Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 4

NIBO LAN BAIYE LO

Chorus :solo nibo lan lan baye yi lo


All nibo lan baye yi lo oo
Alcofe gbo ti olorun mo ohun auye loku tan lepa, onigbagbo ekiye sara oo nibo lan
baye yi loo
1) Aiye, aiye, aiye, akamara, ohun aiye abaye lo alco mohun kohu wasaiye
alwni mohun kohu pada lo, eye ka ma le pa ile wa oo ibi isin mi mani
2) Ewo ile aye bose deri kodo ,ohun gbogbo wale koko koko, an lo le aiye
botiwu wa, alio ranti ibi ti atiwa ati gbagbe pe olorun nbe, oni gbagbo eje
alaye sara o, nibo lan baye yi lo, oo
3) Ologun lolese alagbada, lole gbawa sebun lan bukiri an se rawa botiwuwa
atije,atimu, wa dogun funwa jesu Kristi dakun wa gbawa oo nibo lan baye yi
lo oo
4) Olugbala dakun wa gba wa iwo nikan lo le kowa yo, ninu gbogbo wahala
won yi, boje esewa ni leyan dariji, wa, ko fanu ko wa yo, iwo nikan lole gba
wa baba wo ile wa san.

Solo : olorun wa gba wa oo


All: baba dakun gba wa
Solo: ninu iji aiye gbogbo
Solo:ninu hila hila
Solo: fa nu re ko way o
Solo: eyin lole ba wa se
Solo:wagba wa/2x

OHUN RERE NI LATI MA DUPE


Chorus: ohun rere ni lati ma fope fun olorun oba to dawasi lati korin iyin si
oruko re oga ogo.
1. Eni mo re olorun ko dupe, eni mo re olorun ko fi yin fu abore lori wa
kolorun kaa ope ye ooo oba wa
2. Oluwa isere ti tobi to lori aye wa, aro aro jinle gidigidi aso wipe ese,
asiwere eni a ni kole dupe o, amo riri re baba
3. Ayin o,o oba wa to da wasi dojo oni eleru ni iyin eseun fun anu re lori,
aiye wa , gbogbo ogo loye o, oban giji emese oo ee
4. Adura ore re baba, alkcei ninu lore re loriwa , oro ewu rewa iluja ikinse
mime se wa anu lari gba oo oro ofe re mari

Solo : anu larigba oo


All; lase wa dupe ore, ore alen mye lori aye wa oo baba amawa dupe
Solo: baba amawa dupe
All:
Solo: fin ara abore
Solo:Oba to pawa mo
Solo:Tomu wa rujo oni
Solo:aso wipe ese
Solo:ose olore awa
Solo:adupe pe ayin oo 12x

AMU IYIN WA
Solo:ah amope wa baba o amu iyin wa fun oo /2x ilwo nil cen to pe tosi iwo
niken ni iyin ye, gbo pe iyin tamu wa fun o
1. Awa dupe baba tomu wa ni ajodun ojo onii opo ewu loti gbe fo wa
da ninu odun tawa yi, opo irin ajo lati rin tade oo, oka waye titi do
ni kaseni toto o baba
2. One voice (haa mo baa rin re) adupe ore ,ore atigba de igba, lori
aye wao , baba baba oo iwo nikan loni gbogbo ogo
3. Bawa balegbegun, ahon ko yo lati fi yin gbe oga, sugbon iyin la
mu wa fun o baba tewo gba iyin wa
4. Oni sarku so wipe, emi yio korin titu si olorun awon baba wa alabo
ile goseni, ohin lalabe, aye wa kin sun beni kin togbe lori aye wa o
eru jeje leti okun pupa, baba iyin ye o
Solo : toto ola re oo /4x
All: tooto ola re /4x
Solo: alagbara giga emase
Solo: kosalagbara tooto baba
Solo: ajikan lukan pa mani o
Solo: oba to laju afoju
Solo: agbani latan mani oo
Solo: oba to sekun derin
Chorus: amande oo, olorun ipinnu, ayin ooon olorun tawa fun ojo oni ti o bawa
leiye laye wa oo ayin oo olrun ipinnu
Solo : awade olorun baba, ayinoo olorun emimimo, ojo on bawa laye laye wa oo
agbe o ge, oyigiyigi, eleruniyan eseun oo
Solo 2:olope lope yefun afone fun baba oniyin niyim ye iyin ye jesu oba wa ,
atorire kari aye ayino o oba awon oba.
Solo 3: onibu ore baba oo oseun to lawa ye lairo ti ese wa ese o afope fun oo baja
iwoloba nla toju gbogbo ayelo gba iyin re
ARA
Chorus : ara nla olorun ara nla, wa faiye mi dara rere /2x
1. Ara ire nimotoro olorun aldara kin lowo lowo kin ri ifokanbale kaiye mi
gbatuse kin mase seru egbe be, motutro oba alagbara
2. Oni kin bere wipe mari o oni kin kanlekin aosisi funmi ilekun ayomrkan
kemi kope laiye kesirimi boo oba ala ara ire
Solo: alagbara nla baba ala ranla
All:alara nla faiye mi dare rere
Solo:alagbara nla olorun onibu ore
Solo:oba to mohun gbogbo tutun sohun gbogbo
Solo:aara aiye mi lowore lowa
Solo:baba aalara wa sogbami dotun
Solo:oluran lowo mi baba gbe waa funmi
Solo:oba to da orun osupa ati irawo
Solo; wa gbo temi baba olorun aiyeraye
Solo:ofayaye esteri dace od ayaba
Solo: mo de kai nkan eru di omo oba
Solo:obedidomu otosi odi oloro
Solo:ama foju riran omu aro rin
Solo:oku ojo meric iwo loji dide.

ISE RE MO LALA
Solo:isere re ko baba (baba)
All:ise re kio lata
Solo:iwo kodaiye iwo lloo ba orun o
Solo:wo da imole ati olunkun o
Solo:wo da san mo o ati o gha eranko
Solo:wo de iyangbe ile ughin gbogbo oni
Liawo muwo gbe baba
All: wo tobeee wo reebee olorun aiyera ye ipalila gbogbo ililiawo re dansanala reee
ooo
Solo:olorun gbo tobi
All: wo tobi tititititi
Aiye erie gbe woo, orun eme gbowo (smart) womorun sele,umun aybo
Se apopo itehinre ilabi esi ooo
Solo: wo laigba baba gba
All: olorun gbo lagbara titi 6x
Wo laiaju afoju, womaro lara de
Wo ji olu liaale ara ho eru d baa
Solo: ise owo re koto bee
All: bakoo baba gba aditu lo amowo tu oro orun kiwo mu duye oro ki wo nu de
orun o
Wo merun pe dee eniyon, wo ra min emin iye hi
Woli omin abe orin, uwoju po hibikan,iyangbe ile uli hele di ile ughu gba gban
mukole ghan mu koko ijeje ghaa
Solo: ise re ko o baba
All: ise re ko o ise re ko oo, ise re koko olula emeje sakan wa 2x.

You might also like