka kan, ao
ma wa je ni igbin kan, eyin kan, eran akile kan, titi ao fi jetan, tia bajetan, ao wa la obe naa ninu isasun
aseje yii, ao gbe isasun naa pamo, ao ni jeki o fo ooo, tio bafo aba ise naa je niyen, Ao ma se saara pelu
nkan tia bani ikapa tori awon eniyan yio ma yo mowa, ti yio sima mu aanu wa, Sugbon owo ti nkan yii
bamu wa kia fi ra motor ti awa gangan yio ma gun funra wa, tabi kia mafi kole, Iseyii Dara kia mase larin
osu meta meta. EDANWO.

*OSHO OLA TODAMILOJU BIIKU* TESTED AND CONFIRMED*

Ao wa aso tiwon fi sin oku, ko pon dandan kotobi ju, kio sati to lati fi di nkan tia fe di, ao te sile, ao wa
dangboroku mejeji, ao fo si wewe, ao ko lori aso naa, ao gbe ori aguntan oojo si, ao fi odidi atare 36 pelu
eyin adire ibile 36 si lori, ao dii papo, ao gbe sinu ape, ao jo papo, ao lo kunna, ao ro sinu igo funfun, Ao
ma loo larolaro pelu oti toba lagbara

#Nb: irawo omi ko gbodo loo ooo, a si gbodo bere fun nkan etutu ti a Ba se tan.

**OSHOLE TODAJU**

Ao lo wa eiyele dudu kan tiko lami rara, abo adire dudu kan tikolami rara, eran asiri basi kan, ao kan igi
iroko ni posi, ao te aso funfun sinu re, ao pa eiyele ati adire yii sori aso funfun yii, ao fi eje awon mejeji te
EJIOGBE sori aso funfun naa, ao wa mu ori eiyele ati ori adire naa pelu lami yen, ao gun meteta papo, ao
poo mose dudu, ao ko ose naa sori eje naa, ao fi aso funfun yen boo monle, ao fi ese osi wa ti posi naa,
ao lo gbe pamo si aye owo ninu Ile wa

*IKILO* Ao bere wiwe ose yii lati ibi ori wa de ese wa, larolaro lao mafi ose yii we, odaju gan, Enikeni
toba fe sise yii ko koko se saara tabi ko lo ose atude todara ko to lo iseyii.

#Ko si irawo ti ko Ba sise, koda o wa Lara ise ti mo ti lo seyin...

You might also like