Download as pdf or txt
Download as pdf or txt
You are on page 1of 1

!

0 ratings · 724 views · 34 pages


Screenshot 2023-04-27 at
10.25.29 AM
Uploaded by Adeyemi Alwaraky

Full description

( ! " # $ %
Save 0% 0% Embed Share Print

Download now 8 of 34 & Search document '

Emi Alfa OKANLAWON ko awon ogun imule yi jo lati le je anfani fun gbogbo olugbiyanju nigbati o
jasi wipe o se o je ni aye yii,be ise imule po ninu Ajo,olohun koni kodi aimose si gbogbo wa ooo.

IMULE AWON AGBA E MA SOKOLASA EYE IYA-MI

Moki Gbogbo Eyin Agbalagba Akoni Sebi Eyin Agbalagba Leni Imule Lolori Ogun Nitori Ibiti Osole
ati Awure kole Gbeni de Imule A gbe ni koja re,Alfa Okanlawon mo seba Agba ooo.
Odidi Asa Awodi Merindilogun (16)
Opolo Gbigbe Merindilogun (16)
Oga Gbigbe Merindilogun (16)
Eku Asin Merindilogun (16)
Obi Ifin Merindilogun (16)
Obi Ipa Merindilogun (16)
Odidi Atare Merindilogun (16)
Iye Agbe Merindilogun (16)
Iye Aluko Merindilogun (16)
Ikode Merindilogun(16)
Awo Igala Odidi tia ge si Merindilogun (16)
Ao to gbogbo re base ko yii,Ao jo Ama wa teni ifa Osa meji Odu Awon Agbalagba Ao pe Ofore
si,Ao ro sinu Ado sere Nla kan,Ao wa paa Obuko Ibile Togbo kan Fun,Ao fi eje re yii Ara Ado yii
daada.
Sara re::
Eni tio ni ise yii,Iyawo re,pelu Omo re ko gbodo je ninu Eran yii Ao fi se Sara fun Awon
Eniyan,Gbogbo nkan inu re ipese lao fise leyin tia toju re tan.
Lilo re:::
Ao ma fi foko tutu mu laro,Ao tun ma fi Epo pupa la lalale
OFO RE::
E MA SÒKÒ LU ÀSÁ,EYE IYA-MI NI OOO 3×,ENI BA SOKO LU ASA,ASO RE ÁFÀYA,ÁFÀYA
LÁKÉ,ÁFÀYA LÓKÒ OOO,ÁFÀYA LÓLÀ,TIO FI DELE AWÁ ÒRÀNGÚN OMO OGBOYE OOO.

IPESE IMULE AJE ORUN TODAJU.

kosi nkan tia le lo ipese yi fun.Ale fi fi tu alare sile,ale fi pe eeyan lati ilu oyinbo wale,ale fi tu ejo
court,ale fi da seria fun eeyan,etc.O DAJU

Segiaorun(Segisorun) 3
Adaripon 3
Afomo ati egbo igi lapalapa funfun
Odidi atare kan
Ao jo papo,ao ro sinu ato.Ao wa fi akuko ati abo adie bo ado ato yi.Ao gbe ko sibi kan.Ao ni jeki idi
re kanle mo

Lilore:
Ao ma fi gbe eran ewure tia ti gesi 16. Si Orita meta (T-junction).
Ao ta ebu die si opon ifa,ao wa teni osa meji,ao pe ohun re si.Ao wa dasi ori eran naa.
Ohun re:
Osa meji ooo,osa eleye 3*
Iwo lose eyin koto topon awon iyami osoronga wasi ode isalu aiye.Mopeo loni.Kio wa bami gbe
etutu mi losi ode orun.Ki awon eleye orun somi di eni imule aiye.Eiyekeye kii binu botuje.Tigitope
ni nsanu afomo.Eyin eleiye ooo ,e paropo kie wa saanu mi.Alaamu ki kohun ogiri.Segisorun
kolapa,kolese,kolori ti nfi ru eru tie de isalu orun.Leyin ofo,ao daniyan.Ao wa da ebu na sori eran

na.Ao gbe losi orita ODAJU.

IMULE ADO META

Eku eda 3,odidi atare 3,eye ega 3,eye kowee 3,oga gbigbe 3,Adan 3,ikode 3,ado ijamo 3,ila jije
lopolopo,ewe alupaida lopolopo..SISE RE :-
A maa fi nkan tirin lu ado kan,a o ki ikode bo,tiko ni wole tan,a maa fi obe tomu daada la ado keji
si meji,a o ki ikode kan bo laarin,a o lu ado keta fo,a o ko Nile,ao fi ikode kan sii,awon ado meteta
yi la maa fi tele ape,a o wa ko awon nkan toku lee Lori,a o wa ko ewe alupaida lopolopo lee Lori,ti
awon nkan yen koni han sita rara,a o jopo,a maa fi epo pupa yi aaro ka,a o lo kunna,a maa da sinu
opon ifa,a o te ni osa meji laarin,irete olota legbe otun,otura meji legbe osi,a o pe gbolohun re sii,a
o ro sinu seere,ao pa abo adie dudu kan ati eyele toni irun nibi ese sii,a o fi eje awon mejeji si ara
seere yen,a o le iye awon mejeji mo sere yen lara.
OFO RE:
IRIFIN LAWO INANARAN,ALAWO KOSE OLOHUN BAMI LERU,AWO WON NI JEJE ENI LORUN OJA
BABALAWO ILA,EYIN IYA MI OSORONGA,MO PEYIN O,KI E DAMI LOHUN LONI,EYIN IYA MI
OSORONGA,EDA LONI KI E DA TEMI SI RERE LAYE, ALUPAIDA LONI KI E PA IRE TEMI L OMO L
DASI ODO MI,EYIN IYA MI OSORONGA,ADO META LADO YIN,OKAN BALE,O FO,OKAN BALE O LA,
OKAN TOKU LEFI TANA OJU YINRINYINRIN,ASURE FARA YI EPO NI A NPE EYIN IYA MI,ORO
BALE SE SOSO LANPE EYIN IYA MI,EYE ABIYE HE HE HE LANPE EYIN IYA MI,OGBOYA LOHUN
ATA SOSO JAKO, LANPE EYIN IYA MI,EMI L OMO L NIMO WOLE DE O,ERAN GBIGBE NIMI,ERAN
TUTU BEJEBEJE NI KI E WALO,AWA YIN LAJO PE,AWA YIN LAJO JE,AWA YIN LAJO MULE
NIJOHUN ANA,EEWO ORISA,AKII BANI MULE KATUN DANI,AWA YIN LAJO DOGBA,OGBON WONU
OGBON,EYE WONU EYE,ADAN WONU ADAN EGA WONU EYE,KOWEEE 3*EYE IMULE NIFE,KOWE
NKE,EYE AJE KO HA,OGBINGBIN HIN HIN HIN NIFE,KOWE NKE,ADAN DE ALAROYE EYE,IGBE IKU
KO KANMI LEYE ADAN NKE,OSA MEJI ELEYE,IRETE OLOTA ELEYE,OTURA MEJI ELEYE, ELEYE
MA MA BINU, ELEYE MA MA SE JA,EMI YIN LAJO PE LONI,EMI NAA DI ELEYE LONI,AJE RERE NI
KI NMAA RI,AJE RERE NI KO MAA RIMI, (ANIYAN)
Ao fi die ninu ebu yi po ose toto we fun ojo meje,ao maa fi ose yen we lalale,ao maa fi ebu toku
fokomu leyin ti a bati wetan.IKILO:-
AKO GBODO SUNMO OBINRIN LOJO TI A BA LO ISE YI OOO.

OSO GBARIYE SANGO KEKERE.

Eiyele dudu, olongbo dudu, ase ale ati aro igi iroko, aso waji, kowe kan, eiye alagbede orun, eiye
oge, awo igala odidi kan ao ge si 16, asin 16, oga gbigbe 16, opolopo gbigbe 16,eso idoo agolo
kan, eso werenjeje agolo kan, iye agbe 16, iye aluko 16, ikode 16,odidi eiye igun kan Tonifun
kan,Odidi aso eegun (complete),Adaripipon 16, egbo senifiran, eresile ewe lapalapa funfun, ere
sile ewe ajeobale ,ori oka kan, ori ere kan,Afatan irun ori eni tofe se ise yii, ao jo loru, ao pa akuko
adie kan fun, oju meji kogbodo ri ise yii mo, ao ma fi schnap loo lararo.

IMULE ELEMI MEJE

- Ako alangba meta


- aso dudu,
- aso pupa,
- aso funfun,
- iye agbe kan
- iye aluko kan
- iye lekeleke kan

ao la ako alangba kan, ao te aso pupa si lele, ao fi iye aluko si ninu, ao te aso dudu si lele, ao gbe
ako alangba keji si, ao la inu re, ao fi iye agbe kan si, ao te aso funfun si lele, ao fi alangba keta si,
ao la laya, aofi iye lekeleke si, ao wa fi owu pupa ran ako alangba alaso pupa, owu dudu fi ran
alangba alaso dudu, owu funfun fi ran alangba alaso funfun laya won, ao fi atare kan kan sinu
alangba kan kan, toba si wu wa ale pin kan sona meta ni oko atare, ao wa we bi oku, taba tiwe
tan, ao ko won sinu ape, ao ko enu won sira won ninu ape, ao jo po, ao fi epo pupa yika aro, ao fi
ewe iyalode funfun bo mole ti koni han mo, toba jo tan, ao pin sona meji, ao po idakan Mose dudu,
ao da
- adin eyan,
-ori,
- ogere epo pupa
papo ninu abo kan, ti aba we iseyi fun ojo meta, ao gbodo sun mo obirin oooo, taba we ose
alakoko kan, ao sese ma lo ebu elepo yen, bi epo bati fetan Lori ebu yen, ao da epo si
NB : obinrin ko gbodo lo ogun yi oooo, enitoba nlo iseyi ko gbodo sun mo obinrin ooo, ebu yen ko
gbodo tan siwaju ose.

IMULE ADEGBALU.......

Odidi igun Toni ifun ninu kan... Ewe agogo igun (ewe Ogbe ori Akuko)oojo..odidi atare kan..ao
jopo ... Ao lo kuna..ao ma fii epo pupa LA ninu awo ipese lalale....awo ti won fii gbe ipese rii lo
dara ju.

IMULE IYAKERE

Opolopo ewe roroo, epo igi ose, ewe alupaida , isu koko pupa, lefun- losun, odidi atare kan ,ao jo
won po , ao lo kunna ,ao d'à sinu opon Ifa, ao te ni Ifa osa méta, ao pe ohun re si, ao pa agbebo
adie ,ao ro eje le sinu ise yen , ao ro ise yen sinu séré nla kan,ao tun ro eje adie yen ti o ku si ara
sere yen ,ao le iye adie na mo sere na l'Ara , a le fi oti lo, abi eko tutu, abi epo pupa ninu Awo sobi
ni Dédé ago kan ori
OFORE:
Eiye werewere eiye ori ogun, oni omo ogun ni ohun nse×3, eiye gbogagboga ori igi ose oke,oni
omo ici ose ni ohun nse×3, iwapele ni t'etu omo agbonmiregun, oni omo agbonmiregun ni ohun
nse×3, awon meteta ni won ikole orun bo wa si ikole aiye, won pade awon arugbo meta ni orita
meta apata agba nsala, awon arugbo yi ni ki won pada seyin , won ni awon o ni pada ,igba ti won
burin gada , iwapelenitetu pada losi odo babare , agbonmiregun, oni awon ri awon arugbo méta ni
orita méta méta AGBA nsala , oni won ni ki awon pada seyin , awon si so wipe awon o ni pada
seyin, oni nitorie ni oun se wa so fun iwo baba oun agbonmiregun, agbonmiregun ni o seun , igba
yi ni oun to mo wipe omo oun gidi ni iwo nse, orunmila wa fun omo le ni nkan merin , akoko , o fun
ni imule , ekeji , o fun ni isu koko, eketa, o fun ni epo igi ose, o tun fun ni ewe roro se ikerin, oni ki
iwapelenitetu ma lo s'ode aiye , oni gbogbo nkan ti iwapelenitetu ba dawole l'ode aiye ,oni aiye o ni
baje mo l'owo , oni gbogbo Oran yo wu ti o ba da , oni asegbe ni yoo ma'a se, oni toripe arugbo
akoko, ti o ma koko Ri bi o ti se nlo yi, ASAKE ni oruko re nje , arugbo ekeji, to télé, ODERE ni oruko
re nje, oni arugbo to gbe yin, IYA KERE l'oruko le nje, orunmila ni, ti o ba de odo won, ti won ba da
oro s'ile ki owo na da oro s'ile , ti won ba sope OLOMU ki iwo na sope OTUKANRAN, ti won ba
sope OFUNJA, ki iwo na sope , OFUNKO, nigba ti iwapelenitetu yo si won, won d'à oro s'ile, ni
tooto ,oun na si d'à oro si won, won nje o mo oruko awon ,oni oun mo oruko yin, iwapelenitetu ni
arugbo akoko, ASAKE ni oruko re nje, arugbo keji ODERE ni oruko re nje, sebi IYA KERE ni arugbo
keta , iwapelenitetu wa s'enu koto orin Awo bo si l'enu, oni ASAKE mohun mi o , ODERE mohun mi
o, gbogbo eleiye mo ba yin mule l'oni o IYA KERE l'ohun mi , oni koko l'oni ki oro emi L omo L ki o

ko l'oni si rere ×3 , ASAKE mohun mi o ODERE mohun mi o , gbogbo eleiye mo bayin mule l'oni o ,
IYA KERE mohun mi, alupaida l'oni ki e pa gbogbo ibi to ba nbe l'Ara mi da si rere l'oni×3, ASAKE
mohun mi o ,ODERE mohun mi o, gbogbo eleiye mo bayin mule l'oni o IYA KERE mohun mi, se bi
igbo kii roro , ki roro ma ba gbe×3,ASAKE mohun mi o , ODERE mohun mi o, gbogbo eleiye mo ba
yin mule l'oni o ,IYA KERE mohun mi aje kii roro ki o je igi ose×3, ASAKE mohun mi o, ODERE
mohun mi o, gbogbo eleiye mo ba yin mule l'oni o IYA KERE mohun mi, atare kii kere KO ma l'omo
n'inu×3, Lati kekere mi ni ki nti ma ni owo l'owo , imule owo nlanla, ni mo bayin se, mi o fi omo mi
seda, mi o fi aya mi seda, mi o fi ara mi seda ooo, imule owo nlanla ni mo bayin se, ki e bere si ni
dari awon olowo nlanla s'odo mi,t'owo t'owo owo won.

IMULE GBARIYE

AO WA ODIDI ASO EEGUN TOGBAJUMA DADA KAN.

ODIDI EYE KOWE MOKANLA,ODIDI EYE KANAKANA META,ODIDI EYE OGESHA(OLOGESA)


META,EPO IGI APA ASE ALE ATI TARO.EPO IGI IROKO ASE ALE ATI TARO, EPO IGI ORURU ASE
ALE ATI TARO,EDUN ARA GIDI (ORIGINAL)META. AO DA GBOGBO E SINU AGBADA. AO GBE
KANA.AO MA FI ATA IJOSI KO INA RE TIO FI JO TAN.AO SI SO ERAN OBUKO IBILE KAN MO TOSI
IBI TI ATI NJO OGUN YI LATI IBERE PELU OKUN TONI PON DADA LAO FI SO MALE. ATI WIPE INU
ARO ONIGUN META LAO TI JO OGUN YI ATI WIPE INU IGBO LAO SI TI JO.TO BAWA KU DIE KI
OGUN YI JO TAN. AO WA PA ERAN OBUKO TIA SO MALE YI SINU RE. AO RO GBOGBO EJERE SI
DADA. TO BAWA JO TAN AO LO KUN DADA TIO NI KANLE.GBOGBO OHUN TI ABA F ILO OGUN YI
NA O GBODO KANLE O. AO PIN WON SINU ADO ATO,AO WA MU NINU ORIKERIKE ERAN TIA PAA
YI. AO KO SINU AWO SOBI NLA KAN AO FON EBU YI LE LORI DIE.PELU EPO PUPA. AO SADUA
SI,AO GBE LO SI ORITA. OKUN TO NIPON TA FI SO ERAN YI LORUN KIATO PA TELE. OHUN LA FI
SE OSUKA LORI ITA,AO WA GBE IPESE YI LE LORI,TOBAWADI ARO KUTU OJO KEJI,AO LO GBE
OKUN ATI AWO IPESE YI WALE. AO TUN TOJU WON PA MO BAKANA NIJO TIA BA JO ISE YI TAN.
AO BU DIE NINU EBU NA. AO FISE EYE EGA AKO KAN JE PELU EPO ATI IYO. AKO EGA NAA YIO
JE AIYE. AO SI FUN LORUN PA NI OOO AO NI DU EYE NAA AO JE ASEJE YI BE FUN OSU META.
BAKANA LOJO TI ABAJO OGUN YI TAN,AO TUN BU NINU EBU YI AO FI PO OSE DUDU PELU EJE
ADIE ABO DUDU KAN AO KO OSE NA SINU IGBA ONIKOKO. AO WAFI ORI ADIE YI GUN OSE YI
LORI.TI YIO KO ENU SOKE. AO MAFI OSE YI WE LEKAN LOSE. AO SI TUN MAFI EBU YI LAA EPO
PUPA LALALE O TAN. ENIKENI TI OGUN YI BA WA MU WA. AO MA SO FUN WON PE KI WON O
LORA ERAN EWURE KAN WA.AO WA LO MU OKUN TIA FI PAMO YI. AO FI SI ERAN NA LORUN,AO
YO EYI TO BA BAWA DANU,AO WA FA ERAN NA WOLE. AO SO FUN ALEJO NA KOHUN NAA O
TELE WA WOLE. TI ABAJO WOLE TAN,AO NI KI ALEJO NA BO RARE SI IHOHO,KIO KUNLE,AO WA
YO OKUN ORUN ERAN YI AO KI BO ONITOHUN LORUN BI ERAN. AO WA NI KOTORO GBOGBO
OHUN TO BA FE,TOBATISE TAN AO WA GBA ESE RE YO OKUN ERAN YI LARA RE,AO NI KO WO
ASO PADA. AO SI TUN DA OKUN NAA PADA SI ORUN ERAN YI. AO JO JADE SITA. AO PA ERAN YI.
AO YO GBOGBO ORIKE ARA RE SINU AWO SOBI TAKOKO LO LOJO SI,AO FON EBU YI LE LORI,AO
BU EPO SI,AO SADUA SI,AO GBE LO SORI ITA AO FI OKUN ERAN YI SE OSUKA AO GBE IPESE NAA
LE,TILE BAMA NIDAJI AO LO GBE AWO IPESE ATI OKUN NA WALE TORI OJO IMI.

IMULE OGBE OGUN

Àidan 16,odidi atare kan ao jo papo ao teni ifa (ogbe gún) ao pe ofore sí.
OFO RE:
ajigboko 3x ajigbeda3x ajigbeda munre3x osu mare toju òrun soko si aye3x ajigboko lórúko ti a
pe iwọ iku3x ajigbeda ni oruko ti a npe iwọ àrùn 3x ajigbeda munre ni oruko ti a npe eyin iyami

osoronga 3x osumare ti oju orun sọ kò sí ayé ni oruko ti a npe iwọ sànpònná 3x ṣebi ẹyin mererin
ni elosi ọdọ eledumare lojo kinni anan ti elogba àṣẹ ilé ayé ẹba ogbe gún nibe ni gbati ẹgba aṣẹ
naa tán enlo epade ogbe gún lorita meta ebere lowo re wipe nibo ni onlo ? Ogbe gún sope ohun
losi ile ayé ẹni lati l'ose kinni? Oni ohun felo tun ile ayé ṣe ẹfun lesipe àṣẹ ilé ayé tí àwa ti Logba
lọdọ eledumare ogbe gún sope bẹ ni soju ohun ogbè gún ni eledumare seko àṣẹ ilé ayé leyin lọwọ
eni toba ṣepe soju iwo ogbè gún ni eledumare Se ko àṣẹ ilé ayé leyin lọwọ ẹni toba ṣepe soju iwo
ogbè gún ni eledumare seko àṣẹ ilé ayé lewa lowo dárúkọ awa mererin ati oriki wa ogbegun sope
ajigboko ajigbeda ajigbeda ajigbeda munre. osumare toju òrun sọ kosi ayé ajigboko ni oruko ti a
npe iwọ iku ajigbeda ni oruko ti a npe iwọ àrùn ajigbeda munre ni oruko ti a npe eyin iyami
àjé.osumare to ju orun sọ òkò sí ayé ni oruko ti a npe iwọ sànpònná.eyin mererin isoju ara yín ẹni
Ha.Ha.Ha oti mọn oruko wa ati oriki wa ewaba ogbe gún munle pe ìdí igi Àidan ni eman joko sí ti
won finso aburu Aye. ẹni ki ogbe gún lomun Àidan ki Ojo ninan ki ofi tẹ odu tode ogbe gún sí ẹni
tí kobarije eniti kobarimun ti korinan ti korilo eni tobaya àgan tikori ọmọ bi ẹni tí osi ndalamun
gbogbo inkan to ti nu emi Lagbaja ọmọ Lagbaja koseri pada wasi dára dára aniyan lilore ẹkọ fífọ
mun tabi epo lila lago kan oru

IMULE BANTE MUSA

E bami lowa obi pupa 1, ao ge si ona (201), obi funfun 1,ao ge si ona (201), eyo atare (201), Ewe
owu akese , owo(Takada) paper to tobi ni ilu wa, ao wa jo ako alangba kan pelu abo alangba kan ,
ao jo po. Ao gbe okuta Ti anfi nlo kan, sinu iyara wa, ao fi gun awon nkan akoko yen mo ose dudu ,
ao wa fi etu Ti ajo yen fite odu Ifa merindilogun , ao pe ofore si , ao da sinu ose na , ao wa fi po
ose na, ao tun fi eje akuko Adie kan fi po ose na, pelu eje eyele funfun kan ao fi po ose na,ao wa fi
eyele yi fi se ipese sori ita Meta, ao si tun gbodo je ninu akuko adie Ti apa yi (ewo ni)
Ao wa ko ose yi sinu igba olomori , ao gbe ose na sinu apoti iroko, ao wa ma fiwe pelu ofore, ao
ma we ose yi ni dede agogo mejila oru Ti eni kankan kogbodo riwa
IKILO PATAKI:
(1)Ako gbodo je ki enikan fi oju ri apoti ti agbe ose yi si ooo,Ti eyan bafi oju kan yio ku ni ojo naa
, ko lero oooo. Ebe la nbe osika oooo
(2) eniti koba bai ti pe ogun odun kogbodo se ose yi ooo
(3) eniti ko bai Ti bimo kogbodo se ose yi oooo
GBOLOHUN:
oni bante Musa 3x, inu ofin ni mo wa yi ooo, kie wa yo mi ninu ofin yi loni 3x, eni to yo mi ninu ofin
ore lo fi semi 3x, e wa fi ore aje fi semi loni 3x, ako alangba ki npa ohun abo da 3x, abo alangba ki
npa ohun ako da 3x, ki awon omo araiye mapa ohun mi da 3x, Ti akese ni nse lawujo owu 3x, temi
ni ko mase lawujo awon omo araiye 3x, larin obi pupa laari funfun 3x, larin obi funfun laari pupa
3x, atare ki ko ile tie koma kun 3x, olodu merindilogun ki nse nkan tie lete 3x, ao wa da aniyan si
ao fi po ose yi, ao tun pe ohun lasiko Ti aba nwe.

OSO GBARIYE OBA SANGO 2

Awo igala odidi kan,rasu odidi kan,ori ekun kan, ori inaki iro kan, ewe oloyin, ewe aragba, ewe esisi,
ewe ekuku,ao ko won sinu apo awo igala tia ti ran ni apo, ewe ekuku yen lao fi di apo yen lenu, ao
pa akuko adie si lori ina, ao jo po sinu sere nla,ao gbe sere yen sinu apo aso funfun lehin tia tifi
akuko keji bo sere yen, ao wa mo san YERI SANGO TIA FI ASO PUPA RAN modi tia ba fe lo pelu
schnap. N.b o dara tia ba le yeri ( skirt) oni sango ti won ti lo dada sugbon tia o bari ale ran fun
rawa.

OSOLE IMULE OLONGBO OMO ODO AGBA

Ao wa olongb ehana nla kan ao wa obi abata oloju mefa (6) odidi atare (6) orogbo (6) ati ewe
orijin tutu ojo pelu oyin, epo pupa, ori, adin
Sisere
Ao wa pa olongbo na ao la die lati idire atare mefefa yi ni ao koko ko si inun olongbo yi obi
abata na yo tele ao sese wa ko orogbo na si ao gbe olongbo yi si inun ape ijogun ao wa da ewe
orijin le lori ao gbe kanna ao jo ti aba jo lowo ao po ori adin epo pupa oyin papo si inun ikekere
kan ti ise ba ti fe jo tan ao mo bu awon kini ti popapo yi si diedie ti yo fi jo tan ti o ba ti jo tan ao lo
papo ao ro si inun igo funfun kan ao fi OTI lo ni araro
GBOLOHUN RE:
Olongbo omo odo agba 3*,emi lagbaja omo lagbaja modi omo odo agba loni o toripe toso taje
ni won parapo sin olongbo,ati oso ati aje e wa parapo sina ola fun emi lagbaja omo lagbaja
loni,toripe orogbo ki kohun sango araye e ma ko ohun mi obi abata ko ohun orisa, gbogbo oro ti
nba ba eyin oni jalabi mi so e ma ko ohun mi,toripe orijin loni ki e fi gbogbo ire owo yin jin mi,orijin
loni kie fi gbogbo ire aye jin mi si ola,jin mi si rere.

IMULẸ́ AGBA GBOJU-GBOYA

Orí Ákọ Ájá kán, Orì Ábó ájá kán, Éwé Tanapowo pupọ́, Éwé Ábíríkólo pupọ́, Éwé Ájẹ́óbálé óójọ́,
Èpo Obo, Éípó igi nlá, Álákán méji, Ọ́ pọ́lọ́ nlá méjí, odidi átáré kán,Ẹ́ yín óróró mẹ́tá,Áo kọkọ sé ẹ́yín
yẹ́n jíná, kiá ko ẹ́yín náá tẹ́lẹ́ ápẹ́, áo wá ko áwọn nkán toku léé lorí, jijo pọ, Áo rọ́ sínu ádo ṣẹ́ rẹ́ kán,
Tíá bá fẹ́ lóó, áo máá bu díẹ́ sínu éwé ọ́gẹ́dẹ́ ágbágbá, Áo tẹ́ nífá írẹ́tẹ́-méjí léé lorí, áo pé ohun rẹ́
síí, áo dá sínu ẹ́k ó ̣ odi mímu. Ọ́FỌ́ RẸ́-----Ẹ́yín íyámí ẹ́lẹ́íyẹ́ ooo, ọ́látáká, ọ́láráká, ọ́látikánrán
rágbádá, ọ́lọ́mọ́ tí nmọ́rí ọ́lọjá mẹ́ríndínlogun, oní yárá ókíkí igbo, idágíríndá tí ndámọ́ lẹ́kun áríṣé
kándu, Ẹ́yín ní oná ọ́mọ́ ki iyárẹ́ bá sunkun,Ákọ́ ájá áboju méjí, Ábo ájá áboju méjí, Ákọ́ ájá áboju
mẹ́rín, Ábo ájá áboju mẹ̀rín, Ákọ́ ájá áboju mẹ́jọ́, Ábo ájá áboju mẹ́jọ́, Ákọ́ ájá áboju mẹ́ríndínlógun,
Ábo ájá áboju mẹ́ríndínlogun, ikọ́ nikọ́ ájá, ikọ́ nikọ́ inákí, ẹ́ yín íyámí ẹ́lẹ́íyẹ́ ooo, ẹ́yín lẹ́ni ábẹ̀rẹ́ áíyé,
kíẹ́ lọ fí ábẹ́rẹ̀ yin gun áwọ́n ọtá mí páá. ki émí máṣé mọ́ ínírá ooo, kíẹ́ wá lánọ́ fun mí,kin nríjẹ́ , ki
nrí mu, kí épé lọ́pá élépè, ásásí pá álásáásí, ki ọ́ná émí lágbájá kíó lá pérégédé, Áfáílá ọ́jọ́ bọjọ́
bálá ki nlá, itọ́ kii bálẹ́ kío tun pádá sẹ́ nu mọ́, odi áṣẹ́, odí ímulẹ́, Áo ṣé ádurá si.

IMULẸ́ ÀGBÀ Ẹ́ÍYẸ́ ṢẸ́RẸ́ṢẸ́RẸ́ INÚ ÎGBÁ

Ògà óríyẹ́ kàn, ọ̀mọ́ pẹ́pẹ́íyẹ́ áìyé kàn,Ẹ́íyẹ́ ápàró gbígbẹ́ kàn,ódìdì àtàré kàn, Éwé óríjí óójọ́, Éwé
Ajẹ́óbàlé óójọ́, Igbà ádému nlá nkán, ígbá ónìkólóbó kékérè kàn, Áo fì ọ́ mọ́ pẹ́pẹ́ìyẹ́ yẹ́n sínú ìgbá
kólóbò yẹ́n pẹ́lu ọ̀gán áìyé yẹ́n, Áó dépá, aó gbé ígbá kólóbó yén sínu ígbá ádému yẹ́ n, áo wá kó
èwé àwón éwé yẹ́n léé lórí, ao fì ẹ́íyẹ́ ápáró léé lórí pẹ́lu ódìdì àtàré kàn, Aó tun déé páá, aó wà gbé
sínu apẹ́ íjógun, tìa ba jó tán, ào lọ̀ kuná dá sìnu áwó fúnfún ọ̀ lọ̀mọrí tíá tẹ́ àṣọ fúnfún sinu rẹ́,Aó
dé ào má fì fọ́ kọ́ tutu mu ní álẹ́ ọ̀ jọ̀ álámìsí(Thursday) súgbọ́ n ákó gbọ́dọ́ bá óbìnrín sun títí dí ọ́ jọ́
sunday.
Ọ́ FỌ́ RẸ́------Ẹ́íyẹ́ ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́ ẹ́íyẹ́ ínu ígbá, íṣẹ́ ówó nì nṣé, íṣẹ́ ọ́ lá nì nṣé, íṣẹ́ íyí ní nṣé, íṣẹ́ ókíkí gbọ́
níṣé fun émí L ọ́mọ́ L , Ẹ́íyẹ́ ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́ Alálééku ẹ́íyẹ́ tíyín nìṣé, íṣẹ́ íbí ní nmá jẹ́ fun yín, kíẹ́ máṣé fí
ẹ́íyẹ́ ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́ tíyín dí émí L ọ́ mọ̀ L lọ́wọ́ mọ̀ óóó, Nìtórípé ẹ́yín ẹ́lẹ́íyẹ́ émì ẹ́lẹ́íyẹ́, ẹ́lẹ́íyẹ́ kíí dí ẹ́lẹ́íyẹ́
lọ́wọ́, kíẹ́ máṣé bámì já mọ óóó, kíẹ́ jẹ́kì nráíyé ṣé, kíí nkọ́lé mọ́lé, kíí nrá ọ́kọ́ átáátá, kí nṣé dáádá
láíyé mí, Ẹ́yín ẹ́lẹíyẹ́ émì ẹ́lẹ́íyẹ́, ẹ́lẹ́íyẹ́ kíí ba árá wọ́n bínu, kíẹ́ má bá mí bínu mọ́ ooo, Áo ṣé ádurá,
áṣọ funfun lá o má fí bórá sun tíá bá fẹ́ló, áṣọ́ funfun láo má tẹ́ sun sórí íbusun wá.Áo tẹ́ ẹbu náá

Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or
interruptions!

Start Free Trial

Cancel Anytime.

ní ọ́sá-méjí.

IMULE IFA OMI KUN BORI AFARA

Ewe iroko 201,Ewe Ahun 201,Ao lo won Lototo,Ori kowe, Ori akala,Ori igun,AFARA oyin,ebole awo
ejola,Pataki ese esin mereerin,(Tia ba Fe ki Ise Yi bera gan ogbodoje to esin Kan soso )Epo Ara igi
towo sinu omi,igbin ipinnu Kan,Ata ijosi(koni odi won),Ao gun gbogbo e Lototo,ao wa dapapo,Ao
Fi Se Alabahun je lepo niyo.Ao Fi iyere-Osun teifa Ejilogbe ninu Opon IFA tabi paper funfun,Ao PE
ohun re si,Ao wa da sinu obe Yi,Ao je.
OHUN RE:
Omi kunkunkun omi bori AFARA,igbin Fi ailese Fi ailara gbokun sorun,esin sare ihoho gedengbe
wolu,Adifa fun adapakun wori-wori,won darijo,won pa aidegbe,iya aidegbe gbo,o gbowo igbona,o
gbowo igboru,o mu ere,ofi se apako,o mu ejola o fise Igbodi,omu akeke o fise oruka ibowo,oyin
gbo olosi Koko igi,olukoso gbo olo ilu irawo,oba Olu- aiyegbo olo ilu opa,awon aje gbo won lo Ori
igi iroko oluwere,orunmila gbo o gbe iruke re lowo odi Odo eledumere,Oni eledumere Niki oun te
iku mole,ki ohun re Arun mole,ki oun mayanku,Oni oun ti Odo eledumere bowa Oni oun ba
gunugun Oni oun ba kowe eye ose yin,oun ba akalamagbo abiye roi roi,Oni eledumere Niki oun
oma Yan Ku,ki oun o ma fise Orin Ko,ma PE: Motifi ewe Ahun Se Ahun je ooo x2,Oro gbogbo
kogbodo Hun mi Mo,Moti fi ewe Ahun Se Ahun je,Ao wa ma mi irukere esin Tia ti Se sile.Ao ma
Mii bi aba se PE ohun yii.ati igba ti a ba je Aseje naaa.odaju gan.

IMULE OMILOKUN LOMI KOJA AFARA MIRAN

Odidi ijapa aye totobi dada 1,ewe oruru,ewe odundun,ewewbTete Abalaye,ewe Woro,Eto iroko(Ita
inu iroko) iyere 25,ao lo won si nu isasun,ao lo Egusi ito sinu re,fi se ijapa naa je lepo niyo,ao soka
ori osuka,toba tutu ao fi iyere-osun te ifa Ogunda meji lotun-Osetura kosi,EJI-OGBE labe.
OHUNRE::-
Omilokun lomi koja afara,igbin lo fai moran ki okun-bo ara re lorun,Awon Esin ni won nsare ihoho
gidigbi-gidigb lawujo,Otata Iroko awon ni won darijo ti won paa ayajo omo iya igede toku
lana,Agbe gbo o Aare ilu idaro,Akuko gbo o Aare ilu ikosun,Lekeleke gbo o Aare ilu ikefun,Oya gbo
o Aare ira,Osha oko gbo o safe ilu Ifinran,Orumila gbo o dogba,o sugbon,o sare ilu orun Alakeji,o
pade agun-fomo luyeye-ntuyeye,ko ye emi lagbaja omo lagbaja,ko ye misowo,ko te mi somo,ko ye
mi si ohun rere gbogbo aye,won pe won ni kilode baba,oni aye ti daru,omi titun koja
Afara,Orunmila Abidi Yakatayuku,gbogbo ona ire gbogbo si sile fun emi lagbaja omo lagbaja
latoni lo,owo,omo,Aje,ile kilo motor rora e.t.c,ki ara o tu mi si Owo,sire gbogbo,ibi ero pese la nba
tete,ibi tutu la nba odundun,kara o tu mi sowo,sire gbogbo,ibi tutu la nba worowo,nje kinni iroko
nso,Ero wo,kire gbogbo o ro wa bani,ogunda wa lo hire aje temi wa fun mi,Idea Ahun ni won fi paa
Ahun,ki oga mi fi owo ara re se ara re,igi oruru Niki o lo fi mu ota mi paa,igi oruru,osetura fi ase le
bee,Ejiogbe gbere gbogbo wa Fun mi,Ase Edunmare 3×.

IMULẸ́ AGBA GBOJU-GBOYA

Orí Ákọ Ájá kán, Orì Ábó ájá kán, Éwé Tanapowo pupọ́, Éwé Ábíríkólo pupọ́, Éwé Ájẹ́óbálé óójọ́,
Èpo Obo, Éípó igi nlá, Álákán méji, Ọ́ pọ́lọ́ nlá méjí, odidi átáré kán,Ẹ́ yín óróró mẹ́tá,Áo kọkọ sé ẹ́yín
yẹ́n jíná, kiá ko ẹ́yín náá tẹ́lẹ́ ápẹ́, áo wá ko áwọn nkán toku léé lorí, jijo pọ, Áo rọ́ sínu ádo ṣẹ́ rẹ́ kán,
Tíá bá fẹ́ lóó, áo máá bu díẹ́ sínu éwé ọ́gẹ́dẹ́ ágbágbá, Áo tẹ́ nífá írẹ́tẹ́-méjí léé lorí, áo pé ohun rẹ́

síí, áo dá sínu ẹ́kó ̣ odi mímu. F ̣ Ṛ -----


̣ yíṇ íyámí ẹ́lẹ́íyẹ́ ooo, ọ́látáká, ọ́láráká, ọ́látikánrán
rágbádá, ọ́lọ́mọ́ tí nmọ́rí ọ́lọjá mẹ́ríndínlogun, oní yárá ókíkí igbo, idágíríndá tí ndámọ́ lẹ́kun áríṣé
kándu, yín ̣ ní oná ọ́mọ́ ki iyárẹ́ bá sunkun, kọ́ ájá áboju méjí, bo ájá áboju méjí, kọ́ ájá áboju
mẹ́rín, bo ájá áboju mẹ̀rín, kọ́ ájá áboju mẹ́jọ́, bo ájá áboju mẹ́jọ́, kọ́ ájá áboju mẹ́ríndínlógun,
bo ájá áboju mẹ́ríndínlogun, ikọ́ nikọ́ ájá, ikọ́ nikọ́ inákí, ẹ́ yín íyámí ẹ́lẹ́íyẹ́ ooo, ẹ́yín lẹ́ni ábẹ̀rẹ́ áíyé,
kíẹ́ lọ fí ábẹ́rẹ̀ yin gun áwọ́n ọtá mí páá. ki émí máṣé mọ́ ínírá ooo, kíẹ́ wá lánọ́ fun mí,kin nríjẹ́ , ki
nrí mu, kí épé lọ́pá élépè, ásásí pá álásáásí, ki ọ́ná émí lágbájá kíó lá pérégédé, fáílá ọ́jọ́ bọjọ́
bálá ki nlá, itọ́ kii bálẹ́ kío tun pádá sẹ́ nu mọ́, odi áṣẹ́, odí ímulẹ́, o ṣé ádurá si .

IMULẸ́ ÀGBÀ Ẹ́ÍYẸ́ ṢẸ́RẸ́ṢẸ́RẸ́ INÚ ÎGBÁ

Ògà óríyẹ́ kàn, ọ̀mọ́ pẹ́pẹ́íyẹ́ áìyé kàn,Ẹ́íyẹ́ ápàró gbígbẹ́ kàn,ódìdì àtàré kàn, Éwé óríjí óójọ́, Éwé
Ajẹ́óbàlé óójọ́, Igbà ádému nlá nkán, ígbá ónìkólóbó kékérè kàn, Áo fì ọ́ mọ́ pẹ́pẹ́ìyẹ́ yẹ́n sínú ìgbá
kólóbò yẹ́n pẹ́lu ọ̀gán áìyé yẹ́n, Áó dépá, aó gbé ígbá kólóbó yén sínu ígbá ádému yẹ́ n, áo wá kó
èwé àwón éwé yẹ́n léé lórí, ao fì ẹ́íyẹ́ ápáró léé lórí pẹ́lu ódìdì àtàré kàn, Aó tun déé páá, aó wà gbé
sínu apẹ́ íjógun, tìa ba jó tán, ào lọ̀ kuná dá sìnu áwó fúnfún ọ̀ lọ̀mọrí tíá tẹ́ àṣọ fúnfún sinu rẹ́,Aó
dé ào má fì fọ́ kọ́ tutu mu ní álẹ́ ọ̀ jọ̀ álámìsí(Thursday) súgbọ́ n ákó gbọ́dọ́ bá óbìnrín sun títí dí ọ́ jọ́
sunday.
Ọ́ FỌ́ RẸ́-----
Ẹ́íyẹ́ ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́ ẹ́íyẹ́ ínu ígbá, íṣẹ́ ówó nì nṣé, íṣẹ́ ọ́lá nì nṣé, íṣẹ́ íyí ní nṣé, íṣẹ́ ókíkí gbọ́ níṣé fun émí L
ọ́mọ́ L , Ẹ́íyẹ́ ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́ Alálééku ẹ́íyẹ́ tíyín nìṣé, íṣẹ́ íbí ní nmá jẹ́ fun yín, kíẹ́ máṣé fí ẹ́ íyẹ́ ṣẹ́rẹ́ṣẹ́rẹ́
tíyín dí émí L ọ́ mọ̀ L lọ́ wọ́ mọ̀ óóó, Nìtórípé ẹ́yín ẹ́lẹ́íyẹ́ émì ẹ́lẹ́íyẹ́, ẹ́lẹ́íyẹ́ kíí dí ẹ́ lẹ́íyẹ́ lọ́wọ́, kíẹ́
máṣé bámì já mọ óóó, kíẹ́ jẹ́ kì nráíyé ṣé, kíí nkọ́lé mọ́lé, kíí nrá ọ́kọ́ átáátá, kí nṣé dáádá láíyé mí,
Ẹ́yín ẹ́lẹíyẹ́ émì ẹ́lẹ́íyẹ́, ẹ́lẹ́íyẹ́ kíí ba árá wọ́n bínu, kíẹ́ má bá mí bínu mọ́ ooo, Áo ṣé ádurá, áṣọ
funfun lá o má fí bórá sun tíá bá fẹ́ ló, áṣọ́ funfun láo má tẹ́ sun sórí íbusun wá.Áo tẹ́ ẹbu náá ní
ọ́sá-méjí.

IMULE ARINAKO AWON AGBALAGBA

Ise timo mu wa leni yi je ise tokere loju sugbon atakere iyodun ni,bi ise yi bawa Lara wa kia wa lo
si irin ajo ,awon AJE ati OSO ilu yi won yio ma yonu siwa ni,kowasi ibiti abatide bai dandan niki
awon agba ma yonu siwa,,,,enikeni kogbodo post ise yi si group Miran ooo
Ao lo wa aso awon agba 16,,eko elewe eyokan
Sise Re :ao fi owo wa pin eko yi si 16,ao wa ti aso agba yi bo inu eko na ni okookan ao wa te aso
funfun sile ,ao fi aso pupa pakaja si àrawa,ao joko le aso na,ao ma ju si enu ni ikookan .ao nije
ooo, ao ma mi nioo..
Majemu ise :-kie se adua fun egbe yi ni ooo..eni toba ko lati comment konije fun enina oo ,olohun
ma wo ola pe mio yo nkan kan kuro ninu ise YI 0OO
NOTICE:----AGO KAN ORU NI AO SE ISE YI OOO,,,BENI KOSI WAHALA KANKAN BENI KOSi aburu
kankan rara walahi.

OSHOLE IMULE TI ENIYAN FIN NI CUSTOMER NLANLA TABI ALEJO TUNTUN TABI OMO
YAHOO TI KO TI NI CLIENT

Ao wa ako alangba 6, ikode 6, obi iwarefa(oloju mefa) 6, odidi atare 6, ao ma la inu alangba yii
leyokokan, ao mafi ikode kan obi iwarefa kan sinu re leyo kokan titi yio fi pe mefa, ao gbe sinu
agbada, ao ko odidi atare mefa yen si, ao jopo lai ni siwo titi yio fi jo tan, ao lo kunna, ao da sinu
keg kan, ao da oti sinu re pelu milk olope kan, ao ma mu larolaro.
Wallahi ojumo koni mo ki alejo tuntun mawa ba wa. Ise todaju ni ooo.

IMULE MOSIJU

O ye ki Atiri Awon Ti Won O ti Dan Imule yi Wo


O daa Pupo
Eje ki Atun Se Lodun Tuntun Yi
Ogun Gidi Ni
Agbebo Adie Dudu
Omo Olongbo kan
Eye EGA Ako kan
Ao la Inu olongbo Ao ko Egbo Ajeobale si Ati Eye Ega ao ran ao tun ko ewe ajeobale le Lori,ao wa
gbe olongbo yen sinu adie tiala ayare,ao wa aso waji to fe ao gbe eyin adie yen le,ao wa fi aso yen
we gbogbo ara adie yen ao Jo tia ba jo tan.. aro lao ma lo pelu Oti(Haraara).
Ohun re:
mosiju wapa mi otun, mori igba eleye won fi ori gun ara won igege igege, mosiju
wapa mi osi mo ri igba eleye won fi ori gun ara won igege igege,odifa fun orunmila ni ojo ti baba
nbe larin awon eleye , won ni a won yo ba ise baba je awon yio da ise baba ru,orunmila ni iro ni
won pa tori ati ile ati ona ni won fin jin olongini,E MA fi gbogbo ti mo ba se jin mi,balaso waji ba
koja loru oro re aru eleye loju,ki oro Emi L omo L Ma ru awon eleye loju lati eni lo,gbogbo ohun ti
mo ba dawole ko ma yori so rere.
Ase!!!

IMULE AGBA TODAJU

Eye owiwi kan


Opolo gbigbe 2
Oga gbigbe 2
Atare 1
Ao jo papo ao lo kuna dada ao ro sinu igo funfun

OHUN RE:
Bi ale bale gbogbo eye afi ori bale fun owiwi, osho ilu yi, aje ilu yi, baba lawo ilu yi ati gbogbo
alagbara ilu yi ki efi ori bale fun emi lagbaja omo lagbaja
LILO RE:-Epo ni ao mafi lo ninu awo sobi ti aba tife sun lale...odaju gan ni ooo.

IMULE EBE ATUWO AWON AGBALAGBA

odidi eye owiwi


eye onbe

odidi atare kan


ao jo papo ao te ni ifa osa meji
ao pe ofore si ao da si inu epo pupa
ao ma fi ogede omini je

ofo re::-

abiye werewere lanpe Aje ile Ado 3x


abiye foroforo lanpe Aje Ota 3x
Sobosoro Lanpe Aje Ile- Ife
Osa Meji Ni Mofi bayin mule ni emere odo, ohun lodifa fun Orunmila lojo ti baba nlo ba awon eleye
mu ni emere odo, oni eyin Aje nibo le nlo, woni awon losi ile aiye, pe awon yio ma tun ile aiye se,
awon yio si tun ma ba ile aiye je, Orunmila wa bere lowo won pe awon omo ti ohun nko, wo ni
awon yi o se imule lori awon omore, Orunmila ni kinni ohun imule na, won ni ki o lo mu odidi owiwi
ki o ma fi je ogede omini, ki o si ma fi onbe be awon ni gbogbo igba, nitori bi Osho ba mu epo ni
se ni oju e ro, ti Aje bamu epo ni se ni oju e ro ni, ojo na le so fun Orunmila pe e ko ni ba nkan re
je mo, ema se ba nkan emi L omo L, e se mi ki l'owo l'owo, kin nko ile mo ile,etc.....

a le ni odara ju lati ma lo die die titi ebu yen ma fi tan.

EYONU/IMULE AGBA-

ewe ewuro ati oromo adie ti koti gun iye Kan,odindi atare kan.ao jo won papo,ao ro sibikan,nigba
tia ba fe lo ao te ni ifa osa meji,ao peOfore si ,ao da eyiti ape ofo si yen si meji, idakan ao po mose,
idakeji ao da sinu ori, ao mafi ose yen we, ti aba wetan ao ma fi tinu ori yen para.
OHUN RE:-
kekere eiye a madun katiako-katiako, awon agbagba eiye won a fohun lukese-lukese,adifa fun
awon iyami agba meta,nigbati won ti ikole orun bowa si ikole aye,won pade orunmila ni orita meta
ajantala orunmila ni nibo le nlo bayi won ni awon losi ile aiye lati lofun omo ajero ni ajadi apo lati
ma pa owo tire si, won ni awon losi ile aye lati lopa omo owarangun aga,orunmila ni omo bibi inu
ohun nbe lode isalu aye,oni bawo ni e se mase ti e ni pawon,bawo ni e se mase ti e ni fun won ni
ajadi apo lati mapa owo tire si, won wa bere lowo orunmila pe se omo nkan imule Orunmila ni
ohun mo,oni eku meje oluwereje,eja meje ajugbada,obi ipa, obi ifin ni nkan imule,won ni orunmila
komo nkan imule,won wa sofun orunmila pe,ewe ewuro ati oromodie tio ti gun iye,tio ba wa ribe
emi lagbaja omo lagbaja ba yin mule loni ooo,e gbodo da mi,Adura.

ASIRI IMULE ARINURODE AWON AGBALAGBA TODAJU

Egbo tude idi meje, Aidan onigun meje ,Omo ologbo tikolaju, Odidi atare meta, Epo obo topo dada,
Akuko adie kan, Igba onikoko,Opon ifa tiwon fi igi iroko gben, Ape ijogun tuntun, Seere nla kan,
Ose dudu ,Eso lara mejeji oojo, Ewe ajeobale oojo......Ao lu ologbo tikoti laju yen pa ao wa fi ewe
ajeobale oojo tele ape tuntun ao gbe ologbo na lelori ao ko egbo tude si ao ko Aidan si ao ko
atare meta yen si ao ko epo obo topo ao fo were were dada ao kosi ao ko eso lara mejeji oojo si
ao tun wa fi ewe ajeobale bo lori dada pada........Ao fi epo yi aro ka ao jo ise na ninu ape tuntun
yen ao lokuna dada ao wa da ebu na sori opon ifa ao fite odu ifa merindinlogun si, ao daniyan
ohun tia bafe si......Ao pin si ona meta ao po idakan mo ose dudu ao kosinu igba onikoko yen. Ao
wa pa akuko adie kan togbo dada ao ro eje re sinu ose yen ao fi owo po ao da meji toseku papo
ao rosinu ado seere yen ao fi eje adie toseku yen bo seere yen lara pelu iye igbaaya re ao gbe
mejeji sinu aso funfun otooto.....Ao gbe sinu apoti tabi cupboard wa tori oju meji ko gbodo

rimon ao gbe pamo fun ojo meje, lehin na ao wa se sara re bayii, ao mafi akara elepo pupa tabi
ekuru funfun se sara re lojojumo fun ojo meje yen lehin ojo keje ao bere lilo re.....
Ao mafi ose yen we lale lehin agogo mewa.....Ao mafi ebu inu seere na fo eko tutu mu larolaro
kato fohun si enikeni..... Obinrin kogbodo lo imule yio, o ni e wu nla fun obirin to ba lo ise YII.... E
gbo ikilo ooooo......Odaju pupo #INULAYEWA☘

IMULE AWON AGBALAGBA TIWON FI NSINA ORE FUN EYAN

Alangba ako ayé kan, alangba abo ayé meta, Ọsẹ dúdú, Lofinda Bintu meta, igba olomori, aso
funfun diẹ.....Ao gun alangba abo meta pọ pẹlu Ose dúdú, ào fi bintu kan popo, ào wa fi aso
funfun tẹ inu igba olomori, ào fi alangba ako ayé sì inú igba yen Lori aso yen , ao wa sáré gbe Ose
le lori monlé. Ào wa se aso bo lori, ào wa tu bintu meji yoku le lori. Ào wa de ,ao gbé pa mon fún
16 days, ào ma fiwe lale leyin ojo merindilogun(16days) yen....Odaju pupo, Yoo je fun wa laase
edumareee........

EYONU ASINA TIPATIPA

Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun,
ao se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni
gbogbo igba..... Odaju

EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU

Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon
fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba
olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni
yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo.
Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise

EYONU AYE

Oga meta 3,asin meta 3,opolo meta 3,eso ido,eso werenjeje,ewe ajeobale, ewe orijin,ewe
kileofimise,odidi atare meta 3,ao Jo po ao ma fi epo ogere la ninu fitila oloju kan. Tested ok

ASEJE IMULE ASINA

Ewe afeloru merindilogun(16), iyere meridilogun(16) ao lo papo ao fi din eyin ororo mefa(6) je
lepo-niyo ao fi iye-reosun tefa ejiogbe sinu opon tabi inu paper funfun ao pe ofore si ao je.

OFO RE...
Gberumi awo ile aye, somi kale awo ode orun, osu mi ore mi agara da mi,ohun lodifa fun orunmila

lojoti baba nlo ree ba eleye mule ni mo rele apesin, oni won gbe ori ile won je eku, won gbe ori ile
won je eja, won gbe ori ile won se ibaje,ase dowo ile tia jo mu loni, inu kibi ogun koba nkan ara re
je,inu kibi babalawo kola opon ifa dana, owo mi ba ewe afeloru abiyeregiregi okerere ni kibi o ma
lo,kibi o ma sele si emi--omo-- ati awon omo mi, ao se adua si bia ba se fe ao wa je...

N. B... Ale la ma nje aseje yio.

EYONU ASINA TIPATIPA

Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun,
ao se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni
gbogbo igba..... Odaju

EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU

Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon
fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba
olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni
yio koju sinu ose, ao ti koko dogbon fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo.
Ao ma bu we nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojo naa ni yio bere ise

IMULE_ATUDE_TOLAGBARA_GIDI_TESTED_COMFIRM_ALWAYS

AWON_agba_ma mu wa_rinrin_ajo_be deni_gbogbo_ide_ara wa_maja_lesekese

GBIYANJU RE WO

ISENARE_ ewe egele ff tutu, egbo ajeobale, enu opinye, oro agogo, oro adete, ose dd tabi ose ff,

SISERE_ao gun awon eroja yi lotooto,ao wa sese po won mo ose yen,ao ko ose naa si ini apo aso
asunwon pupa,Ao gbe ko.

LILORE_
ao ma bu ose yi we lalale pelu omi tolo-woro,ori ako okuta lama duro le taba nwe lowo ooo

APERE TAMARI_ ojo akoko tabawe ise yii,ama laala awon ala tolagbara,amo kosewu ooo, gbogbo
ide ara pata lo ma tu kia kia,

Kosi ani ani nipa ise yii rara

Trusted by over 1 million members

Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or
interruptions!

Start Free Trial

Cancel Anytime.

Download

You might also like