Speak Woe

You might also like

Download as pdf
Download as pdf
You are on page 1of 2
ORI OKE INA ATI ISE IYANU Olu lle Ise Iranse, Ipinle Eko, Nigeria. sORO EGBE Sf AWON 1SORO OLOIO PIPE \jéwo Bibéli: Orin Dafidi 2; Orin Dafidi 17; Orin Dafidi 35 Orin lyin K6k6 Adura 1. Qlorun dide, run agbara awon aléni-ma-déyin oldrikunkun si wéwé bi ikokd amd, ni orkoJést 2. Awonisoro itaktn elésé gigiin ninu ayé mi, kt nipa ina, niortiko Jésu 3. Isoro yodwii td kd lati jé kin lo, segbé nipa ind, nforuko Jésu. 4 ]wo aléni-ma-déyin oldrikunkun ilé baba mi, émi ki {se lje re, Iépa ara re, kosi kU, nf orukoJésu 5. Olérun, dide ninu irunu agbara Re, jé ki dpd-éyin aléni-ma-déyin oldrikunkun ati ti okiinrin alagbara f6, nioruko Jésu. 6. Okunrin alagbara irandiran, to n jé kiisoro ma ruwé pada ninu ayé mi, mo gbéo sin lonii, nioruko Jésu. 7. Nipa agbara to so kd pa ori Gdliati, jé ki awon isoro oldrikunikun mi ku loni, nforuko Jést. 8. — Awon okinrin aldgbara towa nidi gbogbo isoro oldrikunkun ninu ila idilé mi, ku, niortkoJést 9. Gbogbo oktinrin alagbara towa nidi awon isoro oldrikunkun ninu ayé mi, ku, nioruko Jésu 10. Nipa agbara to jé ki Far: é ki gbogbo isoro oldrikunkun mi kU, ni oruko Jés. 11. Oldrun, dide, jé ki dye awon aléni-ma-déyin oldrikunkun mi paré dant, ni oruko Jésu. 12. Mo pase ki awon irawd ninu ipa won, kd ba gbogbo ota ayanmd olérikunkun mija, nf ortiko Jést 13. Mo mu éjé Jésti wa sori aléni-ma-déyin oldrikunkun ti kd fé jé kin lo, ni ortko Jésu. 14. Eyin dngéli Oldrun Alayé, e lépa gbogbo aléni-ma-déyin oldrikunkun ti (ménubaisoro naa), ni oruko Jésu. Mountain of Fire and Miracles Ministries International Headquarters, Lagos, Nigeria PRAYER POINTS SPEAK WOE UNTO LONG-TERM PROBLEMS Bible Confession: Psalms 2; Psalm 17; Psalm 35 Praise Worship Prayer Points 1. 10. aa. 12. 13, 14 God, arise and dash the power of stubborn pursuers in pieces like a potter's vessel, in the name of Jesus. Problems with long legs in my life die by fire, in the name of Jesus. Any problem that has refused to let me go, perish by fire, in the name of Jesus You stubborn pursuers of my father’s house, | am not your victim, pursue yourselves and die, in the name of Jesus. © God, arise in the wrath of Your power and let every backbone of stubborn pursuer and strongman break, in the name of Jesus. Ancestral strongman, renewing any problem in my life, | bury you today, in the name of Jesus By the power that stoned the head of Goliath, let my stubborn problems die today, in the name of Jesus. Strongmen behind stubborn problems in my family line, die, in Jesus’ name. Every strongman, behind stubborn problemsin my life, die, inthe name of Jesus. By the power that sank Pharaoh, let my stubborn problems, die, in Jesus’ name. OGod, arise and let understanding of my stubborn pursuers be wiped out, in the name of Jesus | command the stars in their courses to fight against my every stubborn pursuer of my destiny, in the name of Jesus. | bring the blood of Jesus over the stubborn pursuer that does not want me to go, in the name of Jesus. Angels of the living God, pursue the stubborn pursuers of my (mention the case), in the name of Jesus.

You might also like