Ape Iferan Tosi

You might also like

Download as doc, pdf, or txt
Download as doc, pdf, or txt
You are on page 1of 1

APE IFERAN TOSISE GIDI GAN TIA TI CONFIRM DAADA

KOSI ENITI KO LE LOO, KODA ALE FI DE CLIENT TABI OGA NIBI ISE WA

ISENARE:-

Obi gbanja oloju meji funfun, ao la si meji, ao fi abere(needle)te Ifa ejiogbe soju awe obi kan, ao so awe
Keji nu, ao wa mu eyo atare mejo, ao kii soju ejiogbe tia fi abere te yen leyokookan,

Tio bati di ago kan oru ti eniti a fe sa iseyii fun bati sun, ao wa bosi enu ona wa to jasi ita, ao wa bu iyo
die si atelewo osi wa, ao wa gbe obi tia te ejiogbe silori, Ihoho omoluabi lao sise yii lago kan oru yen, o
wafi owo otun wa mu ilekun yen duro aowa pe gbolohun resi

OHUN RE:

Ao se Haaa lemeta x3

Amororo loruko tia npe oko(hoe) aronigbebikan jifa loruko tia npe obo, afojuboju loruko tia npe omidan
weere, ile(house) kii di titi ki aala ma wonu re, Ejiogbe ooo, gbe aworan mi loba L omo L kori mi bayii
bayii, tio badi ojo Keji jeki kio pemi pe ohun ti nife mi, Ao wa se adura nkan tia nfe si daada, ao wa da
gbogbo nkan towa lowo wa yii senu pata ati iyo ati obi, ao je, ao wa fon eyiti owa lenu wa sita lemeta,
Ao wa pa ilekun yen de leekanna, Ilekun tia pade yen loma ji nibi ti o wa. Ao wa pada lo sun.

IKILOPATAKI

RIDAJU PE O COMMENTS AND SHARE FUN AFANI ELOMI

NOTE:-IWO TI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TI KOSI AYE ABI TI O MON BI OSE FESE MOLE SE FUN O

FUN IBEERE ABI ALAYE ATI FUN IRANLOWO ONA ABAYO CALL OR WHATSAPP OLAIFA AWAYE WA SE
RERE TIOBA NIGBAGBO ((09027426795))

You might also like