Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 11

Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo

Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Odù Ejì Òkò

Characters in each verse:


1 Elése ilé àti elése oko
2 Ẹlẹ́ni meré àti ẹlẹsi mẹkọ
3 Onítàké
4 Àkèrèngbè
5 Elése
6 Tẹ̀ là Òkò
7 Lapetun tíí ṣe yèyé àdán
8 Ẹ̀yẹ̀ lé
9 Iná àti èéfín
10 Elésèé àti Ajísọlá.

EJÌ ÒKÒ 1

Elégédé ni yìí gbirigbiri káko


Kí tẹ̀ tẹ̀ ó gbákẹsan wò
Kówó iṣẹ́ ti gbẹ́gi ń ṣe
A dífá fún elése ilé abù fún toko
Nígbàtí wọ́n ń fomi ojú sògbére ọmọ
Ẹbọ lawo kí wọ́n ó ṣe
Wọ́n sì gbẹ́bọ wọ́n rubọ
Wọ́n gbẹrù wọ́n tù
Njẹ́ Ajíṣọlà ọmọ lẹ́wà ẹni
Elése ọmọ lẹ́wà
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Translation:
Elegede ni yii gbirigbiri kako
Ki tete o gbakesan wo
Kowo ise ti gbẹgi n ṣe
Cast for both Elese at town and village
When they were crying of no children
The priest ask them to do ebo
And they comply
They start singing:
Ajisola children is beautiful human
Oko irese beautiful of human is child

Ẹbọ: two pigeon, two hens, two snails, palm oil, cold water and 20000
naira.

EJÌ ÒKÒ 2

Osì níí tà lósìlósì kọ̀ lù ara wọn


Adífá fún Ẹlẹ́ni meré
Abù fún Elésì mẹkọ
Ní ọjọ́ tíwọn fomi ojú sogbére ire gbogbo
Ẹbọ ni wọ́n kí wọ́n ó ṣe
Wọ́n sì gbẹ́bọ wọ́n rubọ
Wọ́n gbẹrù wọ́n tù
Njẹ́ báyé ṣe ń yẹ ẹlẹ́ni meré
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Bẹ́ẹ̀ni ni ń yẹ elésì mẹkọ


Ẹ̀yin ò mò pé orí ló dájà tó ò lè rùn

Translation:
Osi ni ta losilosi kolu ara won
Cast for Elenimere and elesimeko
When they are lacking all good things
They ask them to do the sacrifices
And they comply
Later all fortune come to Elenimere and Elesimeko
You cant see that only head can create market than can never perish

Ẹbọ: A lot of money, two cock, erankun, two pigeon, two cock, palm oil,
cold water and twnty two cowries.

EJÌ ÒKÒ 3

Takéké ń tàké awo ilé onítàké


Adífá fún onítàké a rìn pagi dà sógi dọ̀ tọ́tọ́ ènìyàn
Lọ́jọ́ tó ń fomi ojú sogbére ire ajé
Èyí tí ó mọ̀ dobalẹ̀ gbọ́rọ́ gbọ̀ rọ̀ gbọrọ fúngi
Njẹ́ kín ló so onítàké dolówó?
Ẹdun, Ẹdun òrìṣà méjì ọ̀ rọ̀
Ẹdun
Kín ló ṣe onítàké tó fi níre gbogbo?
Ẹdun, Ẹdun òrìṣà méjì ọrọ̀ , Ẹdun
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Translation:
Takeke n take the priest of onitake
Cast for onitake who turn wood to human being
When he cry for good fortune
Which we always prostrate for wood
So who make onitake to be rich?
Edun, the identical twins
Who make onitake to have all good fortune?
Edun, the identical twins

Ẹbọ: Two hens, one goat, cola nut, 2000 naira, 22 pigeons, beans, gin.
Offer to Ibeji.

EJÌ ÒKÒ 4

Balẹ̀ lẹ̀ balẹ̀ igi oko apá késekése


A kò pẹ́ ẹ̀ lùjì ekiyèsígbà
Adífá fún àkèrèngbè
Tíí ń sunkún aláìlẹ́nìkan
Ẹbọ lawo ní kó ṣe
O sì gbẹ́bọ níbẹ̀ ó rubọ
Ó gbẹrù ó tù
Njẹ́ ọmọ kékeré ìlú
Ti tani ẹ̀ yin ó ṣe?
Takèrèngbè, takèrèngbè la ó ṣe
Àgbàlagbà ìlú
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Ti ta lẹ̀ yin ó ṣe?


Takèrèngbè, takèrèngbè làwa ó ṣe.

Translation:
Balele bale igi oko apa kesekese
Akope eluju ekiyesigba
Divine for gourd who cry for lonely
The priest ask him to do the sacrifice and he comply
So the children of town
Whom you are support?
Its gourd we are support.
The elders of town
Whom you are support?
Its gourd we are support

Ẹbọ: akerengbe kan, two pigeons, two hens, palm oil, cold water,
cold pap, a lot of money, black cloth. To offer all the things to Egbe.

EJÌ ÒKÒ 5

Sinkin sinkin laa sin wo orí


Jìngbìnnì jingbini laa tẹ̀ pá ilẹ̀ kẹ̀
Adífá fún elése tí wọn ní kó fẹbọ ẹwa sílẹ̀
ẹbọ ọmọ ni kó máa ṣe
Ẹbọ lawo ní kó ṣe
Ó sì gbẹbọ ó rubọ
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Ó gberù ó tù
Njẹ́ elése ọmọ lẹ́wà ẹni
Oko ìrèsé ọmọ lẹ́wà ẹni

Translation:
Sinkin sinkin laa sin wo ori
Jingbinni jingbinni laa tepa ileke
Divine for elese who told to leave beauty sacrifice
And do children sacrifice
She comply
So Elese, children is human beauty
Oko irese, the beauty of human is the child

Ẹbọ: jewelry, two pidgeons, two hens, face powder, cold water,
palm oil, 2000 naira in both hands. The person must offer to ibeji.

EJÌ ÒKÒ 6

Temi tiṣẹ toun tiṣe


Mo jinwó lóko
Mo jamu ilẹ̀ kẹ̀ lọ́jà
A dífá fún tẹla oko tó ń lọ oko lọ ọ là
Ẹbọ lawo ní kó ṣe
Ó sì gbẹ́bọ ó rúbọ
Ó gberù ó tù
Njẹ́ temi tiṣẹ toun tiṣẹ
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Mo jinwó lóko
Mo jamu ilẹ̀ kẹ̀ lọ́jà
Mo jinwó lóko

Translation:
Temitise tountise
Mo jinwo loko
Mo jamu ileke loja
Cast for Tela oko
When he went to farm for good fortune
He was asked to to Ebo
He did and it was accepted.

Ẹbọ: Orogbo to po, two cocks, two ducks, apo asunhan N22000,
palm oil, water, hoes, rag clothes, cowries.

EJÌ ÒKÒ 7

In ti ba n dun ni
A mo pe in dun ni
In ti ba dun eeyan
A mo pe n dun eeyan
Oro dunni dunni
Larankan eni
A dífá fún Lapetun tíí ṣe yèyé àdán
Lọ́jọ́ tó ń fomi ojú sógbere ọmọ
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Ẹ bọ lawo ní kó ṣe
O sì gbẹ́bọ ó rubọ
O gberu o tù
Njẹ́ aromodomo n tàdán
Ẹnìkan kìí rágàn àdán
Aromodomo ni tàdán

Translation:
In ti ba n dun ni
A mo pe in dun ni
In ti ba dun eeyan
A mo pe n dun eeyan
Oro dunni dunni
Larankan eni
Divine for Lapetun, the bat mother
When she was crying for being barren
The priest asks her to do ebo and she comply
So the generation of bat cant disapear
No one can see bat barren generation
Of generation is the bat

Ẹbọ: A lot of money, palm oil, egberun meji meji lona meji lona
meji lona mejilelogun, adan meji, pap and corn.

EJÌ ÒKÒ 8
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Orí tí ó gbeni
Ẹkùn ni dá pani
Adífá fún ẹ̀ yẹ̀ lé
Tí ń fomi ojú sunkún alairibi
Òun fara gbaawe airipon sẹ́yìn
Ẹbọ lawo ni kó ṣe
Ó sì gbẹ́bọ ó rubọ
Ó gberù ó tù
Ẹbọ rẹ̀ ló dàdà jù
Njẹ́ méjì méjì lẹ̀ yẹ̀ lé bí
ẹ̀ yẹ̀ lé kìí bíkan ṣoṣo
Méjì méjì lẹ̀ yẹ̀ lé bí

Translation:
Orí tí ó gbeni
Ẹkùn ni dá pani
Divine for pigeon
When she was crying because of unborn babies
And no one to carry on her back
The priest ask her to do the sacrifice
And she complied. Her sacrifice was totally accepted
So the pigeon cant born a single child
But always twins

Ẹbọ: A lot of money, beans, ground but, cola, bitter cola, calm wood,
two pieces of clothes, two hens, two cocks, ekuru, akara, moinmoin.
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

EJÌ ÒKÒ 9

Ewé ni ń bẹ lórí iṣu


La n bowo kan-in kan-in
A dífá fún iná abù fún èéfín
Lọ́jọ́ wọ́n ń sunkún arayegbe
Ẹbọ lawo ni kí wọ́n ó ṣe
Èéfín nìkan ló ń bẹ̀ lẹ́yìn tó ṣebọ
Njẹ́ bíná bá kú èéfín a sì dàgbà sókè

Translation:
Ewé ni ń bẹ lórí iṣu
La n bowo kan-in kan-in
Divine for fire and smoke
When they are fight for last longer
The priest asked them to do ebo
But only smoke comply to do ebo
So when fire die, smoke will be higher

Ẹbọ: Eeru, omi tutu, apo meji lona mejilelogun, eyele kan, akukọ
kan, abodiẹ kan ogunna kan.

EJÌ ÒKÒ 10
Compilation made by Ibuowo Sangodiran Adebayo
Ile Ase Olukoso Temple (+234 810 763 4033)

Akiriboto níí lójú awẹ


Ẹ̀là ilẹ̀ kẹ̀ ni ó lójú àtókùn bọ̀
A dífá fún elésèé òun ajísọlá
Ojú ọmọ ló ń pọ́n wọn
Ẹbọ lawo ní kí wọ́n ó ṣe
Wọ́n sì gbẹ́bọ níbẹ̀ wọ́n rubọ
Atùbọ ni wọ́n ní kí wọ́n máa ṣe lọ ìdí Èṣù
Akiriboto o lójú awẹ
Ẹ̀là ilẹ̀ kẹ̀ o lójú àtókùn bọ̀
Ẹbọ wọ́n sì dà ni wọ́n bá di ọlọ́mọ wẹ́ẹŕ ẹ́

Translation:
Akiriboto níí lójú awẹ
Ẹ̀là ilẹ̀ kẹ̀ ni ó lójú àtókùn bọ̀
Made divination for Elese and Ajisola
When they were lacking children
The pries ask them to do sacrifice and they comply
And the priest ask them to say:
“Akiriboto níí lójú awẹ
Ẹ̀là ilẹ̀ kẹ̀ ni ó lójú àtókùn bọ̀ ”
When they carry the sacrifice to Esu
They did it
After that, they were blessedwith many children

Ẹbọ: Ẹ̀là ilẹ̀ kẹ̀ , obì lakiriboto, 22000 Naira, eyele meji, akuko meji,
agbebo meji, epo pupa, igo meji, omi tutu, erankun. Offer to Ibeji.

You might also like