Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 20

YARA AGBARA ATI ASEYORI

LATI OWO PRESIDENT EGBE Sheikh Yusuf olatunji Algambari


WOLI IGE IBIKUNLE 08067205440

1. EYONU ASINA TIPATIPA

Ao gun ewe Afeloru nkuna daadaa ,ao waapo pelu Osedudu ,aote Ifa
EjiOgbe si ori-iyere Osun, aose Adura Isina si daadaa aowaapo pelu ose yen
aoko sinu igba Olomori, aomaa fiweni gbogboigba.... .Odaju

2. EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU

Alubosa elewe tutu kopo die aogun dada aopo po ma ose dudu aowa eyin
adie Oojo aodogbon folori die ti korofo eyi� yi koni baje aojo omi eyin yi
sinu ose yi aotun gun dada aowa igba olomori aoko ose yi sininu aowa
fikorofo eyin yi gun oseyi lori logangan ibi tiati fo eyin na ni yio koju sinu
ose, ao ti kokodogbon fowo ji ni bibe katofi eyin nagun kikorofo eyin na
mabafo. Ao mabuwe nigba to bawuwa.

3. EYONU ASINA TODARA GAN.

Ebami wa, Igbin apinnu nla kan, ebami so sinu Odo, ebami gun tikarahun
tikarahun, ebami fisile die ko yo Omi jade, oya, ebami wa ako alangba kan ,
ebami du eje re sinu igbin ti atigun yen ninu Odo , ao ge ori alangbe yen ati
ase re, ao ki ase re yen si enu ori alangba yen, ao wa gun mo igbin yen ninu
odo, ao gun Ewe ajeobale Oojo, ewe Orijin oojo, mo awon eroja ti atigun yen
ninu odo ao wa pomo ose dudu leyin ti atigun kuna daada, ao ko sinu ike
funfun olomori kan, ao ma fiwe ni araaro. Eyan kan nio. #Ayeniromo#

4. OSHOLE OWO TODAY FROM AJAKAYE

Odindi igunnugun kan , ori oni kan, ori oka nla kan, ori ere meta,ori sebe
meta, odindi atare meta, egbo ajeobale oojo , egbo orijin oojo, ao jo won
papo ao wa fi orii pupo po, ao ma fi po ogi gbigbona mu die die.

BI A SE LE LO OYIN-IGAN
1. OGUN OJU; Ti Oju re ban se pin, tabi ti o nyun o, ti o pon . Po Oyin ati
alubosa funfun pomon ara won. Maa kan si oju mejeji.

2. INU RIRUN ; Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi meji lehin onje ale.


3. EGBO; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo na.

4. EYIN OMODE; Oyin Igan ati Omi Osan wewe mon ara won. Ki o si fun
Omo na ni sibi kan lemeji lojumo lehin onje.

5. IKO IFE (TUBERCULUS); Lo Atare, Ayu, Iyo ati Orogbo pelu O yin
Igan sinu Igo. Agba sibi meji ni igba meta lojumo.

6. AIRI ORUN SUN; Maa mu Oyin Igan sun. Sibi meji lalale.

7. AILERA NINU OSU OBINRIN; Nkan osu to nse segesege tabi to dudu
(STOMACHPAIN) Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.

8. ARONMOLEGUN; Lo Ewuro po mo oyin Igan fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo


sibi meji li ojojumo ni owuro kutukutu.

9. AKANDUN TABI EEWO(BOIL); Lo Ewa ati Kaun po mo Oyin Igan. Ma


fira ibe.

10. OGBE INU(ULCER); Maa mu sibi Oyin meta ni owuro kutukutu ni


wakati kan ki o to jeun aaro.

11. FUN ATO KIKI(SEMEN BOOST); Po eyin tutu po mo Oyin sibi


Maarun Lo gbogbo re leekan naa.

12. IKO EGBE; Po Omi Igbin ati Oyin po mo ara won .Sibi nla meta
leemeta lojojumo. Omode sibi kan laaro ati lale.

13. JEDIJEDI; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo Oyin Igan . sibi meta laro
ati lale. Lojojumon.

14. ARUN ETI; Ti eti ban se oyun tabi ti o nrin eniyan, fi omi gbigbona po
iyo die ati oyin mo ara won ma kan si eti mejeji laro ati lale.

15. KOKORO ENU; Po Oyin Igan po mo Osan wewe fifo enu ni igba meta
lojojumo.

16. ILE GBIGBONA; Lo ewuro po mo Oyin Igan fi pa gbogbo ara sibi


mejimeji, lemeta lojumo.

17. INU DIDUN LEHIN TO BINRIN BA BIMO; Obinrin naa yio malo oyin
sibi mejimeji lemeta lojumo.
18. OMO TI O NTO SILE; Ki o maa mu sibi Oyin Igan mejimeji sun titi
tiko fi ni to sile mo.

19. IKO; Lo orogbo ki o daa sinu Oyin Igan lehin nab ere si laa tabi ki o
maa loo sibi kan kan ni wakati metameta. Omode sibi kekere.

20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O dara

21. OGUN OJUPIPON; Ma kan oyin si lemeta loojumo.

22. ARUNSU; Lo ewe ejirin po mo oyin igan sibi merin lemeta lojumo.

23. ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan sibi merin lemeta lojumo.

24. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.

25. EJE RIRUN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lojumo laro ati lale.

26. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sise kan oyin je.

27. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin Igan sibi meta loojo,.

28. INU RIRUN; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta lojumo.

29. FUN ARA DIDAN; Po Oyin Igan mo adiagbon ma fi pa ara.

30. FUN IFA RUN AGBON; Po etu mo oyin igan ma fi pa.

31. FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu po mo oyin igan mafi pa
ara.

32. FUN ARAN ; Omi osan wewe po mo oyin igan sibi meta meta lojumo.

33. KI INU OBIRIN GBONA; Lo ayu po mo oyin igan sibi merin lemeta
lojumo.

34. FUN IBA REFUNREFUN; Lo ayu po mo omi osan wewe eyin ati oyin
igan sibi merin ni igba meta lojumo.

35. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni gbogbo igba.

36. BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi oyin igan pa.

37. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etui mi ojo po mo Oyin Igan
ma fi pa ni gbogbo igba (mase te fo rara).
38. OGUN EJE; Omi csan wewe eyin tutu mo oyin igan sibi merin ni igba
meta lojumo.

39. BI ARA BAUN GBONA:- Omi ewuro ti agbo la ifi omi si ale fi iyo gbo a
po mon Oyin Igan sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.

40. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi meta lee meta
lojumo.

41. OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo oyin igan sibi meta lee meta
lojumo.

42. NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE; Lo ayu po mo omi osan


wewe ati oyin igan .sibi meta lee meta lojumo.

43. OGUN ATOSI; Omi jaganyin ;kun die, ayu po mo Oyin Igan .sibi merin
lee meta lojumo.

44. KI ENI TO BA NI ATOGBE; Ma fi Oyin Igan mu Ogi ati Tea. ma din


sugar ku lara.

45. Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN IGAN mu Ogi tabi Tea.

46. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki afi omi sa haha agbado ki oma fi oyin
igan mu bi tea ni aro ATI lale.

47. Ki agbalagba ma lo oyin lati mu tea tabi ogi ni ara ro ,oma jeki
opolo jipepe....

48. IWULO OYIN FUN OPOLO OMO AKEKO: A o wa oyin gidi a omo
akeko yio ma la sibi meta meta siwaju laro Toba koko ji

49. Eni ti kori orun sun ko lo ra epo igi asufeyeje lodo awon alagbo,ko lo
die Kuna po papo mo oyin, ki o ma lo ni sibi meji tabi meta ni asale. Oorun
dee.

 EBU ATUDE/ ABILU LARA

EKU ASIN 1
IKODE 1 Sheikh Yusuf olatunji
ATARE DINDI 1
JIJO PAPO
Algambari 08067205440
A FI ITO (URINE) AIFOHUN LO LARO KUTU LEKAN SOSO KA TO SORO SI
ENIKENI

 AWURE ASINA OSHOLE OWO TODAJU SAKA DADA: ORI AJA


GBIGBE KAN TONIRUN, 100 TITUN, AO KI SI ETI OTUN, AO WAFI 200,
TITUN WE IGBO AO KISI ENU AJA YEN, AO WAFI EWE SAWEREPEPE OOJO
SU OSUKA, AO SORI AJA NA NINU ISASUN AO FI ODIDI ATARE KAN SI
LEGBE AO JO PO, AO LO KUNA DADA, AO DASI SINU IGO FUNFUN TABI
IKE FUNFUN, AO MAFI OTI TOGBONA SCHNAPPS LO LAROLARO PELU
ADURA, OPO ENIYAN LELO ISE YI DAJU.

 KI OBINRIN LE NI OMI LOYAN; A OO JOO AWO LIILII DASINU ADIN


EYAN. A O MAA FI PA OMU NAA,A O GUN EWE ETIPONLA DASI OSE DUDU
YOO MAA FIWE OYAN NAA.ODAJU

 AGADAGODO¤
Ao wa awo ekun, awo egbin ori adaripon kan, ori pepeye ati esere mejeji, ao
Jo po, ao fi owu dudu ati owu funfun Di po mo ara agadagodo, ao pe ofo re si
ao wa ti pa, OFO RE,,, agbin sinu ni egbin gbin, akun sinu ni ekun ku, ori ti
adaripon bale ki fi ba ogiri soro, igbagbe se eledumare ko la ese pepeye,
owu dudu ati owu funfun won ki jara won niyan, ki lagbaja omo lagbaja ma
jami niyan loni o, ao ti pa

 Ao lo ewe bombom kan ao polori, ao ko si ewe bombom omiran, ao


tee ni ifa OFUN meji si, ao mafi pa oju.
OHUN:- HA - HA - HA -
Ajikawo paper, Bi filani kobai tiri bombom wara koi ti ni di jije, Ajikawo
paper ki tokunrin tobinrin kiwon ka OWO (money) temi wa funmi loni.

0000

0. 0

0000

1. 0

2. EYONU
Eye Ega kan
Sheikh Yusuf olatunji Algambari
Afara oyin topo die 08067205440
Odidi atare kan
Ao jopo ao lo kunna daada ao da sinu oyin ao ma la ni araro Olohun yoo fii
alalubarika
3. OSOLE OMO YAHOO
Adan kan,ewe jeminiho,ewe abamoda,odidi atare kan,aojopo aoda ebu na si
meji aofi ikan singbere si orun owo mejeji idakeji aoda sinu oyin aomala.

4. OSOLE OMO YAHOO


Ewe afaimonikonimora,ewe ogbo,ewe esinsin,ewe aragba,eye kowe tako
tabo,eye ega,eye alanpadede,ori oka to lase lenu kan,efun,osun,odidi atare
kan,aojo gbogbo repo,aolo kuna bulebule,aowalo efun ati osun papomon
ebu yen,aopo gbogbo re lose,aofi foto clients won yen si sale igba ti aoko
ose yen si,aofi foto yen tele igba yen,aofi owo toba wuwa sori foto
yen,aogbe oga aye lelori,lehin na aowa ko ose yen sori won ninu igba yen,
aofi iyo yi ibiti afegbe ose yisi,aomafi we lago kan oru pelu adura fi asefe ki
awon clients yen maya owo funwa.

5. EBE AWON AGBA


Aojo igbe adie ati enpo obo pelu odidi atare kan po,aopo po mo
ori,aomamun pelu koko gbonan laro laro.

6. ISOLE FUN AWON AGBA


opolo aye kan,aoki odidi atare kan si lenu ti yio wonu re dada,aojo ,aolo
kuna,aoro ebu yen sinu ado kan,aosi enu ado kale,aowa ta owu dudu ati
funfun man lorun,aofiko senu onan ile.awon iyami koni lewole yen lose
aburu.

7. OSE IKORIRA
ifun alangba ako ati orire,ati ifun eyele eyikeyi,ewe oriji tutu,ewe
awerepepe tutu,ewe rekureku,epo obo,egbo tude,erun alamon,aogun
gbogbo repo,aofi ko ose ,aomafiwe ni gbogbo igba.
Mojuba agbalagba,eje kojumi seo.

8. AWURE OGUNDA_OLA
Ao se eyin adie ibile mefa ao se jina, ao bo epo re ao ko sinu awo tabi ike
funfun ao wata oyin gidi lee lori. Leyinna, ao wafi iyere-osun te ifa ogunda
ola (Ogundabede) ao pe ofore si ao wadale lori ao wa run papo bi ekuru.
Aowaa pe khutbah yii sii

9. KHUTBA:- Atanna pe aje loruko ti anpe ifa, ole roro loruko ta npe iwo
ogun, olomo afojuko owo olowo loruko ta npe eyin iyami aje , eyin meteta
ni olodumare ko kokoro olale lowo, kie mun kokoro ola na kie wafisilekun
funmi loni igba igba lona marun apo owo nimofe loni inu osuyi ati osu to
nbo, kie bami wa owona lowo okunrin lowo obinrin, arundinlogojo adun
lowa nile aiye oyin lodun ji gbogbo wan lo ki eledumare jeki ayemidun juti
gbogbo awon egbemilo nitori ona kiidi, ona kiha, ki adie o made ibi eyin re,
ki ona owo maedi momi ki tokunrin tobinrin mafi owo won ke
emi.....omo.....kiwon maafi ire nlanla tamilore. Ogunda bede olori ole owo
nlanla niki won omaagbe wasi odo emi .....omo... kiwon maawaabemi nise,
ki won maagbe wa fun mi, iyere osun majeki ire mi osun lona ase. Ase. Ase

Aowa kooje bi ekuru

10. ODAJU OWO KONI WAN ENITOBASE ISEYI pelu atileyin oluwa.

""""
Ifa ogunda ola (Ogundabede...ogunda ogbe) naa Ni yii

''
''
''
'"
Bi oseri ni yii
Oluwayoofi alubarka sii. Esee lojoojumo fun ojo meta telaraawon. Leyinna,
eomaasee lose ose.

11. AWURE TO MUN OWO ATI ALEJO GIDI WAA


Iye agbe kan iye aluko kan iye odidere kan oga gbigbe kan itun opa kan ifa
opa kan abere aogun papo mose dudu ao wapa eyele funfun kan ao la laya
aoko nkan inu e kuro ao gbe ose yen sinu eyele na ao wada eje eyele naa le
ose naa lori ao ma fi we

Odaju

12. OSO OWO TO DAJU TO BIYA GBOGBO BUKATA


Ori olongbo dudu kan ewe orijin tutu aofi #1000 tuntun kan tele ape tuntun
aogbe ori olongbo naa le aoda ewe orijin bo ao ta epo pupa round aro naa
Ago kan oru laojo ise yii aso funfun lao wo abi kalo aso funfun mon idi oru
na lao loo kuna ao wafi #1000 kan sinu lord aoda gbogbo ebu naa si
aogbesi igun ile ao malo laro kato soro seni keni

Note; Aogbodo loo ni thursday


Aogbodo loo taba sunmo obinrin
Aomase sara fun ni thursday thursday

Osise gan

Anu olohun amawa peluwa gbogbo wa from nuru saman

13. ASEJE OLAA

EWE AJEOBALE
EWE OMISINMISIN
EWE ORIIJIN ATI EGBO RE
ILEKE ITUN
ILEKE IFA
ILEKE SESE EFUN
#1000 NEW NOTE
ATA, EPO, IYO
ODINDI AHON MALU
AO GE SI 16
AO SE PELU ISASUN TITUN, AO JE. PELU ADURA ABAWA LARAMU OO
AMIN TROM (@NURU ZAMAN)

14. AWURE OWO KIAKIA.


Odidi atare kan, Biscuit ti o tobi, Oga gbigbe kan, opolopo ewe abamoda ao
jo po, ao mafi foko tutu mu lai fi omisi, ao ma koo SAN.

15. IPARA AANU


Ewe Anu, Irun iyamopo, Ewe Ola, ao lo meteta papo, ao DASI girisi funfun fi
para.

16. EYONU OWO TI AWON EYAN FI NFI OWO SANU WA AOSI MARI
TAJE SE..
Ako alangba 6 odidi atare 6 esuru pupa lopolopo aojo papo.
Ao mafi schinap loo laro laro...

Awure arisiki....
ewe ehinolobe, eru awonka to dipo mesan, cabin biscuit ao jopo ao da sinu
oti ao ma mu.
Ofore:
olobe ki ji koma ni owo lowo, eru loru tokunrin tobinrin toni owo lowo wa
fun mi,ori gbigbe lo pe ori tutu wa fun mi towotowo owo won,ki oti ma pa
olowo wa bami.

17. IMULE ASINA RIRISE

Ifun okere ojoo ewe ejinrin ojoo ao gun papo mose dudu aoko sinu apo aso
pupa ao gbeko ao mawe lalale.

Ikilo: Ao gbodo fun eni tajowa ni adugbo kan naa we ninu ose naa
oo nitoripe ole mari isegba juwalo oo.
Kosi eni tio lelo koda aomari ise gidi gba taban lo Ise yi lowo....
By okiki ola omo ola���

18. IPARA AANU

Ewe Anu, Irun iyamopo, Ewe Ola, ao lo meteta papo, ao DASI girisi funfun fi
para.

19. AWURE IFERAN

Ao gun ewe omisinmisin pelebe mo OSE, ao wa lira gilasi tuntun, ao bora si


ihoho, ao fi gilasi na wo gbogbo arawa, titi de eyin, ao wale OSE yen mo
glass. Ao mafi we.

20. OSOLE OWO TIMU OWO NLA WA LARIN OSU META!


Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o
Sugbon hmmm!!!

Nkan Ti mofise komabaje'o!!!

:- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AO PO


LOSE, AO FI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AO KO ose na SINU IGBA
OLOMORI, AO GBE PAMO FUN 16DAYS.
Ao ma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo nlala yio wa larin osu meta
pere.
IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope.
Osole yi Koni daun daada ni...

21. APARUN INU


Oyin gidi
Oronro malu
Etu ibon gidi
Dede oronro ni oyin gidi na ma je aoda Etu ibon gidi yen si Leyin ojoketa
aoma mun sibi imuko Kan laro kato jehun ati lale ti aba jehun tan FINGBA 1

22. TURARE AWORO

Odidi lekeleke kajiji erualamon iye Awon Agba aogun papo aoma fin Laro
FINGBA 1

23. ITUWO

Opolo aiye Kan Odidi Atare Kan aoyo omo Atare Kan kuro ninu re
aofipamon ti aba Jo tan aolojunu si Ori akitan gbere Orikerike ara aofi iyoku
la Epo pupa FINGBA 1

24. APARUN

Ewe Oro adete sakiti Aro Alubosa elewe kanhun bilala aojo aolo kunna
Daradara aoma Fi hot lo abi omigbona FINGBA 1

25. APARUN- APAGUN

Ori oka koro isin eko tutu elewe Atare Kan jijopo. Aobo eko elewe yen nio
aose oronbo pelu Oro adete tiyio jina aowa da ebu ti ajo si nigbati aba wa
oroadete yen kuro tan aowa tun se sibikan ni aro sibi Kan lale FINGBA 1

26. ERO AGBANA

Ewe bara ewe igi akoko pelu epo igi pandoro aose aoma fiwe aotun fi we
owo FINGBA 1

27. EDA

Egbo ipeta owo eyo tikoluju 10 aoda Omi osan wewe si Leyin ojo keta aoma
mun Sungbon Eni to ni Ulcer abi oloyun kogbodo mun o FINGBA 1

28. EDA
Okuta yangi oju ona
Enuopiye gun po Mon ose aoma Fi taba ninu okunkun FINGBA 1

29. AAJO OMO NKAN OSU TIKODA

Ao Han si Wala dudu735 ‫رصرصاعايتة‬


Aowa epo igi Ara Ase ale Ase aro aofi ki hantu yi sinu Ike funfun Kan aoma
mun Leyin ojo keje FINGBA 1

30. ARUN INU TINDAMUWA

Ose dudu die


Efinrin aogbo papo dada aoma mun laro lale FINGBA 1

31. ELEYI NI ASEJE AWURE.

Okan maalu kan tikowomi


Aoge si ona merindinlogun 16,
Eyin adie ororo mesan 9,
Ewe anu.
Ewe jeminiho.
Ewe Sawerepepe.
Ewe ina.
Ewe orijin.
Ewe ajeobale.
Ata ijosi.

Aolo papo,
Ao koko bo eyin adie yen,
Ao se lepo niyo pelu iru woro.
Ti oba jina tan,
Ao fi iyerosun te odu Ifa Ogundabede sinu Awo funfun kan,

Ao wa pe ohunre si,
Ao wa da sinu Aseje yen.
GBOLOHUN RE NIYI O Olugbara (3x) Olugbare (3x)
Sebi iwo loni ki tomode tagba gbere owo nla nla wafunmi. Sawerepepe
lobami pewonwa,
Towotowo owo won. Ki omo araye wafi owo owo won sinmi. Olugbare
ajagbare. Iwo lodifa fun ogundabede tonfi ojojumo aiye dawon nigaara owo
nlanla.
Ti mafi kole, timafi se ounrere wafunmi. Nitoripe igbe nlanla ni maalu nke,
Owo nlanla niwon finra maalu.
Owo niki omo araye magbe funmi.
Nitoripe omo araye kan komo ibiti adiye kori kodisi ninu eyin,
Ki omo araye maridimi seniki wonwa fi ire owo nla nla tamilore o,
AKIYESI Aso ti abawo si orun ni ao bo ti ao sin su bi osuka, ti ao sin so aseje
yi le lori ooo,
Ao sin tije ki Aseje yi o tutu dada kato sokale fun jije.
Yio BAWA lara mun o.
AKIYESI ASO TI AFI SOSUKA NA, AO NI WO MON O, ALE DANA SUN TABI KI
LO JUU DANU SORI AKITAN.
Iya Adura ADE ERI

32. OGUN EYONU TI AFI NBA ALANU PADE; Ao eyele funfun ojuda kan
poroporo oka baba,konukoho,osu ao gun gbogbo re papo ti yio kuna dada
ao po lose ao fi bintu si dada ao ma fi we ni araro pelu kahinkahin
tuntun.bi ogo tinje ti olorun ki a to we pe ojo mewa obirin yio po fun wa
gan ni ao si ri alanu ti yio se wa lore yi ba wa lara mu ooo.mose iba agba oo

33. OGUN KI OMOSE MASE JALE OGA-: Ao fi owo mu ese ino kan si ori
olo ati eyin ope kan ti opon dada ao wa gun yio kunna ao ma busi ounje
ajeku oga na fun omose peki oje opari

34. ETO-OSE ENITI ONWA OMO-ODO tabi OMO ISE


Egungun ori esin,awo ewiri,efun,eyo ijalo kan soso,ao jo papo ao po lose ao
ko sinu ajere ao ma bu we.

35. ORORE: afedanu lewiri nfena olorisa ki binu efun ko koferupe kun
oju tomode tagba lo npase fun ijalo ori esin oni buru komani opije ao ma
wi oro yi si ki ato fi we

36. EBE AWON AGBA, TI OMA NJE KI AWON AGBA DARI JIN WA.
Ewe orijin oojo 16, ewe ewuro oojo 16, ewe lapalapa pupa oojo 16, funfun
oojo 16,epo obo die, epo igi nla die, eru alamo 16, fitila oloju 16, ose dudu.
Sise re- A o gun awon eroja yi kuna daada, a o po mon ose dudu, a o ko ose
na sinu fitila yen, ti aba ti ko ose sinu re tan, isasun na ko gbodo kan ile mon.
A o gbe fitila na si ibi ti koti ni kanle.
Wiwe re - A o mafi ose yen we laaro kutu hai ati ni ale patapata.
Ti aba nwe lowo, ki ama je ki kainkan ma jabo sile mon, o ma nba ise je ni.
NOTICE- Ni awon asiko ti aba nwe ose yi lowo, ki a stop awon eran abiye
( birds) ni jije. Eran bi adiye, pepeye, turkey, Bat e.t.c.
But eni toba gbagbe, tosi je eran eye, ki o gbiyanju lati koko da ose na duro,
ki o fi eko ati epo pupa se etutu fun ojo bi meje, ki oto pada mawe ose na.
Ise yi ma nje ki ona eyan tete la, osi ma jeki a ri aanu gba nidi ise wa, ki si
jeki awon agba diwa lowo tabi nkan ini wa. Ise nla ni. Ojojumo ni a o ma we
o. Eni kan sini ise na wa fun.

37. ELEYI NI_OSE_TUDE_ASINA_AWON AGBA TODAJU


walai eleyi kuro ninu anbura ekeo ise ti moma'nse fun awon eniyan mi
daada ni ti kosi saije dola oseyi iwona lodan abo rewo tori tako tabo ni
sugbon abore ni eleyi. Ao lo wa omunu ewe Bomu bomu meta 3 meta pere
nio aogun eyo kookan pelu Ose iwe kookan fisi ori kanikahn kookan. Odo ni
wiwe oseyio. Ose akoko yen waafi epo pupa para. Elekeji yen waafi oyin
para. Elekeeta yen waaafi eeeru oju aro tiwon ti ndano daada ohun ni ao fi
para we Ose eleeketa yen loba pari walai koju beelo meji, meta naani OGUN

38. IMULE AWON AGBA

Ao wa eye adan kan ao fi atare kan si ni abiya osi, aoko ewe orijin oojo ti
kogbodo kanle pelu ewe ajeobale baakana lelori. ikoko yen kogbodo kanle
ti a ma fi jotan. a ma lo pe lu eko ni ago kan oru
NOTE: Agbodo pa gbogbo ina inu ile pata, ina phone agbodo pa, inu
okunkun birimu ni a ma lo.ise yii.........oo...odaju.. ao gbodo sun mo obinrin ni
gbogbo asiko yen.. enikan fun enikan. a le ma lo diedie.....

39. ASIRI TI AWON AGBA O KIN FI N DIYAN LOWO NINU ORIRE SISE
Ao han ayatal-Qursiyu meje-meje ninu peper funfun lona meji,ao de pelu
owu funfun, ao so ikokan Mon APA eyele ff otun ati tosi,ao GBE sinu igba
olomori,ao fi Odidi atare kan si legbe,ao ko opolopo ewe afeloru le Lori
Dada,ao fi omori e de pada.....ao we lowu ff.... Odi jijo..... Ao ma fi ro ekuru
funfun je ni anytime toba wuwa. N/BO tun sise asina owo gidi.
40. ASINA OWO

Eku linli aaye 3


Eso rere tako-tabo agolo FUNFUN Iru wooro Dede agolo milk kan,Odidi
atare kan.... Odi jijo, ao ro sinu akerengbe.Ao toju iye igun,iye akala pelu iye
lekeleke.
LILO-RE; Awon iye yen ni ao ma fi bu ebu yen leyokookan sinu awo ipese
laalale,ao ma la pelu epo pupa fun 16days lerawon. Ti ebu yen basiku leyin
16days yen,ao da awon iye yen sinu akengbe yen,ao lo so sodo tounsan.....ti
ebu yen basitan na,ao lo so akengbe yen sodo nani.
O

Awon asiri confirmed niyio: osole todaju Dada fun aseje:: aowa odindi igbin
togbo Dada totobi kan, pelu isu tannagbowo, iru woro pelu alubosa
elewe ati ata ijosin eyo25, iyepe oja tierotimankundada aobudienibe
aoge igbin yen si25, aowa owo eyo25, aowa gun isu tannapowo ati iru
woro ati iyepe ojana ati ata ijosin aogunwon papo aoni gun owo eyo
mo aose pelu igbin tiagesi25aosepapomorawo aofi epopupa si pelu iyo die
aoko owo eyo na pelu asejena aose tobatijina aosokale siori osuka akisa
aonijeki idirekanle aoda iyereorosun si oju obena aote IFA ogundabeje si
obena::aopa (oforesikiatojeobena) ::ogundabeje ole3 , gbewiri ole3, ogboju
ole3, tiohunmobi ti oni nkan fi nkanresi, agbalagba ole abese siosio,
ogbologbo ole abiese gborogboro jiji laji abi gbigbe logbe abi wiwa lonwa
kiologbe owo wa fun emi lagbaja omo lagbaja Kiomuwa si ilemi
ohun tokunrin tobinrin kiwongbe owo apo mendogbon wafunmi
kiotodiojomendogbon nitoripe ti omode bamu Igbo lowo agba bi agba
bamu Igbo , Igbo agba lore GBA tomode tagba tokunrin tobinrin wa fun mi
kiwon mako owo apo mendogbon wafunmi kiotodiojomendogbon IFA
mope oooo orunmila mope ooo kie maa salai damilohun to ase dandan ,:
aomaje igbiyi ni eyokankan aomamu sienu nikankan tiabajekantan aopon
owowa ekawatogunju aoponla aotunje elekeji aoponla aosebe titidori25
nitoripe 25niage igbin yen si then amosope tiabatinje igbin yen aomasope
tiabatinje igbin kan aosope owo mi di apo NLA kan aotunfielekeji sienu
aotunsope owomi do apo NLA meji aoso be titidori25 koko alomo tuntun
laofise asejeyi tibajetan owo eyo na yiowaninu koko Alamo tuntun na aofi
ideri kokona de aolorimole sinu Igbo odaju
41. AWURE OWO/OSOLE OWO ODAJU

Ori aja gbigbe kan. #1000 tuntun ao ki si eti otun. . Ao wafi #200 we igbo ao
kisi enu ori aja na. Ao wafi ewe sawerepepe su osuka ao gbe ori aja na si. Ao
wagbe gbogbo re sinu agbada ao fi odidi atare kan si. Ao jo papo ao mafi oti
schinap lo laro laro

42. Ise na niyi kose ni tale sefun kosatije eni tolowo lowo
Awon nkan ero njare oju oro osi bata igbi igbin apinnu nkan iyere photo
kekere paspot eni tafe gba nkan lowo re ao lo iyere
ao lo oju oro ti yio kuna dada
ao lo osi bata ti yio kuna dada
ao bo igbin yen lori ino
aowa yo igbin yen kuro ninu ikarahun aowa se igbin yen lepe niyo pelu
gbogbo nkan tati loyen
toba tijino ao sosi ori osuka
Aowa fi iyeru osun te ifa ejiogbe

43. OFO RE
atarara 3 otarara 3
otarara lodo san
igbin o labe tofi kola sehin
alajiki alajife awon ni won se fa foju oro tinloree saya omi won ni oju oro
ogbudo fomi sile oni ti ohun bafomi sile nko
Won ni yio maru yio magbe ni
aowa sope ti langbaja omo langbaja bafi emi lagbaja omo langbaja sile
komaru komagbe
Awon ni won se fa fo sibata lojo tinlore saya odo won ni ogbudo fodo sile
oni tohun ba fodo sile nko won ni toba fodo sile yio ma se bi were bi were
kakikari
aowa sope bi langbaja omo longbaja koba emi omo langbaja koma se bi
were bi were kakiri
Ejiogbe oo 3 emi lagbaja omo langbaja nimofe je ase jeyi ara langbaja omo
langbaja ni koti masise koma losun koma lewo afi toba foju kan emi lagbaja
omo lagbaja aowa da iyeru osun yen sinu ase je yen aowa je
Kawa bere nkan tafe lowo eni na opari

44. AWURE
Pepeye kan a o yo ifun inu re a o jo papo mo atare odindin kan ao pin si ona
meji apa kan ose ikeji epo pupa a o ma la a o fi eran Pepeye na se sara

45. ITAJA
Ewe abifagburu atare kan imi orun a o jo papo a o mo ose a o ma fi fo owo
wa omi re a o fi won ile shop wa

46. ASINA
Ewe akoko oojo a o ro ori sun ti o ba di aro a o gun papo mo ewe taba a o po
mo ose odi wiwe

47. EYONU ASINA


ORI ALAGBA KAN AO FI SINU APE A O FI ATARA KAN SI LEGBE A O LO EPO
OBO KUNA DADA A O FI BOMOLE A O JO A O LO NI ALE PATAPATA PELU
OTI
2
ori ako alagba kan ewe iyalode funfun ewuro a o gun gbogbo re papo mo
ose a o ma fi wiwe ni araro

48. EYONU
Ewe oriji alagba kan eye onbe adan a o gun kuna dada a o po lose a o fi oyin
ati adin po dada odi wiwe

49. ITAJA
EGBO TUDE ATA PUPA 3 ATA DUDU A O GUN GBOGBO RE PAPO ODI WIWE

50. TUDE ASINA


ALOMU FUNFUN ATI DUDU KAHUN BILALA EPO OBO EPO IGI NLA A O
GUN KUNA A O PO NI OSE A O MA FI WIWE

51. KI OWO MA DA LOWO


ORI OKETE TUTU KAN A O GUN PAPO MO OSE A O LE ARA OGIRI NI OKE A
O MA WIWE

52. AWURE
EYE LILI 4 ATARE A O LO KUNA DADA A O LO #1000 KUNA DADA A O PO
PAPO A O PIN SI ONA 7 A O MA FI OTI LO FUN OJO MEJE GBAKO

53. AISIKI ILE KIKO


EYELE FUNFUN KAN EYELE DUDU EYE EGA KAN EYE OTATA KAN ADIE
ALAWO META KAN EWE ORIJI EWE OWU AKESE A O GUN GBOGBO MO
OSE A O FI LOFINDA KAN PO A O MA FI WE NI OJO ALAMISI

54. ASEJE OWO

EJA TITUN KAN AO GE SI META EWE SAWEREPEPE EWE AJE EWE


TANAPOWO EWE ANU EWE IYALODE PUPA EWE OLA DIE A O GUN PO MO
IYERE 16 A O SE NI ASEJE

55. ITAJA

EJINRIN EWE AJEOBALE EPO OBO EYIN ORORO OMI AGBON A O GUN
GBOGBO RE PAPO MO WIWE

56. OSE AWURE


AKO ALAGBA ATI ABO ILEKE ITUN ATI IFA ABERE A O GUN PAPO MO OSE
A O MA FI WE A O KOKO LO FI EWE EJINRIN SE KAINKAIN FUN OJO KI A
TO LO KAINKAIN IBILE

57. ITAJA
EWE RERE A O GUN PA MO OSE PELU OGEDE OMINI PAPO MO ODI WIWE

58. IFERAN GBOGBO OBINRIN


EWE WONJO TUTU A O GUN KUNA DADA A O PO MO BINTU A O MA FI
PARA

59. APORO OFA


Ekun asin gbigbe imi ojo a o lo a o da sinu adi dudu

60. OGUN TIA FI KO OTI SILE


A O WA ORI EKU ASI KOKOKRO IKAMODUN TOPO DIE A O JO PAPO A O DA
SINU OTI FUN ENIA K O MA MU

IPARA ASINA IYE AGBE IYE ALUKO IRUN IYAMOPO A O GUN PAPO KUNA A
O DA SINU LOFINDA

61. OHUNRE
AGBE KI JI KO MA KA OWO ALUKO KI JI KO MA KA OSUN A JI PATE OOWO
KI JI KO MA RISE KI EMI LAGBAJA OMO LAGBAJA RISE LONI ADURA

62. AWURE
EWE EJINRIN EWE AJEOBALE EPO OBO ABERE ILEKE ITUN ATI IFA A
OGUN RE PAPO MO OSE DUDU A O MA FI WE

63. IWE ETO IBILE


YARA AGBARA ATI ASEYORI

Lati owo oludasile Egbe Prophet Ige ibikunle ati gbogbo omo lapapo

1. ORO IYANJU
Mo dupe lowo olorun ati atilehin gbogbo omo egbe patapata
Mo je eniti ofe ki gbogbo ni agbara lati se ise ti o wa ninu iwe yen
Ewe ati egbo odara pupo lati fi ran ara wa lowo enikan ki juba a fi ogun
sinu kun, mo woye wipe opo wa ni o ni ogbon lati le tesiwaju lo mu wa se
akojupo iwe yen,
A ko iwe yi pe eniti oro iwe yi ko ba ye ki o pe number 08134298493
WhatsApp Eje je ki gbogbo wa ko eko ogbon imo ati oye ninu ogun idile ati
bebelo
Ko si ise ti kope ninu ise iwe yen mo ki gbogbo eyin omo bibi ile yoruba ti o
mo ki a to mo

2. EBE AWON AGBA


Opolo gbigbe 7 akara ori akitan ewe imiesu a o gun papo a o po lo ose a o
ma fi we ni ale ati aro

3. EYONU IDARIJI
Ewe oriji ewe ajeobale epo obo a o gun gbogbo re papo mo ose a o bu iyo
die sinu awo sobi ao gbe igbin kan si ori iyo na a o fi ose na bo mole lehin
ojo keta odi wiwe

4. AWORO
Ewe amunimuye a o gun papo mo ose a o fi bo gbogbo ara tagiri kan
patapata a o gbele a o fi epo pupa po yepe inu koto na a o gbe tagiri na si a o
bo mole a o fi eyo atare kan si a o se adura si a o bo mole

5. ADODUN
Ewe omisimisi eso werejeje ewe agbayun atare kan ewe katafe a o lo papo
ao fi oyin ati opolo obuko po mo ose a o fi ma pa nkan wa fi lopo

6. AGBERO
ATARE KAN AKARA ORI APATA ATARI OBUKO A O JO PAPO A O FI SIN
GBERE LATI IKAN ARI OWO TITI DE EJIKA A O SIN OWO MEJEJI

7. ASE ARA
Egbo owu akese iye agbe iye aluko ikode kan eru alamo eyin oka kan osun
ati etu ibon a o lo kuna ao fi si gbere si ete wa

8. APADA
OMO NILE KAN OYE IGBALE TI WON TI FI GBALE DADA A O KA SI MEJE A
O KI BO ENU OMO NILE NI OYE ATARE AJA AO JO A O LO KUNA A O FI JE
AKARA ELEPO JE

9. OGUN TINU BA TA ENIA TABI ARA


Ewe arojoku Ewe patanmo enu opire atare a o jo a o lo kuna a o fi sin gbere
meta meta si rekerike ara wa

10. ASETA TI AWON AGBA FI SIN WA NI GBERE SI ORI


ESo aworoso 9/7 eyo atare 9/7 a o lo papo ni enu ona ile wa a o fi sa ori wa
lati waju ori wa si pako ni ale patapata ti o di ojo keji awon agba a sin wa ni
gbere si ori

11. OGUN OWO TODAJU


Kowe kan eye kanakana kan eyin ororo kan atare odidi kan a o jo gbogbo re
papo a o ma fi oti lo ni araro

12. OSOLE OWO


IGUN OYE KAN A O FI #1000 NAIRA KAN TELE INU APE A O FI ATARE KAN
SINI ORI A O PA IGUN NA EJERE NI A O DA SI ORI OWO NA A O JO A O LO
KUNA TI O BA DI AGO KAN ORU A O SE ADURA OWO NLA NLA SI A O LO NI
EKANA IGUN YEN A O LA SIN BI WON SE SI OKUN ENIKANKAN KO GBODO
RI WA NINU IGBO NI A O SIN SI

13. OSOLE

ORI OLOGBO TO NI IRUN OKA BABA PUPA A O FI ATARE SI A O JO A O MA


FI OTI LO NI ARARO

14. ASINA OWO Sheikh Yusuf olatunji


Algambari 08067205440
EYIN IBILE META IKE MALU 3 EWE ONITIKUTI EWE OLA DIE A O LO PAPO
A O FI SE ASEJE NA PELU ADURA OWO NLANLA

15. OSOLE
EFO GURE IYE IGUN IYE AKALA EWE SEFUNSEFUN AJE OLOKUN A O LO
GBOGBO RE PAPO MO ORI A O PIN SI ONA 16 MEJO A O GBEMI NI ARO
MEJO TOKUN A O GBE MI NI ALE PELU OTI

16. EYONU RIRISE PROMISE


Ewe ejirin a o su ni osuka a o gbe sinu ape a o ko eyin adie meta si ori re a o
fi atare kan si a o tu fi ewe ejirin su osuka mi agbe le ni ori a o jo papo ao da
sinu oyin

17. KI OMO TETE RI


ESE APARO MEJEJI ESE ETU ESE ATI OWO OLOGBO A O JO A O LO KUNA A
O PO MO OSE A FI MA WE OMO NA

18. IFERAN EWE ARINKOSUN A O GUN PAPO MO OSE A O FI ITO IDI WA


PO DADA A O MA FI WE TIA BA TI WE TAN ASO IYAWO WA NI A O MA
FI NU ARA WA IYAWO WA MA NIFE WA DADA

19. OJU DIDUN

OJU OKA MEJEJI A O LO MO TIRO A O MA LE SI OJU ENINA

20. OSOLE OWO NLA

ADAN KAN EYE ONBE KAN EYELE FUNFUN KAN EJA OJIJI KAN AFARA
OYIN EYE LILI KAN EWE ORIJI EWE BOMBOM MEJI EWE KUJEKUJE OWO
TITU NLA KAN EWE OLA OTI SCHINAP KAN ORI PUPO ATARE KAN A O FI
ORI PA EWE BOMBOM YEN DADA A O PA EYELE NA A O FI EJE EYELE YEN
TE EJIOGBE SI EYIN OWO NA A O TU FI EJERE TE IFA OGUNDABEDE SI
WAJU OWO A O DE OJU OWO NA DE EWE BOMBOM YEN A O GBE SINU APE
IJO OGUN WA A O KO GBOGBO NKA TOKUN SI A O FI EWE OLA BOMOLE
DADA A O JO A O LO A O DA SINU ADO ATO KAN A O TU PA EYELE KAN A O
FI BO ADO NA A O GBE SINU ASO FUNFUN KAN

LILO RE A O DA DIE SINU AWO FUN A O TE NI IFA OGUNDABEDE A O SE


ADURA SI A O FI OYIN LA ODAJU

Sheikh Yusuf olatunji


Algambari 08067205440

You might also like