Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 4

S ASEJE OSOLE TAFI NRI ₦200,000 TODAJU BIIKU

Ori oka tolase lenu kan, eyo ata ijosi 9, ewe onitikuti, ewe ola, eyin ibile merin,isasun tuntun, epo pupa.

SISE RE:

Inu yara kan ni ao ti se oogun yi, ao bo ara wa si ihoho omoluabi, aolo gbogbo awon eroja yi lotooto ni
ihoho, ao fi din eyin yen pelu epo pupa, aose adura si daada, ao sare koje ni gbigona, ao wa mu hot lelori
daada. Ihoho naani ao je aseje yii. ODAJU BIIKU....

OGUN TI AFIN DI META NINU AYE TODAJU BIIKU

Okan okete, okan pepeye, egun ajio die,Ao ki egun ajio sinu okan okete, ao waki okan okete sinu okan
pepeye, aowa welowu funfun ati dudu,

LILO RE:

Taba felo ao wani ihoho, aoba pinhun lori isetafe lofun, ao wafi obe oyoo gbemi, odaju pe ti nkan aburu
kan bafe sele, ao dimet

ASIRI TIA FIN PARADA SI NKAN TO BA WUWA LOJU OGUNTODAJU BIIKU

Omi tio da oju ona si meji, ao bu die nibe, ao tun bu erupe otun ati erupe osi ojuona yii, ewe abamonda,
ewe alupaida pupa ati funfun, awo olufa die, awo erindie, ao jopo pelu odidi atare aja kan, ao dii ni
ikobere sinu aso tagba lara oku, aoran ni awo ekun, awo imado pelu awo ikooko, ifunpa ni ao ran si,

OFO RE:
Omipakiti, omi be ona lori, ona pakiti ona be omi lori, ipade omi ationa wa pin si merin ogboogba,
abamonda kii da tie koma se, ewe alasun adakoni sai parada, bi ekun bafiru bale omo eranko atuyaya,
opapa parada.Pelu ogo olohun, ao yii pada si eyikeyi toba wuwa ninu awon eranko tia lo awo won
yii……….

LILO RE:

Ti ifunpa yii batiwa lapa wa, ao je eyo atare mesanlenu lao mafi pe ohun yen, ti aba petan, ao tusi
ifunpa naa, ao wa subu lule,ohun tia bafe lao yi parada si, Tia Bafe Parada Di Eniyan Pada, Ki eranko naa
fiese tabi enu bu erupe nile, toba si jepe inu igbo ni eranko naa wa, yio da ewe mo,kofi enu ja ewe
odundun ati ewe gbegbe kofi gbo oju ibiti ifunpa naa wa lara renigbatowa leeyan, toba fi gbotan, ko gbe
ara yile pada yio di eniyan…….

IKILO RE:

Nigbati abawa leranko, omi ojo (rain) kogbodo kan wa lara, tio bafile kan wa lara onitohun koni di
eniyan mo, Odi ewure jelejele, odi agutan jemo jemo niyen.

AKIYESI PATAKI: Ti eniyan badi eranko tan, yio ma


soro bieniyan, sugbon eniyan tobawa nibe koni gbo nkan ton wi, ti eranko naa ni yio joleti won, sugbon
eranko yii yio gbo ede tiwon, Itumo nipe yio gbo oro ti awoneniyan yen nso, Idi niyii ti eranko naa lefi pe
ofo funrare lati di eniyan pada,Tieranko naa bafi enu tabi ese bu erupe nile yio fi ra deede ibiti ifunpa
naa wa larare nigbati o wa ni eniyan, tobati fi ra koyira monle pada yio di eniyan pada.

ISE IYONU TIA MOFIN PADE ALAANU TI YIO BAYABUKATA WA

Ao wa ewe ewuro oojo, epo obo die, imi orun A o lo meteta lototo a o wa kolose anyone ki base dudu
tabi ose Ghana A o wa mu Owo eyo eyokan leLori A o wa ma buwe larolaro

GBOLOHUN ::

Ajiromotutu ×3

Akiromokuku ×3

OsaaIleasarijiki × 3
Wa sare Tete lati isaluorun wasi isaluaye kio la ona ire Owo nla nla mi loni. Nitori wipe ojumo oni mo ki
orunmola

ojumo tio momi loni kio romidun Nitori adun ni nkeyin ewuro Aje Oso ati gbogbo aburu inu aye ko bu
do de odo mi.

Nitori wipe epo obo ni ipin awon Eleye Eyekeye Osokoso

to baje obo orunlala Ati Omode ati Agbalagba tio bafedimi lowo Ki won ba won gbe nia jule orun
Jatijatirederedeni

ko ba gbogbo eyin otami...Ki EMI.......Omo......Ki man ri

tajese Nitori wipe Aje ki won Nile olokun bAje ogbudo won

mi loni gbogbo ibiti Owo ire gbogbo bawa ni Oni komaje temi....Ase Yio

ITUWO

Isu ogirisoko, ata itosi die, imi ojo pupa, alubosa elewe die, epo obo die, ego igi nla, egbo tude die, eru
alamo, a o gun Mose Ghana tabi lux, odi wiwe laro ati ale..

ASINA

Epo obo die, ego iginla die, ewe ewuro die, ew ajeobale die, eru alamo, ataijosi, alangba ako kan, odidi
atare meta a o Jo po mafifokomu tabi ka po mose fiwe

You might also like