Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 2

The alphabet is the letters we add together to form a word.

All the words are


formed from the alphabet.

Eyi tumo si pe a maa n seda oro ti a n so lati inu alifabeeti. A maa n se eleyii
nipase siso iro konsonanti ati faweli papo lati seda oro ti o ni itumo. The
consonant sounds and the vowel sounds are merged together to give us a
meaningful word. E Let’s see how each word are formed in Yoruba. For example,
Iro ‘R’ and iro ‘A’ joined together is pronounced as ‘RA’ which means ‘BUY’ in
English.
Simple right? Wonderful!

Ninu eko tonii, a ma ko bi a se n seda oro oni silebu kan, sugbon ki a to bere, e je
ki a wo bi itumo silebu.

In English language, silebu is also known as syllable.


Silebu ni ege oro keekeekee ti a le pe jade ni eekan soso lai si idiwo kan tabi
omiran. Oro oni silebu kan je oro ti a le pe jade lekan soso lai si odiwon kan tabi
omiran. Apeere:
OPOLOPO - O-PO-LO-PO (ege kookan yii ni a pe ni silebu)
ege
ege

ege
ege

Oro oni silebu kan je oro ti a le pe jade lekan soso lai si odiwon kan tabi omiran ti
yoo si fun w ani oro to ni itumo.
Apeere.
Lo ko ta. Wa. De ki. Ko. Wi.

Oro oni silebu kan le waye ni ohun oke, ohun aarin tabi ohun oke.
Apeere oro oni silebu kan olohun oke:
Lo. Ko. So. Wa. De. Je. Ja. Ri. Ati bee bee lo.
Apeere oro oni silebu kan olohun aarin
Ro. Pa. fon. San. Ga. Du. Pon je. Ati bee bee lo.
Apeere oro oni silebu kan olohun isale
Gba. Je. Pon. Ko. So. Wa. De. Ja. Ati bee bee lo.

You might also like