Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 1

Ad

VPN Recommended
Tap to Install and Continue Watching ×
, +

Ad
VPN Recommended
Tap to Install and Continue Watching ×
* Want To Know More About OldNaija?

Looking for something?

Search here... Search

History Trends

Military History Sports History Ancient History

Unusual History Archaeology Slavery History

General History Yoruba History Women History

Crime History Social History Political History

! Home >> Cultures and Traditions

Cultures and Traditions Yoruba

Oriki Offa – Eulogy of


Offa Town in Kwara
State
" Teslim Omipidan #1 $ 3 minutes read

Olofa of Offa Palace

Offa is a city located in Kwara State with a


population of about 100,000 inhabitants. Offa is
notable for its weaving and dyeing trade, using
vegetable dyes made from locally grown indigo
and other plants. Offa is also well known for the
cultivation of sweet potatoes and maize which
formed part of the favourite staple foods of the
indigenes in the town.

Offa in one of her eulogy is being addressed as


the home of sweet potatoes. Cattle, goats and
sheep are also raised in the environs. The key
religions practised in the town are Islam,
Christianity and traditional religions.

Below is the long and short version of the


Eulogy of Offa (Oriki Offa). Enjoy!

You Might Also Like

Oriki Oyo (Eulogy of Oyo)

Oriki Offa Short Version:


Iyeru-Okin, Omo Olofa Mojo, Omo Olalomi,
Omo abisu Joruko , ijakadi loro toffa toffa, Ija
kan ijakan ti won nja lofa lojosi, Olalomi oju
talose, Osoju ebe lala, O si soju poro ninu oko,
Ibasoju oloko, iba lawon, Omo ‘laare, Omo bu
re, ikan o gbodo ju kan, Bi kan ba ju kan nile
olofamojo ogun lon’da ni ile baba wan, Omo
omaka, Omo osa oje ba mi ki anomo. Omo
olalomi ni mori, Mo dasa lami lapa, Iyeru okin ni
mori, Mo dasa lami lobe, Mi o pe e mo lami
sugbon, E mo je ko jinle lapa mi, Ijakadi loro
ofa.

Oriki Offa Long Version:


Ede okin olofa mojo, olofa omo ola nlomi ab’isu
joko ijakadi loro Offa, ija peki abe owula, bi ko
ba se oju ebe l’Offa, as óju poro l’oko, iba soju
oloko iba la won, osoju agunmona l’Offa , O
soju agbele yarara, o soju aporuba ka ‘ko, kinni
se kagun-kakanrun ni ile oba, oka ni se kagun
kankanrun, Agbado ni agun-mona l’Offa, Eree
ni agbele yarara, isu ni aporubu ka ‘ko, omo odi
meta mete meta me ti nbe l’Offa mojo, odi
iwaju ti olusan, t’ehin ni se ti olumiran, t’arin
gungun ni se ti olugbenise omo ayejin, omo odo
meta meta ti ntun nbe l’Offa mojo, okan ni apa
erinla boo un ki oun dókun, okan ni apa agbo
boo un ki oun d’osa, okan ni ki apa akuko
gagara boo un ki oun di agunloko l’Offa oba ni
okookan Offa ti t’agbo ra, ododo won ti to erinla
pa sugbon ni okan ba d’okun, ti okan ba d’osa
nibo ni ako omo yebiye wonyisi.

Eyi ti won wapa akuko ganga boo a ni owa di


agunloko l’Offa olofa omo la ki Offa kun tele,
olalomi ede okin olofa mojo Olofa Omo laare ki
o dogba, okan ko gbodo ju kan bi okan ba ju
kan, oba ni ko won roro, oba ko wa ri ti awa
d’iran peki mob a odofin dimu, mose ojomu
Karin, mo fi ehin saawo ra’le l’Offa o m’aka
Arijasoro, olalomi lo laare.

Offa o m’aka egun wole l’Offa to ju ti omo okuta


meta nsese, okan ko mi lese okansemi pele,
okan semi nrora, Okan n’gbati emi mona , kinni
mo wade ilu ete okan n’gbati emi ko mona kinin
mo wa de ilu ero Okan n’gbati emi mona , kinni
mo wa de ilu awon-won ni ile olalomi ti omi ti
won ti oju lo Ede Okin timo ri okin bamuiti mofi
abata sin ese l’Offa ti mo wari abelenje boju mo
la k’Offa okun keekee Aral ale, olalomi omo
orubo nla ti osubu l’aro papa ni ohun bata, oki
mi o nla mi, olalomi tani osehun ninu ara won
ileyi ko gbaye, a ko lo si loffa nigbati iloffa o gba
wa a ko lo s’Offa oro nigbati Offa oro o gba wa,
a ko los’Offa irese nigbati Offa irese ko gba wa,
ako losi igbolutu nigbati igbolutu ko gba wa
mo, a tun pada si Offa Eesun nigbati Offa
eesun o gbawa mo ni awa kowa si Offa Arinlolu
olofa se pele o aro ko ya bumu, Ede olele aro
ko ya buwe Ede olele aro ko ya buboju igun ni
a rini a dasa geru, Akala nia rini a sasa l’edo
olofa imole ni arin ni a wa dasa lami labe lapa
se olofa lo ni omo , ko si Eku ti oju Offa o di oyo
olofa ni oni omo gbengbeleku ni ara yoku nsan
ni nwon ki olalomi iyeru okin.

Thanks for reading, OldNaija.com

Cite this article as: Teslim Omipidan.


(January 27, 2020). Oriki Offa – Eulogy of
Offa Town in Kwara State. OldNaija.
Retrieved from
https://oldnaija.com/2020/01/27/oriki-offa-
eulogy-of-offa-town-in-kwara-state/

Questions? Advert? Click here to mail us or click here to

call us.

You Might Also Like

Titles of Traditional Rulers Oriki Ilorin Afonja


in Yorubaland (Panegyric of Ilorin)

Atilogwu Dance of the Igbo Owambe: A Glance into


People Nigeria’s Grand
Celebration Culture

Oruko Amutorunwa (Pre- Sharo Festival- How Fulani


Destined Names) In boys endure flogging to
Yorubaland pass into manhood and get
married

Drop/View Comments

© 2014 - 2024 | All Rights Reserved | OldNaija

About Us Contact Us Advertise Submit Article

Terms & Conditions Content Removal

% & ' (
)

% & - . /

You might also like