Professional Documents
Culture Documents
Yoruba Content 3
Yoruba Content 3
Arrangement: 1
Recap:
Ki a to wo ohun ti a m pe ni gbolohun, a gbodo mo ohun ti a n pe ni oro -ise ati oro
– oruko.
this means, before we look into what gbolohun is, let’ first learn about oro-ise
and oro-oruko.
Oro oruko: oro – oruko ni a fi ma n toka si oruko eyan, oruko eranko, oruko ibi,
tabi oruko nkan. Bi apeere; sola, mara, seun, maalu, kiniun, ejo, sukulu, sibi, ile ati
bee bee lo.
Gbolohun ni akojopo oro lati seda oro ti o ni itumo tabi ti o pe. this translate to;
the combination of words to make a complete sense/ thought. Bi apeere;
Ade lo
ojo wa
Oluko ko wa
ade ri olu
iyabo pon omi
Ti a ba wo awon apeere yii, a ma ri wipe eyo oro ise kan soso lo wa ninu okookan
awon gbolohun oke wonyi. Idi niyii ti a fi pe won ni gbolohun abode.
Gbolohun ase, eyi ti o je eyo oro-ise kan soso naa le duro gege bi i gbolohun
abode. A maa n lo lati fi pase fun eniyan ni. Apeere gbolohun naa ni;
lo,
duro
dake
wa
bere
kuro
jade ati bee bee lo.
ISE SISE:
Dahun awon ibeere wonyii;
Kinni gbolohun?
Gbolohun abode je gbolohun ……………………………
Fala si idi oro-ise ninu awon gbolohun wonyii;
a) Iya ki wa.
b) Mo lo.
c) Ade wole.
d) Yemi ki baba.
e) Sare.
Chapter Summary:
Ni bayii, ati wa fi opin si eko tonii. This means, we have come to the end of
today’s lesson. Lonii, a ko nipa Gbolohun abode. E ma gbagbe pe gbolohun ni
akojopo oro ti o ni oro ise ati oro oruko ninu. Today, we learnt about Gbolohun.
Keep studying and practising. Ki a tun ma pade ninu eko to n bo, odaboo.