Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 1

Lowo

1- EYONU
Ewe ejinrin, ao su losuka ni ona meta, ao gbe eyokan le inu ape ejo ogun, ao ki eyin ororo kan bo
larin ao ko ewe anu bo mole, ao gbe ekeji le lori ao fi eyin ororo kan si ao tun ko ewe anu bo loro, be
lao se to titi de ori eleketa, ao waa paa epo obo ati igi nla le lori pelu odindi ataare kan, ao jo papo
ao gbodo ro raaraa titi yio fi jo tan, ao lo kuna daadaa ao pin si ona meta, ao fi idakan po ose dudu,
ao fi idakan foko tutu mun ao daa idaketa sinu oyin gidi...
Lilore : Ti ose yen ojo meta meta ni ao maa fi we ki a to sun ni ale, edakun ati isale ni ao ti maa we lo
soke ooo. ao gbodo we lati oke waa si isale ooooooooo, iwo ti o baa waa ni ipo giga kan bi o baa file
we ose yii lati oke wa si isale ha!!!!!!! olohun koni so waa di eni ile ooo, oke loke ni ao maa lo, ao ni
waa le lailai.... eyiti ao fi foko mun, owo alafia ni ao fi fo, owo alafia ni ao fi gbemun, ori oke to baa
gaa ni ao ti lo gbemun, bi o baa wuwa ki a gun ori ope lo, ese waa ko gbodo kan ile raaraa, eyiti ao
maa fi oyin laa, ika owo ti o gaa ju ni ao maa fi laa ni araro ki a to soro si enia..... walahi kunfayakun ti
olohun allah ni....

1- ASINA TI ONA BAADI TI KOSI OWO TABI ISE LOWO


ao ra koko isasun tuntun opolopo omi agbon ao da omi na sinu isasun naa ao gbe ka
ina ao lo epo obo kunna daadaa ao dasi ao tun wa da ose dudu si ao wa ma ro bi
amala tabi semo ti o ba ti darapo daadaa ao so kale ko tutu ao ma buwe ijo keji loti
bere si ni maa gba ise ati owo odaju ti aba wa lo gbogbo oseyi tan ona yio ti si fun wa
daadaa ao gbe koko naa lo si egbe ori atan ao so wipe ota to ndina mo emi lagbaja
omo lagbaja tio le pa mi laburu ona ti edi motisi o ti eba ko ti ekoba jawo mon foyin
male loni o eo tun gberi ma ao wa fo koko na male ao ma losi ile tara lai wo eyin.....
mo se ibaa ooo

You might also like