Professional Documents
Culture Documents
434.a&o. Awon Ikilo
434.a&o. Awon Ikilo
AWN IKIL
Heberu 3:7-19; 4:1-13
K 434 -- FUN AGBA
AKSORI: “Nitori r lrun y, o si li agbara, o si m j
idak’ida oloju meji l, o si ngnni ani titi de pipn kn ati
m niya, ati orike ati r inu egungun, on si ni olum ero inu
ati te kn” (Heberu 4:12).
Heberu 3:7-19;
7Nitorina gẹgẹbi Ẹmí Mimọ́ ti wi, Loni bi ẹnyin bá gbọ́ ohùn rẹ̀,
8Ẹ máṣe sé ọkàn nyin le, bi igba imunibinu, bi li ọjọ idanwò li aginjù:
9Nibiti awọn baba nyin dán mi wò, nipa wiwadi mi, ti nwọn si ri iṣẹ mi li ogoji ọdún.
10Nitorina inu mi bajẹ si iran na, mo si wipe, Nigbagbogbo ni nwọn nṣìna li ọkàn wọn;
nwọn kò si mọ̀ ọ̀na mi.
11Bi mo ti bura ni ibinu mi, nwọn ki yio wọ̀ inu isimi mi.
12Ẹ kiyesara, ará, ki ọkàn buburu ti aigbagbọ́ ki o máṣe wà ninu ẹnikẹni nyin, ni lilọ
kuro lọdọ Ọlọrun alãye.
13Ṣugbọn ẹ mã gbà ara nyin niyanju li ojojumọ́, niwọn igbati a ba npè e ni Oni, ki a má
bã sé ọkàn ẹnikẹni ninu nyin le nipa ẹ̀tan ẹ̀ṣẹ.
14Nitori awa di alabapín pẹlu Kristi, bi awa ba dì ipilẹṣẹ igbẹkẹle wa mu ṣinṣin titi de
opin;
15Nigbati a nwipe, Loni bi ẹnyin bá gbọ́ ohùn rẹ̀, ẹ máṣe sé ọkàn nyin le, bi igba
imunibinu.
16Nitori awọn tani bi nyin ninu nigbati nwọn gbọ́? Ki ha iṣe gbogbo awọn ti o ti ipasẹ
Mose jade lati Egipti wá?
17Awọn tali o si binu si fun ogoji ọdún? Ki ha iṣe si awọn ti o dẹṣẹ, okú awọn ti o sun
li aginjù?
18Awọn tali o si bura fun pe nwọn kì yio wọ̀ inu isimi on, bikoṣe fun awọn ti kò
gbọran?
19Awa si ri pe nwọn kò le wọ̀ inu rẹ̀ nitori aigbagbọ́..
Heberu 4:1-13
1NITORINA, ẹ jẹ ki a bẹ̀ru, bi a ti fi ileri ati wọ̀ inu isimi rẹ̀ silẹ fun wa, ki ẹnikẹni ninu
nyin ki o má bã dabi ẹnipe o ti kùna rẹ̀.
2Nitoripe a ti wasu ihinrere fun wa gẹgẹ bi fun awọn na, ṣugbọn ọ̀rọ ti nwọn gbọ́ kò ṣe
wọn ni ire, nitoriti kò dàpọ mọ́ igbagbọ́ ninu awọn ti o gbọ́ ọ.
3Nitoripe awa ti o ti gbagbọ́ wọ̀ inu isimi gẹgẹ bi o ti wi, Bi mo ti bura ninu ibinu mi,
nwọn ki yio wọ̀ inu isimi mi: bi o tilẹ ti ṣe pe a ti pari iṣẹ wọnni lati ipilẹ aiye.
4Nitori o ti sọ nibikan niti ọjọ keje bayi pe, Ọlọrun si simi ni ijọ keje kuro ninu iṣẹ rẹ̀
gbogbo.
5Ati nihinyi ẹ̀wẹ pe, Nwọn ki yio wọ̀ inu isimi mi.
6Nitorina bi o ti jẹ pe, o kù ki awọn kan wọ̀ inu rẹ̀, ati awọn ti a ti wasu ihinrere nã fun
niṣãju kò wọ inu rẹ̀ nitori aigbọran:
7Ẹ̀wẹ, o yan ọjọ kan, o wi ninu Iwe Dafidi pe, Loni, lẹhin igba pipẹ bẹ;̃ bi a ti wi niṣãju,
Loni bi ẹnyin ba gbọ́ ohùn rẹ̀, ẹ máṣe sé ọkàn nyin le.
8Nitori ibaṣepe Joṣua ti fun wọn ni isimi, on kì ba ti sọrọ nipa ọjọ miran lẹhinna.
9Nitorina isimi kan kù fun awọn enia Ọlọrun.
10Nitoripe ẹniti o ba bọ́ sinu isimi rẹ̀, on pẹlu simi kuro ninu iṣẹ tirẹ̀, gẹgẹ bi Ọlọrun ti
simi kuro ni tirẹ̀.
11Nitorina ẹ jẹ ki a mura giri lati wọ̀ inu isimi na, ki ẹnikẹni ki o má ba ṣubu nipa apẹrẹ
aigbagbọ́ kanna.
12Nitori ọ̀rọ Ọlọrun yè, o si li agbara, o si mú jù idàkídà oloju meji lọ, o si ngúnni ani
tìti de pipín ọkàn ati ẹmí niya, ati oríke ati ọrá inu egungun, on si ni olumọ̀ erò inu ati
ète ọkàn.
13Kò si si ẹda kan ti kò farahan niwaju rẹ̀, ṣugbọn ohun gbogbo ni o wà nihoho ti a si
ṣipaya fun oju rẹ̀ ẹniti awa ni iba lo.
Kikun Israli
A ti m nipa kikun awn m Israli laaarin irin-ajo wn ni aginju. It wn
ekinni fara hn ni eti Okun Pupa nibi ti wn ti wi fun Mose pe “Nitoriti is k si ni
Egipti, ki iw e m wa w lati k ni ij?” (ksodu 14:11). Bayii ni wn wi fun
Mose, ugbn lrun gb. Sib lrun mu wn la Okun Pupa j plu w agbara.
Eyi j kan ninu awn iriri ti o yanilnu ni Israli, eyi ti Paulu, Onipsalmu ati
awn wolii k si kan ninu awn igbala nla ninu itan igbesi-ay wn. ugbn wn
fr ma i ti kuro ni agbegbe ibi ti i-iyanu nla yii ti lrun e lati m wn kja lori
il gbigb gb l nigba ti wn de aal ti wn si br si kn nitori ounj.
lrun e i-iyanu miiran ni akoko naa. O rn manna si wn lati run w, eyi ti
o n b sil fun wn ni ojoojum fun ogoji dun. Itju lrun lori wn ni pipese
manna fun wn ko dkun titi awn m Israli fi kja odo Jrdani ti wn si de Il-
Ileri, nibi ti wn ti j ounj il naa. Nipa bayii i-iyanu nla meji ni lrun e, ekeji j
i-iyanu ojoojum eyi ti o rn wn leti itju lrun lori wn nigbakuugba ati ipese
iyanu R fun wn.
Ni gr lyin eyi, wn de aarin aal nibi ti omi k si, lkan sii wn tn kn,
Oluwa si tun rn wn lw. O pa fun Mose lati sr si apata, omi si t jade . Lyin
naa ni wn de Oke Sinai; bi Mose si ti w ni ori Oke Sinai fun ogoji j wn wi pe
“Dide, d oria fun wa, ti yio ma aju wa l; bi o e ti Mose yi ni, kunrin ni ti o m
wa goke lati il Egipti w, awa k m ohun ti o e e” (ksodu 32:1).
“ugbn plp wn ni inu lrun k dn si: nitoripe a b wn ubu li
aginj.
“Nkan wnyi si jasi apr fun awa….. ”(1 Krinti 10:5, 6).
Awn ti o k iwe Majmu Titun n lo il wnyii; wn si n tka si aeyri ati
awn ikuna awn eniyan lrun wnyii gg bi ikil, apr ati ikil nipa ti mi fun
iw ati fun emi lj oni.
Ifasyin
“ kiyesara, ar, ki kn buburu ti aigbagb ki o me w ninu nikni nyin,
ni lil kuro ld lrun alye” (Heberu 3:12).
Lati inu “ilkuro” ld lrun ni “ilkuro ninu igbagb” ati “íyapa” ti w. Itum
r ni ifasyin kuro ld lrun to b ti ko si ayipada tabi atune, jijingiri sinu .
Nigba ti eniyan ba w ninu ipo yii o ti di ni ti iy r ra. r lrun k wa pe o e e
fun awn wnni ti o ti w ninu iml ti o si ti m otit r lrun lkan ri, lati ubu
si iru ipo yii.
A ni aksil nipa r yii ti kunrin olufkansin kan ti o w nigba ay Wesley k
sil, eyi ti mo f k seti igb yin.
“Awn r wnyii (ti o br lati s keje titi de ipari) tnum n gidigidi, gg bi
gbogbo Episteli naa ti tnum n bi o ti e e e lati ubu kuro ninu oore-f lrun ki
a si egbe titi ayeraye. Lai si itum yii, gbogbo awn r wnyii ati awn b b ti o
j m n, ti o ju idameji ninu mta ifihan lrun, ki yoo ni itum tabi gbn ninu.
r itmblu tabi ilana asn meloomeloo ni awn eniyan ko ti l tn lati fi tako r
lrun. Awn Angli ubu, Adamu ubu, Slomni ubu, plp awn Onigbagb
si ti ubu plu; ati gg bi a ti m, wn k dide m. Sib a n s fun wa pe a ko le s
anfaani iyipada kn wa n patapata. Iwaasu Satani ni eyi fun awn obi wa iaaju;
wn gba a gb, wn d, wn si ubu, wn si m iparun b gbogbo agbaye”.
Ko si pisteli miiran ti o s ni pato ju iwe Heberu pe ko si ohun ti o n j aabo
ayeraye eyi ti k duro lori adehun.
Isimi
Nisisiyii wo s kkanla:
“Bi mo ti bura ninu ibinu mi, wn ki yio w inu isimi mi.”
“Isimi” nihin n tka si il Kenaani. Eyi ko tum si pe wn ki yoo i nigba ti
wn ba de il Kenaani. Wn ni awn ilu lati gb, ugbn lyin ogun jija wn, wn o j
igbadun alaafia ati ibukun il Kenaani. Wn ni gba-ajara ti wn k gbin, igbo olifi ti
wn k i fun. Awn ilu ti wn ko k yoo j ti wn. Iru isimi yii ni lrun e ileri
fun wn ni il Kenaani.
Isimi inu ay kan w ti a fi e apr isimi ti run ti lrun ti pese sil fun awn
m R. Koko ti ni ti o k iwe yii n e aaro lori r nihin ni eyi. Emi ko gbagb pe
isimi wa run yoo j isimi alaini bi ko e iru isinmi ti o j ti awn m Israli ni il
Kenaani. Mo ni igbagb pe a o i ni Ilu Daradara ni ti lrun ti eleri fun awn
eniyan R. Iru i ti yoo j ni awa k m. ugbn ohun kan wa nipa r, awa yoo ni
ara: ara kiku yii ni a o yipada si iru ara ologo ti Oluwa ati Olugbala wa. Ara iyara wa
ki yoo le farada ipalarada ay il ni. Awa yoo j igbadun awn ibukun r gg bi ati
m Israli w si il ileri lati j igbadun awn ibukun wnni.
Awn ibukun wnni tay ohun ti m eniyan le iro. Paulu s fun wa pe, “Ohun
ti oju k ri, ati ti et k gb, ti k si w kn enia l, ohun wnni ti lrun ti pse sil
fun awn ti o f ” (l Krinti 2:9).
Johannu, nigba ti o w ni Erekuu Patmo, ri firi wn o si oro fun un lati ri ede
m eniyan ti oun yoo l lati fi e apejuwe awn ohun ti o ri lna ti wn yoo gba y
m eniyan, awn ibukun wnni tobi lplp.
Lati Kuna
Awn m Israli ti o egbe fi w ara wn tilkn awn ibukun wnni m ara
wn sode. O e e fun wn lati wle, ugbn nigba ti wn de eti il naa, ti wn ti wn
si ri awn ioro ati awn ohun idalwk ti o doju k wn, iwn iba igbagb di ti
wn ni kuna; wn ko tun le ri nin w Jehofa alagbara. Gbogbo ohun ti wn le ri ni
awn omiran, awn ilu olodi giga -- awn ohun idiw ti ko le j ki wn w il naa.
Wn gbagbe awn i iyanu ti lrun ti e, abayrisi r ni pe a d wn pada si
aginju nibi ti wn ti ako fun dun mejidinlogoji. Oluwa bura pe wn ki yoo w inu
r. Pe oku wn sun ni aginju ki i e idaj ailt ti Oluwa rn sori wn; o j ohun ti ko
le ai de ba wn fun ohun ti wn yn.
“Nitori awa di alabapin plu Kristi, bi awa ba di ipil igbkle wa mu
insin titi de opin” (Heberu 3:14).
e akiyesi awn ohun ti yoo gb lati wle. Ki i e gbogbo ni ti o br ire ije naa
ni o pari r. Ohun ti o e pataki ju ni lati pari ire-ije naa, nigba naa gbogbo eniyan yoo
m pe o ti br r.
Itum “igbkle” ni ipil. Ko si ewu pe Ipil naa yoo y; Ipil naa daju.
“Nitori ipil miran ni nikan k le fi lel j eyiti a ti fi lel l, ti ie Jesu Kristi” (l
Krinti 3:11). A n duro lori Ipil naa nipa iriri ti awa ni nipas R. Ipil yii ko le y
b ni ki yoo di alailagbara; o lagbara ju gbogbo awn oke ayeraye. ugbn ewu wa
lati y kuro lori ipil wa. Pup ni o ti y kuro.
“Nigbati a nwipe, Loni….”
“Loni” j akoko isisiyii. w fun awn m Israli ni j ti Onipsalmu k iwe
r; w fun awn Heberu Onigbagb ni akoko ti Paulu k iwe r; w fun iw ati
fun emi ni akoko ti awa w laaye. Oluwa fiyesi “oni” lati j de j ninu gbogbo r
R. Ohun kan naa ni Paulu n tka si nigba ti o wa pe “Nisisiyi ni j igbala”.
“Awn tali o si bura fun pe nwn ki yio w inu isimi on, bikoe fun
awn ti k gbran?” (Heberu 3:18).
Aigbagb ni o pil gbogbo iynu ti o de ba awn m Israli ni aginju. Aigbagb
yii kan naa ni o pil gbogbo wahala ti wa ninu ay. Aigbagb br ninu gba Edni
nigba ti Eu wi fun awn baba wa iaaju pe, “t li lrun wipe?” ti o si fi ibeere ni
sinu kn wn; o si ti j ibeere ninu kn gbogbo ti ko ti i ni idande lati igba ni titi di
j oni yii. Gbogbo wa ni a ti jogun da awn baba wa iaaju. Lati ib ni gbogbo ,
egbe ati aiedeedee ti gbogbo ay ti jogun r ti br. Aigbagb!
“Nitorina, j ki a bru, bi a ti fi ileri ati w inu isimi r sil fun wa, ki
nikni ninu nyin ki o m b dabi nipe o ti kna r” (Heberu 4:1).
Awn r “ti kuna” j eyi ti a m jade lati inu awn er kan ti wn n e ni ilu
Griki. A n lo gbolohun yii nigba ti ni kan ba kuna lati bori ninu er naa. A o y ni
ti o ba sa ti le kuna di kuro bi o ti le w ki ijatil r ti kere t; oun ki i e ni ti o bori.
ni ti o k iwe yii mu r yii l nitori o m pe ohun ti eniyan ni i e ni pe ki o saa
kuna – boya ikuna di kinun – lati d opin ire ije, oun a si di ni ti o kuna.
Awn Ohun ti o N Fa Ikuna
“Nitoripe a ti wasu ihinrere fun wa gg bi fun awn na, ugbn r ti
nwn gb k e nwn ni ire, nitoriti k dap m igbagb ninu awn ti gb
” (Heberu 4:2).
“Dap m” j r ti a m jade lati inu ool ounj ninu eniyan. Gg bi a ti i mu
ounj l sinu ool ounj ti o si n dap m awn ohun wnni ti n sun jade lati inu ara ki
o to le w inu j, bakan naa ni r lrun ni lati dap daradara ki a to gb e m, ki o
si di mi wa. r yii kun fun ero lplp.
Nihin a ri ohun ti o gbd l bi a ba f ki r lrun ti a n gb ki o e wa ni ire.
Wo iru iyat ti o le w laaarin awn eniyan ti o n gb r yii kan naa!
Awn orii eniyan mrin ni a mnu b ninu owe afunrugbin. Irugbin kan naa ni a
fn si ibi mrrin -- k si si aleebu kan ninu irugbin naa; b ni k si abuku kan ninu
r naa. Ninu gbigb r yii ni abuku w. Fun awn kan, k e wn ni ire rara, fun
awn kan o e wn ni ire di, ugbn laip o parun. Fun awn miiran o e wn loore
ju ti awn iaaju, ugbn nitori aniyan ati igbadun ay yii a fn wn pa. krin ni il
rere ti o m ere w, awn kan gbgbn, awn kan gtta ati awn kan
grrun.
Bayi ni o n ri ni gbogbo itan igbesi-ay eniyan. r naa n e awn kan ni ire, b
ni r naa ko si e awn miiran ni ire. Ki ni iyat? Nitori ko dap to -- gg bi o ti ri
fun awn m Israli wnni ni aginju. Ounj mi ti wn j k d. r ti wn gb ni
gbogbo ohun ti o e pataki lati fun ni lokun. O ni gbogbo ohun ti n mu ki eniyan
dagba ti o y ki ounj ni. K si ohun ti o dinku. Pip ni r lrun.
Ko si ohun kan ti o le l ninu igbesi-aye eniyan ti ko ni ri ohun ti o le fi e
odiwn r ninu r lrun. kan ninu awn anfaani nla ti a ni ni eyi ninu kika Iwe
Majmu Laelae: gbogbo ohun ti awn m Israli la kja ni o ni ibamu ninu iriri
Onigbagb. Bi o til j pe nnkan wnni ti a k sinu Majmu Laelae n s nipa ti nnkan
ay yii; ugbn fun Onigbagb, o gba pe ki a ni iduroinin iru kan naa, igbagb kan
naa, imkanle bakan naa ati ipinnu kan naa lati de opin ire ije gg bi iru eyi ti o gba
awn m Israli lati w Il Kenaani; ati ti wn fi gba a patapata.
Awa plu ni ogun lati j ati il lati gb. Lati e aeyri, yoo gba ki emi ati iw ni
iru iwa-rere ti a n f ni igbesi-ay awn m Israli. Idi r ni yii ti a fi ri ohun ti o j
ara wn ni iriri wn ati igbesi-ay awn Onigbagb. r lrun fun wa ni gbogbo
apr, ilana, a, igbaniniyanju, ikinilaya ati imisi ti awn Onigbagb n f.
A gbd ni awn oye ati im ti o ju gbn-ori wa l; a gbd ni agbara ti o tay
agbara im-ori wa bi a ba f j anfaani ti o w ninu r lrun. Kika r lrun
nigba miiran ko ju ohun ti a fi oye gbn ori m fun awn lomiran. Anfaani di ni
eyi mu wa – bi idaraya nipa ti ara; ugbn lrun ni idaraya ti o sn ju yii l fun wa.
lrun f idaraya nipa ti mi fun wa ki i e idaraya nipa ti gbn-ori lasan. Oun n f
ki r yii ki o w inu wa jinl ju bi a ti le fi oye-ori wa m l. lrun f ki a lo
gbogbo oye, im ati gbn wa to b ti r naa yoo di mi wa, ki a ba le dagba ninu
igbagb mim yii ani ki a di kunrin alagbara ninu Kristi.
Im Onigbagb
Ohun ti a gbd fi po o p ni igbagb. kn ti ara, eyi ti a ko i ti tun d, ko le gba
ohun ti lrun nitori ohun ti mi ni a fi n wadii wn. Nigba ti a ba tn wa bi a ni
gbn kan ti o tay, eyi ti mi lrun alaaye n gbin sinu kn wa – ati nipa r ni
igbagb ti n w. Ki i e ti awa tikara wa, bun lrun ni; nitori naa lati oke ni o ti n
w. Ohun ti a ni lati e ni pe ki a rn ni gbogbo ilana ti lrun fi lel. Nigba naa
lrun yoo e eyi ti o k. Oun ni yoo fi gbn naa fun wa.
Onigbagb a maa ni ohun ti a le pe ni gbn kfa ti lrun n fi fun un. A le e
iwadi awn ohun ay yii nipa gbn da ti a ti fun wa, a ni iriran, igbran, itwo,
igboorun, ati ifwba; ugbn nigba ti o ba di awn nnkan ti lrun n naw si aye ibi
ti awn gbn wa maraarun-un ko le de. Wn ko le is nib. Otit ni r yii pe, nipa
oju wa, awa n ka r lrun; ugbn awn nnkankan wa nisal awn r ti a t sinu
iwe wnni ti a ni lati di mu. Nitori eyi, yoo gba ki a ni gbn kfa ti Oluwa n fi fun
wa.
O j ohun iyanu bi Oluwa ti n e wa y lati moye ati lati j r yii, ti o n di
egungun ninu egungun wa ati ran ara ninu ran ara wa. Ohun ti Jesu n s ni eyi nigba
ti o wi bayii pe, “Lt, lt ni mo wi fun nyin, Bikoepe nyin ba j ara m-enia, ki
nyin si mu j r, nyin k ni iye ninu nyin” (Johannu 6:53). Lai p sii O tum r
yii ni kikn nigba ti O wi bayii pe, “Ara k ni re kan; r wnni ti mo s fun nyin,
mi ni, iye si ni.”
Otit yii ni o fara han ninu Majmu Laelae ninu d -agutan ti a pa. Awn m
Israli gbd j gbogbo d agutan naa; wn ni lati j kunna ki wn si gbe e mi ki o
ba le di egungun ninu egungun wn ati ran ninu ran ara wn. r lrun ni d-
Agutan yii. Bakan naa ni r naa n di egungun ninu egungun wa ati ran ara ninu
ran ara wa. Bi r yii ti maa e wa ni anfaani to duro le bi igbagb wa ti t.
Nnkan miiran ti o tun e pataki ni eyi pe: “Nipa gbigb ni igbagb ti iw, ati
gbigb nipa r lrun” (Romu 10:17). Gg bi ororo ool ti n ti inu ounj ti a j w
inu wa, ti a si n lo ororo wnyii fun lil iyoku ounj ti awa n j sinu, bakan naa ni r
lrun ti o n w inu wa n di igbagb ninu wa ti o si n ran wa lw lati s r naa di
ara wa. Awn mejeeji ni o n i pap. Bi a ba e gba r lrun to b ni igbagb ti
a oo ni yoo ti p t; bi igbagb ti a ni ba ti p t b gg ni a o e le gba r yii sinu
wa to ti yoo si di ara fun wa.
Isinmi Ni is-n-tl
“Nitoripe awa ti o ti gbagb w inu isimi gg bi o ti wi, bi mo ti bura ninu
ibinu mi, nwn ki yio w inu isimi mi: bi o til ti e pe a ti pari i wnni lati
ipil aiye” (Heberu 4:3).
O le e akiyesi pe “w” j ohun isisiyii. Awa brsi w isinmi wa ni gr ti
iyipada ba ti l ninu wa; isinmi ni ti awa n ni iriri r j itwo tabi ifkansi ohun ini
wa. Nitori naa nigba gbogbo ni a isinmi yii ugbn a ki yoo w inu isinmi naa ni
kikn titi di j naa ti Oluwa yoo de lati gba awn ayanf R.
Igbala j is-n-tle ti o n t siwaju ti o si n gbooro si i titi awa yoo fi de pipe im
ti lrun f ki a ni.
“Nitori o ti s nibikan niti j keje bayi pe, lrun si simi ni ij keje
kuro ninu i r gbogbo” (Heberu 4:4).
Nihin Iwe Heberu n s nipa iru isimi iaaju, isinmi ti lrun ni lyin ti O pari i
did ay. Lori iru isinmi yii ni a gbe gbogbo eto j-isimi lrun fun gbogbo oril-
de Israli le. Wn n ni isinmi jj isinmi; wn n ni isinmi awn s ti a yipada si
Pnteksti. Wn n ni isinmi ooou ni ou meje meje, eyi ti i e ti Aj Ag. Wn n
ni isinmi ti awn dun: dun keje-keje ni dun isinmi ninu eyi ti il yoo gba isinmi, ti
a o e atunro gbese, ati ninu eyi ti awn iran le l lf kuro ld oluwa wn bi wn
ba f. Isinmi dun meje igba meje w – eyi ni pe ni araadta dun ni dun Jubeli.
Gbogbo eto isinmi yii ni a e ni apr isinmi iaaju ti a fifun ni ninu Gnsisi ni
akoko dida ay; ati nitori eyi a ni t lati wi pe Isinmi ti gbrun dun yoo w.
O dabi ni pe iiro gbrun dun, eyi ti a s ninu Iwe Mim pe, o dabi j kan ni
lrun fi n e i R. A w ni akoko ikyin gbrun j kfa, ni bi gbaata dun.
Eredi r ni yii ti awa fi gbagb pe awa n sn m igba gbrun dun nla ni ti yoo d
b ay yii.
“Nitorina isimi kan k fun awn enia lrun.”
A le e akiyesi pe “isimi” ti o n tka si nihin yat si eyi ti a n sr nipa r ninu k
yii lati yin w. Isinmi ti o n tka si ni il Kenaani ti o dabi eyi ti eniyan maa n ni
nigba ti o ba sinmi kuro ninu gbogbo i r. ugbn r yii tum si j-isinmi kan. O
ti e apr isinmi iaaju, eyi ti lrun fi idi r mul ni ateteke. ugbn nihin o n s
nipa isinmi nitori o j eyi ti o larinrin ti o si ga j, ati ti o si tobi ju gbogbo isinmi ti
wn ni ni il Kenaani. Eyi j isinmi ayeraye; isinmi yii w fun awn eniyan lrun.
Isinmi ti Dida Ay Titun
“Nitoripe niti o ba b sinu isimi r, on plu simi kuro ninu ie tir gg
bi lrun ti simi kuro ni tir” (Heberu 4:10).
Eyi w, lai si aniani, fun gbogbo awn Onigbagb lapap, nitori ni ti o ti w
isinmi r ti sinmi kuro ni i r gg bi lrun ti sinmi kuro ninu ti R. ugbn niwn
igba ti Jesu ti l si run nigba ti i R laye ti pari, mo gbagb pe Jesu ni eyi n tka si.
ni ti i e aaaju igbagb wa, bakan naa. Gg bi lrun ti sinmi kuro ninu gbogbo
i R nigba dida ay, eyi ti a k sinu Majmu Laelae, bakan naa ni Jesu Kristi sinmi
kuro ninu gbogbo i R ni ti dida ay titun.
Paulu wi pe, “Nitorina bi nikni ba w ninu Kristi, o di da titun” (2 Krinti
5:17) tabi “da tun,” gg bi ati le tum r si. Awa n gb ninu ay tun, ki i e ti
ogbologbo. O j na miiran lati fi ay Ofin w ti Igba Oore-f; Kristi si ni lda
eto titun naa. O w inu isinmi R nigba ti O jinde kuro ninu iboji R ni j kin-in-ni
s.
Nipa bayii a ri ohun pataki r m fun jijsin ni j kin-in-ni s. Ninu dida aye
titun, lab eyi ti iw ati emi n gb, lyin ti Kristi ti pari gbogbo i R, O pari i
iran R. r R ikyin lori Agbelebu Kalfari ni pe, “O pari.” O w inu isinmi R
nigba ti O jinde ni j kta kuro ninu iboji ni j ikinni s. Nitori naa, a ni idi pup
ti a fi n pa j Oluwa m bi j-isimi.
Id lrun
“Nitori r lrun y, o si li agbara, o si m j idak’ida oloju meji l, o si
ngnni ani titi de pipn kn ati m niya, ati orike ati r inu egungun, on si ni
olum ero inu ati te kn” (Heberu 4:12).
O le ri bi o ti j danindanin to lati feti sil si r lrun. Bi a ba e b yoo i
naa ninu wa.
“K si si da kan ti k farahan niwaju r, ugbn ohun gbogbo ni o w
nihoho ti a si ipaya fun oju r niti awa ni iba lo” (Heberu 4:13).
Ki a s lna miiran, gbogbo eniyan ni yoo duro niwaju R lj kan ni idaj, ko si
si ohun ti yoo pam, tabi ti yoo fi ara sin, gbogbo r ni yoo fara hn. A o d wa lj
nigba naa nipa r naa ti o y ti o si lagbara, ti o m ju idakida oloju meji. Jesu tikara
R s bayii pe:
“Emi k w lati e idaj aiye, bikoe lati gb aiye l”
Paulu Apsteli e alaye bi awn eniyan e le ri igbala, ugbn o tun kil fun wn
plu ohun ti yoo el bi wn ba k ihin igbala. Nigba kan ti Paulu n kwe si awn ara
Krinti nipa awn ti awn m Israli d nigba ti wn n rin kiri ninu aginju, o ni
“Nkan wnyi si e si wn bi apr fun wa: a si kwe wn fun ikil awa” (l Krinti
10:11), tabi gg bi k fun wa. Wn j awn ikil nipa ijiya ti lrun rn jade nitori
s, bi awa ko ba f j ir iya kan naa, a ni lati ra ki a m e d.
kan ti o Sle
A ti k k nipa ni Mta Ti Iwa-lrun. Ninu k yii, mi Mim (ti a sr R
gg bi ni Kta) ni O n sr, O n fi ara R hn bi ni kan. mi Mim kil fun fun
awn m Israli nigba Majmu laelae. Paulu plu tun n kil fun wa pe ki a ma e s
kn wa le. Bawo eniyan e le s kn r le? Nipa kik lati gbran si awn a
Oluwa. Nigbakigba ti eniyan ba e aigbran, kn r yoo sele di si i ju ti atyinwa
l. Ni akk inu r le baj pup nigba ti o ba d, ugbn lyin ti o ba ti e aigbran
si lrun nigba pup, kn r yoo sele to b ti ki yoo til ronu m pe oun e ohun ti
k t. ri kn r ki yoo jam nnkan kan fun un m.
Aigbagb plu a maa s kn eniyan le: kik lati gbagb pe lrun yoo mu ijiya
wa fun ; ie aigbagb pe Jesu le gba ni kuro ninu gbogbo ; ie aigbagb pe
ranyan ni fun eniyan lati gbe igbesi-ay iwa mim. Bi a ba n e iyemeji si apa kan
ninu r lrun, kn wa yoo sele.
Ewu tun wa sib lyin ti a ti ri igbala pe a le y kuro lori igbkle wa ninu Jesu, ki
a si br si i e iyemeji r r -- boya di kiun ninu r. Bi igbagb wa nisisiyii ko ba
lagbara to bi o ti ri nigba ti Oluwa kk gba kn wa la, y ki a wadii ara wa wo bi
a ba i ni igbala sib. O le j pe a ti s “if iaju” ni n. Paulu ka a si ran ti o wuwo
lplp. O ni: “ kiyesara.” Fi kan sii ! “ m gb ara nyin niyanju.” Ki a maa
kil fun ara wa, ki a ma e j ki ohun rere wnni ti lrun fi fun wa y snu kuro ninu
ay wa.
a maa tan ni j. Satani le fi ohun ti o dabi ni pe o dara tn wa j, ki a si ro pe
ko si ohun ti o buru ninu ie ohun ti o n s fun wa. ugbn bi a ba feti si mi
lrun, oun yoo kil fun wa nipa awn ohun ti ko t. Bi a ba k lati gbran si ikil
naa, a o ubu nitori idanwo naa, kan wa yoo si sle.
Didimu inin
Paulu e alaye pe a o gba wa l titi ayeraye, a o si j igbadun Ijba Kristi plu R
gg bi awn m ati alabaip plu R, kiki bi awa ba “di ipil igbkle wa mu
inin titi de opin” (Heberu 3:14). Eyi ni pe bi a ba ti gba wa l lkan, a gbd pa
iriri yii m -- ki a maa gb igbesi-ay naa ni ojoojum -- ki a ba le wa ni imurasil
nigba ti Jesu ba d. Nigba ti a ba s wa di mim yoo rrun ju b l lati l “di
igbkle wa mu,” yoo rrun lati ma le pada syin. Lyin ti a ba ti fi mi Mim w
w, a oo ni agbara sii lati bori . Nigba naa a ni mi Mim ninu wa lati maa kil
fun wa nipa tan .
lrun ti e i iyanu nla nla nigba ti O m awn m Israli jade kuro ninu oko
ru ti Egipti. r ni wn j ni Egipti, ugbn ni al j kan, wn jade lai si idojuk
kankan -- lrun wi pe aja kan kii yoo “y ahn r” si wn. lrun yoo e itoju
awn eniyan R.
Ipese lrun
ugbn lyin igbala nla yii, awn m Israli k gba lrun gb -- wn e
aigbran si I. Nitori naa irin-ajo ti wn i ba rin ni dun meji (laaarin akoko yii ni wn
mura gg bi oril-ede lati w il Kenaani) gba wn ni ogoji dun titi o fi fr j pe
gbogbo awn ti wn ti to ni ogn dun tabi ju b l nigba ti wn jade ni Egipti ni o
ti k. Ni gbogbo ogoji dun wnni ni wn n mu lrun binu. Iw yoo ro pe idasil
wn i ba j wn loju, bib ti wn b lw ada-nikan-pas kikoro ni Farao, ni ti o ti fi
agbara mu wn i lile, ti o si fi paan n wn nigba ti wn ba mu un binu. lrun
fun wn ni ounj ti o to wn ni ojoojum lati mu ara wn le – “enia j onj awn
angli; o rn onj si wn li ajyo” (Orin Dafidi 78:25); a wn ko gb -- “A r k
gb m lara, bli s r k w, lati ogoji dn yi wa” (Deuteronomi 8:4); lrun fi
awsanm iji bo won kuro lw ooru nigba san ati wn ina lati fun wn ni iml
ni oru (Orin Dafidi 105:39). fun wn ni omi mu ninu aginju aal ati il gbigb ni
– “O l apata, omi si t jade; od nan nibi gbigb” (Orin Dafidi 105:41). Gbogbo
nnkan wnyii ni lrun e fun Israli, sib “nwn k gb lrun gb, nwn k si
gbkle igbala r” (Orin Dafidi 78:22). Nitori eyi lrun e binu si wn, O si wi fun
wn pe wn ki yoo le w Kenaani. Wn ko le gb inu ilu nla tabi ile ti o duro p titi --
inu ag ni wn n gb. Nigba miiran wn ni lati l b awn eniyan ti ko f ki wn la
il wn kja jagun. Wn la inira nla kja, ugbn awn ni o fa a.
Nigba miiran idaj a skal sori awn m Israli, gbgbrun wn a si k.
Nigba ti Datani ati Abiramu d, awn ati gbogbo bi wn ni il lanu ti o si gb m;
aadtalerugba (250) eniyan sii ni o k nigba ti wn daa lati fi turari jona, lodi si a
lrun. Ni j keji plp eniyan tun kn nitori idaj wnyii, lrun si j ki arun
kan b sil laaarin wn, gbaa meje o le dgbrin eniyan ni o k. Nikyin lrun wi
pe: “Nigba gbogbo ni nwn nina ni kn wn; nwn k si m na mi. Bi mo ti bura
ni ibinu mi, nwn ki yio w inu isimi mi” (Heberu 3:10,11).
Il Isimi
Il Kenaani j ilu lwa, plu il ti o lra, o si ni oju j ti o dara lati mu ki ohun-
gbin wn maa so eso lplp. lrun eleri lati le awn oril-ede abria naa kuro
niwaju wn bi wn ti n t siwaju, eyi yii fi han pe ib j il isimi nitoot. ugbn
isimi kan ti o tobi ju eyi l w niwaju fun wa: run.
Lyin ti lrun d awn run ati ay ati gbogbo ohun ti o w ninu wn, O sinmi.
Nigba ti Jesu pari i irapada R ni ay -- lyin ti a kan an m agbelebu ti O si jinde --
o pada l si run lati l sinmi. Nisisiyii awa ni i wa lati e ni aye, jijere kn fun
Jesu bi a ti n gb igbesi-aye Onigbagb ti ko ni abawn, ati lyin eyi awa o w run
lati sinmi, plu. Isinmi yii n duro d w, ugbn a gbd pese kn wa sil nisisiyii ki
a ba le e tan lati w inu r.
lrun n e ohun pup fun wa lj oni nitori O fran wa O si n f ki a j rere ati
ni mim ki a ba le ba A gb ni run. ugbn bi a ko ba gba awn ileri R gb, bi a
ba si k lati e ifara-rub ay wa to fun Un ki Oun ba le fun wa ni igbagb lati gba
awn ibukun ti ileri R, awa ki yoo w inu isinmi R. Paulu s fun wa pe a ni lati bru
ki a ma ba a e ohun ti yoo mu ki a j alaiy fun run. A le ri awn nnkan ti awn
m Israli e, eyi ti ko j ki wn le w il Kenaani, wn si j ikil rere fun wa ki a
ma baa e iru ohun kan naa.
I rere wa nikan ko ni t lati e wa y fun run. lrun m kn, o si ri ero
buburu gbogbo ati ilepa ti o le fara pam sib. “nitori r lrun y , o si li agbara, o
si m j idak’ida oloju meji l, o si ngnni ani titi de pipin kn ati mi niya, ati orike
ati r inu egungun, on si ni olum ero inu ati te kn” (Heberu 4:12). r lrun
ni yoo d wa lj nigba ti a ba duro niwaju It Idaj, a si ti fun wa ni gbogbo ofin
iakoso iwa wa ni ay yii ninu Bibeli. Gbogbo ohun ti k t ti a ti e (bi a ko ba i ti i
dari wn ji wa, ki j Jesu si ti bo wn ml) ni a o fi hn. “Ohun gbogbo ni o w
nihoho ti a si ipaya fun oju r niti awa ni iba lo” (Heberu 4:13).
AWN IBEERE
Ta ni n fi oye y awn eniyan?
Bawo ni awn eniyan e n s kan wn le?
Daruk di ninu awn ohun rere ti lrun e fun awn m Israli ni aginju.
Bawo ni akoko ti a ti pese wn sil lati w il Kenaani ti p to? Ki ni e ti wn
ko le w ni akoko naa?
Ki ni l si awn m Israli nigba ti wn aigbran si lrun?
e apejuwe il Kenaani?
Ki ni lrun e lyin ti O ti pari did ay?
Ki ni yoo j isinmi wa bi a ba j Onigbagb agun?