Professional Documents
Culture Documents
Yoruba Content 7
Yoruba Content 7
Silebu ni ege oro kekeke ti a le pe jade ni eekan soso lai ni odiwon kan tabi
omiran. Bi apeere:
OPOLOPO - O-PO-LO-PO (ege kookan yii ni a pe ni silebu)
Oro onisilebu meji ni awon oro ti o ni silebu meji ninu won lati fun wa ni oro kan
soso ti o si ni itumo. Apeere.
Do ati do fun wa ni do-do
E ati wa fun w ani e-wa
A ati ta fun w ani a-ta
I ati isu fun w ani i-su
E ati mu fun w ani e-mu
Oro oni silebu meji le waye ni ohun oke, ohun aarin tabi ohun oke.
Apeere oro oni silebu meji olohun oke:
Ji-de =jide
Tu- wo =tu-wo
Ran -ti = ran-ti
Ko – la = ko-la
Bi – si = bi-si