Professional Documents
Culture Documents
Ohunmo Aiye
Ohunmo Aiye
Ajiromotutu ×3
Akiromokuku ×3
OsaaIleasarijiki × 3
Wa sare Tete lati isaluorun wasi isaluaye kio la ona ire Owo nla nla mi loni. Nitori
wipe ojumo oni mo ki orunmola
ojumo tio momi loni kio romidun Nitori adun ni nkeyin ewuro Aje Oso ati gbogbo
aburu inu aye ko bu do de odo mi.
to baje obo orunlala Ati Omode ati Agbalagba tio bafedimi lowo Ki won ba won
gbe nia jule orun Jatijatirederedeni
tajese Nitori wipe Aje ki won Nile olokun bAje ogbudo won
mi loni gbogbo ibiti Owo ire gbogbo bawa ni Oni komaje temi....Ase Yio
ITUWO
Isu ogirisoko, ata itosi die, imi ojo pupa, alubosa elewe die, epo obo die, ego igi
nla, egbo tude die, eru alamo, a o gun Mose Ghana tabi lux, odi wiwe laro ati ale..
ASINA
Epo obo die, ego iginla die, ewe ewuro die, ew ajeobale die, eru alamo, ataijosi,
alangba ako kan, odidi atare meta a o Jo po mafifokomu tabi ka po mose fiwe
Ori oka tolase lenu kan, eyo ata ijosi 9, ewe onitikuti, ewe ola, eyin ibile merin,isasun tuntun, epo pupa.
SISE RE:
Inu yara kan ni ao ti se oogun yi, ao bo ara wa si ihoho omoluabi, aolo gbogbo awon eroja yi lotooto ni
ihoho, ao fi din eyin yen pelu epo pupa, aose adura si daada, ao sare koje ni gbigona, ao wa mu hot lelori
daada. Ihoho naani ao je aseje yii. ODAJU BIIKU....
Okan okete, okan pepeye, egun ajio die,Ao ki egun ajio sinu okan okete, ao waki okan okete sinu okan
pepeye, aowa welowu funfun ati dudu,
LILO RE:
Taba felo ao wani ihoho, aoba pinhun lori isetafe lofun, ao wafi obe oyoo gbemi, odaju pe ti nkan aburu
kan bafe sele, ao dimet
OFO RE:
Omipakiti, omi be ona lori, ona pakiti ona be omi lori, ipade omi ationa wa pin si merin ogboogba,
abamonda kii da tie koma se, ewe alasun adakoni sai parada, bi ekun bafiru bale omo eranko atuyaya,
opapa parada.Pelu ogo olohun, ao yii pada si eyikeyi toba wuwa ninu awon eranko tia lo awo won
yii……….
LILO RE:
Ti ifunpa yii batiwa lapa wa, ao je eyo atare mesanlenu lao mafi pe ohun yen, ti aba petan, ao tusi
ifunpa naa, ao wa subu lule,ohun tia bafe lao yi parada si, Tia Bafe Parada Di Eniyan Pada, Ki eranko naa
fiese tabi enu bu erupe nile, toba si jepe inu igbo ni eranko naa wa, yio da ewe mo,kofi enu ja ewe
odundun ati ewe gbegbe kofi gbo oju ibiti ifunpa naa wa lara renigbatowa leeyan, toba fi gbotan, ko gbe
ara yile pada yio di eniyan…….
IKILO RE:
Nigbati abawa leranko, omi ojo (rain) kogbodo kan wa lara, tio bafile kan wa lara onitohun koni di
eniyan mo, Odi ewure jelejele, odi agutan jemo jemo niyen.
GBOLOHUN ::
Ajiromotutu ×3
Akiromokuku ×3
OsaaIleasarijiki × 3
Wa sare Tete lati isaluorun wasi isaluaye kio la ona ire Owo nla nla mi loni. Nitori wipe ojumo oni mo ki
orunmola
ojumo tio momi loni kio romidun Nitori adun ni nkeyin ewuro Aje Oso ati gbogbo aburu inu aye ko bu
do de odo mi.
to baje obo orunlala Ati Omode ati Agbalagba tio bafedimi lowo Ki won ba won gbe nia jule orun
Jatijatirederedeni
tajese Nitori wipe Aje ki won Nile olokun bAje ogbudo won
mi loni gbogbo ibiti Owo ire gbogbo bawa ni Oni komaje temi....Ase Yio
ITUWO
Isu ogirisoko, ata itosi die, imi ojo pupa, alubosa elewe die, epo obo die, ego igi nla, egbo tude die, eru
alamo, a o gun Mose Ghana tabi lux, odi wiwe laro ati ale..
ASINA
Epo obo die, ego iginla die, ewe ewuro die, ew ajeobale die, eru alamo, ataijosi, alangba ako kan, odidi
atare meta a o Jo po mafifokomu tabi ka po mose fiwe